ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 November ojú ìwé 7
  • Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Ẹni Tó Ń Fúnni Pẹ̀lú Ìdùnnú

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Ẹni Tó Ń Fúnni Pẹ̀lú Ìdùnnú
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • ‘Ẹyọ Owó Kéékèèké Méjì’ Tó Níye Lórí
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • “Ẹ̀bùn Tá A Mú Dání Wá fún Jèhófà”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Ibo Làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ti Ń Rówó Tí Wọ́n Ń Ná?
    Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Sábà Máa Ń Béèrè Nípa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
  • Jehofa Nífẹ̀ẹ́ Awọn Olufunni Ọlọ́yàyà
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1992
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 November ojú ìwé 7
Arábìnrin kan mú fóònù dání

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Ẹni Tó Ń Fúnni Pẹ̀lú Ìdùnnú

2 Kọ́ríńtì 9:7 gbà wá níyànjú pé: “Kí kálukú ṣe gẹ́gẹ́ bí ó ti pinnu nínú ọkàn rẹ̀, kì í ṣe pẹ̀lú lílọ́ra tàbí lábẹ́ àfipáṣe, nítorí Ọlọ́run nífẹ̀ẹ́ ẹni tó ń fúnni pẹ̀lú ìdùnnú.” Lónìí, tá a bá fẹ́ fi ọrẹ ṣètìlẹ́yìn fún iṣẹ́ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà lágbègbè wa tàbí kárí ayé, onírúurú ọ̀nà tó rọrùn la lè gbà ṣe bẹ́ẹ̀ látorí íńtánẹ́ẹ̀tì.

WO FÍDÍÒ NÁÀ ÀLÀYÉ LÓRÍ BÁ A ṢE LÈ FI ỌRẸ ṢÈTÌLẸ́YÌN LÁTORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ, KÓ O SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Ẹ̀rọ tablet àti fóònù kan ṣí ìkànnì jw.org

    Báwo la ṣe lè rí ìsọfúnni nípa bá a ṣe lé fi ọrẹ ṣètìlẹ́yìn látorí íńtánẹ́ẹ̀tì, ká lè mọ onírúurú ọ̀nà tá a lè gbà ṣètọrẹ lórílẹ̀ èdè wa?

  • Tọkọtaya kan ń sọ̀rọ̀ nípa bí wọ́n ṣe lè fi ọrẹ ṣètìlẹ́yìn

    Báwo làwọn kan ṣe jàǹfààní látinú bí wọ́n ṣe fi ọrẹ ṣètìlẹ́yìn látorí íńtánẹ́ẹ̀tì?

  • Àwọn àmì fífi ọrẹ ṣètìlẹ́yìn

    Onírúurú ọ̀nà wo la lè gbà fi ọrẹ ṣètìlẹ́yìn?

  • Arákùnrin kan tó jẹ́ ọ̀dọ́ ń ran arákùnrin àgbàlagbà kan lọ́wọ́ láti fi ọrẹ ṣètìlẹ́yìn látorí íńtánẹ́ẹ̀tì

    Tí ọ̀nà tá à ń gbà ṣètìlẹ́yìn látorí íńtánẹ́ẹ̀tì kò bá yé wa, kí la lè ṣe?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́