ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Jòhánù 3
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Jòhánù

      • Ọmọ Ọlọ́run ni wá (1-3)

      • Àwọn ọmọ Ọlọ́run yàtọ̀ sí àwọn ọmọ Èṣù (4-12)

        • Jésù máa fọ́ àwọn iṣẹ́ Èṣù túútúú (8)

      • Ẹ nífẹ̀ẹ́ ara yín (13-18)

      • Ọlọ́run ju ọkàn wa lọ (19-24)

1 Jòhánù 3:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 3:16
  • +Jo 1:12, 13
  • +Jo 15:19
  • +Jo 17:25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2015, ojú ìwé 18

1 Jòhánù 3:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 8:15, 16; Ef 1:5
  • +1Kọ 15:49; Flp 3:20, 21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2020, ojú ìwé 8-9

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2008, ojú ìwé 27

1 Jòhánù 3:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 7:1

1 Jòhánù 3:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 16:21, 22; Ais 53:11; Jo 1:29

1 Jòhánù 3:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 6:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    3/1/1991, ojú ìwé 27

1 Jòhánù 3:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “látìgbà tí ó ti bẹ̀rẹ̀.”

  • *

    Tàbí “kó lè run àwọn iṣẹ́ Èṣù.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 3:14; Jo 8:44
  • +Jo 16:33; Heb 2:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/1999, ojú ìwé 11

    7/1/1998, ojú ìwé 11-12

1 Jòhánù 3:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, irúgbìn tó lè méso jáde tàbí kó bí sí i.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Jo 5:18
  • +1Pe 1:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/1998, ojú ìwé 13

1 Jòhánù 3:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Jo 4:8

1 Jòhánù 3:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 13:34; 1Jo 2:7; 2Jo 5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Olùkọ́, ojú ìwé 225

1 Jòhánù 3:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 4:8
  • +Jẹ 4:5
  • +Jẹ 4:4; Heb 11:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Olùkọ́, ojú ìwé 225

1 Jòhánù 3:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 5:11; Jo 15:18; 2Ti 3:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    7/2020, ojú ìwé 24

1 Jòhánù 3:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 5:24; Ro 8:2
  • +1Jo 2:10
  • +Jo 3:36

1 Jòhánù 3:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 5:21, 22; Ef 4:31
  • +Jẹ 9:6; Nọ 35:31; Ifi 21:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 7/2021,

    ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run’, ojú ìwé 82

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2006, ojú ìwé 27

1 Jòhánù 3:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

  • *

    Tàbí “ọkàn wa.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 3:16; 13:1; 15:13
  • +Jo 13:15; Ro 16:3, 4; 1Tẹ 2:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 18

    “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” ojú ìwé 177-178

1 Jòhánù 3:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 15:7, 8; Lk 3:11; Ro 12:13; Jem 2:15, 16; 1Jo 4:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    7/2020, ojú ìwé 24

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/1997, ojú ìwé 32

1 Jòhánù 3:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 12:9
  • +Jem 1:22; 2:17
  • +1Pe 1:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2017, ojú ìwé 7-11

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/1997, ojú ìwé 32

1 Jòhánù 3:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “máa yí èrò ọkàn wa pa dà; máa mú kó dá ọkàn wa lójú.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 240-249

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/2008, ojú ìwé 9

    7/15/2007, ojú ìwé 16-17

    5/1/2000, ojú ìwé 30-31

1 Jòhánù 3:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 4:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2021, ojú ìwé 23-24

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 240-249

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/2008, ojú ìwé 9

    7/15/2007, ojú ìwé 16-17

    8/1/2005, ojú ìwé 30

    5/1/2000, ojú ìwé 29-30

1 Jòhánù 3:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 4:16; 1Jo 5:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2007, ojú ìwé 16-17

1 Jòhánù 3:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 34:15; Mt 7:8; 1Pe 3:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2007, ojú ìwé 16-17

1 Jòhánù 3:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 6:29
  • +Jo 13:34

1 Jòhánù 3:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Jo 2:24
  • +Jo 14:23

Àwọn míì

1 Jòh. 3:1Jo 3:16
1 Jòh. 3:1Jo 1:12, 13
1 Jòh. 3:1Jo 15:19
1 Jòh. 3:1Jo 17:25
1 Jòh. 3:2Ro 8:15, 16; Ef 1:5
1 Jòh. 3:21Kọ 15:49; Flp 3:20, 21
1 Jòh. 3:32Kọ 7:1
1 Jòh. 3:5Le 16:21, 22; Ais 53:11; Jo 1:29
1 Jòh. 3:6Ro 6:12
1 Jòh. 3:8Jẹ 3:14; Jo 8:44
1 Jòh. 3:8Jo 16:33; Heb 2:14
1 Jòh. 3:91Jo 5:18
1 Jòh. 3:91Pe 1:23
1 Jòh. 3:101Jo 4:8
1 Jòh. 3:11Jo 13:34; 1Jo 2:7; 2Jo 5
1 Jòh. 3:12Jẹ 4:8
1 Jòh. 3:12Jẹ 4:5
1 Jòh. 3:12Jẹ 4:4; Heb 11:4
1 Jòh. 3:13Mt 5:11; Jo 15:18; 2Ti 3:12
1 Jòh. 3:14Jo 5:24; Ro 8:2
1 Jòh. 3:141Jo 2:10
1 Jòh. 3:14Jo 3:36
1 Jòh. 3:15Mt 5:21, 22; Ef 4:31
1 Jòh. 3:15Jẹ 9:6; Nọ 35:31; Ifi 21:8
1 Jòh. 3:16Jo 3:16; 13:1; 15:13
1 Jòh. 3:16Jo 13:15; Ro 16:3, 4; 1Tẹ 2:8
1 Jòh. 3:17Di 15:7, 8; Lk 3:11; Ro 12:13; Jem 2:15, 16; 1Jo 4:20
1 Jòh. 3:18Ro 12:9
1 Jòh. 3:18Jem 1:22; 2:17
1 Jòh. 3:181Pe 1:22
1 Jòh. 3:20Heb 4:13
1 Jòh. 3:21Heb 4:16; 1Jo 5:14
1 Jòh. 3:22Sm 34:15; Mt 7:8; 1Pe 3:12
1 Jòh. 3:23Jo 6:29
1 Jòh. 3:23Jo 13:34
1 Jòh. 3:241Jo 2:24
1 Jòh. 3:24Jo 14:23
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Jòhánù 3:1-24

Ìwé Kìíní Jòhánù

3 Ẹ wo irú ìfẹ́ tí Baba ní sí wa+ tí a fi ń pè wá ní ọmọ Ọlọ́run!+ Ohun tí a sì jẹ́ nìyẹn. Ìdí nìyẹn tí ayé ò fi mọ̀ wá,+ torí kò tíì mọ̀ ọ́n.+ 2 Ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, a ti wá di ọmọ Ọlọ́run,+ àmọ́ a ò tíì fi ohun tí a máa jẹ́ hàn kedere.+ A mọ̀ pé nígbà tí a bá fi í hàn kedere a máa dà bíi rẹ̀, torí a máa rí i bó ṣe rí gẹ́lẹ́. 3 Gbogbo ẹni tó bá sì ní ìrètí yìí nínú rẹ̀ ń wẹ ara rẹ̀ mọ́+ bí ẹni yẹn ṣe jẹ́ mímọ́.

4 Gbogbo ẹni tó bá sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà ń rú òfin, ẹ̀ṣẹ̀ ni rírú òfin. 5 Bákan náà, ẹ mọ̀ pé a fi í hàn kedere láti mú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa kúrò,+ kò sì sí ẹ̀ṣẹ̀ nínú rẹ̀. 6 Gbogbo ẹni tó bá wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀ kì í sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà;+ ẹnikẹ́ni tó bá sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà kò tíì rí i, kò sì tíì mọ̀ ọ́n. 7 Ẹ̀yin ọmọ kéékèèké, kí ẹnikẹ́ni má ṣì yín lọ́nà; gbogbo ẹni tó bá ń ṣe òdodo jẹ́ olódodo, bí ẹni yẹn ṣe jẹ́ olódodo. 8 Ẹni tó bá ń sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà wá látọ̀dọ̀ Èṣù, torí láti ìbẹ̀rẹ̀* ni Èṣù ti ń dẹ́ṣẹ̀.+ Ìdí tí a ṣe fi Ọmọ Ọlọ́run hàn kedere nìyí, kó lè fọ́ àwọn iṣẹ́ Èṣù túútúú.*+

9 Gbogbo ẹni tí a bí látọ̀dọ̀ Ọlọ́run kì í sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà,+ torí irúgbìn* Rẹ̀ wà nínú ẹni náà, kò sì lè sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà, torí ọ̀dọ̀ Ọlọ́run la ti bí i.+ 10 Ohun tí a máa fi dá àwọn ọmọ Ọlọ́run àti àwọn ọmọ Èṣù mọ̀ nìyí: Ẹnikẹ́ni tí kì í ṣe òdodo kò wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run, bẹ́ẹ̀ sì ni ẹni tí kò nífẹ̀ẹ́ arákùnrin rẹ̀.+ 11 Torí ọ̀rọ̀ tí ẹ ti gbọ́ láti ìbẹ̀rẹ̀ ni pé ká nífẹ̀ẹ́ ara wa;+ 12 kì í ṣe bíi Kéènì, tó jẹ́ ti ẹni burúkú náà, tó sì pa àbúrò rẹ̀.+ Kí nìdí tó fi pa á? Torí àwọn iṣẹ́ rẹ̀ burú,+ àmọ́ ti àbúrò rẹ̀ jẹ́ òdodo.+

13 Ẹ̀yin ará, ẹ má ṣe jẹ́ kó yà yín lẹ́nu pé ayé kórìíra yín.+ 14 A mọ̀ pé a ti tinú ikú wá sí ìyè,+ torí pé a nífẹ̀ẹ́ àwọn ará.+ Ẹni tí kò nífẹ̀ẹ́ ṣì wà nínú ikú.+ 15 Gbogbo ẹni tó bá kórìíra arákùnrin rẹ̀ jẹ́ apààyàn,+ ẹ sì mọ̀ pé kò sí apààyàn kankan tí ìyè àìnípẹ̀kun ṣì wà nínú rẹ̀.+ 16 Ohun tó jẹ́ ká mọ ìfẹ́ ni pé ẹni yẹn fi ẹ̀mí* rẹ̀ lélẹ̀ fún wa,+ torí náà ó di dandan kí àwa náà fi ẹ̀mí wa* lélẹ̀ fún àwọn ará wa.+ 17 Àmọ́ ẹnikẹ́ni tó bá ní ohun ìní ayé yìí, tó sì rí i pé arákùnrin rẹ̀ ṣaláìní síbẹ̀ tí kò ṣàánú rẹ̀, báwo ni ìfẹ́ Ọlọ́run ṣe wà nínú rẹ̀?+ 18 Ẹ̀yin ọmọ kéékèèké, kò yẹ kí ìfẹ́ wa jẹ́ ọ̀rọ̀ ẹnu tàbí ti ahọ́n,+ àmọ́ ó yẹ kó jẹ́ ní ìṣe+ àti òtítọ́.+

19 Èyí ló máa jẹ́ ká mọ̀ pé a wá látinú òtítọ́, a sì máa jẹ́ kí ọkàn wa balẹ̀* níwájú rẹ̀ 20 nínú ohunkóhun tí ọkàn wa ti lè dá wa lẹ́bi, torí Ọlọ́run ju ọkàn wa lọ, ó sì mọ ohun gbogbo.+ 21 Ẹ̀yin ẹni ọ̀wọ́n, tí ọkàn wa kò bá dá wa lẹ́bi, a lè sọ̀rọ̀ ní fàlàlà níwájú Ọlọ́run;+ 22 a sì ń rí ohunkóhun tí a bá béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ gbà,+ torí à ń pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́, a sì ń ṣe àwọn ohun tó dáa lójú rẹ̀. 23 Lóòótọ́, àṣẹ tó pa nìyí pé: ká ní ìgbàgbọ́ nínú orúkọ Ọmọ rẹ̀ Jésù Kristi,+ ká sì nífẹ̀ẹ́ ara wa+ bó ṣe pàṣẹ fún wa gẹ́lẹ́. 24 Bákan náà, ẹni tó bá ń pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́ wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀, ó sì máa wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú ẹni náà.+ Ẹ̀mí tó fún wa sì jẹ́ ká mọ̀ pé ó wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú wa.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́