ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jòhánù 17
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jòhánù

      • Jésù gbàdúrà tó kẹ́yìn pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ (1-26)

        • Tí a bá wá mọ Ọlọ́run, ó máa yọrí sí ìyè àìnípẹ̀kun (3)

        • Àwọn Kristẹni kì í ṣe apá kan ayé (14-16)

        • “Òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ rẹ” (17)

        • “Mo ti jẹ́ kí wọ́n mọ orúkọ rẹ” (26)

Jòhánù 17:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 12:23; 13:31, 32

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 280

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2013, ojú ìwé 27

Jòhánù 17:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “aráyé; èèyàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Flp 2:9, 10
  • +Jo 6:37
  • +Jo 4:14; 6:27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 280

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2013, ojú ìwé 27

Jòhánù 17:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kí wọ́n gba ìmọ̀ ìwọ Ọlọ́run tòótọ́ kan ṣoṣo sínú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 10:25-28
  • +1Jo 5:20
  • +Ef 4:11, 13; 2Pe 3:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2021, ojú ìwé 4-5

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 2 2021 ojú ìwé 10-12

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 23

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 2 2017 ojú ìwé 6-7

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2015, ojú ìwé 21

    10/15/2013, ojú ìwé 27-28

    10/15/2006, ojú ìwé 5-7

    4/15/2005, ojú ìwé 4-7

    12/15/2002, ojú ìwé 8

    8/1/2001, ojú ìwé 10

    10/1/2000, ojú ìwé 23

    10/15/1993, ojú ìwé 29

    3/1/1992, ojú ìwé 23

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 280

    Olùkọ́, ojú ìwé 255

    Jí!,

    2/8/1999, ojú ìwé 9

    Ìmọ̀, ojú ìwé 7-8, 170

Jòhánù 17:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 13:31
  • +Jo 4:34

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    9/2018, ojú ìwé 6

Jòhánù 17:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 1:1; 8:58; Kol 1:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 280

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2013, ojú ìwé 27

Jòhánù 17:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Mo ti jẹ́ kí àwọn èèyàn tí o fún mi látinú ayé mọ orúkọ rẹ.”

  • *

    Tàbí “ṣègbọràn sí ọ̀rọ̀ rẹ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 22:22; Iṣe 15:14; Heb 2:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 280

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2013, ojú ìwé 28-29

    Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, ojú ìwé 1721

Jòhánù 17:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 6:68; 8:28; 12:49; 14:10
  • +Jo 16:27
  • +Jo 16:30

Jòhánù 17:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 280

Jòhánù 17:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 16:15

Jòhánù 17:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “wà ní ìṣọ̀kan.”

  • *

    Tàbí “wà ní ìṣọ̀kan.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 13:1
  • +1Pe 1:5; Jud 24
  • +Jo 10:30; 17:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 134

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 110

Jòhánù 17:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 6:39; 10:28
  • +Jo 18:9
  • +Mk 14:21
  • +Sm 41:9; 109:8; Iṣe 1:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 280

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2005, ojú ìwé 16

    9/15/1992, ojú ìwé 9-10

Jòhánù 17:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 15:11

Jòhánù 17:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 15:19; Jem 4:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2012, ojú ìwé 5

    7/15/2005, ojú ìwé 29-30

    11/1/1997, ojú ìwé 8

    7/1/1993, ojú ìwé 12-17

    Ìmọ̀, ojú ìwé 123-126

Jòhánù 17:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 6:13; 2Tẹ 3:3; 1Jo 5:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 134

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2004, ojú ìwé 17

    4/15/2003, ojú ìwé 13

    11/1/1997, ojú ìwé 8

    Jí!,

    9/8/1997, ojú ìwé 12

Jòhánù 17:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Kol 1:13
  • +Jo 18:36

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 45

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 134

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 280

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 15

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2005, ojú ìwé 29-30

    Jí!,

    9/8/1997, ojú ìwé 12-13

    Ìmọ̀, ojú ìwé 49-50

Jòhánù 17:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Yà wọ́n sọ́tọ̀; Jẹ́ kí wọ́n di mímọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 5:25, 26; 1Tẹ 5:23; 2Tẹ 2:13; 1Pe 1:22
  • +Sm 12:6; 119:151, 160

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 14

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2018, ojú ìwé 6

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 280-281

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2013, ojú ìwé 29

    7/1/2005, ojú ìwé 5

    3/1/2002, ojú ìwé 14

Jòhánù 17:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 20:21

Jòhánù 17:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 12:5; 1Kọ 1:10; Ga 3:28
  • +Jo 10:38; 14:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    6/2018, ojú ìwé 8

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2015, ojú ìwé 6

    10/15/2013, ojú ìwé 29

    7/15/1996, ojú ìwé 11-12

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 281

Jòhánù 17:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 14:20; 17:11; 1Jo 3:24

Jòhánù 17:23

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kí a lè mú kí wọ́n ṣọ̀kan délẹ̀délẹ̀.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2013, ojú ìwé 29-30

Jòhánù 17:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 22:28-30; 1Tẹ 4:17
  • +Jo 17:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 281

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2013, ojú ìwé 30

Jòhánù 17:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 8:55; 15:21
  • +Mt 11:27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2013, ojú ìwé 30

Jòhánù 17:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 6:9; Jo 17:6
  • +Jo 15:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 17

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 281

    Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, ojú ìwé 1721

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2008, ojú ìwé 21

    10/1/2006, ojú ìwé 21-22

    Orukọ Atọrunwa, ojú ìwé 28

Àwọn míì

Jòh. 17:1Jo 12:23; 13:31, 32
Jòh. 17:2Flp 2:9, 10
Jòh. 17:2Jo 6:37
Jòh. 17:2Jo 4:14; 6:27
Jòh. 17:3Lk 10:25-28
Jòh. 17:31Jo 5:20
Jòh. 17:3Ef 4:11, 13; 2Pe 3:18
Jòh. 17:4Jo 13:31
Jòh. 17:4Jo 4:34
Jòh. 17:5Jo 1:1; 8:58; Kol 1:15
Jòh. 17:6Sm 22:22; Iṣe 15:14; Heb 2:12
Jòh. 17:8Jo 6:68; 8:28; 12:49; 14:10
Jòh. 17:8Jo 16:27
Jòh. 17:8Jo 16:30
Jòh. 17:10Jo 16:15
Jòh. 17:11Jo 13:1
Jòh. 17:111Pe 1:5; Jud 24
Jòh. 17:11Jo 10:30; 17:21
Jòh. 17:12Jo 6:39; 10:28
Jòh. 17:12Jo 18:9
Jòh. 17:12Mk 14:21
Jòh. 17:12Sm 41:9; 109:8; Iṣe 1:20
Jòh. 17:13Jo 15:11
Jòh. 17:14Jo 15:19; Jem 4:4
Jòh. 17:15Mt 6:13; 2Tẹ 3:3; 1Jo 5:18
Jòh. 17:16Kol 1:13
Jòh. 17:16Jo 18:36
Jòh. 17:17Ef 5:25, 26; 1Tẹ 5:23; 2Tẹ 2:13; 1Pe 1:22
Jòh. 17:17Sm 12:6; 119:151, 160
Jòh. 17:18Jo 20:21
Jòh. 17:21Ro 12:5; 1Kọ 1:10; Ga 3:28
Jòh. 17:21Jo 10:38; 14:10
Jòh. 17:22Jo 14:20; 17:11; 1Jo 3:24
Jòh. 17:24Lk 22:28-30; 1Tẹ 4:17
Jòh. 17:24Jo 17:5
Jòh. 17:25Jo 8:55; 15:21
Jòh. 17:25Mt 11:27
Jòh. 17:26Mt 6:9; Jo 17:6
Jòh. 17:26Jo 15:9
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Jòhánù 17:1-26

Àkọsílẹ̀ Jòhánù

17 Jésù sọ àwọn nǹkan yìí, ó gbójú sókè wo ọ̀run, ó sọ pé: “Baba, wákàtí náà ti dé. Ṣe ọmọ rẹ lógo, kí ọmọ rẹ lè ṣe ọ́ lógo,+ 2 bí o ṣe fún un ní àṣẹ lórí gbogbo ẹran ara,*+ kó lè fún gbogbo àwọn tí o ti fún un+ ní ìyè àìnípẹ̀kun.+ 3 Èyí túmọ̀ sí ìyè àìnípẹ̀kun,+ pé kí wọ́n wá mọ ìwọ Ọlọ́run tòótọ́ kan ṣoṣo*+ àti Jésù Kristi,+ ẹni tí o rán. 4 Mo ti yìn ọ́ lógo ní ayé,+ ní ti pé mo ti parí iṣẹ́ tí o ní kí n ṣe.+ 5 Torí náà, ní báyìí, Baba, ṣe mí lógo lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ pẹ̀lú ògo tí mo ti ní lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ kí ayé tó wà.+

6 “Mo ti fi orúkọ rẹ hàn kedere fún àwọn èèyàn tí o fún mi látinú ayé.*+ Ìwọ lo ni wọ́n, o sì fi wọ́n fún mi, wọ́n sì ti pa ọ̀rọ̀ rẹ mọ́.* 7 Wọ́n ti wá mọ̀ báyìí pé ọ̀dọ̀ rẹ ni gbogbo ohun tí o fún mi ti wá; 8 torí pé àwọn ọ̀rọ̀ tí o sọ fún mi ni mo ti sọ fún wọn,+ wọ́n sì ti gbà á, ó dájú pé wọ́n ti wá mọ̀ pé mo wá bí aṣojú rẹ,+ wọ́n sì ti gbà gbọ́ pé ìwọ lo rán mi.+ 9 Mo gbàdúrà nípa wọn; kì í ṣe nípa ayé, àmọ́ nípa àwọn tí o fún mi, torí pé ìwọ lo ni wọ́n; 10 ìwọ lo ni gbogbo ohun tí mo ní, èmi ni mo sì ni tìrẹ,+ a sì ti ṣe mí lógo láàárín wọn.

11 “Mi ò sí ní ayé mọ́, àmọ́ àwọn wà ní ayé,+ mo sì ń bọ̀ lọ́dọ̀ rẹ. Baba mímọ́, máa ṣọ́ wọn+ nítorí orúkọ rẹ, tí o ti fún mi, kí wọ́n lè jẹ́ ọ̀kan* bí àwa ṣe jẹ́ ọ̀kan.*+ 12 Nígbà tí mo wà pẹ̀lú wọn, mo máa ń ṣọ́ wọn+ nítorí orúkọ rẹ, tí o ti fún mi; mo ti dáàbò bò wọ́n, ìkankan nínú wọn ò sì pa run+ àfi ọmọ ìparun,+ kí ìwé mímọ́ lè ṣẹ.+ 13 Àmọ́ ní báyìí, mò ń bọ̀ lọ́dọ̀ rẹ, mo sì ń sọ àwọn nǹkan yìí ní ayé, kí wọ́n lè ní ayọ̀ mi ní ẹ̀kún rẹ́rẹ́ nínú wọn.+ 14 Mo ti sọ ọ̀rọ̀ rẹ fún wọn, àmọ́ ayé ti kórìíra wọn, torí wọn kì í ṣe apá kan ayé,+ bí èmi ò ṣe jẹ́ apá kan ayé.

15 “Mi ò ní kí o mú wọn kúrò ní ayé, àmọ́ kí o máa ṣọ́ wọn torí ẹni burúkú náà.+ 16 Wọn kì í ṣe apá kan ayé,+ bí èmi ò ṣe jẹ́ apá kan ayé.+ 17 Sọ wọ́n di mímọ́* nípasẹ̀ òtítọ́;+ òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ rẹ.+ 18 Bí o ṣe rán mi wá sí ayé, èmi náà rán wọn lọ sínú ayé.+ 19 Mo sì ń sọ ara mi di mímọ́ nítorí wọn, kí a lè sọ àwọn náà di mímọ́ nípasẹ̀ òtítọ́.

20 “Kì í ṣe àwọn yìí nìkan ni mò ń gbàdúrà nípa wọn, mo tún ń gbàdúrà nípa àwọn tó máa ní ìgbàgbọ́ nínú mi nípasẹ̀ ọ̀rọ̀ wọn, 21 kí gbogbo wọn lè jẹ́ ọ̀kan,+ bí ìwọ Baba ṣe wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú mi, tí mo sì wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ,+ kí àwọn náà lè wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú wa, kí ayé lè gbà gbọ́ pé ìwọ lo rán mi. 22 Mo ti fún wọn ní ògo tí o fún mi, kí wọ́n lè jẹ́ ọ̀kan bí àwa ṣe jẹ́ ọ̀kan.+ 23 Èmi wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú wọn, ìwọ sì wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú mi, kí a lè mú kí wọ́n jẹ́ ọ̀kan délẹ̀délẹ̀,* kí ayé lè mọ̀ pé ìwọ lo rán mi àti pé o nífẹ̀ẹ́ wọn bí o ṣe nífẹ̀ẹ́ mi. 24 Baba, mo fẹ́ kí àwọn tí o fún mi wà pẹ̀lú mi níbi tí mo bá wà,+ kí wọ́n lè rí ògo mi tí o ti fún mi, torí pé o ti nífẹ̀ẹ́ mi ṣáájú kí o tó pilẹ̀ ayé.+ 25 Baba olódodo, ní tòótọ́, ayé ò tíì wá mọ̀ ọ́,+ àmọ́ èmi mọ̀ ọ́,+ àwọn yìí sì ti wá mọ̀ pé ìwọ lo rán mi. 26 Mo ti jẹ́ kí wọ́n mọ orúkọ rẹ, màá sì jẹ́ kí wọ́n mọ̀ ọ́n,+ kí ìfẹ́ tí o ní fún mi lè wà nínú wọn, kí n sì wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú wọn.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́