ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 15
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Móábù (1-9)

Àìsáyà 15:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 9:25, 26; Isk 25:11
  • +Nọ 21:28; Di 2:9
  • +2Ọb 3:24, 25; Jer 48:31

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 192-193

Àìsáyà 15:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Tẹ́ńpìlì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 48:18
  • +Jer 48:1
  • +Nọ 21:30; Joṣ 13:15-17
  • +Di 14:1
  • +Jer 48:36, 37

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 193

Àìsáyà 15:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “aṣọ àpò ìdọ̀họ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 48:38

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 193

Àìsáyà 15:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ọkàn rẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 32:37; Ais 16:9
  • +Ond 11:20

Àìsáyà 15:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 13:10
  • +Jer 48:34
  • +Jer 48:3, 5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 193

Àìsáyà 15:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 193

Àìsáyà 15:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 48:20

Àìsáyà 15:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 17:25, 26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 193

Àwọn míì

Àìsá. 15:1Jer 9:25, 26; Isk 25:11
Àìsá. 15:1Nọ 21:28; Di 2:9
Àìsá. 15:12Ọb 3:24, 25; Jer 48:31
Àìsá. 15:2Jer 48:18
Àìsá. 15:2Jer 48:1
Àìsá. 15:2Nọ 21:30; Joṣ 13:15-17
Àìsá. 15:2Di 14:1
Àìsá. 15:2Jer 48:36, 37
Àìsá. 15:3Jer 48:38
Àìsá. 15:4Nọ 32:37; Ais 16:9
Àìsá. 15:4Ond 11:20
Àìsá. 15:5Jẹ 13:10
Àìsá. 15:5Jer 48:34
Àìsá. 15:5Jer 48:3, 5
Àìsá. 15:8Jer 48:20
Àìsá. 15:92Ọb 17:25, 26
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 15:1-9

Àìsáyà

15 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Móábù:+

Torí a ti pa á run ní òru kan,

A ti pa Árì+ ti Móábù lẹ́nu mọ́.

Torí a ti pa á run ní òru kan,

A ti pa Kírì+ ti Móábù lẹ́nu mọ́.

 2 Ó ti gòkè lọ sí Ilé* àti sí Díbónì,+

Lọ sí àwọn ibi gíga láti sunkún.

Móábù ń sunkún torí Nébò+ àti torí Médébà.+

Wọ́n fá gbogbo orí korodo,+ wọ́n gé gbogbo irùngbọ̀n mọ́lẹ̀.+

 3 Wọ́n wọ aṣọ ọ̀fọ̀* lójú ọ̀nà.

Gbogbo wọn ń pohùn réré ẹkún lórí àwọn òrùlé àtàwọn ojúde ìlú wọn;

Wọ́n ń sunkún bí wọ́n ṣe ń sọ̀ kalẹ̀ lọ.+

 4 Hẹ́ṣíbónì àti Éléálè+ ké jáde;

Wọ́n gbọ́ ohùn wọn ní Jáhásì+ lọ́hùn-ún lọ́hùn-ún.

Ìdí nìyẹn tí àwọn ọkùnrin Móábù tó dira ogun fi ń kígbe ṣáá.

Ó* ń gbọ̀n rìrì.

 5 Ọkàn mi ń ké jáde torí Móábù.

Àwọn tó sá níbẹ̀ ti sá lọ sí Sóárì+ àti Ẹgilati-ṣẹ́líṣíyà+ lọ́hùn-ún lọ́hùn-ún.

Wọ́n ń sunkún bí wọ́n ṣe ń gòkè lọ sí Lúhítì;

Wọ́n ń ké lójú ọ̀nà Hórónáímù torí àjálù náà.+

 6 Torí omi Nímúrímù ti gbẹ táútáú;

Koríko tútù ti gbẹ dà nù,

Kò sí koríko mọ́, kò sì sí ewéko tútù kankan mọ́.

 7 Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi ń kó àwọn ohun tó ṣẹ́ kù ní ilé ìkẹ́rùsí wọn àti ọrọ̀ wọn;

Wọ́n ń sọdá àfonífojì àwọn igi pọ́pílà.

 8 Torí igbe wọn ń dún ní gbogbo ilẹ̀ Móábù.+

Ìpohùn réré ẹkún náà dé Égíláímù;

Ó lọ títí dé Bia-élímù.

 9 Torí ẹ̀jẹ̀ kún inú omi Dímónì,

Mo ṣì máa ṣe jù bẹ́ẹ̀ lọ fún Dímónì:

Kìnnìún máa pa àwọn tó yè bọ́ ní Móábù

Àti àwọn tó ṣẹ́ kù ní ilẹ̀ náà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́