Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
January 8, 2000
Ìtọ́jú àti Iṣẹ́ Abẹ Láìlo Ẹ̀jẹ̀—Laráyé Ń Gba Tiẹ̀ Báyìí
Iṣẹ́ abẹ láìlo ẹ̀jẹ̀ ti wá gbajúmọ̀ báyìí o, a ò rírú ẹ̀ rí. Ó ṣe wá jẹ́ pé èyí làwọn èèyàn ń gba tiẹ̀ báyìí? Ó ha fini lọ́kàn balẹ̀ ju ìfàjẹ̀sínilára bí?
3 Àwọn Òléwájú Nínú Iṣẹ́ Ìṣègùn
4 Ó Pẹ́ Tí Ìfàjẹ̀sínilára Ti Ń Fa Arukutu
7 Ìtọ́jú àti Iṣẹ́ Abẹ Láìlo Ẹ̀jẹ̀ Laráyé Ń Gba Tiẹ̀ Báyìí
12 “Àwọn Ìwé Ìròyìn Tó Dáa Jù Lọ”
13 Jíjí Èèyàn Gbé Ti Di Òwò Tó Kárí Ayé
14 Jíjí Èèyàn Gbé—Òwò Àwọn Apanilẹ́kún-Jayé
18 Jíjí Èèyàn Gbé—Lájorí Ohun Tó Ń Fà Á
20 Jíjí Èèyàn Gbé—Ǹjẹ́ Ojútùú Kan Tiẹ̀ Wà?
23 Ìrànlọ́wọ́ Fáwọn Èèyàn Tí Wọ́n Dá Lóró
26 Àwọn Ìyá Tó Ní Àrùn Éèdì Ko Ìṣòro
30 Píà Avocado—Èso Tó Wúlò Lọ́nà Púpọ̀ Ni!
Ojú Ìwòye Tó Wà Níwọ̀ntúnwọ̀nsì Nípa Àwọn Àṣà Olókìkí 28
Ọ̀pọ̀ àṣà ló jẹ yọ látinú ìgbàgbọ́ nínú ohun asán àti àwọn èròǹgbà tó lòdì sí Bíbélì. Ojú wo ló yẹ kí Kristẹni máa fi wo irú àwọn àṣà bẹ́ẹ̀?