ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 3/12 ojú ìwé 8
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2012
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2012
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2013
  • Ohun Tó O Lè Sọ Nípa Àwọn Ìwé Ìròyìn
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2011
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2012
Àwọn Míì
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2012
km 3/12 ojú ìwé 8

Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

Láti Bẹ̀rẹ̀ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ní Saturday Àkọ́kọ́ Lóṣù April

“Ọ̀pọ̀ Kristẹni ló máa ń ṣe ìbatisí. Ǹjẹ́ ó ṣe pàtàkì kéèyàn ṣe ìbatisí? Kí lèrò ẹ? [Jẹ́ kó fèsì.] Àpilẹ̀kọ yìí sọ àwọn kókó tó wọni lọ́kàn gan-an.” Fún onílé ní ẹ̀dà Ilé Ìṣọ́ April 1, kẹ́ ẹ sì jọ jíròrò àlàyé tó wà lábẹ́ ìsọ̀rí àkọ́kọ́ ní ojú ìwé 16 nínú ìwé ìròyìn náà àti ẹsẹ Ìwé Mímọ́ kan, ó kéré tán. Fún un ní àwọn ìwé ìròyìn náà kẹ́ ẹ sì ṣàdéhùn ìgbà tí wàá pa dà wá kẹ́ ẹ lè jíròrò ìbéèrè tó kàn.

April 1

“Onírúurú nǹkan ni àwọn èèyàn ń sọ nípa Jésù. Àwọn kan rò pé òun ni Mèsáyà tí Ọlọ́run ṣèlérí. Àwọn míì gbà pé ṣe ló wulẹ̀ jẹ́ ẹni rere kan. Àwọn míì tiẹ̀ wà tí kò gbà pé ẹnì kan wà tó ń jẹ́ Jésù. Kí lèrò ẹ? [Jẹ́ kó fèsì.] Gẹ́gẹ́ bí Bíbélì ṣe sọ, ó ṣe pàtàkì pé kéèyàn mọ ẹni tí Jésù jẹ́ gan-an. [Ka Jòhánù 17:3.] Ìwé ìròyìn yìí jẹ́ ká mọ ohun tí Bíbélì sọ nípa àwọn ìbéèrè tí àwọn èèyàn ń béèrè nípa Jésù.”

April–June

“Lóde òní, àwọn èèyàn sábà máa ń lọ́wọ́ nínú oríṣiríṣi ìwà àìṣòótọ́ lẹ́nu iṣẹ́ ajé, irú bíi kí wọ́n máa gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ tàbí owó ẹ̀yìn. Èrò àwọn kan ni pé ó pọn dandan kéèyàn lọ́wọ́ sí irú àwọn ìwà àìṣòótọ́ kan kéèyàn tó lè rọ́wọ́ mú nídìí iṣẹ́ ajé. Kí lèrò tìẹ? [Jẹ́ kó fèsì.] Jẹ́ ká wo òwe kan nínú Bíbélì tó ń múni ronú jinlẹ̀. [Ka Òwe 20:17.] Ìwé ìròyìn yìí ṣàlàyé ìdí tó fi bọ́gbọ́n mu pé kéèyàn jẹ́ olóòótọ́.”

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́