ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Pétérù 5
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Pétérù

      • Ẹ máa ṣe olùṣọ́ àgùntàn agbo Ọlọ́run (1-4)

      • Ẹ jẹ́ onírẹ̀lẹ̀, kí ẹ sì wà lójúfò (5-11)

        • Ẹ máa kó gbogbo àníyàn yín lé Ọlọ́run (7)

        • Èṣù dà bíi kìnnìún tó ń ké ramúramù (8)

      • Ọ̀rọ̀ ìparí (12-14)

1 Pétérù 5:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “gba àwọn alàgbà tó wà láàárín yín níyànjú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 8:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 20

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2011, ojú ìwé 20

    Yiyan, ojú ìwé 140-142

1 Pétérù 5:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ẹ máa tọ́jú wọn dáadáa.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 40:11; Jo 21:16; Iṣe 20:28
  • +Jo 10:11
  • +1Ti 3:2, 3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 20

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    5/2019, ojú ìwé 6-7

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2011, ojú ìwé 20-23

    6/15/2007, ojú ìwé 19-20

    6/1/2006, ojú ìwé 6

    4/1/2006, ojú ìwé 20

    7/1/2000, ojú ìwé 28-29

    7/15/1997, ojú ìwé 13

    10/1/1994, ojú ìwé 15-20

    5/15/1993, ojú ìwé 20

    Yiyan, ojú ìwé 140-141, 143-146

1 Pétérù 5:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 1:24
  • +Flp 3:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 20

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    5/2019, ojú ìwé 6-7

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2014, ojú ìwé 5

    11/15/2013, ojú ìwé 27-29

    6/15/2011, ojú ìwé 23-24

    6/15/2007, ojú ìwé 19-20

    5/1/2006, ojú ìwé 17-21

    4/1/2006, ojú ìwé 20

    4/15/1992, ojú ìwé 25

    Ìwé Ọdọọdún—2013, ojú ìwé 159-161

    Jeremáyà, ojú ìwé 129-131

    Yiyan, ojú ìwé 140-141, 146-147

1 Pétérù 5:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 13:20
  • +1Kọ 9:25; 2Ti 4:8; 1Pe 1:3, 4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2011, ojú ìwé 24

    Yiyan, ojú ìwé 147

1 Pétérù 5:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọn alàgbà.”

  • *

    Tàbí “ìrẹ̀lẹ̀ ọkàn.”

  • *

    Tàbí “fi ìrẹ̀lẹ̀ di ara yín lámùrè.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 5:21; Jem 3:17
  • +Owe 3:34; Ais 57:15; Jem 4:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” ojú ìwé 33-34

    Ilé Ìṣọ́,

    8/1/1999, ojú ìwé 11, 15-16

    3/1/1999, ojú ìwé 31

    9/15/1996, ojú ìwé 23

    Yiyan, ojú ìwé 94

1 Pétérù 5:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 23:12; Lk 14:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2008, ojú ìwé 13

    1/15/2007, ojú ìwé 19

    11/15/1994, ojú ìwé 22-24

    Yiyan, ojú ìwé 136-137

1 Pétérù 5:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ohun tó ń jẹ yín lọ́kàn; ìdààmú.”

  • *

    Tàbí “ó bìkítà fún yín.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 6:25
  • +Sm 55:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 1 2021 ojú ìwé 6

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 8

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2008, ojú ìwé 21

    3/15/2008, ojú ìwé 12-13

    1/15/2007, ojú ìwé 18-19

    11/15/1994, ojú ìwé 21-25

    Yiyan, ojú ìwé 136-137

1 Pétérù 5:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ó ń wá ẹni tó máa pa jẹ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Tẹ 5:6
  • +Lk 22:31

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2015, ojú ìwé 9

    8/15/2012, ojú ìwé 17-18

    2/15/2012, ojú ìwé 4

    1/15/2007, ojú ìwé 19-20

    9/15/2004, ojú ìwé 12-13

    3/15/1996, ojú ìwé 24-25

    12/1/1995, ojú ìwé 9

    11/15/1992, ojú ìwé 22

    ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run’, ojú ìwé 183-185, 197

    Jí!,

    2/8/1999, ojú ìwé 15

    Yiyan, ojú ìwé 137-138

1 Pétérù 5:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “ẹgbẹ́ àwọn ará yín.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 6:11; Jem 4:7
  • +Iṣe 14:22; 2Ti 3:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2015, ojú ìwé 14-18

    Yiyan, ojú ìwé 138

1 Pétérù 5:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 4:17; 1Tẹ 2:12
  • +2Tẹ 2:16, 17
  • +Ef 6:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 60

    Ilé Ìṣọ́,

    8/1/2012, ojú ìwé 30

    10/1/2002, ojú ìwé 28-30

    1/15/1995, ojú ìwé 13-14

    Yiyan, ojú ìwé 138-139

1 Pétérù 5:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wọ́n tún ń pè é ní Sílà.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 15:27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/1999, ojú ìwé 28-29

1 Pétérù 5:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 12:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2010, ojú ìwé 8

    Jíjẹ́rìí Kúnnákúnná, ojú ìwé 118

1 Pétérù 5:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 5/2019, ojú ìwé 4-5

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/15/1993, ojú ìwé 15

Àwọn míì

1 Pét. 5:1Ro 8:18
1 Pét. 5:2Ais 40:11; Jo 21:16; Iṣe 20:28
1 Pét. 5:2Jo 10:11
1 Pét. 5:21Ti 3:2, 3
1 Pét. 5:32Kọ 1:24
1 Pét. 5:3Flp 3:17
1 Pét. 5:4Heb 13:20
1 Pét. 5:41Kọ 9:25; 2Ti 4:8; 1Pe 1:3, 4
1 Pét. 5:5Ef 5:21; Jem 3:17
1 Pét. 5:5Owe 3:34; Ais 57:15; Jem 4:6
1 Pét. 5:6Mt 23:12; Lk 14:11
1 Pét. 5:7Mt 6:25
1 Pét. 5:7Sm 55:22
1 Pét. 5:81Tẹ 5:6
1 Pét. 5:8Lk 22:31
1 Pét. 5:9Ef 6:11; Jem 4:7
1 Pét. 5:9Iṣe 14:22; 2Ti 3:12
1 Pét. 5:102Kọ 4:17; 1Tẹ 2:12
1 Pét. 5:102Tẹ 2:16, 17
1 Pét. 5:10Ef 6:10
1 Pét. 5:12Iṣe 15:27
1 Pét. 5:13Iṣe 12:12
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Pétérù 5:1-14

Ìwé Kìíní Pétérù

5 Torí náà, bí èmi náà ti jẹ́ alàgbà, tí mo fojú ara mi rí àwọn ìyà tí Kristi jẹ, tí mo sì máa pín nínú ògo tí a máa ṣí payá,+ mò ń rọ àwọn alàgbà tó wà láàárín yín* pé: 2 Ẹ máa ṣe olùṣọ́ àgùntàn agbo Ọlọ́run+ tó wà níkàáwọ́ yín, kí ẹ máa ṣe alábòójútó,* kì í ṣe tipátipá àmọ́ kó jẹ́ tinútinú níwájú Ọlọ́run;  + kó má ṣe jẹ́ nítorí èrè tí kò tọ́,+ àmọ́ kí ẹ máa fi ìtara ṣe é látọkàn wá; 3 ẹ má ṣe jẹ ọ̀gá lórí àwọn tó jẹ́ ogún Ọlọ́run,+ àmọ́ kí ẹ jẹ́ àpẹẹrẹ fún agbo.+ 4 Tí a bá sì fi olórí olùṣọ́ àgùntàn+ hàn kedere, ẹ máa gba adé ògo tí kì í ṣá.+

5 Bákan náà, kí ẹ̀yin ọ̀dọ́kùnrin máa tẹrí ba fún àwọn àgbà ọkùnrin.*+ Àmọ́ kí gbogbo yín gbé ìrẹ̀lẹ̀* wọ̀* nínú àjọṣe yín, torí Ọlọ́run dojú ìjà kọ àwọn agbéraga, àmọ́ ó ń fi inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí hàn sí àwọn onírẹ̀lẹ̀.+

6 Torí náà, ẹ rẹ ara yín sílẹ̀ lábẹ́ ọwọ́ agbára Ọlọ́run, kó lè gbé yín ga ní àkókò tó yẹ,+ 7 ẹ máa kó gbogbo àníyàn* yín lọ sọ́dọ̀ rẹ̀,+ torí ó ń bójú tó yín.*+ 8 Ẹ máa ronú bó ṣe tọ́, ẹ wà lójúfò!+ Èṣù tó jẹ́ ọ̀tá yín ń rìn káàkiri bíi kìnnìún tó ń ké ramúramù, ó ń wá bó ṣe máa pani jẹ.*+ 9 Àmọ́ ẹ kọjú ìjà sí i,+ kí ẹ dúró gbọn-in nínú ìgbàgbọ́, ẹ mọ̀ pé irú ìyà kan náà ló ń jẹ gbogbo àwọn ará yín* nínú ayé.+ 10 Àmọ́ lẹ́yìn tí ẹ bá ti jìyà fún ìgbà díẹ̀, Ọlọ́run onínúure àìlẹ́tọ̀ọ́sí gbogbo, ẹni tó pè yín sí ògo àìlópin rẹ̀+ ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi, máa fúnra rẹ̀ parí ìdálẹ́kọ̀ọ́ yín. Ó máa fún yín lókun,+ ó máa sọ yín di alágbára,+ ó sì máa fẹsẹ̀ yín múlẹ̀ gbọn-in. 11 Kí agbára jẹ́ tirẹ̀ títí láé. Àmín.

12 Mo fi ọ̀rọ̀ díẹ̀ tí mo kọ yìí ránṣẹ́ sí yín nípasẹ̀ Sílífánù,*+ arákùnrin olóòótọ́, kí n lè fún yín níṣìírí, kí n sì lè jẹ́rìí taratara pé inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tòótọ́ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run nìyí. Ẹ dúró gbọn-in nínú rẹ̀. 13 Obìnrin tó wà ní Bábílónì, tó jẹ́ àyànfẹ́ bíi tiyín ń kí yín. Máàkù+ ọmọ mi náà ń kí yín. 14 Ẹ fi ìfẹnukonu ìfẹ́ kí ara yín.

Kí gbogbo ẹ̀yin tí ẹ wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi ní àlàáfíà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́