ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sefanáyà 3
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sefanáyà

      • Jerúsálẹ́mù, ìlú tí ọ̀tẹ̀ àti ìwàkiwà kún inú rẹ̀ (1-7)

      • Ìdájọ́ àti ìpadàbọ̀sípò (8-20)

        • Ìyípadà sí èdè mímọ́ (9)

        • A ó gba àwọn onírẹ̀lẹ̀ àtàwọn aláìní là (12)

        • Jèhófà máa yọ̀ nítorí Síónì (17)

Sefanáyà 3:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 5:7; Jer 6:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    5/1/1991, ojú ìwé 19-20

Sefanáyà 3:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 22:21; 32:23
  • +Sm 50:17; Ais 1:5; Jer 5:3
  • +Sm 78:22; Jer 17:5
  • +Ais 29:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    5/1/1991, ojú ìwé 19-20

Sefanáyà 3:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 1:23; Isk 22:27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ọjọ́ Jèhófà, ojú ìwé 78

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    3/1/1996, ojú ìwé 9, 14

    5/1/1991, ojú ìwé 19-20

Sefanáyà 3:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ida 2:14
  • +Jer 23:11
  • +Isk 22:25, 26; Mik 3:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 21-22

    5/1/1991, ojú ìwé 19-20

Sefanáyà 3:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:4
  • +Jer 21:12
  • +Jer 3:3; 8:12; Sef 2:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 22

Sefanáyà 3:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 18:28

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 22

Sefanáyà 3:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìtọ́sọ́nà.”

  • *

    Tàbí “jìyà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 5:3, 4; 63:8; 2Pe 3:9
  • +Jer 7:5-7; 25:5, 6
  • +Mik 2:1

Sefanáyà 3:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “fi sùúrù dúró dè mí.”

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “ṣe ẹlẹ́rìí sí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 37:34; 130:7; Ais 30:18
  • +Ais 34:2; Joẹ 3:2; Ifi 16:14; 19:19
  • +Isk 36:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ọjọ́ Jèhófà, ojú ìwé 152-154

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 23

    3/1/1996, ojú ìwé 11-14

    5/1/1991, ojú ìwé 13

    4/1/1991, ojú ìwé 22

Sefanáyà 3:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ní èjìká kan.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sek 8:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 56

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    1/2020, ojú ìwé 6

    A Ṣètò Wa, ojú ìwé 168

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2012, ojú ìwé 12

    1/15/2011, ojú ìwé 6

    8/15/2008, ojú ìwé 21-25

    11/15/2007, ojú ìwé 11

    11/15/2002, ojú ìwé 14-19

    9/15/2001, ojú ìwé 5-6

    2/15/2001, ojú ìwé 23-24, 27-28

    3/1/1996, ojú ìwé 15-16

    5/1/1991, ojú ìwé 10-14, 15-20

    4/1/1991, ojú ìwé 20-25

    “Kí Ijọba Rẹ Dé,” ojú ìwé 174-175, 182-183

Sefanáyà 3:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 60:4

Sefanáyà 3:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 45:17; 54:4
  • +Ais 11:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 24

Sefanáyà 3:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 57:15; 61:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2011, ojú ìwé 5

    2/15/2001, ojú ìwé 24

    3/1/1996, ojú ìwé 14

Sefanáyà 3:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “jẹko.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 10:22; Mik 4:7
  • +Ais 60:21
  • +Jer 30:10; Isk 34:28; 39:25, 26; Ho 2:18; Mik 4:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 24

    3/1/1996, ojú ìwé 14

Sefanáyà 3:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹsr 3:11; Ais 12:5, 6; Sek 2:10
  • +Mik 4:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 24-25

Sefanáyà 3:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 40:2; Sek 8:13
  • +Mik 7:10; Sek 2:8, 9
  • +Isk 48:35
  • +Emọ 9:15; Sek 14:11

Sefanáyà 3:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “kí ọwọ́ rẹ wálẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 46:28

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    3/1/1996, ojú ìwé 16-18

Sefanáyà 3:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “fọkàn balẹ̀; ní ìtẹ́lọ́rùn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 12:6
  • +Di 30:9; Sm 147:11; Ais 62:3; 65:19; Jer 32:41

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2011, ojú ìwé 5

    2/15/2001, ojú ìwé 26-27

    3/1/1996, ojú ìwé 16, 17-18

Sefanáyà 3:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ida 1:4; 2:6
  • +Ida 5:1

Sefanáyà 3:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “orúkọ kan.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 60:14; Sek 14:3
  • +Mik 4:6, 7
  • +Ais 11:11, 12; 27:12; Isk 28:25; 34:15, 16; Emọ 9:14

Sefanáyà 3:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “orúkọ kan.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 60:15
  • +Ais 61:7; Jer 30:10; 33:7, 9; Isk 39:25, 27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 24-25, 28

    3/1/1996, ojú ìwé 15

Àwọn míì

Sef. 3:1Ais 5:7; Jer 6:6
Sef. 3:2Jer 22:21; 32:23
Sef. 3:2Sm 50:17; Ais 1:5; Jer 5:3
Sef. 3:2Sm 78:22; Jer 17:5
Sef. 3:2Ais 29:13
Sef. 3:3Ais 1:23; Isk 22:27
Sef. 3:4Ida 2:14
Sef. 3:4Jer 23:11
Sef. 3:4Isk 22:25, 26; Mik 3:9
Sef. 3:5Di 32:4
Sef. 3:5Jer 21:12
Sef. 3:5Jer 3:3; 8:12; Sef 2:1
Sef. 3:6Le 18:28
Sef. 3:7Ais 5:3, 4; 63:8; 2Pe 3:9
Sef. 3:7Jer 7:5-7; 25:5, 6
Sef. 3:7Mik 2:1
Sef. 3:8Sm 37:34; 130:7; Ais 30:18
Sef. 3:8Ais 34:2; Joẹ 3:2; Ifi 16:14; 19:19
Sef. 3:8Isk 36:5
Sef. 3:9Sek 8:23
Sef. 3:10Ais 60:4
Sef. 3:11Ais 45:17; 54:4
Sef. 3:11Ais 11:9
Sef. 3:12Ais 57:15; 61:1
Sef. 3:13Ais 10:22; Mik 4:7
Sef. 3:13Ais 60:21
Sef. 3:13Jer 30:10; Isk 34:28; 39:25, 26; Ho 2:18; Mik 4:4
Sef. 3:14Ẹsr 3:11; Ais 12:5, 6; Sek 2:10
Sef. 3:14Mik 4:8
Sef. 3:15Ais 40:2; Sek 8:13
Sef. 3:15Mik 7:10; Sek 2:8, 9
Sef. 3:15Isk 48:35
Sef. 3:15Emọ 9:15; Sek 14:11
Sef. 3:16Jer 46:28
Sef. 3:17Ais 12:6
Sef. 3:17Di 30:9; Sm 147:11; Ais 62:3; 65:19; Jer 32:41
Sef. 3:18Ida 1:4; 2:6
Sef. 3:18Ida 5:1
Sef. 3:19Ais 60:14; Sek 14:3
Sef. 3:19Mik 4:6, 7
Sef. 3:19Ais 11:11, 12; 27:12; Isk 28:25; 34:15, 16; Emọ 9:14
Sef. 3:20Ais 60:15
Sef. 3:20Ais 61:7; Jer 30:10; 33:7, 9; Isk 39:25, 27
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Sefanáyà 3:1-20

Sefanáyà

3 Ìlú tó ń ṣọ̀tẹ̀ gbé! Ó ti di ẹlẹ́gbin, ó sì ń ni àwọn èèyàn rẹ̀ lára.+

 2 Kò ṣègbọràn;+ kò gba ìbáwí.+

Kò gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà;+ kò sì sún mọ́ Ọlọ́run rẹ̀.+

 3 Àwọn olórí tó wà nínú rẹ̀ jẹ́ kìnnìún tó ń ké ramúramù.+

Àwọn onídàájọ́ rẹ̀ jẹ́ ìkookò ní alẹ́;

Wọn kì í jẹ egungun kankan kù di òwúrọ̀.

 4 Aláfojúdi ni àwọn wòlíì rẹ̀, oníbékebèke ni wọ́n.+

Àwọn àlùfáà rẹ̀ ń sọ ohun mímọ́ di ẹlẹ́gbin;+

Wọ́n ń rú òfin.+

 5 Jèhófà jẹ́ olódodo ní àárín rẹ̀;+ kò ní ṣe àìtọ́.

Àràárọ̀ ló ń jẹ́ ká mọ ìdájọ́ rẹ̀,+

Kì í yẹ̀ bí ojúmọ́ kì í ti í yẹ̀.

Ṣùgbọ́n àwọn aláìṣòdodo kò ní ìtìjú.+

 6 “Mo pa àwọn orílẹ̀-èdè run; àwọn ilé gogoro tó wà ní àwọn ìkángun odi wọn ti di ahoro.

Mo pa àwọn ojú ọ̀nà wọn run, tí kò fi sí ẹni tó ń gbà á kọjá.

Àwọn ìlú wọn ti di àwókù tí kò sí ẹnì kankan níbẹ̀, tí kò sì ní olùgbé kankan.+

 7 Mo sọ pé, ‘Dájúdájú, wàá bẹ̀rù mi, wàá sì gba ìbáwí,’*+

Kí ibùgbé rẹ̀ má bàa pa run+

Màá pè é wá jíhìn* nítorí gbogbo nǹkan yìí.

Síbẹ̀, ara túbọ̀ ń yá wọn láti hùwàkiwà.+

 8 ‘Nítorí náà, ẹ máa retí mi,’*+ ni Jèhófà wí,

‘Títí di ọjọ́ tí màá wá gba* ohun tí ẹ ti gbà lọ́wọ́ àwọn èèyàn,

Nítorí ìdájọ́ mi ni láti kó àwọn orílẹ̀-èdè jọ, kí n sì kó àwọn ìjọba jọ,

Kí n lè da ìrunú mi sórí wọn, gbogbo ìbínú mi tó ń jó fòfò;+

Torí ìtara mi tó ń jó bí iná máa jó gbogbo ayé run.+

 9 Nígbà náà, màá yí èdè àwọn èèyàn pa dà sí èdè mímọ́,

Kí gbogbo wọn lè máa pe orúkọ Jèhófà,

Kí wọ́n lè máa sìn ín ní ìṣọ̀kan.’*+

10 Láti agbègbè àwọn odò tó wà ní Etiópíà,

Ni àwọn tó ń pàrọwà sí mi, ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi tí wọ́n tú ká, ti máa mú ẹ̀bùn wá fún mi.+

11 Ní ọjọ́ yẹn, ojú ò ní tì ọ́

Nítorí gbogbo ohun tí o ṣe láti fi ṣọ̀tẹ̀ sí mi,+

Torí nígbà náà, màá mú àwọn agbéraga tó ń fọ́nnu kúrò láàárín rẹ;

O ò sì ní gbéra ga mọ́ ní òkè mímọ́ mi.+

12 Màá jẹ́ kí àwọn onírẹ̀lẹ̀ àti àwọn aláìní wà ní àárín rẹ,+

Wọ́n á sì fi orúkọ Jèhófà ṣe ibi ààbò.

13 Àwọn tó ṣẹ́ kù lára Ísírẹ́lì+ kò ní hùwà àìṣòdodo;+

Wọn kò ní parọ́, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò ní fi ahọ́n wọn tanni jẹ;

Wọ́n á jẹun,* wọ́n á sì dùbúlẹ̀, ẹnì kankan ò sì ní dẹ́rù bà wọ́n.”+

14 Kígbe ayọ̀, ìwọ ọmọbìnrin Síónì!

Kígbe ìṣẹ́gun, ìwọ Ísírẹ́lì!+

Máa yọ̀, sì jẹ́ kí ayọ̀ kún inú ọkàn rẹ, ìwọ ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù!+

15 Jèhófà ti mú àwọn ìdájọ́ kúrò lórí rẹ.+

Ó ti lé ọ̀tá rẹ dà nù.+

Ọba Ísírẹ́lì, Jèhófà, wà ní àárín rẹ.+

Ìwọ kò ní bẹ̀rù àjálù mọ́.+

16 Ní ọjọ́ yẹn, a ó sọ fún Jerúsálẹ́mù pé:

“Má bẹ̀rù, ìwọ Síónì.+

Má ṣe jẹ́ kí ọkàn rẹ domi.*

17 Jèhófà Ọlọ́run rẹ wà ní àárín rẹ.+

Ó máa gbani là bí Alágbára ńlá.

Ó máa yọ̀ gidigidi nítorí rẹ.+

Á dákẹ́ jẹ́ẹ́* nínú ìfẹ́ rẹ̀.

Á dunnú nítorí rẹ pẹ̀lú igbe ayọ̀.

18 Àwọn tí ẹ̀dùn ọkàn bá torí pé wọn ò wá sí àwọn àjọyọ̀ rẹ ni màá kó jọ;+

Wọn ò sí lọ́dọ̀ rẹ torí pé wọ́n wà ní ìgbèkùn, níbi tí wọ́n ti ń kẹ́gàn wọn.+

19 Wò ó! Ní àkókò yẹn, màá dojú ìjà kọ gbogbo àwọn tó ń pọ́n ọ lójú;+

Màá gba ẹni tó ń tiro là,+

Màá sì kó àwọn tó ti fọ́n ká jọ.+

Màá sọ wọ́n di ẹni iyì àti olókìkí*

Ní gbogbo ilẹ̀ tí ìtìjú ti bá wọn.

20 Ní àkókò yẹn, màá mú yín wọlé,

Ní àkókò tí mo kó yín jọ.

Nítorí màá sọ yín di olókìkí* àti ẹni iyì+ láàárín gbogbo aráyé,

Tí mo bá kó àwọn èèyàn yín tó wà ní oko ẹrú pa dà lójú yín,” ni Jèhófà wí.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́