ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Pétérù 3
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Pétérù

      • Àwọn ọkọ àti àwọn aya (1-7)

      • Ẹ máa bára yín kẹ́dùn; ẹ máa wá àlàáfíà (8-12)

      • Tí a bá ń jìyà nítorí òdodo (13-22)

        • Ẹ ṣe tán láti gbèjà ìrètí yín (15)

        • Ìrìbọmi àti ẹ̀rí ọkàn rere (21)

1 Pétérù 3:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 7:2; 1Kọ 11:3; Ef 5:22
  • +1Kọ 7:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 49

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2015, ojú ìwé 27

    3/15/2013, ojú ìwé 31-32

    2/15/2007, ojú ìwé 20-21

    3/1/2005, ojú ìwé 19

    6/15/2000, ojú ìwé 14-15

    8/1/1996, ojú ìwé 18

    4/15/1994, ojú ìwé 28-29

    Yiyan, ojú ìwé 77

1 Pétérù 3:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 2:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 49

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2007, ojú ìwé 20-21

    3/1/2005, ojú ìwé 19

    6/15/2000, ojú ìwé 14-15

    8/1/1996, ojú ìwé 18

    Yiyan, ojú ìwé 77

1 Pétérù 3:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 11:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2007, ojú ìwé 21

    6/15/1999, ojú ìwé 32

    8/15/1992, ojú ìwé 14

    6/1/1991, ojú ìwé 30

    3/15/1991, ojú ìwé 30

    Jí!,

    8/8/1998, ojú ìwé 17

    Yiyan, ojú ìwé 80

1 Pétérù 3:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 4:24; Kol 3:10, 12; 1Ti 2:9, 10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 49

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2007, ojú ìwé 22-23

    2/15/2007, ojú ìwé 21

    3/1/2005, ojú ìwé 19-20

    10/15/2001, ojú ìwé 18-19

    7/15/2000, ojú ìwé 5

    8/15/1992, ojú ìwé 14

    6/1/1991, ojú ìwé 30

    3/15/1991, ojú ìwé 30

    Jí!,

    8/8/1998, ojú ìwé 17

    Yiyan, ojú ìwé 80-83

1 Pétérù 3:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 49

    Yiyan, ojú ìwé 81-82

1 Pétérù 3:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 18:12; Ef 5:33
  • +Owe 3:25; Flp 1:28

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2005, ojú ìwé 19-20

    5/15/2004, ojú ìwé 26

    Yiyan, ojú ìwé 82-83, 86

1 Pétérù 3:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “máa gba tiwọn rò; máa fi ìmọ̀ bá wọn gbé.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 5:25
  • +Ga 3:28

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    7/2021, ojú ìwé 22

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 49

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2015, ojú ìwé 23

    5/15/2012, ojú ìwé 6

    5/15/2010, ojú ìwé 11

    7/15/2009, ojú ìwé 8-9

    2/15/2007, ojú ìwé 14-15

    5/15/2006, ojú ìwé 32

    3/1/2005, ojú ìwé 17-18

    6/15/2000, ojú ìwé 19-20

    8/1/1999, ojú ìwé 19-20

    4/1/1998, ojú ìwé 29

    10/15/1996, ojú ìwé 18

    7/15/1995, ojú ìwé 19-20

    2/1/1991, ojú ìwé 22

    Bíbélì Kọ́ Wa, ojú ìwé 146

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 99-100

    Jí!,

    1/2008, ojú ìwé 7, 17

    2/8/2002, ojú ìwé 11

    Ìmọ̀, ojú ìwé 143-144

    Ayọ, ojú ìwé 73, 82

    Yiyan, ojú ìwé 86-93

1 Pétérù 3:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kí ẹ máa fi inú kan bá ara yín lò.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 1:10; Flp 2:2
  • +Ro 12:10
  • +Ro 15:5; Kol 3:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    3/2019, ojú ìwé 14-15

    “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” ojú ìwé 153

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2002, ojú ìwé 24-25

    8/1/1997, ojú ìwé 15-16

    Yiyan, ojú ìwé 106-107

1 Pétérù 3:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 12:17; 1Tẹ 5:15
  • +1Pe 2:23
  • +Ro 12:14; 1Kọ 4:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 107

1 Pétérù 3:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jem 3:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 107

1 Pétérù 3:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 8:13
  • +3Jo 11
  • +1Tẹ 5:13; Jem 3:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/1997, ojú ìwé 13-19

    3/1/1991, ojú ìwé 20-25

    Yiyan, ojú ìwé 107

1 Pétérù 3:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Jo 3:22
  • +Sm 34:12-16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 9

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2002, ojú ìwé 14

    Yiyan, ojú ìwé 107

1 Pétérù 3:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 13:3, 4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 122-123

1 Pétérù 3:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “ẹ má bẹ̀rù ìhàlẹ̀ wọn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 5:11, 12; Iṣe 5:41; 1Pe 2:19
  • +Mt 10:28

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 123

1 Pétérù 3:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 15:1; 2Ti 2:24, 25; Tit 3:1, 2
  • +Kol 4:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 22

    ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run’, ojú ìwé 61

    Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 68, 177-178

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2001, ojú ìwé 23

    1/15/1997, ojú ìwé 14

    7/15/1991, ojú ìwé 23-25

    Jí!,

    7/8/1999, ojú ìwé 13-14

    Yiyan, ojú ìwé 124

1 Pétérù 3:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 23:1; 24:16; 1Ti 1:5, 18, 19; 3:9
  • +Ro 12:21; 1Pe 2:12
  • +Tit 2:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 124-125

1 Pétérù 3:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 1:7; Kol 1:24
  • +1Pe 4:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 125

1 Pétérù 3:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 9:28
  • +Ro 5:6
  • +2Kọ 5:18
  • +1Kọ 15:50
  • +1Ti 3:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 27

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    2/15/1991, ojú ìwé 15

    Yiyan, ojú ìwé 126

1 Pétérù 3:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Pe 2:4; Jud 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2013, ojú ìwé 16

    6/15/2013, ojú ìwé 23

    1/15/2006, ojú ìwé 6-7

    Yiyan, ojú ìwé 126-128

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 74-75

1 Pétérù 3:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    0Ní Grk., “nígbà tí sùúrù Ọlọ́run ń dúró.”

  • *

    0Tàbí “èèyàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 6:2, 3
  • +Jẹ 6:14
  • +Jẹ 7:13, 23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2006, ojú ìwé 6-7

    11/1/2001, ojú ìwé 9-10

    Yiyan, ojú ìwé 126

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 74-75

1 Pétérù 3:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 9:14; 10:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 46

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2020, ojú ìwé 14

    3/2020, ojú ìwé 9

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    3/2018, ojú ìwé 4

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    2/2017, ojú ìwé 11

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2008, ojú ìwé 21

    4/1/1993, ojú ìwé 6

    10/1/1992, ojú ìwé 23

    Jọ́sìn Ọlọ́run, ojú ìwé 116

    Ìmọ̀, ojú ìwé 176

    Yiyan, ojú ìwé 13-14

1 Pétérù 3:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 110:1; Iṣe 7:55; Heb 10:12
  • +Mt 28:18; 1Kọ 15:25; Ef 1:20, 21; Flp 2:9, 10; Heb 1:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 13, 128

Àwọn míì

1 Pét. 3:1Ro 7:2; 1Kọ 11:3; Ef 5:22
1 Pét. 3:11Kọ 7:16
1 Pét. 3:21Pe 2:12
1 Pét. 3:3Owe 11:22
1 Pét. 3:4Ef 4:24; Kol 3:10, 12; 1Ti 2:9, 10
1 Pét. 3:6Jẹ 18:12; Ef 5:33
1 Pét. 3:6Owe 3:25; Flp 1:28
1 Pét. 3:7Ef 5:25
1 Pét. 3:7Ga 3:28
1 Pét. 3:81Kọ 1:10; Flp 2:2
1 Pét. 3:8Ro 12:10
1 Pét. 3:8Ro 15:5; Kol 3:12
1 Pét. 3:9Ro 12:17; 1Tẹ 5:15
1 Pét. 3:91Pe 2:23
1 Pét. 3:9Ro 12:14; 1Kọ 4:12
1 Pét. 3:10Jem 3:8
1 Pét. 3:11Owe 8:13
1 Pét. 3:113Jo 11
1 Pét. 3:111Tẹ 5:13; Jem 3:17
1 Pét. 3:121Jo 3:22
1 Pét. 3:12Sm 34:12-16
1 Pét. 3:13Ro 13:3, 4
1 Pét. 3:14Mt 5:11, 12; Iṣe 5:41; 1Pe 2:19
1 Pét. 3:14Mt 10:28
1 Pét. 3:15Owe 15:1; 2Ti 2:24, 25; Tit 3:1, 2
1 Pét. 3:15Kol 4:6
1 Pét. 3:16Iṣe 23:1; 24:16; 1Ti 1:5, 18, 19; 3:9
1 Pét. 3:16Ro 12:21; 1Pe 2:12
1 Pét. 3:16Tit 2:8
1 Pét. 3:172Kọ 1:7; Kol 1:24
1 Pét. 3:171Pe 4:15
1 Pét. 3:18Heb 9:28
1 Pét. 3:18Ro 5:6
1 Pét. 3:182Kọ 5:18
1 Pét. 3:181Kọ 15:50
1 Pét. 3:181Ti 3:16
1 Pét. 3:192Pe 2:4; Jud 6
1 Pét. 3:20Jẹ 6:2, 3
1 Pét. 3:20Jẹ 6:14
1 Pét. 3:20Jẹ 7:13, 23
1 Pét. 3:21Heb 9:14; 10:22
1 Pét. 3:22Sm 110:1; Iṣe 7:55; Heb 10:12
1 Pét. 3:22Mt 28:18; 1Kọ 15:25; Ef 1:20, 21; Flp 2:9, 10; Heb 1:6
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Pétérù 3:1-22

Ìwé Kìíní Pétérù

3 Bákan náà, kí ẹ̀yin aya máa tẹrí ba fún àwọn ọkọ yín,+ kó lè jẹ́ pé, tí a bá rí ẹnikẹ́ni tí kò ṣègbọràn sí ọ̀rọ̀ náà, a máa lè jèrè wọn nípasẹ̀ ìwà àwọn aya wọn+ láìsọ ohunkóhun, 2 torí pé wọ́n fojú rí ìwà mímọ́ yín+ pẹ̀lú ọ̀wọ̀ tó jinlẹ̀. 3 Kí ẹwà yín má ṣe jẹ́ ti òde ara, bí irun dídì, wíwọ àwọn ohun ọ̀ṣọ́ wúrà+ tàbí wíwọ àwọn aṣọ olówó ńlá, 4 àmọ́ kó jẹ́ ti ẹni ìkọ̀kọ̀ ti ọkàn, kí ẹ fi ìwà jẹ́jẹ́ àti ìwà tútù ṣe ọ̀ṣọ́ tí kò lè bà jẹ́,+ èyí tó níye lórí gan-an lójú Ọlọ́run. 5 Torí pé báyìí ni àwọn obìnrin mímọ́ tó gbẹ́kẹ̀ lé Ọlọ́run nígbà àtijọ́ ṣe máa ń ṣe ara wọn lọ́ṣọ̀ọ́, tí wọ́n sì ń fi ara wọn sábẹ́ àwọn ọkọ wọn, 6 bí Sérà ṣe ń ṣègbọràn sí Ábúráhámù, tó ń pè é ní olúwa.+ Ẹ sì ti di ọmọ rẹ̀, tí ẹ bá ń ṣe ohun tó dáa, tí ẹ ò sì bẹ̀rù.+

7 Bákan náà, kí ẹ̀yin ọkọ máa fi òye bá wọn gbé.* Ẹ máa bọlá fún wọn+ bí ohun èlò ẹlẹgẹ́, tó jẹ́ abo, torí ẹ jọ jẹ́ ajogún+ ojúure ìyè tí a kò lẹ́tọ̀ọ́ sí, kí àdúrà yín má bàa ní ìdènà.

8 Lákòótán, kí èrò gbogbo yín ṣọ̀kan,*+ kí ẹ máa bára yín kẹ́dùn, kí ẹ máa ní ìfẹ́ ará, kí ẹ lójú àánú,+ kí ẹ sì jẹ́ onírẹ̀lẹ̀.+ 9 Ẹ má ṣe fi búburú san búburú,+ ẹ má sì fi ọ̀rọ̀ àbùkù san ọ̀rọ̀ àbùkù.+ Kàkà bẹ́ẹ̀, kí ẹ máa súre,+ torí ọ̀nà yìí la pè yín sí, kí ẹ lè jogún ìbùkún.

10 Torí “ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ràn ìgbésí ayé rẹ̀, tó sì fẹ́ ẹ̀mí gígùn gbọ́dọ̀ ṣọ́ ahọ́n rẹ̀ kó má bàa sọ ohun búburú,+ kó má sì fi ètè rẹ̀ ṣẹ̀tàn. 11 Kí ó jáwọ́ nínú ohun búburú,+ kó sì máa ṣe rere;+ kó máa wá àlàáfíà, kó sì máa lépa rẹ̀.+ 12 Nítorí ojú Jèhófà* wà lára àwọn olódodo, etí rẹ̀ sì ṣí sí ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ wọn;+ àmọ́ Jèhófà* kọjú ìjà sí àwọn tó ń ṣe ohun búburú.”+

13 Lóòótọ́, ta ló máa ṣe yín léṣe tí ẹ bá ń fi ìtara ṣe ohun rere?+ 14 Síbẹ̀, tí ẹ bá tiẹ̀ jìyà nítorí òdodo, inú yín máa dùn.+ Àmọ́ ẹ má bẹ̀rù ohun tí wọ́n ń bẹ̀rù,* ẹ má sì jáyà.+ 15 Ṣùgbọ́n ẹ gbà nínú ọkàn yín pé Kristi jẹ́ mímọ́, òun ni Olúwa, kí ẹ ṣe tán nígbà gbogbo láti gbèjà ara yín níwájú gbogbo ẹni tó bá béèrè ìdí tí ẹ fi ní ìrètí yìí, àmọ́ kí ẹ máa fi ìwà tútù+ àti ọ̀wọ̀ tó jinlẹ̀ ṣe bẹ́ẹ̀.+

16 Ẹ ní ẹ̀rí ọkàn rere,+ kó lè jẹ́ pé nínú ohunkóhun tí wọ́n bá ti sọ̀rọ̀ yín láìdáa, ìwà rere tí ẹ̀ ń hù torí ẹ jẹ́ ọmọlẹ́yìn Kristi+ máa jẹ́ kí ojú ti àwọn tó ń sọ̀rọ̀ yín láìdáa.+ 17 Tó bá wu Ọlọ́run pé kó fàyè gbà á, ó sàn kí ẹ jìyà torí pé ẹ̀ ń ṣe rere,+ ju kó jẹ́ torí pé ẹ̀ ń ṣe ohun tó burú.+ 18 Nítorí àwọn ẹ̀ṣẹ̀, Kristi kú lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo láìtún kú mọ́ láé,+ ó jẹ́ olódodo tó kú nítorí àwọn aláìṣòdodo,+ kó lè mú yín wá sọ́dọ̀ Ọlọ́run.+ Wọ́n pa á nínú ẹran ara,+ àmọ́ a sọ ọ́ di ààyè nínú ẹ̀mí.+ 19 Bẹ́ẹ̀ ló ṣe lọ wàásù fún àwọn ẹ̀mí tó wà lẹ́wọ̀n,+ 20 àwọn tó ṣàìgbọràn nígbà tí Ọlọ́run ń fi sùúrù dúró* ní àwọn ọjọ́ Nóà,+ lákòókò tí wọ́n ń kan ọkọ̀ áàkì,+ tí a fi gba àwọn èèyàn díẹ̀ là nígbà ìkún omi, ìyẹn ọkàn* mẹ́jọ.+

21 Ìrìbọmi tó tún ń gbà yín là báyìí fara jọ èyí, (kì í ṣe pé ó ń wẹ èérí ara kúrò, àmọ́ ó ń bẹ̀bẹ̀ fún ẹ̀rí ọkàn rere lọ́dọ̀ Ọlọ́run),+ nípasẹ̀ àjíǹde Jésù Kristi. 22 Ó wà ní ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run,+ torí ó lọ sí ọ̀run; a sì fi àwọn áńgẹ́lì, àwọn aláṣẹ àti àwọn agbára sí ìkáwọ́ rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́