ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 August ojú ìwé 1
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • JÍ!
  • JÍ!
  • TẸ́TÍ SÍ ỌLỌ́RUN KÓ O LÈ WÀ LÁÀYÈ TÍTÍ LÁÉ
  • KỌ Ọ̀NÀ ÌGBỌ́RỌ̀KALẸ̀ RẸ
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 August ojú ìwé 1
Àwọn tọkọtaya kan ń fi fóònù wàásù ní ìlú Vienna, lórílẹ̀-èdè Austria

Wọ́n ń fi tẹlifóònù wàásù nílùú Vienna, lórílẹ̀-èdè Austria

Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

JÍ!

Jí! No. 4 | Mú Kí Ìwà Rẹ Dáa Sí I

Béèrè ìbéèrè: Ó máa ń gba àkókò kéèyàn tó lè jáwọ́ nínú àṣà tí kò dáa tó ti mọ́ni lára, kéèyàn sí fi èyí tó dáa rọ́pò rẹ̀, àmọ́ ṣé ó lérè?

Ka Bíbélì: Onw 7:⁠8a

Fi ìwé lọni: Àwọn àpilẹ̀kọ yìí sọ àwọn ìlànà Bíbélì tó máa ràn wá lọ́wọ́ láti jáwọ́ nínú àṣà tí kò dáa fún ire ara wa.

JÍ!

Béèrè ìbéèrè: Àwọn àyípadà kan gbọ́dọ̀ ṣẹlẹ̀ nígbèésí ayé wa. Àmọ́, kí lẹ rò pé a lè ṣe tí àwọn àyípadà yẹn á fi bá wa lára mu?

Ka Bíbélì: Onw 7:⁠10

Fi ìwé lọni: [Fi àpilẹ̀kọ tó bẹ̀rẹ̀ ní ojú ìwé 10 hàn án.] Àpilẹ̀kọ yìí sọ àwọn ìlànà Bíbélì tó lè ràn wá lọ́wọ́ tí àyípadà náà á fi bá wa lára mu.

TẸ́TÍ SÍ ỌLỌ́RUN KÓ O LÈ WÀ LÁÀYÈ TÍTÍ LÁÉ

Tẹ́tí Sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé

Béèrè ìbéèrè: Gbogbo wa pátá la ní orúkọ, tó fi mọ́ àwọn ẹbí àtàwọn ọ̀rẹ́ wa. Ǹjẹ́ ẹ tiẹ̀ rò pé Ọlọ́run ní orúkọ?

Ka Bíbélì: Sm 83:18

Fi ìwé lọni: Ìwé ìròyìn yìí ṣàlàyé àwọn nǹkan míì tí Bíbélì fi kọ́ wa nípa Ọlọ́run. [Fi ohun tó wà lójú ìwé 6 àti 7 hàn án.]

KỌ Ọ̀NÀ ÌGBỌ́RỌ̀KALẸ̀ RẸ

Wo àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tá a fi ṣe àpẹẹrẹ yìí, kó o sì kọ ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tìrẹ.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́