ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Oníwàásù 12
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Oníwàásù

      • Rántí Ẹlẹ́dàá kí ọjọ́ ogbó tó dé (1-8)

      • Ìparí ọ̀rọ̀ akónijọ (9-14)

        • Ọ̀rọ̀ ọlọ́gbọ́n dà bí ọ̀pá kẹ́sẹ́ màlúù (11)

        • Bẹ̀rù Ọlọ́run tòótọ́ (13)

Oníwàásù 12:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àjálù.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 71:17; 148:7, 12; Lk 2:48, 49; 2Ti 3:15
  • +Sm 90:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2015, ojú ìwé 12-13

    1/15/2014, ojú ìwé 18, 22-23

    7/1/2011, ojú ìwé 8-9

    4/15/2010, ojú ìwé 3-4

    4/15/2008, ojú ìwé 12-16

    6/15/2005, ojú ìwé 28

    5/1/2004, ojú ìwé 14

    11/15/1999, ojú ìwé 13-18

    9/1/1999, ojú ìwé 20-21

    8/15/1998, ojú ìwé 8-9

    12/15/1996, ojú ìwé 30

    12/1/1996, ojú ìwé 15-20

    Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, ojú ìwé 312-313

    Jí!,

    7/8/2004, ojú ìwé 8-9

Oníwàásù 12:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “pẹ̀lú òjò tó ń rọ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 4:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1999, ojú ìwé 14-15

Oníwàásù 12:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọn olùtọ́jú.”

  • *

    Tàbí “wárìrì.”

  • *

    Tàbí “wíńdò.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 48:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    11/2016, ojú ìwé 6

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2008, ojú ìwé 23

    11/15/1999, ojú ìwé 15

Oníwàásù 12:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 19:34, 35

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    11/2016, ojú ìwé 6

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1999, ojú ìwé 15-16

Oníwàásù 12:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 16:31
  • +Job 30:23; Onw 9:10
  • +Jẹ 50:7, 10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    11/2016, ojú ìwé 6

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/2005, ojú ìwé 22-23

    11/15/1999, ojú ìwé 16-17

Oníwàásù 12:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1999, ojú ìwé 17

Oníwàásù 12:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ohun tó mú kí ẹ̀dá wà láàyè.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 3:19; Sm 146:4
  • +Jẹ 2:7; Job 27:3; 34:14, 15; Sm 104:29; Ais 42:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Bíbélì Fi Kọ́ni, ojú ìwé 211

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2001, ojú ìwé 5-6

    11/15/1999, ojú ìwé 17

    4/1/1999, ojú ìwé 17

    10/15/1996, ojú ìwé 5-6

    6/15/1994, ojú ìwé 5-6

    Nígbà Tí A Bá Kú, ojú ìwé 24

Oníwàásù 12:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Òtúbáńtẹ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 8:1
  • +Onw 1:2, 14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1999, ojú ìwé 18-19

Oníwàásù 12:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “to ọ̀pọ̀lọpọ̀ òwe jọ lẹ́sẹẹsẹ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 10:1, 3, 6, 8
  • +1Ọb 4:29, 32; Owe 1:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1999, ojú ìwé 21

Oníwàásù 12:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 16:24; 25:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 3

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2008, ojú ìwé 10-11

    11/15/1999, ojú ìwé 21

Oníwàásù 12:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 2:37; Heb 4:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2012, ojú ìwé 9

    11/1/2006, ojú ìwé 16

    12/1/2004, ojú ìwé 32

    12/15/1999, ojú ìwé 30

    11/15/1999, ojú ìwé 21

Oníwàásù 12:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Onw 1:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2004, ojú ìwé 32

    10/1/2000, ojú ìwé 10

    11/15/1999, ojú ìwé 21-22

    8/1/1997, ojú ìwé 30

Oníwàásù 12:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Job 28:28; Sm 111:10; Owe 1:7
  • +1Jo 5:3
  • +Di 6:1, 2; 10:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 25

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 1 2017 ojú ìwé 14

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/2011, ojú ìwé 21

    11/15/1999, ojú ìwé 22-23

    2/15/1997, ojú ìwé 13-18

Oníwàásù 12:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 62:12; Onw 11:9; Mt 12:36, 37; Iṣe 17:31; 2Kọ 5:10; 1Ti 5:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1999, ojú ìwé 22-23

Àwọn míì

Oníw. 12:1Sm 71:17; 148:7, 12; Lk 2:48, 49; 2Ti 3:15
Oníw. 12:1Sm 90:10
Oníw. 12:21Sa 4:15
Oníw. 12:3Jẹ 48:10
Oníw. 12:42Sa 19:34, 35
Oníw. 12:5Owe 16:31
Oníw. 12:5Job 30:23; Onw 9:10
Oníw. 12:5Jẹ 50:7, 10
Oníw. 12:7Jẹ 3:19; Sm 146:4
Oníw. 12:7Jẹ 2:7; Job 27:3; 34:14, 15; Sm 104:29; Ais 42:5
Oníw. 12:81Ọb 8:1
Oníw. 12:8Onw 1:2, 14
Oníw. 12:91Ọb 10:1, 3, 6, 8
Oníw. 12:91Ọb 4:29, 32; Owe 1:1
Oníw. 12:10Owe 16:24; 25:11
Oníw. 12:11Iṣe 2:37; Heb 4:12
Oníw. 12:12Onw 1:18
Oníw. 12:13Job 28:28; Sm 111:10; Owe 1:7
Oníw. 12:131Jo 5:3
Oníw. 12:13Di 6:1, 2; 10:12
Oníw. 12:14Sm 62:12; Onw 11:9; Mt 12:36, 37; Iṣe 17:31; 2Kọ 5:10; 1Ti 5:24
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Oníwàásù 12:1-14

Oníwàásù

12 Nítorí náà, rántí Ẹlẹ́dàá rẹ Atóbilọ́lá nígbà ọ̀dọ́ rẹ,+ kí àwọn ọjọ́ wàhálà* tó dé,+ kí àwọn ọdún náà tó dé nígbà tí wàá sọ pé: “Wọn ò mú inú mi dùn”; 2 kí oòrùn àti ìmọ́lẹ̀ àti òṣùpá àti àwọn ìràwọ̀ tó ṣókùnkùn,+ tí ojú ọ̀run á sì tún ṣú lẹ́yìn tí òjò ti rọ̀;* 3 ní ọjọ́ tí àwọn ẹ̀ṣọ́* ilé ń gbọ̀n pẹ̀pẹ̀,* tí àwọn ọkùnrin alágbára sì tẹ̀, tí àwọn obìnrin tó ń lọ nǹkan dáwọ́ dúró nítorí pé wọn ò pọ̀ mọ́, tí àwọn ọmọge tó ń wo ìta lójú fèrèsé* sì rí i pé òkùnkùn ṣú;+ 4 nígbà tí àwọn ilẹ̀kùn tó jáde sí ojú ọ̀nà ti wà ní títì, nígbà tí ìró ọlọ ti lọ sílẹ̀, nígbà tí èèyàn á jí nítorí ìró ẹyẹ, tí ohùn gbogbo àwọn ọmọbìnrin tó ń kọrin kò sì dún sókè mọ́.+ 5 Bákan náà, èèyàn á máa bẹ̀rù ibi tó ga, ẹ̀rù á sì wà lójú ọ̀nà. Igi álímọ́ńdì ń yọ ìtànná,+ tata ń wọ́ ara rẹ̀ lọ, àgbáyun kápérì sì bẹ́, torí pé èèyàn ń lọ sí ilé rẹ̀ ayérayé,+ àwọn tó ń ṣọ̀fọ̀ sì ń rìn kiri ní ojú ọ̀nà;+ 6 kí okùn fàdákà tó yọ, kí àwo wúrà tó fọ́ sí wẹ́wẹ́, kí ìṣà tó wà níbi ìsun omi tó fọ́, kí kẹ̀kẹ́ ìfami tó wà níbi kòtò omi tó kán. 7 Nígbà náà, erùpẹ̀ á pa dà sí ilẹ̀,+ bó ṣe wà tẹ́lẹ̀, ẹ̀mí* á sì pa dà sọ́dọ̀ Ọlọ́run tòótọ́ tó fúnni.+

8 “Asán* pátápátá gbáà!” ni akónijọ+ wí. “Asán ni gbogbo rẹ̀.”+

9 Kì í ṣe pé akónijọ di ọlọ́gbọ́n nìkan ni, ó tún máa ń kọ́ àwọn èèyàn ní ohun tó mọ̀,+ ó ronú jinlẹ̀, ó sì wádìí fínnífínní, kí ó lè kó ọ̀pọ̀lọpọ̀ òwe jọ.*+ 10 Akónijọ wá bó ṣe máa rí àwọn ọ̀rọ̀ tó ń tuni lára,+ kó sì ṣàkọsílẹ̀ àwọn ọ̀rọ̀ tó péye tó sì jẹ́ òtítọ́.

11 Ọ̀rọ̀ àwọn ọlọ́gbọ́n dà bí ọ̀pá kẹ́sẹ́ màlúù,+ àkójọ ọ̀rọ̀ wọn sì dà bí ìṣó tó wọlé ṣinṣin; ọ̀dọ̀ olùṣọ́ àgùntàn kan ni wọ́n ti wá. 12 Yàtọ̀ sí àwọn nǹkan yìí, ọmọ mi, ṣọ́ra: Kò sí òpin nínú ṣíṣe ìwé púpọ̀, fífi àkókò tó pọ̀ jù kà wọ́n sì ń kó àárẹ̀ bá ara.+

13 Òpin ọ̀rọ̀ náà, lẹ́yìn gbígbọ́ gbogbo rẹ̀ ni pé: Bẹ̀rù Ọlọ́run tòótọ́,+ kí o sì pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́,+ nítorí èyí ni gbogbo ojúṣe èèyàn.+ 14 Nítorí Ọlọ́run tòótọ́ yóò dá àwọn èèyàn lẹ́jọ́ lórí gbogbo ohun tí wọ́n ṣe, títí kan gbogbo ohun tó fara pa mọ́, bóyá ó dára tàbí ó burú.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́