ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 26
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Orin ìgbẹ́kẹ̀lé àti ìgbàlà (1-21)

        • Jáà Jèhófà, Àpáta ayérayé (4)

        • Àwọn tó ń gbé ayé máa kọ́ òdodo (9)

        • “Àwọn òkú rẹ máa wà láàyè” (19)

        • Ẹ wọ àwọn yàrá inú, kí ẹ sì fara pa mọ́ (20)

Àìsáyà 26:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 15:1; 2Sa 22:1; Ais 12:5
  • +Jer 33:10, 11
  • +Sm 48:2, 12
  • +Ais 60:18; Sek 2:4, 5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 17-18

    1/1/1995, ojú ìwé 11

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 276-277

Àìsáyà 26:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 60:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 17-18

    1/1/1995, ojú ìwé 10-16

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 276-277

Àìsáyà 26:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “àwọn tí wọn kì í yí èrò ọkàn wọn pa dà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 119:165; Ais 54:13; Flp 4:6, 7
  • +Sm 9:10; Jer 17:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 18

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 277

Àìsáyà 26:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    “Jáà” ni ìkékúrú Jèhófà.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 20:20; Sm 62:8; Owe 3:5
  • +Di 32:4, 31

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 18

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 277

Àìsáyà 26:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 18-19

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 277-279

Àìsáyà 26:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 18-19

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 277-279

Àìsáyà 26:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tẹ́jú.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 19

Àìsáyà 26:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “wu ọkàn wa.”

  • *

    Ìyẹn ni pé, ká máa rántí Ọlọ́run àti orúkọ rẹ̀, ká jẹ́ káwọn èèyàn mọ̀ ọ́n.

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 19

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 279

Àìsáyà 26:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ara.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 63:6; 119:62; Lk 6:12
  • +Sm 9:8; 58:10, 11; 85:11, 13; 96:13; 97:2; Ais 61:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jọ́sìn Ọlọ́run, ojú ìwé 97-98

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 19

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 279

Àìsáyà 26:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìṣòtítọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 106:43
  • +Jer 2:7; Ho 11:7
  • +Sm 28:5; Ais 5:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 19

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 279-280

Àìsáyà 26:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 6:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 280

Àìsáyà 26:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 57:19; Jer 33:6, 7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 280

Àìsáyà 26:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 12:7, 8
  • +2Ti 2:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 280-281

Àìsáyà 26:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ti sọ wọ́n di aláìlágbára.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 51:39

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 20

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 281

Àìsáyà 26:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 60:21
  • +1Ọb 4:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 20

    1/1/1995, ojú ìwé 11-16

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 281

Àìsáyà 26:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 78:34, 35; Ho 5:15

Àìsáyà 26:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 20

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 282

Àìsáyà 26:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 20

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 282

Àìsáyà 26:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Òkú tó jẹ́ tèmi.”

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “ìrì àwọn ewéko (málò).”

  • *

    Tàbí “ti sọ di aláìlágbára.”

  • *

    Tàbí “máa bí àwọn tí ikú ti sọ di aláìlágbára.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 25:8; Ho 13:14; Mk 12:26; Jo 5:28, 29; 11:24, 25; Iṣe 24:15; 1Kọ 15:21; 1Tẹ 4:14; Ifi 20:12, 13
  • +Jẹ 3:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    5/8/2004, ojú ìwé 22

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2001, ojú ìwé 20

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 282

Àìsáyà 26:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìbáwí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 7:15, 16; Ẹk 12:22, 23; Owe 18:10
  • +Sm 27:5; 91:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2016, ojú ìwé 5

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2014, ojú ìwé 26-27

    5/15/2009, ojú ìwé 8

    3/1/2001, ojú ìwé 20-21

    8/15/1998, ojú ìwé 19

    Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, ojú ìwé 230

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 282-283

Àìsáyà 26:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 282-283

Àwọn míì

Àìsá. 26:1Ẹk 15:1; 2Sa 22:1; Ais 12:5
Àìsá. 26:1Jer 33:10, 11
Àìsá. 26:1Sm 48:2, 12
Àìsá. 26:1Ais 60:18; Sek 2:4, 5
Àìsá. 26:2Ais 60:11
Àìsá. 26:3Sm 119:165; Ais 54:13; Flp 4:6, 7
Àìsá. 26:3Sm 9:10; Jer 17:7
Àìsá. 26:42Kr 20:20; Sm 62:8; Owe 3:5
Àìsá. 26:4Di 32:4, 31
Àìsá. 26:9Sm 63:6; 119:62; Lk 6:12
Àìsá. 26:9Sm 9:8; 58:10, 11; 85:11, 13; 96:13; 97:2; Ais 61:11
Àìsá. 26:10Sm 106:43
Àìsá. 26:10Jer 2:7; Ho 11:7
Àìsá. 26:10Sm 28:5; Ais 5:12
Àìsá. 26:11Ais 6:9
Àìsá. 26:12Ais 57:19; Jer 33:6, 7
Àìsá. 26:132Kr 12:7, 8
Àìsá. 26:132Ti 2:19
Àìsá. 26:14Jer 51:39
Àìsá. 26:15Ais 60:21
Àìsá. 26:151Ọb 4:21
Àìsá. 26:16Sm 78:34, 35; Ho 5:15
Àìsá. 26:19Ais 25:8; Ho 13:14; Mk 12:26; Jo 5:28, 29; 11:24, 25; Iṣe 24:15; 1Kọ 15:21; 1Tẹ 4:14; Ifi 20:12, 13
Àìsá. 26:19Jẹ 3:19
Àìsá. 26:20Jẹ 7:15, 16; Ẹk 12:22, 23; Owe 18:10
Àìsá. 26:20Sm 27:5; 91:4
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 26:1-21

Àìsáyà

26 Ní ọjọ́ yẹn, wọ́n máa kọ orin yìí+ ní ilẹ̀ Júdà:+

“A ní ìlú tó lágbára.+

Ó fi ìgbàlà ṣe àwọn ògiri rẹ̀, ó sì fi mọ òkìtì yí i ká.+

 2 Ẹ ṣí àwọn ẹnubodè,+ kí orílẹ̀-èdè olódodo lè wọlé,

Orílẹ̀-èdè tó ń fìgbà gbogbo jẹ́ olóòótọ́.

 3 O máa dáàbò bo àwọn tó gbára lé ọ pátápátá;*

O máa fún wọn ní àlàáfíà tí kò lópin, +

Torí pé ìwọ ni wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé.+

 4 Ẹ gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà títí láé,+

Torí pé Àpáta ayérayé ni Jáà* Jèhófà.+

 5 Torí ó ti rẹ àwọn tó ń gbé ibi gíga sílẹ̀, ìlú tó ga.

Ó rẹ̀ ẹ́ wálẹ̀,

Ó mú un wá sílẹ̀ pátápátá;

Ó mú un wá sínú iyẹ̀pẹ̀.

 6 Ẹsẹ̀ máa tẹ̀ ẹ́ mọ́lẹ̀,

Ẹsẹ̀ àwọn tí ìyà ń jẹ, ìṣísẹ̀ àwọn tó rẹlẹ̀.”

 7 Ọ̀nà àwọn olódodo tọ́.*

Torí pé o jẹ́ olóòótọ́,

O máa mú kí ọ̀nà àwọn olódodo dán mọ́rán.

 8 Bí a ṣe ń tọ ọ̀nà àwọn ìdájọ́ rẹ, Jèhófà,

Ìwọ la gbẹ́kẹ̀ lé.

Orúkọ rẹ àti ìrántí rẹ ń wù wá* gan-an.*

 9 Ní òru, gbogbo ọkàn* mi wà lọ́dọ̀ rẹ,

Àní, ẹ̀mí mi ń wá ọ ṣáá;+

Torí tí àwọn ìdájọ́ bá ti ọ̀dọ̀ rẹ wá sí ayé,

Àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà máa kọ́ òdodo.+

10 Tí a bá tiẹ̀ ṣojúure sí ẹni burúkú,

Kò ní kọ́ òdodo.+

Kódà ó máa hùwà burúkú ní ilẹ̀ ìwà títọ́,*+

Kò sì ní rí títóbi Jèhófà.+

11 Jèhófà, ọwọ́ rẹ wà lókè, ṣùgbọ́n wọn ò rí i.+

Wọ́n máa rí ìtara tí o ní fún àwọn èèyàn rẹ, ojú á sì tì wọ́n.

Àní, iná tó wà fún àwọn ọ̀tá rẹ máa jó wọn run.

12 Jèhófà, o máa fún wa ní àlàáfíà,+

Torí pé gbogbo ohun tí a ṣe,

Ìwọ lo bá wa ṣe é.

13 Jèhófà Ọlọ́run wa, àwọn ọ̀gá míì ti jẹ lé wa lórí yàtọ̀ sí ìwọ,+

Àmọ́, orúkọ rẹ nìkan là ń dá.+

14 Òkú ni wọ́n; wọn ò ní wà láàyè.

Ikú ti pa wọ́n,* wọn ò ní dìde.+

Torí o ti yíjú sí wọn,

Kí o lè pa wọ́n rẹ́, kí ẹnikẹ́ni má sì dárúkọ wọn mọ́.

15 O ti mú kí orílẹ̀-èdè náà tóbi sí i, Jèhófà,

O ti mú kí orílẹ̀-èdè náà tóbi sí i;

O ti ṣe ara rẹ lógo.+

O ti sún gbogbo ààlà ilẹ̀ náà síwájú gan-an.+

16 Jèhófà, wọ́n yíjú sí ọ nígbà wàhálà;

Wọ́n gbàdúrà sí ọ kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́ látọkàn wá nígbà tí o bá wọn wí.+

17 Bí aláboyún tó fẹ́ bímọ,

Tó ń rọbí, tó sì ń ké torí ó ń jẹ̀rora,

Bẹ́ẹ̀ ni a ṣe rí nítorí rẹ, Jèhófà.

18 A lóyún, a sì ní ìrora ìrọbí,

Àmọ́ ṣe ló dà bíi pé afẹ́fẹ́ la bí.

A ò mú ìgbàlà wá sí ilẹ̀ náà,

A ò sì bí ẹnì kankan tó máa gbé ilẹ̀ náà.

19 “Àwọn òkú rẹ máa wà láàyè.

Àwọn òkú mi* máa jíǹde.+

Ẹ jí, ẹ sì kígbe ayọ̀,

Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé inú iyẹ̀pẹ̀!+

Torí pé ìrì yín dà bí ìrì àárọ̀,*

Ilẹ̀ sì máa mú kí àwọn tí ikú ti pa* tún pa dà wà láàyè.*

20 Ẹ lọ, ẹ̀yin èèyàn mi, ẹ wọnú yàrá yín tó wà ní inú,

Kí ẹ sì ti àwọn ilẹ̀kùn yín mọ́ ara yín.+

Ẹ fi ara yín pa mọ́ fúngbà díẹ̀,

Títí ìbínú* náà fi máa kọjá lọ.+

21 Torí pé, wò ó! Jèhófà ń bọ̀ láti àyè rẹ̀,

Láti pe àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà pé kí wọ́n wá jẹ́jọ́ torí ẹ̀ṣẹ̀ wọn,

Ilẹ̀ náà sì máa tú ìtàjẹ̀sílẹ̀ rẹ̀ síta,

Kò ní lè bo àwọn èèyàn rẹ̀ tí wọ́n pa, bó ṣe ń ṣe tẹ́lẹ̀.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́