ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Tí Èèyàn Bá Kú, Ṣé Ó Tún Lè Wà Láàyè?”
Kò sí ohun táwa èèyàn lè ṣe tá ò fi ní kú, a ò sì lè jí òkú dìde (Job 14:1, 2, 4, 10; w99 10/15 3 ¶1-3)
Àwọn tó ti kú lè jíǹde pa dà (Job 14:7-9; w15 4/15 32 ¶1-2)
Kì í ṣe pé Jèhófà lágbára láti jí àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ dìde nìkan, ó tún ń wù ú láti ṣe bẹ́ẹ̀ (Job 14:14, 15; w11 3/1 22 ¶5)
RONÚ LÓRÍ ÌBÉÈRÈ YÌÍ: Kí nìdí tó fi ń wu Jèhófà láti jí àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ dìde? Kí sì nìyẹn jẹ́ kó o mọ̀ nípa Jèhófà?