October Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ October 12 Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Bí O Ṣe Lè Kọ́ Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Rẹ Láti Máa Dá Kẹ́kọ̀ọ́ Dáadáa Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ October 19 Bí A Ṣe Lè Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Wa Wọ Àwọn Tí À Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Lọ́kàn Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ October 26 Àtúnyẹ̀wò Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run Ǹjẹ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ń Nípa Lórí Ìgbésí Ayé Rẹ Lójoojúmọ́? Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ November 2 Àwọn Ìfilọ̀ Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò