ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 November ojú ìwé 8
  • ‘Ẹyọ Owó Kéékèèké Méjì’ Tó Níye Lórí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • ‘Ẹyọ Owó Kéékèèké Méjì’ Tó Níye Lórí
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • A Dúpẹ́ Lọ́wọ́ Jèhófà Torí Ìfẹ́ Tẹ́ Ẹ̀ Ń Fi Hàn
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Ẹni Tó Ń Fúnni Pẹ̀lú Ìdùnnú
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • “Ẹ̀bùn Tá A Mú Dání Wá fún Jèhófà”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Ẹ̀bùn Wo La Lè Fún Jèhófà?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2018
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 November ojú ìwé 8
Obìnrin opó kan ń wo ẹyọ owó méjì tó wà lọ́wọ́ ẹ̀ kó tó fi ṣètọrẹ.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

‘Ẹyọ Owó Kéékèèké Méjì’ Tó Níye Lórí

Owó tí opó yìí fi ṣètọrẹ ò tó láti ra oúnjẹ ẹ̀ẹ̀kan ṣoṣo. (Wo “gbogbo ohun tó ní láti gbé ẹ̀mí rẹ̀ ró” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lúùkù 21:4, nwtsty.) Àmọ́ ohun tó ṣe yìí fi hàn pé ó nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, ó sì mọyì ìjọsìn rẹ̀. Ìyẹn ló mú kí ohun tó fi ṣètọrẹ ṣeyebíye gan-an lójú Jèhófà.​—Mk 12:43.

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ ‘WỌ́N MÚ Ẹ̀BÙN WÁ FÚN JÈHÓFÀ’, KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Apá kan nínú fídíò ‘Wọ́n Mú Ẹ̀bùn Wá fún Jèhófà.’ Wọ́n ń fowó ṣètọrẹ kí wọ́n lè fi kọ́ àwọn ilé ìjọsìn.

    Kí la máa ń fi owó tá a fi ń ṣètọrẹ ṣe?

  • Apá kan nínú fídíò ‘Wọ́n Mú Ẹ̀bùn Wá fún Jèhófà.’ Ọmọdébìnrin kan ń fi owó sí àpótí ọrẹ tó wà nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba.

    Kí nìdí táwọn ọrẹ wa fi ṣeyebíye tó bá tiẹ̀ dà bíi pé kò tó nǹkan?

  • Apá kan nínú fídíò ‘Wọ́n Mú Ẹ̀bùn Wá fún Jèhófà.’ Àwòrán: Owó tá a fi ń ṣètọrẹ la fi ń ti iẹ́ ìwàásù lẹ́yìn kárí ayé. 1. Iṣẹ́ Bẹ́tẹ́lì. 2. Àwọn ilé ẹ̀kọ́ ètò Ọlọ́run . 3. Ìrànwọ́ nígbà àjálù. 4. Ìṣẹ́ ìkọ́lé. 5. Àwọn àpéjọ wa.

    Ibo la ti lè rí ìsọfúnni nípa àwọn ọ̀nà míì tẹ́ ẹ lè gbà ṣètọrẹ lágbègbè yín?​—Wo àpótí náà “Mọ Púpọ̀ Sí I Lórí Ìkànnì”

MỌ PÚPỌ̀ SÍ I LÓRÍ ÌKÀNNÌ

Tẹ ìlujá “Donations” tó wà nísàlẹ̀ ètò ìṣiṣẹ́ JW Library. Ó ṣeé ṣe kí ìlujá “Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Máa Ń Béèrè” wà lórílẹ̀-èdè yín, wàá rí ìdáhùn sáwọn ìbéèrè nípa bó o ṣe lè ṣètọrẹ níbẹ̀. Bákan náà, fídíò Àlàyé Lórí Bá A Ṣe Lè Fi Ọrẹ Ṣètìlẹ́yìn Látorí Íńtánẹ́ẹ̀tì máa jẹ́ kó o rí ìsọfúnni nípa àwọn ọ̀nà míì tó o lè gbà ṣètọrẹ.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́