ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 January ojú ìwé 8
  • Bí A Ṣe Lè Fi Ìwé Ìròyìn Ayọ̀ Darí Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Bí A Ṣe Lè Fi Ìwé Ìròyìn Ayọ̀ Darí Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Bá A Ṣe Lè Fi Ìwé Ìròyìn Ayọ̀ Kọ́ Àwọn Èèyàn Lẹ́kọ̀ọ́
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2015
  • Àwọn Àpilẹ̀kọ Tuntun Tá A Lè Fi Bẹ̀rẹ̀ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2010
  • Bá A Ṣe Lè Lo Ìwé Ìròyìn Ayọ̀ Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run!
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2013
  • Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Máa Fi Bí A Ṣe Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Nínú Ìwé Bíbélì Fi Kọ́ni Han Àwọn Èèyàn
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2014
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 January ojú ìwé 8

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

Bí A Ṣe Lè Fi Ìwé Ìròyìn Ayọ̀ Darí Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì

  1. Ka ìbéèrè tá a kọ nọ́ńbà sí, tá a sì fi lẹ́tà tó dúdú yàtọ̀ kọ, èyí táá jẹ́ kí onílé rí kókó pàtàkì inú ẹ̀kọ́ náà.

  2. Ka ìpínrọ̀ tó wà nísàlẹ̀ ìbéèrè náà.

  3. Ka àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a fi lẹ́tà wínníwínní kọ, kó o sì fi ọgbọ́n béèrè àwọn ìbéèrè tó máa jẹ́ kí onílé rí bí Ìwé Mímọ́ ṣe dáhùn ìbéèrè tá a kọ nọ́ńbà sí náà.

  4. O lè tẹ̀ lé ìtọ́ni tó wà ní kókó 2 àti 3 tí ìbéèrè náà bá ní ìpínrọ̀ míì. Tí fídíò kan bá wà lórí ìkànnì jw.org/yo tó bá ìbéèrè tá a kọ nọ́ńbà sí tí ẹ̀ ń jíròrò mu, o lè fi han ẹni náà láàárín kan nínú ìjíròrò yín.

  5. Sọ pé kí onílé dáhùn ìbéèrè tá a kọ nọ́ńbà sí kó o lè mọ̀ bóyá ó ti lóye ohun tẹ́ ẹ kọ́.

Ẹ̀kọ́ 2 nínú ìwé Ìròyìn Ayọ̀ Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run!
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́