ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • wp20 No. 1 ojú ìwé 16
  • Àǹfààní Tí Wàá Rí Tó O Bá Mọ Òtítọ́

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àǹfààní Tí Wàá Rí Tó O Bá Mọ Òtítọ́
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2020
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • KÍ LÓ YẸ KÓ O ṢE?
  • “Ó Bìkítà fún Ẹ”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2019
  • Ṣé O Ti Béèrè Rí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2020
  • O Lè Sún Mọ́ Ọlọ́run
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2019
  • Kí Ló Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Ọ̀la?
    Kí Ló Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Ọ̀la?
Àwọn Míì
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2020
wp20 No. 1 ojú ìwé 16

Àǹfààní Tí Wàá Rí Tó O Bá Mọ Òtítọ́

Ọlọ́run kì í parọ́, ó máa fún ẹ ní ìrètí “ìyè àìnípẹ̀kun.”​—Jòhánù 3:16.

KÍ LÓ YẸ KÓ O ṢE?

Ọ̀dọ́bìnrin kan ń ka Bíbélì lórí tablet rẹ̀ nílé kọfí
  • Máa kẹ́kọ̀ọ́ òtítọ́ látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.​—Jòhánù 17:3, 17.

  • Máa gbọ́ràn sí Ọlọ́run lẹ́nu.​—Diutarónómì 30:19, 20.

  • Máa fi ìmọ̀ràn Ọlọ́run sílò láyé rẹ̀.​—Jémíìsì 1:25.

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà kárí ayé ń jàǹfààní bá a ṣe ń kẹ́kọ̀ọ́ òtítọ́ látinú Bíbélì. Inú wa máa dùn láti fi àwọn ohun tá à ń kọ́ nínú Bíbélì hàn ẹ́.

Kó o lè túbọ̀ mọ àwọn ẹ̀kọ́ òtítọ́ tó wà nínú Bíbélì, wo ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe é, ó sì wà lórí ìkànnì www.jw.org/yo.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́