Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
June 8, 2004
Èèyàn Lè Nìkan Wà Kó Má Sì Dá Wà
Kí ló fà á tí ọ̀pọ̀ èèyàn fi ń dá wà? Kí la lè ṣe nípa rẹ̀? Ǹjẹ́ ìgbà kan á wà nígbà tí ẹnikẹ́ni ò ní dá wà mọ́?
3 Kí Ló Fà Á Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Fi Dá Wà?
9 Ìgbà Kan Ń Bọ̀ Tí Ẹnikẹ́ni Ò Ní Dá Wà Mọ́
12 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
13 Ọjọ́ Pẹ́ Táráyé Ti Ń Gbógun Ti Àrùn
17 Ibi Táráyé Ṣẹ́gun Àrùn Dé àti Ibi Tó Kù Sí
21 Ayé Kan Níbi Tí Kò Ti Ní Sí Àrùn
26 Wíwo Ayé
30 Kí Ló Dé Tí Ọ̀fìnkìn Tí Nǹkan Tó Ń Kù Ń Fà fi Ń Yọ Ọ̀pọ̀ Èèyàn Lẹ́nu?
31 Ó Yẹ Ká Kó Ahọ́n Wa Níjàánu Bíi Tẹṣin
Ṣé Ẹní Bá Ń Ṣàníyàn Ò Nígbàgbọ́ Ni? 24
Kí ni Bíbélì sọ nípa ọ̀rọ̀ yìí?
Kí Ló Fà Á Tó Fi Ń Hu Irú Ìwà Yìí sí Mi? 27
Ọ̀pọ̀ èèyàn ti rí i pé ẹni táwọn jọ ń fẹ́ra àwọn sọ́nà máa ń fìyà jẹ àwọn ó sì máa ń nà wọ́n ní pàṣán ọ̀rọ̀.