ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Tẹsalóníkà 4
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Tẹsalóníkà

      • Ìkìlọ̀ lórí ìṣekúṣe (1-8)

      • Ẹ túbọ̀ nífẹ̀ẹ́ ara yín (9-12)

        • “Ẹ má yọjú sí ọ̀rọ̀ ọlọ́rọ̀” (11)

      • Àwọn tó kú nínú Kristi ló máa kọ́kọ́ dìde (13-18)

1 Tẹsalóníkà 4:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Kol 1:10; 1Pe 2:12

1 Tẹsalóníkà 4:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọn àṣẹ.”

1 Tẹsalóníkà 4:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Lédè Gíríìkì, por·neiʹa. Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 17:19; Ef 5:25-27; 2Tẹ 2:13; 1Pe 1:15, 16
  • +Ef 5:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 41

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2012, ojú ìwé 21

    7/15/1997, ojú ìwé 18

    Ayọ, ojú ìwé 66

1 Tẹsalóníkà 4:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “ohun èlò.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Kol 3:5; 2Ti 2:22
  • +Ro 6:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    10/8/2003, ojú ìwé 27

1 Tẹsalóníkà 4:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 6:18; Ef 5:5
  • +Sm 79:6; Ef 4:17, 19; 1Pe 4:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    11/2013, ojú ìwé 7

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2012, ojú ìwé 21

1 Tẹsalóníkà 4:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 7/2019, ojú ìwé 3

    Jí!,

    1/2007, ojú ìwé 23

    5/8/2000, ojú ìwé 14-15

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2002, ojú ìwé 20-21

    1/15/2001, ojú ìwé 7

    7/15/1997, ojú ìwé 18

1 Tẹsalóníkà 4:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 12:14; 1Pe 1:15, 16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2012, ojú ìwé 21

1 Tẹsalóníkà 4:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 6:18, 19
  • +1Jo 3:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 7/2019, ojú ìwé 3

1 Tẹsalóníkà 4:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 12:10
  • +Jo 13:34, 35; 1Pe 1:22; 1Jo 4:21

1 Tẹsalóníkà 4:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2003, ojú ìwé 13-14

1 Tẹsalóníkà 4:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Tẹ 3:11, 12
  • +1Pe 4:15
  • +1Kọ 4:11, 12; Ef 4:28; 2Tẹ 3:10; 1Ti 5:8

1 Tẹsalóníkà 4:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 12:17

1 Tẹsalóníkà 4:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “a ò fẹ́ kí ẹ ṣaláìmọ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 11:11; Iṣe 7:59, 60; 1Kọ 15:6
  • +1Kọ 15:32

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    7/8/2001, ojú ìwé 26-27

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    2/15/1995, ojú ìwé 32

1 Tẹsalóníkà 4:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 14:9; 1Kọ 15:3, 4
  • +1Kọ 15:22, 23; Flp 3:20, 21; 2Tẹ 2:1; Ifi 20:4

1 Tẹsalóníkà 4:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2007, ojú ìwé 28

    1/15/1993, ojú ìwé 5

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 103-104

1 Tẹsalóníkà 4:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jud 9
  • +1Kọ 15:51, 52

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 5 2017 ojú ìwé 5

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2007, ojú ìwé 28

    1/15/1993, ojú ìwé 5-6

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 103-104, 180-181

    Jí!,

    2/8/2002, ojú ìwé 13

1 Tẹsalóníkà 4:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 1:9
  • +2Tẹ 2:1
  • +Jo 14:3; 17:24; 2Kọ 5:8; Flp 1:23; Ifi 20:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2015, ojú ìwé 18-19

    9/15/2008, ojú ìwé 29

    1/1/2007, ojú ìwé 28

    1/15/1993, ojú ìwé 4-6

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 103-104, 211

Àwọn míì

1 Tẹs. 4:1Kol 1:10; 1Pe 2:12
1 Tẹs. 4:3Jo 17:19; Ef 5:25-27; 2Tẹ 2:13; 1Pe 1:15, 16
1 Tẹs. 4:3Ef 5:3
1 Tẹs. 4:4Kol 3:5; 2Ti 2:22
1 Tẹs. 4:4Ro 6:19
1 Tẹs. 4:51Kọ 6:18; Ef 5:5
1 Tẹs. 4:5Sm 79:6; Ef 4:17, 19; 1Pe 4:3
1 Tẹs. 4:7Heb 12:14; 1Pe 1:15, 16
1 Tẹs. 4:81Kọ 6:18, 19
1 Tẹs. 4:81Jo 3:24
1 Tẹs. 4:9Ro 12:10
1 Tẹs. 4:9Jo 13:34, 35; 1Pe 1:22; 1Jo 4:21
1 Tẹs. 4:112Tẹ 3:11, 12
1 Tẹs. 4:111Pe 4:15
1 Tẹs. 4:111Kọ 4:11, 12; Ef 4:28; 2Tẹ 3:10; 1Ti 5:8
1 Tẹs. 4:12Ro 12:17
1 Tẹs. 4:13Jo 11:11; Iṣe 7:59, 60; 1Kọ 15:6
1 Tẹs. 4:131Kọ 15:32
1 Tẹs. 4:14Ro 14:9; 1Kọ 15:3, 4
1 Tẹs. 4:141Kọ 15:22, 23; Flp 3:20, 21; 2Tẹ 2:1; Ifi 20:4
1 Tẹs. 4:16Jud 9
1 Tẹs. 4:161Kọ 15:51, 52
1 Tẹs. 4:17Iṣe 1:9
1 Tẹs. 4:172Tẹ 2:1
1 Tẹs. 4:17Jo 14:3; 17:24; 2Kọ 5:8; Flp 1:23; Ifi 20:6
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Tẹsalóníkà 4:1-18

Ìwé Kìíní sí Àwọn Ará Tẹsalóníkà

4 Lákòótán, ẹ̀yin ará, bí ẹ ṣe gba ìtọ́ni lọ́dọ̀ wa nípa bó ṣe yẹ kí ẹ máa rìn kí ẹ lè ṣe ohun tí Ọlọ́run fẹ́,+ tí ẹ sì ń ṣe bẹ́ẹ̀ lóòótọ́, a fi Jésù Olúwa bẹ̀ yín, a sì tún fi rọ̀ yín pé kí ẹ túbọ̀ máa ṣe bẹ́ẹ̀ ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́. 2 Nítorí ẹ mọ àwọn ìtọ́ni* tí a fún yín nípasẹ̀ Jésù Olúwa.

3 Ohun tí ìfẹ́ Ọlọ́run jẹ́ nìyí, pé kí ẹ jẹ́ mímọ́,+ kí ẹ sì ta kété sí ìṣekúṣe.*+ 4 Kí ẹnì kọ̀ọ̀kan yín mọ bó ṣe máa kó ara* rẹ̀ níjàánu+ nínú jíjẹ́ mímọ́  + àti nínú iyì, 5 kì í ṣe nínú ojúkòkòrò ìbálòpọ̀ tí kò níjàánu+ bíi ti àwọn orílẹ̀-èdè tí kò mọ Ọlọ́run.+ 6 Kí ẹnikẹ́ni má kọjá ààlà tó yẹ, kó má sì yan arákùnrin rẹ̀ jẹ nínú ọ̀ràn yìí, torí Jèhófà* ń fìyà jẹni nítorí gbogbo àwọn nǹkan yìí, bí a ṣe sọ fún yín ṣáájú, tí a sì tún kìlọ̀ fún yín gidigidi. 7 Nítorí Ọlọ́run pè wá fún jíjẹ́ mímọ́, kì í ṣe fún ìwà àìmọ́.+ 8 Torí náà, ẹni tí kò bá ka èyí sí, kì í ṣe èèyàn ni kò kà sí, Ọlọ́run+ tó ń fún yín ní ẹ̀mí mímọ́ rẹ̀+ ni kò kà sí.

9 Àmọ́, ní ti ìfẹ́ ará,+ ẹ kò nílò ká kọ̀wé sí yín, nítorí Ọlọ́run ti kọ́ yín láti máa nífẹ̀ẹ́ ara yín.+ 10 Kódà, ẹ̀ ń ṣe bẹ́ẹ̀ sí gbogbo àwọn ará ní gbogbo Makedóníà. Àmọ́, ẹ̀yin ará, a rọ̀ yín pé kí ẹ máa ṣe jù bẹ́ẹ̀ lọ. 11 Ẹ fi ṣe àfojúsùn yín láti máa ṣe jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́,+ ẹ má yọjú sí ọ̀rọ̀ ọlọ́rọ̀,+ kí ẹ máa fi ọwọ́ yín ṣiṣẹ́,+ bí a ṣe sọ fún yín, 12 kí ẹ lè máa rìn lọ́nà tó bójú mu lójú àwọn tó wà níta,+ kí ẹ má sì ṣe aláìní ohunkóhun.

13 Yàtọ̀ síyẹn, ẹ̀yin ará, a fẹ́ kí ẹ mọ̀* nípa àwọn tó ń sùn nínú ikú,+ kí ẹ má bàa banú jẹ́ bí àwọn tí kò ní ìrètí ṣe máa ń ṣe.+ 14 Nítorí tí a bá nígbàgbọ́ pé Jésù kú, ó sì jí dìde,+ lọ́nà kan náà, Ọlọ́run yóò mú àwọn tó ti sùn nínú ikú nítorí Jésù wá sí ìyè pẹ̀lú rẹ̀.+ 15 Nítorí ohun tí a sọ fún yín nípasẹ̀ ọ̀rọ̀ Jèhófà* nìyí, pé àwa alààyè tí a bá kù nílẹ̀ di ìgbà tí Olúwa bá wà níhìn-ín kò ní ṣáájú àwọn tó ti sùn nínú ikú lọ́nàkọnà; 16 nítorí Olúwa fúnra rẹ̀ yóò sọ̀ kalẹ̀ láti ọ̀run pẹ̀lú ìpè àṣẹ, pẹ̀lú ohùn olú áńgẹ́lì+ àti pẹ̀lú kàkàkí Ọlọ́run, àwọn tó ti kú nínú Kristi ló sì máa kọ́kọ́ dìde.+ 17 Lẹ́yìn náà, àwa alààyè tí a kù nílẹ̀ ni a ó gbà lọ pẹ̀lú wọn nínú àwọsánmà+ láti pàdé Olúwa+ nínú afẹ́fẹ́; a ó sì tipa báyìí máa wà pẹ̀lú Olúwa nígbà gbogbo.+ 18 Nítorí náà, ẹ máa fi àwọn ọ̀rọ̀ yìí tu ara yín nínú.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́