ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jòhánù 14
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jòhánù

      • Nípasẹ̀ Jésù nìkan la fi lè dé ọ̀dọ̀ Baba (1-14)

        • ‘Èmi ni ọ̀nà, òtítọ́ àti ìyè’ (6)

      • Jésù ní òun máa rán ẹ̀mí mímọ́ (15-31)

        • “Baba tóbi jù mí lọ” (28)

Jòhánù 14:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 14:27
  • +Mk 11:22; 1Pe 1:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2021, ojú ìwé 20

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    8/2019, ojú ìwé 27-28

Jòhánù 14:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọ̀pọ̀ ibùjókòó.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 12:32; 1Pe 1:3, 4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, ojú ìwé 35-36

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2010, ojú ìwé 6

    8/15/2009, ojú ìwé 11

    4/15/2008, ojú ìwé 32

    11/15/1994, ojú ìwé 4-5

    6/15/1994, ojú ìwé 6

Jòhánù 14:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 17:24; Ro 8:17; Flp 1:23; 1Tẹ 4:16, 17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    11/15/1994, ojú ìwé 4-5

    6/15/1994, ojú ìwé 6

Jòhánù 14:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 11:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 274

Jòhánù 14:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 10:9; Ef 2:18; Heb 10:19, 20
  • +Jo 1:17; Ef 4:21
  • +Jo 1:4; 6:63; 17:3; Ro 6:23
  • +Iṣe 4:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 15

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 7, 274

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2009, ojú ìwé 4

    5/15/2009, ojú ìwé 31-32

    11/1/2005, ojú ìwé 25

    3/1/1992, ojú ìwé 18

    “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” ojú ìwé 15-22

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    11/2002, ojú ìwé 1

Jòhánù 14:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 11:27; Jo 1:18

Jòhánù 14:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 274

Jòhánù 14:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 12:45; Kol 1:15; Heb 1:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 17

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2015, ojú ìwé 5

    2/15/1992, ojú ìwé 11

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 274

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 22

    “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” ojú ìwé 18

Jòhánù 14:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 10:38; 17:21
  • +Jo 7:16; 8:28; 12:49

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 274

Jòhánù 14:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 5:36

Jòhánù 14:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 21:21; Iṣe 1:8; 2:41
  • +Iṣe 2:32, 33

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2019, ojú ìwé 5

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 274-275

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2011, ojú ìwé 32

    5/15/1997, ojú ìwé 13-14

    2/15/1992, ojú ìwé 15-16

    “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” ojú ìwé 88-89

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    9/1998, ojú ìwé 1

    “Kí Ijọba Rẹ Dé,” ojú ìwé 80

Jòhánù 14:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 15:16; 16:23

Jòhánù 14:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 275

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    12/15/1994, ojú ìwé 25

Jòhánù 14:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 13:34; 15:10; Jem 1:22

Jòhánù 14:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “olùtùnú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 24:49; Jo 15:26; 16:7; Iṣe 1:5; 2:1, 4; Ro 8:26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 275

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2003, ojú ìwé 17-18

    3/15/2003, ojú ìwé 6

    2/1/2002, ojú ìwé 19-20

    11/1/1996, ojú ìwé 10

    9/15/1992, ojú ìwé 15-16, 18

    Mẹtalọkan, ojú ìwé 22

Jòhánù 14:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 10:19, 20; Jo 16:13; 1Kọ 2:12; 1Jo 2:27
  • +1Kọ 2:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 275

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    9/15/1992, ojú ìwé 15-16

    Mẹtalọkan, ojú ìwé 22

Jòhánù 14:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “bí àwọn ọmọ aláìlóbìí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 28:20

Jòhánù 14:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 10:40, 41

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 275

Jòhánù 14:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 10:38; 17:21

Jòhánù 14:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 28

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2002, ojú ìwé 16

    2/1/1997, ojú ìwé 19

Jòhánù 14:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 6:13, 16; Iṣe 1:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 275

Jòhánù 14:23

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ibùjókòó.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 15:10
  • +1Jo 2:24; Ifi 3:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 17

    Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, ojú ìwé 197

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2002, ojú ìwé 16

Jòhánù 14:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 5:19; 7:16; 12:49

Jòhánù 14:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 24:49; Jo 15:26; 16:13; 1Jo 2:27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    6/2017, ojú ìwé 13

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 1 2017 ojú ìwé 15

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 311

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2011, ojú ìwé 14-15

    10/1/2010, ojú ìwé 27-28

    7/15/2010, ojú ìwé 20-21

    4/15/2008, ojú ìwé 32

    5/1/2003, ojú ìwé 17

    2/1/2002, ojú ìwé 19-20

    10/15/2000, ojú ìwé 21-22

    4/1/2000, ojú ìwé 8-9

    9/15/1992, ojú ìwé 15-16

    Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 19-20

    Mẹtalọkan, ojú ìwé 22

    Yiyan, ojú ìwé 41-42

Jòhánù 14:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 16:33; Ef 2:14; Flp 4:6, 7; Kol 3:15; 2Tẹ 3:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    5/2018, ojú ìwé 20

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 275

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2009, ojú ìwé 9

    4/15/1997, ojú ìwé 12

Jòhánù 14:28

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 20:17; 1Kọ 11:3; 15:28; Flp 2:5, 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 15

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/15/1993, ojú ìwé 29

Jòhánù 14:29

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 13:19; 16:4

Jòhánù 14:30

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kò sì ní àṣẹ kankan lórí mi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 12:31; 16:11
  • +Jo 16:33

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 275

Jòhánù 14:31

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 10:18; 12:49; 15:10; Flp 2:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 17

    “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” ojú ìwé 129, 136-137

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2002, ojú ìwé 4

    2/1/2002, ojú ìwé 14-15

Àwọn míì

Jòh. 14:1Jo 14:27
Jòh. 14:1Mk 11:22; 1Pe 1:21
Jòh. 14:2Lk 12:32; 1Pe 1:3, 4
Jòh. 14:3Jo 17:24; Ro 8:17; Flp 1:23; 1Tẹ 4:16, 17
Jòh. 14:5Jo 11:16
Jòh. 14:6Jo 10:9; Ef 2:18; Heb 10:19, 20
Jòh. 14:6Jo 1:17; Ef 4:21
Jòh. 14:6Jo 1:4; 6:63; 17:3; Ro 6:23
Jòh. 14:6Iṣe 4:12
Jòh. 14:7Mt 11:27; Jo 1:18
Jòh. 14:9Jo 12:45; Kol 1:15; Heb 1:3
Jòh. 14:10Jo 10:38; 17:21
Jòh. 14:10Jo 7:16; 8:28; 12:49
Jòh. 14:11Jo 5:36
Jòh. 14:12Mt 21:21; Iṣe 1:8; 2:41
Jòh. 14:12Iṣe 2:32, 33
Jòh. 14:13Jo 15:16; 16:23
Jòh. 14:15Jo 13:34; 15:10; Jem 1:22
Jòh. 14:16Lk 24:49; Jo 15:26; 16:7; Iṣe 1:5; 2:1, 4; Ro 8:26
Jòh. 14:17Mt 10:19, 20; Jo 16:13; 1Kọ 2:12; 1Jo 2:27
Jòh. 14:171Kọ 2:14
Jòh. 14:18Mt 28:20
Jòh. 14:19Iṣe 10:40, 41
Jòh. 14:20Jo 10:38; 17:21
Jòh. 14:22Lk 6:13, 16; Iṣe 1:13
Jòh. 14:23Jo 15:10
Jòh. 14:231Jo 2:24; Ifi 3:20
Jòh. 14:24Jo 5:19; 7:16; 12:49
Jòh. 14:26Lk 24:49; Jo 15:26; 16:13; 1Jo 2:27
Jòh. 14:27Jo 16:33; Ef 2:14; Flp 4:6, 7; Kol 3:15; 2Tẹ 3:16
Jòh. 14:28Jo 20:17; 1Kọ 11:3; 15:28; Flp 2:5, 6
Jòh. 14:29Jo 13:19; 16:4
Jòh. 14:30Jo 12:31; 16:11
Jòh. 14:30Jo 16:33
Jòh. 14:31Jo 10:18; 12:49; 15:10; Flp 2:8
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Jòhánù 14:1-31

Àkọsílẹ̀ Jòhánù

14 “Ẹ má ṣe jẹ́ kí ìdààmú bá ọkàn yín.+ Ẹ ní ìgbàgbọ́ nínú Ọlọ́run;+ ẹ ní ìgbàgbọ́ nínú èmi náà. 2 Nínú ilé Baba mi, ọ̀pọ̀ ibùgbé* ló wà. Àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, ǹ bá ti sọ fún yín, torí pé mò ń lọ kí n lè pèsè ibì kan sílẹ̀ fún yín.+ 3 Bákan náà, tí mo bá lọ, tí mo sì pèsè ibì kan sílẹ̀ fún yín, màá tún pa dà wá, màá sì gbà yín sílé sọ́dọ̀ ara mi, kí ẹ̀yin náà lè wà ní ibi tí mo wà.+ 4 Ẹ mọ ọ̀nà ibi tí mò ń lọ.”

5 Tọ́másì+ sọ fún un pé: “Olúwa, a ò mọ ibi tó ò ń lọ. Báwo la ṣe fẹ́ mọ ọ̀nà ibẹ̀?”

6 Jésù sọ fún un pé: “Èmi ni ọ̀nà+ àti òtítọ́ + àti ìyè.+ Kò sí ẹni tó ń wá sọ́dọ̀ Baba àfi nípasẹ̀ mi.+ 7 Ká ní ẹ mọ̀ mí ni, ẹ̀ bá mọ Baba mi náà; láti ìsinsìnyí lọ, ẹ ti mọ̀ ọ́n, ẹ sì ti rí i.”+

8 Fílípì sọ fún un pé: “Olúwa, fi Baba hàn wá, ìyẹn sì máa tó wa.”

9 Jésù sọ fún un pé: “Fílípì, pẹ̀lú bó ṣe pẹ́ tó tí mo ti wà pẹ̀lú yín, ṣé o ò tíì mọ̀ mí ni? Ẹnikẹ́ni tó bá ti rí mi ti rí Baba náà.+ Kí ló dé tí o wá sọ pé, ‘Fi Baba hàn wá’? 10 Ṣé o ò gbà pé mo wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Baba àti pé Baba wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú mi ni?+ Kì í ṣe èrò ara mi+ ni àwọn nǹkan tí mò ń sọ fún yín, àmọ́ Baba tó ṣì wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú mi ló ń ṣe àwọn iṣẹ́ rẹ̀. 11 Ẹ gbà mí gbọ́ pé mo wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Baba, Baba sì wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú mi; tàbí kẹ̀, kí ẹ gbà gbọ́ nítorí àwọn iṣẹ́ náà fúnra wọn.+ 12 Lóòótọ́-lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, ẹnikẹ́ni tó bá ní ìgbàgbọ́ nínú mi náà máa ṣe àwọn iṣẹ́ tí mò ń ṣe; ó sì máa ṣe àwọn iṣẹ́ tó tóbi ju ìwọ̀nyí lọ,+ torí pé mò ń lọ sọ́dọ̀ Baba.+ 13 Bákan náà, ohunkóhun tí ẹ bá béèrè ní orúkọ mi, màá ṣe é, ká lè tipasẹ̀ Ọmọ+ yin Baba lógo. 14 Tí ẹ bá béèrè ohunkóhun ní orúkọ mi, màá ṣe é.

15 “Tí ẹ bá nífẹ̀ẹ́ mi, ẹ máa pa àwọn àṣẹ mi mọ́.+ 16 Màá béèrè lọ́wọ́ Baba, ó sì máa fún yín ní olùrànlọ́wọ́* míì tó máa wà pẹ̀lú yín títí láé,+ 17 ẹ̀mí òtítọ́,+ tí ayé ò lè gbà, torí pé kò rí i, kò sì mọ̀ ọ́n.+ Ẹ̀yin mọ̀ ọ́n, torí ó wà pẹ̀lú yín, ó sì wà nínú yín. 18 Mi ò ní fi yín sílẹ̀ ní ẹni tí ọ̀fọ̀ ṣẹ̀.* Mò ń bọ̀ lọ́dọ̀ yín.+ 19 Ní ìgbà díẹ̀ sí i, ayé ò ní rí mi mọ́, àmọ́ ẹ máa rí mi,+ torí pé mo wà láàyè, ẹ sì máa wà láàyè. 20 Ọjọ́ yẹn lẹ máa mọ̀ pé mo wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Baba mi àti pé ẹ wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú mi, mo sì wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú yín.+ 21 Ẹnikẹ́ni tó bá ní àwọn àṣẹ mi, tó sì ń pa wọ́n mọ́ ni ẹni tó nífẹ̀ẹ́ mi. Lọ́wọ́ kejì, ẹnikẹ́ni tó bá nífẹ̀ẹ́ mi, Baba mi máa nífẹ̀ẹ́ rẹ̀, èmi náà máa nífẹ̀ẹ́ rẹ̀, màá sì fi ara mi hàn án kedere.”

22 Júdásì,+ tí kì í ṣe Ìsìkáríọ́tù, sọ fún un pé: “Olúwa, kí ló ṣẹlẹ̀ tó fi jẹ́ pé àwa lo fẹ́ fi ara rẹ hàn kedere sí, tí kì í ṣe ayé?”

23 Jésù dá a lóhùn pé: “Tí ẹnikẹ́ni bá nífẹ̀ẹ́ mi, ó máa pa ọ̀rọ̀ mi mọ́,+ Baba mi sì máa nífẹ̀ẹ́ rẹ̀, a máa wá sọ́dọ̀ rẹ̀, a sì máa fi ọ̀dọ̀ rẹ̀ ṣe ibùgbé* wa.+ 24 Ẹnikẹ́ni tí kò bá nífẹ̀ẹ́ mi kì í pa àwọn ọ̀rọ̀ mi mọ́. Ọ̀rọ̀ tí ẹ̀ ń gbọ́ kì í ṣe tèmi, àmọ́ ó jẹ́ ti Baba tó rán mi.+

25 “Mo ti sọ àwọn nǹkan yìí fún yín nígbà tí mo ṣì wà pẹ̀lú yín. 26 Àmọ́ olùrànlọ́wọ́ náà, ẹ̀mí mímọ́, tí Baba máa rán ní orúkọ mi, máa kọ́ yín ní gbogbo nǹkan, ó sì máa rán yín létí gbogbo ohun tí mo sọ fún yín.+ 27 Mo fi àlàáfíà sílẹ̀ fún yín; mo fún yín ní àlàáfíà mi.+ Mi ò fún yín lọ́nà tí ayé gbà ń fúnni. Ẹ má ṣe jẹ́ kí ìdààmú bá ọkàn yín, kí ìbẹ̀rù má sì mú kí ọkàn yín dà rú. 28 Ẹ gbọ́ tí mo sọ fún yín pé, ‘Mò ń lọ, mo sì ń pa dà bọ̀ sọ́dọ̀ yín.’ Tí ẹ bá nífẹ̀ẹ́ mi, inú yín máa dùn pé mò ń lọ sọ́dọ̀ Baba, torí pé Baba tóbi jù mí lọ.+ 29 Torí náà, mo ti sọ fún yín báyìí kó tó ṣẹlẹ̀, kí ẹ lè gbà gbọ́ tó bá ṣẹlẹ̀.+ 30 Mi ò ní bá yín sọ̀rọ̀ púpọ̀ mọ́, torí alákòóso ayé+ ń bọ̀, kò sì ní agbára kankan lórí mi.*+ 31 Àmọ́ torí kí ayé lè mọ̀ pé mo nífẹ̀ẹ́ Baba, ohun tí Baba pa láṣẹ fún mi pé kí n ṣe gẹ́lẹ́ ni mò ń ṣe.+ Ẹ dìde, ẹ jẹ́ ká kúrò níbí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́