ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kíróníkà 1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Kíróníkà

      • Látọ̀dọ̀ Ádámù dé ọ̀dọ̀ Ábúráhámù (1-27)

      • Àwọn àtọmọdọ́mọ Ábúráhámù (28-37)

      • Àwọn ọmọ Édómù àti àwọn ọba wọn pẹ̀lú àwọn Séríkí wọn (38-54)

1 Kíróníkà 1:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 4:25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 62-63

1 Kíróníkà 1:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 5:12, 15
  • +Jẹ 5:18

1 Kíróníkà 1:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 11:5
  • +Jẹ 5:25, 28

1 Kíróníkà 1:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 5:29
  • +Jẹ 11:10
  • +Jẹ 6:10

1 Kíróníkà 1:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 66:19
  • +Isk 27:13
  • +Jẹ 10:2

1 Kíróníkà 1:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 10:3; Isk 27:14

1 Kíróníkà 1:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 11:11
  • +Jẹ 10:6

1 Kíróníkà 1:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 72:10
  • +Isk 27:22
  • +Jẹ 10:7

1 Kíróníkà 1:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 10:8, 9

1 Kíróníkà 1:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 46:9
  • +Jẹ 10:13, 14

1 Kíróníkà 1:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 29:14
  • +Joṣ 13:2, 3
  • +Di 2:23; Emọ 9:7

1 Kíróníkà 1:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 23:2
  • +Jẹ 10:15-18

1 Kíróníkà 1:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ond 1:21
  • +Jẹ 15:16; Nọ 13:29; Di 3:8
  • +Di 7:1

1 Kíróníkà 1:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 9:3, 7

1 Kíróníkà 1:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 27:11

1 Kíróníkà 1:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Àwọn tó tẹ̀ lé e yìí ni àwọn ọmọ Árámù. Wo Jẹ 10:23.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹsr 4:9
  • +Isk 27:23
  • +Jẹ 10:22, 23

1 Kíróníkà 1:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 11:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2005, ojú ìwé 8-9

1 Kíróníkà 1:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó túmọ̀ sí “Pín Sọ́tọ̀.”

  • *

    Tàbí “aráyé.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 11:19

1 Kíróníkà 1:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 10:26-29

1 Kíróníkà 1:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 9:28
  • +Jẹ 2:11; 25:18

1 Kíróníkà 1:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 11:19
  • +Jẹ 11:21

1 Kíróníkà 1:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 11:23
  • +Jẹ 11:25
  • +Jẹ 11:26

1 Kíróníkà 1:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 17:5

1 Kíróníkà 1:28

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 21:3
  • +Jẹ 16:11, 12

1 Kíróníkà 1:29

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 28:9
  • +Isk 27:21
  • +Jẹ 25:13-15

1 Kíróníkà 1:32

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìyàwó onípò kejì.” Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀, “Wáhàrì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 25:1-4
  • +Jẹ 37:28
  • +Job 2:11
  • +Ais 21:13

1 Kíróníkà 1:33

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 60:6

1 Kíróníkà 1:34

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 7:8
  • +Jẹ 25:25
  • +Jẹ 32:28

1 Kíróníkà 1:35

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 36:4, 5

1 Kíróníkà 1:36

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ọbd 9
  • +Jẹ 36:11, 12

1 Kíróníkà 1:37

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 36:13

1 Kíróníkà 1:38

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 36:8
  • +Jẹ 36:20, 21

1 Kíróníkà 1:39

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 36:22

1 Kíróníkà 1:40

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 36:23, 24

1 Kíróníkà 1:41

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Àwọn ọmọ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 36:25, 26

1 Kíróníkà 1:42

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 1:38
  • +Jẹ 36:27, 28

1 Kíróníkà 1:43

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 32:3
  • +Jẹ 36:31-39

1 Kíróníkà 1:44

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 49:13

1 Kíróníkà 1:46

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “pápá.”

1 Kíróníkà 1:51

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Séríkí jẹ́ olóyè láàárín ẹ̀yà kan.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 36:40-43

Àwọn míì

1 Kíró. 1:1Jẹ 4:25
1 Kíró. 1:2Jẹ 5:12, 15
1 Kíró. 1:2Jẹ 5:18
1 Kíró. 1:3Heb 11:5
1 Kíró. 1:3Jẹ 5:25, 28
1 Kíró. 1:4Jẹ 5:29
1 Kíró. 1:4Jẹ 11:10
1 Kíró. 1:4Jẹ 6:10
1 Kíró. 1:5Jẹ 10:2
1 Kíró. 1:5Ais 66:19
1 Kíró. 1:5Isk 27:13
1 Kíró. 1:6Jẹ 10:3; Isk 27:14
1 Kíró. 1:8Ais 11:11
1 Kíró. 1:8Jẹ 10:6
1 Kíró. 1:9Sm 72:10
1 Kíró. 1:9Isk 27:22
1 Kíró. 1:9Jẹ 10:7
1 Kíró. 1:10Jẹ 10:8, 9
1 Kíró. 1:11Jer 46:9
1 Kíró. 1:11Jẹ 10:13, 14
1 Kíró. 1:12Isk 29:14
1 Kíró. 1:12Joṣ 13:2, 3
1 Kíró. 1:12Di 2:23; Emọ 9:7
1 Kíró. 1:13Ais 23:2
1 Kíró. 1:13Jẹ 10:15-18
1 Kíró. 1:14Ond 1:21
1 Kíró. 1:14Jẹ 15:16; Nọ 13:29; Di 3:8
1 Kíró. 1:14Di 7:1
1 Kíró. 1:15Joṣ 9:3, 7
1 Kíró. 1:16Isk 27:11
1 Kíró. 1:17Ẹsr 4:9
1 Kíró. 1:17Isk 27:23
1 Kíró. 1:17Jẹ 10:22, 23
1 Kíró. 1:18Jẹ 11:14
1 Kíró. 1:19Jẹ 11:19
1 Kíró. 1:20Jẹ 10:26-29
1 Kíró. 1:231Ọb 9:28
1 Kíró. 1:23Jẹ 2:11; 25:18
1 Kíró. 1:25Jẹ 11:19
1 Kíró. 1:25Jẹ 11:21
1 Kíró. 1:26Jẹ 11:23
1 Kíró. 1:26Jẹ 11:25
1 Kíró. 1:26Jẹ 11:26
1 Kíró. 1:27Jẹ 17:5
1 Kíró. 1:28Jẹ 21:3
1 Kíró. 1:28Jẹ 16:11, 12
1 Kíró. 1:29Jẹ 28:9
1 Kíró. 1:29Isk 27:21
1 Kíró. 1:29Jẹ 25:13-15
1 Kíró. 1:32Jẹ 25:1-4
1 Kíró. 1:32Jẹ 37:28
1 Kíró. 1:32Job 2:11
1 Kíró. 1:32Ais 21:13
1 Kíró. 1:33Ais 60:6
1 Kíró. 1:34Iṣe 7:8
1 Kíró. 1:34Jẹ 25:25
1 Kíró. 1:34Jẹ 32:28
1 Kíró. 1:35Jẹ 36:4, 5
1 Kíró. 1:36Ọbd 9
1 Kíró. 1:36Jẹ 36:11, 12
1 Kíró. 1:37Jẹ 36:13
1 Kíró. 1:38Jẹ 36:8
1 Kíró. 1:38Jẹ 36:20, 21
1 Kíró. 1:39Jẹ 36:22
1 Kíró. 1:40Jẹ 36:23, 24
1 Kíró. 1:41Jẹ 36:25, 26
1 Kíró. 1:421Kr 1:38
1 Kíró. 1:42Jẹ 36:27, 28
1 Kíró. 1:43Jẹ 32:3
1 Kíró. 1:43Jẹ 36:31-39
1 Kíró. 1:44Jer 49:13
1 Kíró. 1:51Jẹ 36:40-43
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
  • 32
  • 33
  • 34
  • 35
  • 36
  • 37
  • 38
  • 39
  • 40
  • 41
  • 42
  • 43
  • 44
  • 45
  • 46
  • 47
  • 48
  • 49
  • 50
  • 51
  • 52
  • 53
  • 54
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Kíróníkà 1:1-54

Kíróníkà Kìíní

1 Ádámù,

Sẹ́ẹ̀tì,+

Énọ́ṣì,

2 Kénánù,

Máhálálélì,+

Járédì,+

3 Énọ́kù,+

Mètúsélà,

Lámékì,+

4 Nóà,+

Ṣémù,+ Hámù àti Jáfẹ́tì.+

5 Àwọn ọmọ Jáfẹ́tì ni Gómérì, Mágọ́gù, Mádáì, Jáfánì, Túbálì,+ Méṣékì+ àti Tírásì.+

6 Àwọn ọmọ Gómérì ni Áṣíkénásì, Rífátì àti Tógámà.+

7 Àwọn ọmọ Jáfánì ni Élíṣáhì, Táṣíṣì, Kítímù àti Ródánímù.

8 Àwọn ọmọ Hámù ni Kúṣì,+ Mísíráímù, Pútì àti Kénáánì.+

9 Àwọn ọmọ Kúṣì ni Sébà,+ Háfílà, Sábítà, Ráámà+ àti Sábítékà.

Àwọn ọmọ Ráámà sì ni Ṣébà àti Dédánì.+

10 Kúṣì bí Nímírọ́dù.+ Òun ló kọ́kọ́ di alágbára ní ayé.

11 Mísíráímù bí Lúdímù,+ Ánámímù, Léhábímù, Náfútúhímù,+ 12 Pátírúsímù,+ Kásílúhímù (ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni àwọn Filísínì+ ti wá) àti Káfítórímù.+

13 Kénáánì bí Sídónì+ àkọ́bí rẹ̀ àti Hétì+ 14 àti àwọn ará Jébúsì,+ àwọn Ámórì,+ àwọn Gẹ́gáṣì,+ 15 àwọn Hífì,+ àwọn Ákì, àwọn Sáínì, 16 àwọn ọmọ Áfádì,+ àwọn Sémárì àti àwọn ará Hámátì.

17 Àwọn ọmọ Ṣémù ni Élámù,+ Áṣúrì,+ Ápákíṣádì, Lúdì àti Árámù

àti* Úsì, Húlì, Gétérì àti Máṣì.+

18 Ápákíṣádì bí Ṣélà, Ṣélà+ sì bí Ébérì.

19 Ọmọ méjì ni Ébérì bí. Ọ̀kan ń jẹ́ Pélégì,*+ torí pé ìgbà ayé rẹ̀ ni ayé* pín sọ́tọ̀ọ̀tọ̀. Orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni Jókítánì.

20 Jókítánì bí Álímódádì, Ṣéléfì, Hasamáfétì, Jérà,+ 21 Hádórámù, Úsálì, Díkílà, 22 Óbálì, Ábímáélì, Ṣébà, 23 Ófírì,+ Háfílà+ àti Jóbábù; gbogbo wọn jẹ́ ọmọ Jókítánì.

24 Ṣémù,

Ápákíṣádì,

Ṣélà,

25 Ébérì,

Pélégì,+

Réù,+

26 Sérúgù,+

Náhórì,+

Térà,+

27 Ábúrámù, ìyẹn Ábúráhámù.+

28 Àwọn ọmọ Ábúráhámù ni Ísákì+ àti Íṣímáẹ́lì.+

29 Ibi tí ìdílé wọn ti wá nìyí: Àkọ́bí Íṣímáẹ́lì ni Nébáótì,+ lẹ́yìn náà ó bí Kídárì,+ Ádíbéélì, Míbúsámù,+ 30 Míṣímà, Dúmà, Máásà, Hádádì, Témà, 31 Jétúrì, Náfíṣì àti Kédémà. Àwọn yìí ni ọmọ Íṣímáẹ́lì.

32 Àwọn ọmọ tí Kétúrà,+ wáhàrì* Ábúráhámù bí ni Símíránì, Jókíṣánì, Médánì, Mídíánì,+ Íṣíbákì àti Ṣúáhì.+

Àwọn ọmọ Jókíṣánì ni Ṣébà àti Dédánì.+

33 Àwọn ọmọ Mídíánì ni Eéfà,+ Éférì, Hánókù, Ábíídà àti Élídáà.

Ọmọ Kétúrà ni gbogbo wọn.

34 Ábúráhámù bí Ísákì. Àwọn ọmọ Ísákì+ ni Ísọ̀+ àti Ísírẹ́lì.+

35 Àwọn ọmọ Ísọ̀ ni Élífásì, Réúẹ́lì, Jéúṣì, Jálámù àti Kórà.+

36 Àwọn ọmọ Élífásì ni Témánì,+ Ómárì, Séfò, Gátámù, Kénásì, Tímínà àti Ámálékì.+

37 Àwọn ọmọ Réúẹ́lì ni Náhátì, Síírà, Ṣámà àti Mísà.+

38 Àwọn ọmọ Séírì+ ni Lótánì, Ṣóbálì, Síbéónì, Ánáhì, Díṣónì, Ésérì àti Díṣánì.+

39 Àwọn ọmọ Lótánì ni Hórì àti Hómámù. Arábìnrin Lótánì sì ni Tímínà.+

40 Àwọn ọmọ Ṣóbálì ni Álífánì, Mánáhátì, Ébálì, Ṣéfò àti Ónámù.

Àwọn ọmọ Síbéónì sì ni Áyà àti Ánáhì.+

41 Ọmọ* Ánáhì ni Díṣónì.

Àwọn ọmọ Díṣónì sì ni Hémúdánì, Éṣíbánì, Ítíránì àti Kéránì.+

42 Àwọn ọmọ Ésérì+ ni Bílíhánì, Sááfánì àti Ékánì.

Àwọn ọmọ Díṣánì ni Úsì àti Áránì.+

43 Àwọn ọba tó jẹ ní ilẹ̀ Édómù+ kí ọba kankan tó jẹ lórí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì+ nìyí: Bélà ọmọ Béórì; orúkọ ìlú rẹ̀ ni Dínhábà. 44 Nígbà tí Bélà kú, Jóbábù ọmọ Síírà láti Bósírà+ bẹ̀rẹ̀ sí í jọba ní ipò rẹ̀. 45 Nígbà tí Jóbábù kú, Húṣámù láti ilẹ̀ àwọn ará Témánì bẹ̀rẹ̀ sí í jọba ní ipò rẹ̀. 46 Nígbà tí Húṣámù kú, Hádádì ọmọ Bédádì, ẹni tó ṣẹ́gun Mídíánì ní agbègbè* Móábù bẹ̀rẹ̀ sí í jọba ní ipò rẹ̀. Orúkọ ìlú rẹ̀ ni Áfítì. 47 Nígbà tí Hádádì kú, Sámúlà láti Másírékà bẹ̀rẹ̀ sí í jọba ní ipò rẹ̀. 48 Nígbà tí Sámúlà kú, Ṣéọ́lù láti Réhóbótì lẹ́gbẹ̀ẹ́ Odò bẹ̀rẹ̀ sí í jọba ní ipò rẹ̀. 49 Nígbà tí Ṣéọ́lù kú, Baali-hánánì ọmọ Ákíbórì bẹ̀rẹ̀ sí í jọba ní ipò rẹ̀. 50 Nígbà tí Baali-hánánì kú, Hádádì bẹ̀rẹ̀ sí í jọba ní ipò rẹ̀. Orúkọ ìlú rẹ̀ ni Páù, orúkọ ìyàwó rẹ̀ sì ni Méhétábélì ọmọ Mátírédì, ọmọbìnrin Mésáhábù. 51 Lẹ́yìn náà, Hádádì kú.

Àwọn séríkí* Édómù ni Séríkí Tímínà, Séríkí Álíífà, Séríkí Jététì,+ 52 Séríkí Oholibámà, Séríkí Élà, Séríkí Pínónì, 53 Séríkí Kénásì, Séríkí Témánì, Séríkí Míbúsárì, 54 Séríkí Mágídíélì, Séríkí Írámù. Àwọn yìí ni séríkí Édómù.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́