ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 15
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Àwọn Ọba

      • Ábíjámù di ọba Júdà (1-8)

      • Ásà di ọba Júdà (9-24)

      • Nádábù di ọba Ísírẹ́lì (25-32)

      • Bááṣà di ọba Ísírẹ́lì (33, 34)

1 Àwọn Ọba 15:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 12:20
  • +2Kr 13:1, 2

1 Àwọn Ọba 15:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 11:20-22

1 Àwọn Ọba 15:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “fún un ní fìtílà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 7:8, 12; Sm 89:33-37; Ais 37:35; Jer 33:20, 21
  • +1Ọb 11:36; 2Kr 21:7; Sm 132:13, 17

1 Àwọn Ọba 15:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 11:4, 15; Sm 51:àkọlé

1 Àwọn Ọba 15:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 14:30; 2Kr 12:15

1 Àwọn Ọba 15:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 13:22
  • +2Kr 13:3

1 Àwọn Ọba 15:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 3:10; Mt 1:7
  • +2Kr 14:1

1 Àwọn Ọba 15:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 11:21, 22

1 Àwọn Ọba 15:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 14:2-5, 11; 15:17

1 Àwọn Ọba 15:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó ṣeé ṣe kí ọ̀rọ̀ Hébérù yìí ní í ṣe pẹ̀lú ọ̀rọ̀ tí wọ́n ń lò fún “ìgbẹ́,” wọ́n sì máa ń lò ó fún ohun tí wọ́n bá kórìíra.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 23:17, 18; 1Ọb 14:24; 22:45, 46
  • +1Ọb 11:7; 14:22, 23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2012, ojú ìwé 8

1 Àwọn Ọba 15:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìyáàfin.”

  • *

    Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 11:18, 20
  • +Di 7:5; 2Ọb 18:1, 4; 2Kr 34:1, 4
  • +2Sa 15:23; 2Kr 15:16-18; Jo 18:1

1 Àwọn Ọba 15:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àwọn ọjọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 33:52; Di 12:2; 1Ọb 22:41, 43

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    3/2017, ojú ìwé 19

1 Àwọn Ọba 15:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 26:26, 27

1 Àwọn Ọba 15:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 16:3, 12

1 Àwọn Ọba 15:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “mọ odi; tún Rámà kọ́.”

  • *

    Tàbí “sí ìpínlẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 18:21, 25
  • +2Kr 16:1-6

1 Àwọn Ọba 15:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ààfin.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 16:7

1 Àwọn Ọba 15:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Májẹ̀mú.”

  • *

    Tàbí “májẹ̀mú.”

1 Àwọn Ọba 15:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 15:29
  • +Ond 18:29; 1Ọb 12:28, 29

1 Àwọn Ọba 15:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “mímọ odi; títún Rámà kọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 14:17; Sol 6:4

1 Àwọn Ọba 15:22

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “mọ odi; tún Gébà kọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 21:8, 17
  • +Joṣ 18:21, 26; Ond 20:1; 1Sa 7:5; Jer 40:6

1 Àwọn Ọba 15:23

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “mọ odi sí; tún kọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 16:11-14

1 Àwọn Ọba 15:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 22:42; 2Kr 17:3, 4; 18:1; 19:4; Mt 1:8

1 Àwọn Ọba 15:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 14:20

1 Àwọn Ọba 15:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 14:7, 9
  • +1Ọb 12:28-30; 13:33

1 Àwọn Ọba 15:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 19:44, 48; 21:20, 23; 1Ọb 16:15

1 Àwọn Ọba 15:29

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 14:9, 10

1 Àwọn Ọba 15:32

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 12:15

1 Àwọn Ọba 15:33

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 16:8

1 Àwọn Ọba 15:34

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 16:7
  • +1Ọb 12:28-30; 13:33

Àwọn míì

1 Ọba 15:11Ọb 12:20
1 Ọba 15:12Kr 13:1, 2
1 Ọba 15:22Kr 11:20-22
1 Ọba 15:42Sa 7:8, 12; Sm 89:33-37; Ais 37:35; Jer 33:20, 21
1 Ọba 15:41Ọb 11:36; 2Kr 21:7; Sm 132:13, 17
1 Ọba 15:52Sa 11:4, 15; Sm 51:àkọlé
1 Ọba 15:61Ọb 14:30; 2Kr 12:15
1 Ọba 15:72Kr 13:22
1 Ọba 15:72Kr 13:3
1 Ọba 15:81Kr 3:10; Mt 1:7
1 Ọba 15:82Kr 14:1
1 Ọba 15:102Kr 11:21, 22
1 Ọba 15:112Kr 14:2-5, 11; 15:17
1 Ọba 15:12Di 23:17, 18; 1Ọb 14:24; 22:45, 46
1 Ọba 15:121Ọb 11:7; 14:22, 23
1 Ọba 15:132Kr 11:18, 20
1 Ọba 15:13Di 7:5; 2Ọb 18:1, 4; 2Kr 34:1, 4
1 Ọba 15:132Sa 15:23; 2Kr 15:16-18; Jo 18:1
1 Ọba 15:14Nọ 33:52; Di 12:2; 1Ọb 22:41, 43
1 Ọba 15:151Kr 26:26, 27
1 Ọba 15:161Ọb 16:3, 12
1 Ọba 15:17Joṣ 18:21, 25
1 Ọba 15:172Kr 16:1-6
1 Ọba 15:182Kr 16:7
1 Ọba 15:202Ọb 15:29
1 Ọba 15:20Ond 18:29; 1Ọb 12:28, 29
1 Ọba 15:211Ọb 14:17; Sol 6:4
1 Ọba 15:22Joṣ 21:8, 17
1 Ọba 15:22Joṣ 18:21, 26; Ond 20:1; 1Sa 7:5; Jer 40:6
1 Ọba 15:232Kr 16:11-14
1 Ọba 15:241Ọb 22:42; 2Kr 17:3, 4; 18:1; 19:4; Mt 1:8
1 Ọba 15:251Ọb 14:20
1 Ọba 15:261Ọb 14:7, 9
1 Ọba 15:261Ọb 12:28-30; 13:33
1 Ọba 15:27Joṣ 19:44, 48; 21:20, 23; 1Ọb 16:15
1 Ọba 15:291Ọb 14:9, 10
1 Ọba 15:322Kr 12:15
1 Ọba 15:331Ọb 16:8
1 Ọba 15:341Ọb 16:7
1 Ọba 15:341Ọb 12:28-30; 13:33
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
  • 32
  • 33
  • 34
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Àwọn Ọba 15:1-34

Àwọn Ọba Kìíní

15 Ní ọdún kejìdínlógún Ọba Jèróbóámù+ ọmọ Nébátì, Ábíjámù di ọba lórí Júdà.+ 2 Ọdún mẹ́ta ló fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Máákà,+ ọmọ ọmọ Ábíṣálómù. 3 Gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ tí bàbá rẹ̀ dá ṣáájú rẹ̀ ni òun náà dá, kò sì fi gbogbo ọkàn rẹ̀ sin Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀ bíi Dáfídì baba ńlá rẹ̀. 4 Àmọ́, nítorí Dáfídì,+ Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀ jẹ́ kí àtọmọdọ́mọ rẹ̀ máa ṣàkóso* ní Jerúsálẹ́mù,+ ó gbé ọmọ rẹ̀ dìde lẹ́yìn rẹ̀, ó sì jẹ́ kí Jerúsálẹ́mù máa wà nìṣó. 5 Dáfídì ṣe ohun tí ó tọ́ ní ojú Jèhófà, ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀, kò kúrò nínú gbogbo ohun tí Ó pa láṣẹ fún un, àfi nínú ọ̀ràn Ùráyà ọmọ Hétì.+ 6 Ogun sì ń wáyé láàárín Rèhóbóámù àti Jèróbóámù ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀.+

7 Ní ti ìyókù ìtàn Ábíjámù àti gbogbo ohun tí ó ṣe, ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn ìgbà àwọn ọba Júdà?+ Bákan náà, ogun wáyé láàárín Ábíjámù àti Jèróbóámù.+ 8 Níkẹyìn, Ábíjámù sinmi pẹ̀lú àwọn baba ńlá rẹ̀, wọ́n sì sin ín sí Ìlú Dáfídì; Ásà+ ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.+

9 Ní ogún ọdún Jèróbóámù ọba Ísírẹ́lì, Ásà bẹ̀rẹ̀ sí í ṣàkóso lórí Júdà. 10 Ọdún mọ́kànlélógójì (41) ni ó fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ àgbà ni Máákà+ ọmọ ọmọ Ábíṣálómù. 11 Ásà ṣe ohun tí ó tọ́ ní ojú Jèhófà,+ bíi Dáfídì baba ńlá rẹ̀. 12 Ó lé àwọn aṣẹ́wó ọkùnrin tó wà ní tẹ́ńpìlì kúrò ní ilẹ̀ náà,+ ó sì mú gbogbo òrìṣà ẹ̀gbin* tí àwọn baba ńlá rẹ̀ ṣe kúrò.+ 13 Ó tiẹ̀ tún yọ Máákà+ ìyá rẹ̀ àgbà kúrò ní ipò ìyá ọba,* torí pé ó ṣe òrìṣà ẹ̀gbin tí wọ́n fi ń jọ́sìn òpó òrìṣà.* Ásà gé òrìṣà ẹ̀gbin+ rẹ̀ lulẹ̀, ó sì sun ún ní Àfonífojì Kídírónì.+ 14 Àmọ́ kò mú àwọn ibi gíga kúrò.+ Síbẹ̀, Ásà fi gbogbo ọkàn rẹ̀ sin Jèhófà ní gbogbo ọjọ́ ayé* rẹ̀. 15 Ó kó àwọn ohun tí òun àti bàbá rẹ̀ ti yà sí mímọ́ wá sínú ilé Jèhófà, ìyẹn fàdákà, wúrà àti àwọn ohun èlò míì.+

16 Ìgbà gbogbo ni ogun ń wáyé láàárín Ásà àti Bááṣà+ ọba Ísírẹ́lì. 17 Torí náà, Bááṣà ọba Ísírẹ́lì wá dojú kọ Júdà, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́* Rámà,+ kí ẹnikẹ́ni má bàa jáde tàbí kí ó wọlé sọ́dọ̀* Ásà ọba Júdà.+ 18 Ni Ásà bá kó gbogbo fàdákà àti wúrà tí ó ṣẹ́ kù nínú àwọn ibi ìṣúra ilé Jèhófà àti àwọn ibi ìṣúra ilé* ọba, ó sì kó wọn fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀. Ọba Ásà wá fi wọ́n ránṣẹ́ sí Bẹni-hádádì ọmọ Tábúrímónì ọmọ Hésíónì, ọba Síríà,+ tó ń gbé ní Damásíkù, ó sọ pé: 19 “Àdéhùn* kan wà láàárín èmi àti ìwọ àti láàárín bàbá mi àti bàbá rẹ. Mo fi ẹ̀bùn fàdákà àti wúrà ránṣẹ́ sí ọ. Wò ó, lọ yẹ àdéhùn* tí o bá Bááṣà ọba Ísírẹ́lì ṣe, kó lè pa dà lẹ́yìn mi.” 20 Bẹni-hádádì ṣe ohun tí Ọba Ásà sọ, ó rán àwọn olórí ọmọ ogun rẹ̀ láti gbéjà ko àwọn ìlú Ísírẹ́lì, wọ́n sì ṣá Íjónì,+ Dánì+ àti Ebẹli-bẹti-máákà balẹ̀ pẹ̀lú gbogbo Kínérétì àti gbogbo ilẹ̀ Náfútálì. 21 Nígbà tí Bááṣà gbọ́ ohun tó ṣẹlẹ̀, ẹsẹ̀kẹsẹ̀ ló jáwọ́ nínú kíkọ́* Rámà, ó sì ń gbé ní Tírísà.+ 22 Ọba Ásà wá pe gbogbo Júdà, láìyọ ẹnì kankan sílẹ̀, wọ́n kó àwọn òkúta àti ẹ̀là gẹdú tó wà ní Rámà, tí Bááṣà fi ń kọ́lé, Ọba Ásà sì fi wọ́n kọ́* Gébà+ ní Bẹ́ńjámínì àti Mísípà.+

23 Ní ti gbogbo ìyókù ìtàn Ásà àti gbogbo agbára rẹ̀ àti gbogbo ohun tí ó ṣe àti àwọn ìlú tí ó kọ́,* ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn ìgbà àwọn ọba Júdà? Àmọ́, nígbà tí ó darúgbó, àìsàn kan mú un ní ẹsẹ̀.+ 24 Níkẹyìn, Ásà sinmi pẹ̀lú àwọn baba ńlá rẹ̀, wọ́n sì sin ín pẹ̀lú wọn ní Ìlú Dáfídì baba ńlá rẹ̀; Jèhóṣáfátì+ ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.

25 Nádábù+ ọmọ Jèróbóámù di ọba lórí Ísírẹ́lì ní ọdún kejì Ásà ọba Júdà, ọdún méjì ló sì fi ṣàkóso lórí Ísírẹ́lì. 26 Ohun búburú ló ń ṣe ní ojú Jèhófà, ó sì ń rìn ní ọ̀nà bàbá rẹ̀+ àti nínú ẹ̀ṣẹ̀ tí bàbá rẹ̀ mú kí Ísírẹ́lì dá.+ 27 Bááṣà ọmọ Áhíjà ará ilé Ísákà dìtẹ̀ mọ́ ọn, Bááṣà sì pa á ní Gíbétónì+ tó jẹ́ ti àwọn Filísínì, nígbà tí Nádábù àti gbogbo Ísírẹ́lì dó ti Gíbétónì. 28 Bí Bááṣà ṣe pa á nìyẹn ní ọdún kẹta Ásà ọba Júdà, ó sì jọba ní ipò rẹ̀. 29 Gbàrà tí ó di ọba, ó ṣá gbogbo ilé Jèróbóámù balẹ̀. Kò ṣẹ́ alààyè kankan kù lára àwọn ará ilé Jèróbóámù; ó ní kí wọ́n pa wọ́n rẹ́ bí ọ̀rọ̀ tí Jèhófà gbẹnu ìránṣẹ́ rẹ̀, Áhíjà ọmọ Ṣílò,+ sọ. 30 Èyí jẹ́ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tí Jèróbóámù dá, tí ó sì mú kí Ísírẹ́lì náà dá àti nítorí pé ó mú Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì bínú gan-an. 31 Ní ti ìyókù ìtàn Nádábù àti gbogbo ohun tí ó ṣe, ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn ìgbà àwọn ọba Ísírẹ́lì? 32 Ìgbà gbogbo ni ogun ń wáyé láàárín Ásà àti Bááṣà ọba Ísírẹ́lì.+

33 Ní ọdún kẹta Ásà ọba Júdà, Bááṣà ọmọ Áhíjà di ọba lórí gbogbo Ísírẹ́lì ní Tírísà, ó sì fi ọdún mẹ́rìnlélógún (24) ṣàkóso.+ 34 Àmọ́ ohun búburú ló ń ṣe ní ojú Jèhófà,+ ó sì rìn ní ọ̀nà Jèróbóámù àti nínú ẹ̀ṣẹ̀ tí ó mú kí Ísírẹ́lì dá.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́