ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 115
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sáàmù

      • Ọlọ́run nìkan ni ògo yẹ

        • Àwọn òrìṣà aláìlẹ́mìí (4-8)

        • Ọlọ́run fi ayé fún àwọn èèyàn (16)

        • “Àwọn òkú kì í yin Jáà” (17)

Sáàmù 115:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Kò sóhun tó jẹ́ tiwa, Jèhófà, kò sóhun tó jẹ́ tiwa.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 48:11; Jo 12:28
  • +Sm 138:2

Sáàmù 115:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 32:12; Nọ 14:15, 16; Di 32:26, 27; Sm 79:10

Sáàmù 115:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 135:15-18; Ais 40:19; 46:6; Jer 10:3, 4, 8, 9; Iṣe 19:26; 1Kọ 10:19

Sáàmù 115:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Hab 2:19

Sáàmù 115:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 5:3; Ais 46:7
  • +Hab 2:18

Sáàmù 115:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 44:9
  • +Sm 97:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    11/15/1992, ojú ìwé 11

Sáàmù 115:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 3:5
  • +Di 33:29; Sm 33:20

Sáàmù 115:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 28:1

Sáàmù 115:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 16:20
  • +Sm 84:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    11/15/1992, ojú ìwé 11

Sáàmù 115:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 12:2

Sáàmù 115:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àwọn ọmọkùnrin.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 13:16

Sáàmù 115:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 3:8
  • +Sm 96:5

Sáàmù 115:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 66:1
  • +Jẹ 1:28; Sm 37:29; Ais 45:18; Iṣe 17:26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    11/15/1992, ojú ìwé 11

Sáàmù 115:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “sínú ìdákẹ́jẹ́ẹ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 6:5; Onw 9:5
  • +Sm 31:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    11/15/1992, ojú ìwé 11

Sáàmù 115:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Halelúyà!” “Jáà” ni ìkékúrú Jèhófà.

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    11/15/1992, ojú ìwé 11

Àwọn míì

Sm 115:1Ais 48:11; Jo 12:28
Sm 115:1Sm 138:2
Sm 115:2Ẹk 32:12; Nọ 14:15, 16; Di 32:26, 27; Sm 79:10
Sm 115:4Sm 135:15-18; Ais 40:19; 46:6; Jer 10:3, 4, 8, 9; Iṣe 19:26; 1Kọ 10:19
Sm 115:5Hab 2:19
Sm 115:71Sa 5:3; Ais 46:7
Sm 115:7Hab 2:18
Sm 115:8Ais 44:9
Sm 115:8Sm 97:7
Sm 115:9Owe 3:5
Sm 115:9Di 33:29; Sm 33:20
Sm 115:10Ẹk 28:1
Sm 115:11Owe 16:20
Sm 115:11Sm 84:11
Sm 115:12Jẹ 12:2
Sm 115:14Jẹ 13:16
Sm 115:15Sm 3:8
Sm 115:15Sm 96:5
Sm 115:16Ais 66:1
Sm 115:16Jẹ 1:28; Sm 37:29; Ais 45:18; Iṣe 17:26
Sm 115:17Sm 6:5; Onw 9:5
Sm 115:17Sm 31:17
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Sáàmù 115:1-18

Sáàmù

115 Kì í ṣe àwa, Jèhófà, kì í ṣe àwa,*

Àmọ́ orúkọ rẹ ni ògo yẹ+

Nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́ rẹ.+

 2 Ṣé ó yẹ kí àwọn orílẹ̀-èdè sọ pé:

“Ọlọ́run wọn dà?”+

 3 Ọlọ́run wa wà ní ọ̀run;

Ó ń ṣe ohun tí ó bá fẹ́.

 4 Àwọn òrìṣà wọn jẹ́ fàdákà àti wúrà,

Iṣẹ́ ọwọ́ èèyàn.+

 5 Wọ́n ní ẹnu, àmọ́ wọn ò lè sọ̀rọ̀;+

Wọ́n ní ojú, àmọ́ wọn ò lè ríran;

 6 Wọ́n ní etí, àmọ́ wọn ò lè gbọ́ràn;

Wọ́n ní imú, àmọ́ wọn ò lè gbóòórùn;

 7 Wọ́n ní ọwọ́, àmọ́ wọn ò lè fọwọ́ ba nǹkan;

Wọ́n ní ẹsẹ̀, àmọ́ wọn ò lè rìn;+

Wọn ò lè mú ìró kankan jáde láti ọ̀fun wọn.+

 8 Àwọn tó ń ṣe wọ́n yóò dà bíi wọn gẹ́lẹ́,+

Bẹ́ẹ̀ ló sì ṣe máa rí fún gbogbo àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé wọn.+

 9 Ísírẹ́lì, gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà+

—Òun ni olùrànlọ́wọ́ wọn àti apata wọn.+

10 Ilé Áárónì,+ ẹ gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà

—Òun ni olùrànlọ́wọ́ wọn àti apata wọn.

11 Ẹ̀yin tí ẹ bẹ̀rù Jèhófà, ẹ gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà+

—Òun ni olùrànlọ́wọ́ wọn àti apata wọn.+

12 Jèhófà ń rántí wa, á sì bù kún wa;

Á bù kún ilé Ísírẹ́lì;+

Á bù kún ilé Áárónì.

13 Á bù kún àwọn tó bẹ̀rù Jèhófà,

Àti ẹni kékeré àti ẹni ńlá.

14 Jèhófà máa mú kí ẹ pọ̀ sí i,

Ẹ̀yin àti àwọn ọmọ* yín.+

15 Kí Jèhófà bù kún yín,+

Aṣẹ̀dá ọ̀run àti ayé.+

16 Ní ti ọ̀run, ti Jèhófà ni,+

Àmọ́ ayé ni ó fún àwọn ọmọ èèyàn.+

17 Àwọn òkú kì í yin Jáà;+

Bẹ́ẹ̀ ni ẹnikẹ́ni tó sọ̀ kalẹ̀ lọ sínú ìdákẹ́jẹ́ẹ́ ikú.*+

18 Àmọ́ a ó máa yin Jáà

Láti ìsinsìnyí lọ àti títí láé.

Ẹ yin Jáà!*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́