ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 121
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sáàmù

      • Jèhófà ń ṣọ́ àwọn èèyàn rẹ̀

        • “Ọ̀dọ̀ Jèhófà ni ìrànlọ́wọ́ mi ti ń wá” (2)

        • Jèhófà kì í sùn (3, 4)

Sáàmù 121:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 125:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2004, ojú ìwé 12

    3/15/1995, ojú ìwé 29-30

Sáàmù 121:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 46:1; Ais 41:13; Jer 20:11; Heb 13:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2004, ojú ìwé 12

Sáàmù 121:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ta gbọ̀n-ọ́n gbọ̀n-ọ́n.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 91:11, 12; Owe 3:26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2004, ojú ìwé 12-13

Sáàmù 121:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 27:3; 40:28

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2004, ojú ìwé 12-13

Sáàmù 121:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 91:1; Ais 25:4
  • +Sm 16:8; 109:31

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2009, ojú ìwé 14

    12/15/2004, ojú ìwé 13

Sáàmù 121:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 49:10; Ifi 7:16
  • +Sm 91:5, 6

Sáàmù 121:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 91:10; Owe 12:21
  • +Sm 97:10; 145:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2004, ojú ìwé 13

Sáàmù 121:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ṣọ́ ìjáde àti ìwọlé rẹ.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2004, ojú ìwé 13

Àwọn míì

Sm 121:1Sm 125:2
Sm 121:2Sm 46:1; Ais 41:13; Jer 20:11; Heb 13:6
Sm 121:3Sm 91:11, 12; Owe 3:26
Sm 121:4Ais 27:3; 40:28
Sm 121:5Sm 91:1; Ais 25:4
Sm 121:5Sm 16:8; 109:31
Sm 121:6Ais 49:10; Ifi 7:16
Sm 121:6Sm 91:5, 6
Sm 121:7Sm 91:10; Owe 12:21
Sm 121:7Sm 97:10; 145:20
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Sáàmù 121:1-8

Sáàmù

Orin Ìgòkè.

121 Mo gbé ojú mi sókè sí àwọn òkè.+

Ibo ni ìrànlọ́wọ́ mi yóò ti wá?

2 Ọ̀dọ̀ Jèhófà ni ìrànlọ́wọ́ mi ti ń wá,+

Aṣẹ̀dá ọ̀run àti ayé.

3 Kò ní jẹ́ kí ẹsẹ̀ rẹ yọ̀.*+

Ẹni tó ń ṣọ́ ọ kò ní tòògbé láé.

4 Wò ó! Ẹni tó ń ṣọ́ Ísírẹ́lì kì í tòògbé,

Bẹ́ẹ̀ ni kì í sùn.+

5 Jèhófà ń ṣọ́ ọ.

Jèhófà ni ibòji+ tó wà ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ.+

6 Oòrùn kò ní pa ọ́ lára ní ọ̀sán,+

Tàbí òṣùpá ní òru.+

7 Jèhófà yóò máa ṣọ́ ọ kí jàǹbá kankan má ṣe ọ́.+

Yóò máa ṣọ́ ẹ̀mí* rẹ.+

8 Jèhófà yóò máa ṣọ́ ọ nínú gbogbo ohun tí o bá ń ṣe*

Láti ìsinsìnyí lọ àti títí láé.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́