ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 November ojú ìwé 3
  • A Dúpẹ́ Lọ́wọ́ Jèhófà Torí Ìfẹ́ Tẹ́ Ẹ̀ Ń Fi Hàn

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • A Dúpẹ́ Lọ́wọ́ Jèhófà Torí Ìfẹ́ Tẹ́ Ẹ̀ Ń Fi Hàn
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Ẹ Sọ Ọ́ Di Àṣà Láti Máa Fúnni”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • ‘Ẹyọ Owó Kéékèèké Méjì’ Tó Níye Lórí
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • “Ẹ̀bùn Tá A Mú Dání Wá fún Jèhófà”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • “Kí Kálukú Yín Ya Ohun Kan Sọ́tọ̀”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 November ojú ìwé 3
Àwòrán: 1. Arákùnrin kan ń fowó sínú àpótí. 2. JW Box. 3. Àwọn ará ń ṣètò ibi tí wọ́n ti fẹ́ ṣe fídíò.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

A Dúpẹ́ Lọ́wọ́ Jèhófà Torí Ìfẹ́ Tẹ́ Ẹ̀ Ń Fi Hàn

Nǹkan ò rọrùn fáwọn ará tó wà ní Tẹsalóníkà, síbẹ̀ wọ́n ń fìfẹ́ hàn síra wọn. (2Tẹ 1:3, 4) Lónìí, àwa èèyàn Jèhófà náà ń fìfẹ́ hàn síra wa kárí ayé. Abala tá a pè ní “Bá A Ṣe Ń Ná Owó Tẹ́ Ẹ Fi Ń Ṣètọrẹ” lórí ìkànnì jw.org á jẹ́ kẹ́ ẹ mọ bá a ṣe ń lo owó tẹ́ ẹ fi ń ṣètọrẹ láti ṣèrànwọ́ fáwọn ará tó wà nínú ìṣòro. A mọyì ẹ̀mí ọ̀làwọ́ yín àti ìfẹ́ tẹ́ ẹ̀ ń fi hàn.

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ À Ń “DÚPẸ́ LỌ́WỌ́ ỌLỌ́RUN NÍGBÀ GBOGBO NÍTORÍ YÍN,” KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

• Àwọn nǹkan wo ni ètò Ọlọ́run ń fi ọrẹ wa ṣe?

• Ọ̀nà wo ló dáa jù láti ṣètìlẹyìn fáwọn ará wa tó jẹ́ aláìní?—Tún wo àpilẹ̀kọ náà “Ohun Tó Ṣẹ́ Kù Níbì Kan Ń Dí Àìtó Àwọn Míì” lórí ìkànnì jw.org

MỌ PÚPỌ̀ SÍ I LÓRÍ ÌKÀNNÌ

Àwọn ọ̀nà wo lo lè gbà fowó ṣètìlẹyìn fún iṣẹ́ táwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń ṣe kárí ayé? Tẹ ìlujá “Donations” tó wà nísàlẹ̀ ibi tó o máa kọ́kọ́ rí tó o bá ṣí JW Library. Àwọn orílẹ̀-èdè kan ní apá tá a pè ní “Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Máa Ń Béèrè” lórí ìkànnì jw.org, apá yìí máa dáhùn àwọn ìbéèrè tó o bá ní nípa bó o ṣe lè ṣètìlẹyìn nírú orílẹ̀-èdè bẹ́ẹ̀.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́