ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 September ojú ìwé 3
  • Jésù Wàásù fún Obìnrin Ará Samáríà Kan

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jésù Wàásù fún Obìnrin Ará Samáríà Kan
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ni Wá Nígbà Gbogbo
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2009
  • O Lè Jẹ́rìí Láìjẹ́-bí-Àṣà!
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2010
  • Máa Yin Jèhófà Nípa Wíwàásù Lọ́nà Àìjẹ́ bí Àṣà
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2003
  • Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Máa Bẹ̀rẹ̀ Ìjíròrò Lọ́nà Àìjẹ́-Bí-Àṣà
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2014
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 September ojú ìwé 3
Jésù ń bá obìnrin ará Samáríà kan sọ̀rọ̀ ní ìdí kànga; obìnrin ará Samáríà náà sọ̀rọ̀ Jésù fún àwọn èèyàn

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÒHÁNÙ 3-4

Jésù Wàásù fún Obìnrin Ará Samáríà Kan

4:6-26, 39-41

Kí ló jẹ́ kí Jésù lè wàásù lọ́nà àìjẹ́-bí-àṣà?

  • 4:7​—Dípò táá fi sọ̀rọ̀ nípa Ìjọba Ọlọ́run tàbí kó sọ fún un pé òun ni Mèsáyà, ńṣe ló kọ́kọ́ béèrè omi mímu lọ́wọ́ obìnrin náà

  • 4:9​—Kò rò ó lọ́kàn rẹ̀ pé obìnrin náà ò ní gbọ́ torí pé ará Samáríà ni

  • 4:9, 12​—Nígbà tí obìnrin yẹn sọ ohun tó lè dá àríyànjiyàn sílẹ̀, ṣe ni Jésù pọkàn pọ̀ sórí ohun tó fẹ́ kọ́ obìnrin yẹn.​—cf 77 ¶3

  • 4:10​—Àpèjúwe kan tó dá lórí ohun tí obìnrin yẹn ń ṣe lójoojúmọ́ ni Jésù fi bẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ rẹ̀

  • 4:16-19​—Bó tílẹ̀ jẹ́ pé obìnrin yẹn máa ń ṣèṣekúṣe, síbẹ̀ Jésù fi ọ̀wọ̀ tiẹ̀ wọ̀ ọ́

Báwo ni ìtàn yìí ṣe jẹ́ ká rí ìdí tó fi ṣe pàtàkì pé ká máa wàásù lọ́nà àìjẹ́-bí-àṣà?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́