ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 61
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • A fòróró yàn án láti kéde ìhìn rere (1-11)

        • “Ọdún ìtẹ́wọ́gbà Jèhófà” (2)

        • “Igi ńlá òdodo” (3)

        • Àwọn àjèjì máa ṣèrànwọ́ (5)

        • “Àlùfáà Jèhófà” (6)

Àìsáyà 61:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 42:1; Mt 3:16
  • +Mt 11:4, 5; Iṣe 10:37, 38
  • +Lk 4:17-21; 7:22; Iṣe 26:17, 18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 16

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2019, ojú ìwé 10-13

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2011, ojú ìwé 10

    6/1/2010, ojú ìwé 22

    10/1/2008, ojú ìwé 5

    7/1/2005, ojú ìwé 19-20

    5/1/2003, ojú ìwé 19-20

    1/1/2002, ojú ìwé 13-14, 16

    6/1/1992, ojú ìwé 16

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 322-324

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 143

Àìsáyà 61:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ojúure.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 34:8
  • +Ais 25:8; Mt 5:4; Lk 6:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 16

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    2/2017, ojú ìwé 5

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2011, ojú ìwé 27

    5/1/2003, ojú ìwé 19-20

    1/1/2002, ojú ìwé 13-14, 16-18

    6/1/1992, ojú ìwé 16

    11/1/1991, ojú ìwé 5-6

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 324-325

Àìsáyà 61:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kó lè bu ẹwà kún un.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 60:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    2/2017, ojú ìwé 5

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 312

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 325-326

Àìsáyà 61:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 49:8; 51:3
  • +Ais 44:26; 58:12
  • +Isk 36:33, 34

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 327

Àìsáyà 61:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 60:10
  • +Ais 14:1, 2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2012, ojú ìwé 25

    4/1/2007, ojú ìwé 25

    5/15/1997, ojú ìwé 19

    7/1/1995, ojú ìwé 23-25

    4/15/1992, ojú ìwé 11, 16-17

    1/1/1991, ojú ìwé 16-17

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 327-328

Àìsáyà 61:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọrọ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 19:6
  • +Ais 23:17, 18; 60:5, 7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2012, ojú ìwé 25

    4/1/2007, ojú ìwé 25

    5/15/1997, ojú ìwé 19

    11/1/1995, ojú ìwé 30

    7/1/1995, ojú ìwé 23-25

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 328-329

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 111

Àìsáyà 61:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sek 9:12
  • +Ais 35:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 329-330

Àìsáyà 61:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:4; Sm 33:5; 37:28
  • +Owe 6:16-19
  • +Ais 55:3; Jer 32:40

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2007, ojú ìwé 11

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 330-332

Àìsáyà 61:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “èso.”

  • *

    Ní Héb., “èso.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sek 8:13
  • +Ais 65:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2007, ojú ìwé 11

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 332-333

Àìsáyà 61:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ọkàn mi.”

  • *

    Tàbí “aṣọ àwọ̀lékè òdodo tí kò lápá.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 65:13
  • +Ais 52:1; Ifi 21:2
  • +Ẹk 28:39, 41

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 333

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 68

Àìsáyà 61:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 45:8; 62:1
  • +Ais 58:11; 60:18; 62:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 333-334

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1993, ojú ìwé 9-10

Àwọn míì

Àìsá. 61:1Ais 42:1; Mt 3:16
Àìsá. 61:1Mt 11:4, 5; Iṣe 10:37, 38
Àìsá. 61:1Lk 4:17-21; 7:22; Iṣe 26:17, 18
Àìsá. 61:2Ais 34:8
Àìsá. 61:2Ais 25:8; Mt 5:4; Lk 6:21
Àìsá. 61:3Ais 60:21
Àìsá. 61:4Ais 49:8; 51:3
Àìsá. 61:4Ais 44:26; 58:12
Àìsá. 61:4Isk 36:33, 34
Àìsá. 61:5Ais 60:10
Àìsá. 61:5Ais 14:1, 2
Àìsá. 61:6Ẹk 19:6
Àìsá. 61:6Ais 23:17, 18; 60:5, 7
Àìsá. 61:7Sek 9:12
Àìsá. 61:7Ais 35:10
Àìsá. 61:8Di 32:4; Sm 33:5; 37:28
Àìsá. 61:8Owe 6:16-19
Àìsá. 61:8Ais 55:3; Jer 32:40
Àìsá. 61:9Sek 8:13
Àìsá. 61:9Ais 65:23
Àìsá. 61:10Ais 65:13
Àìsá. 61:10Ais 52:1; Ifi 21:2
Àìsá. 61:10Ẹk 28:39, 41
Àìsá. 61:11Ais 45:8; 62:1
Àìsá. 61:11Ais 58:11; 60:18; 62:7
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 61:1-11

Àìsáyà

61 Ẹ̀mí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wà lára mi,+

Torí Jèhófà ti yàn mí kí n lè kéde ìhìn rere fún àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+

Ó rán mi láti di ọgbẹ́ àwọn tó ní ọgbẹ́ ọkàn,

Láti kéde òmìnira fún àwọn ẹrú,

Pé ojú àwọn ẹlẹ́wọ̀n sì máa là rekete,+

 2 Láti kéde ọdún ìtẹ́wọ́gbà* Jèhófà

Àti ọjọ́ ẹ̀san Ọlọ́run wa,+

Láti tu gbogbo àwọn tó ń ṣọ̀fọ̀ nínú,+

 3 Láti pèsè fún àwọn tó ń ṣọ̀fọ̀ torí Síónì,

Láti fún wọn ní ìwérí dípò eérú,

Òróró ayọ̀ dípò ọ̀fọ̀,

Aṣọ ìyìn dípò ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn.

A ó sì máa pè wọ́n ní igi ńlá òdodo,

Tí Jèhófà gbìn, kó lè ṣe é lógo.*+

 4 Wọ́n máa tún àwọn ibi tó ti pa run nígbà àtijọ́ kọ́;

Wọ́n máa kọ́ àwọn ibi tó ti dahoro nígbà àtijọ́,+

Wọ́n sì máa mú kí àwọn ìlú tó ti pa run pa dà sí bó ṣe wà tẹ́lẹ̀,+

Àwọn ibi tó ti wà ní ahoro láti ìran dé ìran.+

 5 “Àwọn àjèjì máa dúró, wọ́n sì máa tọ́jú àwọn agbo ẹran yín,

Àwọn àlejò + máa jẹ́ àgbẹ̀ yín, wọ́n á sì máa bá yín rẹ́wọ́ àjàrà.+

 6 Ní tiyín, a ó máa pè yín ní àlùfáà Jèhófà;+

Wọ́n á máa pè yín ní òjíṣẹ́ Ọlọ́run wa.

Ẹ máa jẹ ohun àmúṣọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè,+

Ẹ sì máa fi ògo* wọn yangàn.

 7 Dípò ìtìjú, ẹ máa ní ìpín ìlọ́po méjì,

Dípò ìdójútì, wọ́n máa kígbe ayọ̀ nítorí ìpín wọn.

Àní, ìpín ìlọ́po méjì ni wọ́n máa gbà ní ilẹ̀ wọn.+

Wọ́n á máa yọ̀ títí ayérayé.+

 8 Torí èmi Jèhófà, nífẹ̀ẹ́ ìdájọ́ òdodo;+

Mo kórìíra olè jíjà àti àìṣòdodo.+

Màá fi òótọ́ san èrè iṣẹ́ wọn fún wọn,

Màá sì bá wọn dá májẹ̀mú tó máa wà títí láé.+

 9 Wọ́n máa mọ àwọn ọmọ* wọn láàárín àwọn orílẹ̀-èdè +

Àti àtọmọdọ́mọ wọn láàárín àwọn èèyàn.

Gbogbo àwọn tó bá rí wọn máa dá wọn mọ̀,

Pé àwọn ni ọmọ* tí Jèhófà bù kún.”+

10 Màá yọ̀ gidigidi nínú Jèhófà.

Gbogbo ara mi* máa yọ̀ nínú Ọlọ́run mi.+

Torí ó ti fi ẹ̀wù ìgbàlà wọ̀ mí;+

Ó ti fi aṣọ òdodo* bò mí lára,

Bí ọkọ ìyàwó tó wé láwàní bíi ti àlùfáà+

Àti bí ìyàwó tó fi àwọn ohun ọ̀ṣọ́ rẹ̀ ṣe ara rẹ̀ lọ́ṣọ̀ọ́.

11 Torí bí ilẹ̀ ṣe ń mú irúgbìn jáde,

Tí ọgbà sì ń mú kí ohun tí wọ́n gbìn sínú rẹ̀ hù,

Bẹ́ẹ̀ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ

Ṣe máa mú kí òdodo+ àti ìyìn rú jáde+ níwájú gbogbo orílẹ̀-èdè.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́