ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 10/12 ojú ìwé 8
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2012
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2012
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2012
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2011
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2011
Àwọn Míì
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2012
km 10/12 ojú ìwé 8

Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

Láti Bẹ̀rẹ̀ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ní Sátidé Àkọ́kọ́ Lóṣù November

“Gbogbo wa là ń fẹ́ ìjọba tó dáa. Irú ìjọba wo lo rò pé ó máa yanjú àwọn ìṣòro wa? [Jẹ́ kó fèsì.] Wo ohun tí ìwé yìí sọ.” Fún onílé náà ní Ilé Ìṣọ́ November 1, kí ẹ sì jọ jíròrò ohun tó wà ní abẹ́ ìsọ̀rí àkọ́kọ́ lójú ìwé 16 àti ọ̀kan lára àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tó wà níbẹ̀, ó kéré tán. Fún un ní ìwé ìròyìn náà, kó o sì ṣètò láti pa dà lọ jíròrò ìdáhùn sí ìbéèrè tó kàn.

Ilé Ìṣọ́ November 1

“Jọ̀wọ́ mo fẹ́ mọ èrò rẹ nípa ọ̀rọ̀ kan. Ká sọ pé o láǹfààní láti bi Ọlọ́run ní ìbéèrè kan, kí lo máa bi í ná? [Jẹ́ kó fèsì.] Bí Jésù ṣe sọ, ó dáa ká máa wá ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè tó ń jẹ wá lọ́kan. [Ka Mátíù 7:7.] Ìwé ìròyìn yìí jẹ́ ká mọ ìdáhùn Bíbélì sí àwọn ìbéèrè mẹ́ta tó ṣe pàtàkì yìí.” Fi àwọn ìbéèrè tó wà ní ìsàlẹ̀ ojú ìwé 3 hàn án.

Ji! October–December

“Mo fẹ́ mọ èrò rẹ lórí ohun tí ẹsẹ Ìwé Mímọ́ yìí sọ. [Ka Gálátíà 6:7.] Ẹsẹ Bíbélì yìí jẹ́ ká mọ̀ pé ohun tá a bá fúnrúgbìn la máa ká. Kí nìdí tó o fi rò pé ó yẹ ká jẹ́ olóòótọ́? [Jẹ́ kó fèsì] Àpilẹ̀kọ tó wà lójú ìwé 14 nínú ìwé ìròyìn yìí sọ àǹfààní tó wà nínú kéèyàn jẹ́ olóòótọ́.”

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́