ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 23
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Tírè (1-18)

Àìsáyà 23:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 25:17, 22; 47:4; Isk 26:3; 27:2; Joẹ 3:4; Emọ 1:9, 10; Sek 9:3, 4
  • +2Kr 9:21; Isk 27:25
  • +Jẹ 10:2, 4; Jer 2:10; Isk 27:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 244-245

Àìsáyà 23:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 10:15; Isk 27:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 246

Àìsáyà 23:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Irúgbìn.”

  • *

    Ìyẹn, odò tó ya láti ara odò Náílì.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 2:18
  • +Isk 27:32, 33; 28:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 246

Àìsáyà 23:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àwọn wúńdíá.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 47:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 246-247

Àìsáyà 23:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 19:1, 16
  • +Isk 27:35; 28:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 247

Àìsáyà 23:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 247

Àìsáyà 23:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 247-248

Àìsáyà 23:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 28:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 248-249

Àìsáyà 23:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 4:37; Jem 4:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 249-251

Àìsáyà 23:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “ibi tí ọkọ̀ òkun ń gúnlẹ̀ sí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 23:1; Isk 26:14, 17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 251

Àìsáyà 23:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 26:5, 15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 251

Àìsáyà 23:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 26:13
  • +Isk 27:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2007, ojú ìwé 17

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 251-252

Àìsáyà 23:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 13:19; Hab 1:6
  • +Ais 10:12; Na 3:18; Sef 2:13
  • +Isk 26:8, 9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 252-253

Àìsáyà 23:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 23:1

Àìsáyà 23:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àwọn ọjọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 25:8, 11; 27:3, 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 253-254

Àìsáyà 23:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 253-254

Àìsáyà 23:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 253-254

Àìsáyà 23:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 60:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 254-255

Àwọn míì

Àìsá. 23:1Jer 25:17, 22; 47:4; Isk 26:3; 27:2; Joẹ 3:4; Emọ 1:9, 10; Sek 9:3, 4
Àìsá. 23:12Kr 9:21; Isk 27:25
Àìsá. 23:1Jẹ 10:2, 4; Jer 2:10; Isk 27:6
Àìsá. 23:2Jẹ 10:15; Isk 27:8
Àìsá. 23:3Jer 2:18
Àìsá. 23:3Isk 27:32, 33; 28:4
Àìsá. 23:4Jer 47:4
Àìsá. 23:5Ais 19:1, 16
Àìsá. 23:5Isk 27:35; 28:19
Àìsá. 23:8Isk 28:2
Àìsá. 23:9Da 4:37; Jem 4:6
Àìsá. 23:10Ais 23:1; Isk 26:14, 17
Àìsá. 23:11Isk 26:5, 15
Àìsá. 23:12Isk 26:13
Àìsá. 23:12Isk 27:6
Àìsá. 23:13Ais 13:19; Hab 1:6
Àìsá. 23:13Ais 10:12; Na 3:18; Sef 2:13
Àìsá. 23:13Isk 26:8, 9
Àìsá. 23:14Ais 23:1
Àìsá. 23:15Jer 25:8, 11; 27:3, 6
Àìsá. 23:18Ais 60:5
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 23:1-18

Àìsáyà

23 Ìkéde nípa Tírè:+

Ẹ pohùn réré ẹkún, ẹ̀yin ọkọ̀ òkun Táṣíṣì!+

Torí a ti run èbúté; kò ṣeé wọ̀.

A ti ṣi í payá fún wọn láti ilẹ̀ Kítímù.+

 2 Ẹ dákẹ́ jẹ́ẹ́, ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé ilẹ̀ etíkun.

Àwọn oníṣòwò láti Sídónì,+ tó ń sọdá òkun ti kún inú rẹ.

 3 Ọkà* Ṣíhórì*+ gba orí omi púpọ̀,

Ìkórè Náílì, owó tó ń wọlé fún un,

Tó ń mú èrè wá fún àwọn orílẹ̀-èdè.+

 4 Kí ojú tì ọ́, ìwọ Sídónì, ìwọ ibi ààbò òkun,

Torí òkun ti sọ pé:

“Mi ò ní ìrora ìrọbí, mi ò sì tíì bímọ,

Bẹ́ẹ̀ ni mi ò tọ́ àwọn ọ̀dọ́kùnrin tàbí ọ̀dọ́bìnrin* dàgbà.”+

 5 Bí ìgbà tí wọ́n gbọ́ ìròyìn nípa Íjíbítì,+

Àwọn èèyàn máa jẹ̀rora torí ìròyìn tí wọ́n gbọ́ nípa Tírè.+

 6 Ẹ sọdá sí Táṣíṣì!

Ẹ pohùn réré ẹkún, ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé ilẹ̀ etíkun!

 7 Ṣé ìlú yín tó ń yọ̀ látọjọ́ tó ti pẹ́ nìyí, láti ìgbà àtijọ́ rẹ̀?

Ẹsẹ̀ rẹ̀ máa ń gbé e lọ sí àwọn ilẹ̀ tó jìn kó lè gbé ibẹ̀.

 8 Ta ló pinnu èyí sí Tírè,

Ẹni tó ń déni ládé,

Tí àwọn oníṣòwò rẹ̀ jẹ́ ìjòyè,

Tí wọ́n ń bọlá fún àwọn ọlọ́jà rẹ̀ ní gbogbo ayé?+

 9 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun fúnra rẹ̀ ti pinnu èyí,

Láti tẹ́ńbẹ́lú bó ṣe ń fi gbogbo ẹwà rẹ̀ yangàn,

Láti rẹ gbogbo àwọn tí wọ́n ń bọlá fún ní ayé sílẹ̀.+

10 Sọdá ilẹ̀ rẹ bí odò Náílì, ìwọ ọmọbìnrin Táṣíṣì.

Kò sí ibi tí wọ́n ti ń ṣe ọkọ̀ òkun* mọ́.+

11 Ó ti na ọwọ́ rẹ̀ sórí òkun;

Ó ti mi àwọn ìjọba jìgìjìgì.

Jèhófà ti pàṣẹ pé kí wọ́n pa àwọn ibi ààbò Foníṣíà run.+

12 Ó sì sọ pé: “O ò ní yọ̀ mọ́,+

Ìwọ ẹni tí wọ́n ń fìyà jẹ, ọmọbìnrin Sídónì tó jẹ́ wúńdíá.

Dìde, sọdá sí Kítímù.+

O ò ní ní ìsinmi níbẹ̀ pàápàá.”

13 Wò ó! Ilẹ̀ àwọn ará Kálídíà.+

Àwọn èèyàn náà nìyí, kì í ṣe Ásíríà,+

Wọ́n sọ ọ́ di ibi tí àwọn tó ń lọ sínú aṣálẹ̀ máa ń lọ.

Wọ́n ti kọ́ àwọn ilé gogoro láti dó tì í;

Wọ́n ti ya àwọn ilé gogoro rẹ̀ lulẹ̀,+

Wọ́n ti sọ ọ́ di ibi tó rún wómúwómú.

14 Ẹ pohùn réré ẹkún, ẹ̀yin ọkọ̀ òkun Táṣíṣì,

Torí ibi ààbò yín ti pa run.+

15 Ní ọjọ́ yẹn, wọ́n máa gbàgbé Tírè fún àádọ́rin (70) ọdún,+ bí ayé ìgbà* ọba kan. Lópin àádọ́rin (70) ọdún, ó máa ṣẹlẹ̀ sí Tírè bí orin aṣẹ́wó kan tó sọ pé:

16 “Mú háàpù, lọ yí ká ìlú, ìwọ aṣẹ́wó tí wọ́n ti gbàgbé.

Ta háàpù rẹ dáadáa;

Kọ orin tó pọ̀,

Kí wọ́n lè rántí rẹ.”

17 Ní òpin àádọ́rin (70) ọdún, Jèhófà máa rántí Tírè, ó máa pa dà sídìí ọrọ̀ rẹ̀, á sì máa bá gbogbo ìjọba ayé tó wà lórí ilẹ̀ ayé ṣe ìṣekúṣe. 18 Àmọ́ èrè rẹ̀ àti ọrọ̀ rẹ̀ máa di ohun mímọ́ fún Jèhófà. Kò ní kó o pa mọ́ tàbí kó tò ó jọ, torí pé ọrọ̀ rẹ̀ máa di ti àwọn tó ń gbé iwájú Jèhófà, kí wọ́n lè jẹun ní àjẹyó, kí wọ́n sì wọ aṣọ aláràbarà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́