ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 22
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Sámúẹ́lì

      • Dáfídì yin Ọlọ́run nítorí ìgbàlà tí ó ṣe (1-51)

        • “Jèhófà ni àpáta gàǹgà mi” (2)

        • Jèhófà jẹ́ adúróṣinṣin sí àwọn adúróṣinṣin (26)

2 Sámúẹ́lì 22:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 15:1; Ond 5:1
  • +Sm 34:19
  • +1Sa 23:14; Sm 18:àkọlé

2 Sámúẹ́lì 22:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 31:3
  • +Sm 18:2, 3

2 Sámúẹ́lì 22:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

  • *

    Tàbí “olùgbàlà mi tó lágbára.”

  • *

    Tàbí “ibi gíga mi tó láàbò.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:4; 1Sa 2:1, 2
  • +Jẹ 15:1; Di 33:29; Sm 3:3
  • +Sm 9:9; Owe 18:10
  • +Sm 59:16
  • +Ais 12:2; Lk 1:46, 47; Tit 3:4

2 Sámúẹ́lì 22:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 69:14
  • +Sm 18:4

2 Sámúẹ́lì 22:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ṣìọ́ọ̀lù,” ìyẹn ibojì aráyé. Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 116:3, 4
  • +Sm 18:5

2 Sámúẹ́lì 22:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 142:1; Jon 2:2
  • +Ẹk 3:7; Sm 18:6; 34:15

2 Sámúẹ́lì 22:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ond 5:4
  • +Job 26:11
  • +Sm 18:7-12; 77:18

2 Sámúẹ́lì 22:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 30:27

2 Sámúẹ́lì 22:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 144:5; Ais 64:1
  • +Di 4:11; 1Ọb 8:12; Sm 18:9; 97:2

2 Sámúẹ́lì 22:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìyẹ́ afẹ́fẹ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 4:4; Sm 80:1; 99:1
  • +Heb 1:7

2 Sámúẹ́lì 22:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Job 36:29

2 Sámúẹ́lì 22:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 19:16; 1Sa 2:10
  • +Sm 18:13-16; Ais 30:30

2 Sámúẹ́lì 22:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 7:13; 77:17
  • +Sm 144:6

2 Sámúẹ́lì 22:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 14:21; Sm 106:9; 114:3
  • +Ẹk 15:8

2 Sámúẹ́lì 22:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 18:16-19; 124:2-4; 144:7

2 Sámúẹ́lì 22:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 3:7; 56:9

2 Sámúẹ́lì 22:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 19:11; 23:26; 2Sa 15:10

2 Sámúẹ́lì 22:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ibi tó láyè fífẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 31:8
  • +Sm 149:4

2 Sámúẹ́lì 22:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “mo jẹ́ aláìmọwọ́mẹsẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 26:23; 1Ọb 8:32
  • +Sm 18:20-24; 24:3, 4

2 Sámúẹ́lì 22:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 6:1; Sm 19:9
  • +Di 8:11

2 Sámúẹ́lì 22:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 84:11
  • +Sm 18:23; Owe 14:16

2 Sámúẹ́lì 22:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Job 34:11; Ais 3:10; Heb 11:6
  • +Sm 18:24; Owe 5:21

2 Sámúẹ́lì 22:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 37:28; 97:10
  • +Sm 18:25-30

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2010, ojú ìwé 26

    8/15/2002, ojú ìwé 5

    11/15/1992, ojú ìwé 19

2 Sámúẹ́lì 22:27

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “ìwọ ń ṣe bí ẹni tí kò gbọ́n sí àwọn oníbékebèke.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 5:8; 1Pe 1:16
  • +Sm 125:5

2 Sámúẹ́lì 22:28

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Job 34:28
  • +Da 4:37; 1Pe 5:5

2 Sámúẹ́lì 22:29

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 27:1
  • +Sm 97:11

2 Sámúẹ́lì 22:30

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “akónilẹ́rù.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 18:29; Flp 4:13; Heb 11:33, 34

2 Sámúẹ́lì 22:31

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:4
  • +Sm 12:6; Owe 30:5
  • +Sm 35:2; 91:4

2 Sámúẹ́lì 22:32

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 44:6
  • +Di 32:31; Sm 18:31-42

2 Sámúẹ́lì 22:33

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 27:1; Ais 12:2
  • +Ais 26:7

2 Sámúẹ́lì 22:34

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 33:15, 16; Hab 3:19

2 Sámúẹ́lì 22:36

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 18:35; 113:6-8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    8/2020, ojú ìwé 8

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2012, ojú ìwé 17

    9/15/2010, ojú ìwé 14

    11/1/2004, ojú ìwé 29

2 Sámúẹ́lì 22:37

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọrùn ẹsẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 17:5

2 Sámúẹ́lì 22:39

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 14:13

2 Sámúẹ́lì 22:40

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 23:5
  • +1Sa 17:49; Sm 44:3, 5

2 Sámúẹ́lì 22:41

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Wàá jẹ́ kí n gbá ẹ̀yìn ọrùn àwọn ọ̀tá mi mú.”

  • *

    Ní Héb., “lẹ́nu mọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 49:8
  • +Sm 18:40

2 Sámúẹ́lì 22:42

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 28:6; Owe 1:28; Ais 1:15; Mik 3:4

2 Sámúẹ́lì 22:44

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 30:6; 2Sa 15:12
  • +2Sa 8:3; Sm 2:8; 60:8
  • +Sm 18:43-45

2 Sámúẹ́lì 22:45

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Tí wọ́n bá gbọ́ ìró mi, wọ́n á ṣègbọràn sí mi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 33:29

2 Sámúẹ́lì 22:46

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Àwọn àjèjì á pòórá.”

2 Sámúẹ́lì 22:47

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:4
  • +Sm 18:46; 89:26

2 Sámúẹ́lì 22:48

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 25:29; 2Sa 18:19
  • +Sm 18:47; 110:1; 144:1, 2

2 Sámúẹ́lì 22:49

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 5:12; 7:9
  • +Sm 18:48

2 Sámúẹ́lì 22:50

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kọ orin sí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:43; Sm 117:1
  • +1Kr 16:9; Sm 145:2; Ro 15:9

2 Sámúẹ́lì 22:51

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìṣẹ́gun.”

  • *

    Ní Héb., “èso.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 2:6; 21:1
  • +Sm 89:20, 29; Lk 1:32, 33

Àwọn míì

2 Sám. 22:1Ẹk 15:1; Ond 5:1
2 Sám. 22:1Sm 34:19
2 Sám. 22:11Sa 23:14; Sm 18:àkọlé
2 Sám. 22:2Sm 31:3
2 Sám. 22:2Sm 18:2, 3
2 Sám. 22:3Di 32:4; 1Sa 2:1, 2
2 Sám. 22:3Jẹ 15:1; Di 33:29; Sm 3:3
2 Sám. 22:3Sm 9:9; Owe 18:10
2 Sám. 22:3Sm 59:16
2 Sám. 22:3Ais 12:2; Lk 1:46, 47; Tit 3:4
2 Sám. 22:5Sm 69:14
2 Sám. 22:5Sm 18:4
2 Sám. 22:6Sm 116:3, 4
2 Sám. 22:6Sm 18:5
2 Sám. 22:7Sm 142:1; Jon 2:2
2 Sám. 22:7Ẹk 3:7; Sm 18:6; 34:15
2 Sám. 22:8Ond 5:4
2 Sám. 22:8Job 26:11
2 Sám. 22:8Sm 18:7-12; 77:18
2 Sám. 22:9Ais 30:27
2 Sám. 22:10Sm 144:5; Ais 64:1
2 Sám. 22:10Di 4:11; 1Ọb 8:12; Sm 18:9; 97:2
2 Sám. 22:111Sa 4:4; Sm 80:1; 99:1
2 Sám. 22:11Heb 1:7
2 Sám. 22:12Job 36:29
2 Sám. 22:14Ẹk 19:16; 1Sa 2:10
2 Sám. 22:14Sm 18:13-16; Ais 30:30
2 Sám. 22:15Sm 7:13; 77:17
2 Sám. 22:15Sm 144:6
2 Sám. 22:16Ẹk 14:21; Sm 106:9; 114:3
2 Sám. 22:16Ẹk 15:8
2 Sám. 22:17Sm 18:16-19; 124:2-4; 144:7
2 Sám. 22:18Sm 3:7; 56:9
2 Sám. 22:191Sa 19:11; 23:26; 2Sa 15:10
2 Sám. 22:20Sm 31:8
2 Sám. 22:20Sm 149:4
2 Sám. 22:211Sa 26:23; 1Ọb 8:32
2 Sám. 22:21Sm 18:20-24; 24:3, 4
2 Sám. 22:23Di 6:1; Sm 19:9
2 Sám. 22:23Di 8:11
2 Sám. 22:24Sm 84:11
2 Sám. 22:24Sm 18:23; Owe 14:16
2 Sám. 22:25Job 34:11; Ais 3:10; Heb 11:6
2 Sám. 22:25Sm 18:24; Owe 5:21
2 Sám. 22:26Sm 37:28; 97:10
2 Sám. 22:26Sm 18:25-30
2 Sám. 22:27Mt 5:8; 1Pe 1:16
2 Sám. 22:27Sm 125:5
2 Sám. 22:28Job 34:28
2 Sám. 22:28Da 4:37; 1Pe 5:5
2 Sám. 22:29Sm 27:1
2 Sám. 22:29Sm 97:11
2 Sám. 22:30Sm 18:29; Flp 4:13; Heb 11:33, 34
2 Sám. 22:31Di 32:4
2 Sám. 22:31Sm 12:6; Owe 30:5
2 Sám. 22:31Sm 35:2; 91:4
2 Sám. 22:32Ais 44:6
2 Sám. 22:32Di 32:31; Sm 18:31-42
2 Sám. 22:33Sm 27:1; Ais 12:2
2 Sám. 22:33Ais 26:7
2 Sám. 22:34Ais 33:15, 16; Hab 3:19
2 Sám. 22:36Sm 18:35; 113:6-8
2 Sám. 22:37Sm 17:5
2 Sám. 22:39Ẹk 14:13
2 Sám. 22:401Sa 23:5
2 Sám. 22:401Sa 17:49; Sm 44:3, 5
2 Sám. 22:41Jẹ 49:8
2 Sám. 22:41Sm 18:40
2 Sám. 22:421Sa 28:6; Owe 1:28; Ais 1:15; Mik 3:4
2 Sám. 22:441Sa 30:6; 2Sa 15:12
2 Sám. 22:442Sa 8:3; Sm 2:8; 60:8
2 Sám. 22:44Sm 18:43-45
2 Sám. 22:45Di 33:29
2 Sám. 22:47Di 32:4
2 Sám. 22:47Sm 18:46; 89:26
2 Sám. 22:481Sa 25:29; 2Sa 18:19
2 Sám. 22:48Sm 18:47; 110:1; 144:1, 2
2 Sám. 22:492Sa 5:12; 7:9
2 Sám. 22:49Sm 18:48
2 Sám. 22:50Di 32:43; Sm 117:1
2 Sám. 22:501Kr 16:9; Sm 145:2; Ro 15:9
2 Sám. 22:51Sm 2:6; 21:1
2 Sám. 22:51Sm 89:20, 29; Lk 1:32, 33
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
  • 32
  • 33
  • 34
  • 35
  • 36
  • 37
  • 38
  • 39
  • 40
  • 41
  • 42
  • 43
  • 44
  • 45
  • 46
  • 47
  • 48
  • 49
  • 50
  • 51
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
2 Sámúẹ́lì 22:1-51

Sámúẹ́lì Kejì

22 Dáfídì kọ ọ̀rọ̀ yìí lórin+ sí Jèhófà ní ọjọ́ tí Jèhófà gbà á lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀+ àti lọ́wọ́ Sọ́ọ̀lù.+ 2 Ó sọ pé:

“Jèhófà ni àpáta gàǹgà mi àti odi ààbò+ mi àti Ẹni tó ń gbà mí sílẹ̀.+

 3 Ọlọ́run mi ni àpáta+ mi, ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,

Apata+ mi àti ìwo* ìgbàlà mi,* ibi ààbò+ mi,*

Àti ibi tí mo lè sá sí,+ olùgbàlà+ mi; ìwọ tí o gbà mí lọ́wọ́ àwọn oníwà ipá.

 4 Mo ké pe Jèhófà, ẹni tí ìyìn yẹ,

Yóò sì gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi.

 5 Ikú yí mi ká bí ìgbì òkun;+

Àwọn ọkùnrin tí kò ní láárí ya lù mí bí omi.+

 6 Àwọn okùn Isà Òkú* yí mi ká;+

Ikú dẹ pańpẹ́ síwájú mi.+

 7 Mo ké pe Jèhófà nínú wàhálà mi,+

Mo sì ń pe Ọlọ́run mi.

Nígbà náà, ó gbọ́ ohùn mi láti tẹ́ńpìlì rẹ̀,

Igbe mi fún ìrànlọ́wọ́ sì dé etí rẹ̀.+

 8 Ayé bẹ̀rẹ̀ sí í mì síwá-sẹ́yìn, ó sì ń mì jìgìjìgì;+

Àwọn ìpìlẹ̀ ọ̀run mì tìtì+

Wọ́n sì ń mì síwá-sẹ́yìn nítorí a ti mú un bínú.+

 9 Èéfín jáde láti ihò imú rẹ̀,

Iná tó ń jóni run jáde láti ẹnu rẹ̀,+

Ẹyin iná sì ń jó láti ọ̀dọ̀ rẹ̀.

10 Ó tẹ ọ̀run wálẹ̀ bí ó ṣe ń sọ̀ kalẹ̀,+

Ìṣúdùdù tó kàmàmà sì wà lábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀.+

11 Ó gun kérúbù,+ ó sì ń fò bọ̀.

A rí i lórí ìyẹ́ apá áńgẹ́lì kan.*+

12 Ó wá fi òkùnkùn bò ó bí àgọ́,+

Nínú ojú ọ̀run tó ṣú dẹ̀dẹ̀.

13 Láti inú ìmọ́lẹ̀ tó wà níwájú rẹ̀ ni ẹyin iná ti ń jó.

14 Nígbà náà, Jèhófà bẹ̀rẹ̀ sí í sán ààrá láti ọ̀run;+

Ẹni Gíga Jù Lọ mú kí a gbọ́ ohùn rẹ̀.+

15 Ó ta àwọn ọfà+ rẹ̀, ó sì tú wọn ká;

Mànàmáná kọ, ó sì kó wọn sínú ìdàrúdàpọ̀.+

16 Ìsàlẹ̀ òkun hàn síta;+

Àwọn ìpìlẹ̀ ayé hàn síta nítorí ìbáwí Jèhófà,

Nípa èémí tó tú jáde ní ihò imú rẹ̀.+

17 Ó na ọwọ́ rẹ̀ láti òkè;

Ó mú mi, ó sì fà mí jáde látinú omi jíjìn.+

18 Ó gbà mí lọ́wọ́ ọ̀tá mi alágbára,+

Lọ́wọ́ àwọn tó kórìíra mi, tí wọ́n sì lágbára jù mí lọ.

19 Wọ́n kò mí lójú ní ọjọ́ àjálù mi,+

Ṣùgbọ́n Jèhófà ni alátìlẹyìn mi.

20 Ó mú mi jáde wá sí ibi ààbò;*+

Ó gbà mí sílẹ̀ nítorí pé inú rẹ̀ dùn sí mi.+

21 Jèhófà san èrè fún mi nítorí òdodo mi;+

Ó san èrè fún mi nítorí pé ọwọ́ mi mọ́.*+

22 Nítorí mo ti pa àwọn ọ̀nà Jèhófà mọ́,

Mi ò hùwà burúkú, kí n wá fi Ọlọ́run mi sílẹ̀.

23 Gbogbo ìdájọ́ rẹ̀+ wà ní iwájú mi;

Mi ò ní yà kúrò nínú àwọn òfin rẹ̀.+

24 Màá jẹ́ aláìlẹ́bi+ níwájú rẹ̀,

Màá sì pa ara mi mọ́ kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀.+

25 Kí Jèhófà san èrè fún mi nítorí òdodo mi +

Àti nítorí mo jẹ́ aláìṣẹ̀ ní iwájú rẹ̀.+

26 Ìwọ jẹ́ adúróṣinṣin sí ẹni tó jẹ́ adúróṣinṣin;+

Ìwọ ń hùwà àìlẹ́bi sí akíkanjú ọkùnrin aláìlẹ́bi;+

27 Ìwọ jẹ́ mímọ́ sí ẹni tí ó mọ́,+

Àmọ́ ìwọ ń jẹ́ kí àwọn oníbékebèke mọ̀ pé òmùgọ̀ ni wọ́n.*+

28 Ò ń gba àwọn ẹni rírẹlẹ̀ là,+

Ṣùgbọ́n o kì í fi ojú rere wo àwọn agbéraga, o sì ń rẹ̀ wọ́n wálẹ̀.+

29 Jèhófà, ìwọ ni fìtílà mi,+

Jèhófà ló sì ń tan ìmọ́lẹ̀ sí òkùnkùn mi.+

30 Ìrànlọ́wọ́ rẹ ni mo fi lè gbéjà ko àwọn jàǹdùkú;*

Agbára Ọlọ́run ni mo fi lè gun ògiri.+

31 Pípé ni ọ̀nà Ọlọ́run tòótọ́;+

Ọ̀rọ̀ Jèhófà jẹ́ èyí tí a yọ́ mọ́.+

Apata ló jẹ́ fún gbogbo àwọn tó fi í ṣe ibi ààbò.+

32 Ta ni Ọlọ́run bí kò ṣe Jèhófà?+

Ta sì ni àpáta bí kò ṣe Ọlọ́run wa?+

33 Ọlọ́run tòótọ́ ni odi ààbò mi tó lágbára,+

Yóò sì mú kí ọ̀nà mi jẹ́ pípé.+

34 Ó ṣe ẹsẹ̀ mi bíi ti àgbọ̀nrín,

Ó sì mú mi dúró ní àwọn ibi gíga.+

35 Ó ń kọ́ ọwọ́ mi ní ogun,

Apá mi sì lè tẹ ọrun tí a fi bàbà ṣe.

36 O fún mi ní apata rẹ láti gbà mí là,

Ìrẹ̀lẹ̀ rẹ sì sọ mí di ẹni ńlá. +

37 O fẹ ọ̀nà fún ẹsẹ̀ mi;

Kí ẹsẹ̀* mi má bàa yọ̀.+

38 Màá lépa àwọn ọ̀tá mi, màá sì pa wọ́n run;

Mi ò ní pa dà títí wọ́n á fi pa rẹ́.

39 Màá pa wọ́n run, màá sì fọ́ wọn túútúú, kí wọ́n má bàa gbérí mọ́;+

Wọ́n á ṣubú sábẹ́ ẹsẹ̀ mi.

40 Wàá fún mi lókun láti jagun,+

Wàá sì mú kí àwọn ọ̀tá mi ṣubú sábẹ́ mi.+

41 Wàá mú kí àwọn ọ̀tá mi pa dà lẹ́yìn mi;*+

Màá pa àwọn tó kórìíra mi run.*+

42 Wọ́n kígbe fún ìrànlọ́wọ́, àmọ́ kò sí ẹni tó máa gbà wọ́n;

Kódà, wọ́n ké pe Jèhófà, àmọ́ kò dá wọn lóhùn.+

43 Màá gún wọn kúnná bí eruku ilẹ̀;

Màá lọ̀ wọ́n, màá sì tẹ̀ wọ́n mọ́lẹ̀ bí ẹrẹ̀ ojú ọ̀nà.

44 Wàá gbà mí lọ́wọ́ àwọn èèyàn mi tó ń wá àléébù.+

Wàá ṣọ́ mi kí n lè di olórí àwọn orílẹ̀-èdè;+

Àwọn èèyàn tí mi ò mọ̀ yóò sìn mí.+

45 Àwọn àjèjì á wá ba búrúbúrú níwájú mi;+

Ohun tí wọ́n bá gbọ́ nípa mi á mú kí wọ́n ṣègbọràn sí mi.*

46 Ọkàn àwọn àjèjì á domi;*

Wọ́n á jáde tẹ̀rùtẹ̀rù látinú ibi ààbò wọn.

47 Jèhófà wà láàyè! Ìyìn ni fún Àpáta mi!+

Kí a gbé Ọlọ́run tó jẹ́ àpáta ìgbàlà mi ga.+

48 Ọlọ́run tòótọ́ ń gbẹ̀san fún mi;+

Ó ń ṣẹ́gun àwọn èèyàn lábẹ́ mi;+

49 Ó ń gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi.

Ìwọ gbé mi lékè+ àwọn tó ń gbéjà kò mí;

O gbà mí lọ́wọ́ oníwà ipá.+

50 Ìdí nìyẹn tí màá fi dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, Jèhófà, láàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+

Màá sì fi orin yin*+ orúkọ rẹ:

51 Ó ń ṣe àwọn iṣẹ́ ìgbàlà* ńlá fún ọba rẹ̀;+

Ó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí ẹni àmì òróró rẹ̀,

Sí Dáfídì àti àtọmọdọ́mọ* rẹ̀ títí láé.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́