ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 2
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Diutarónómì

      • Wọ́n fi ọdún 38 rìn kiri ní aginjù (1-23)

      • Wọ́n ṣẹ́gun Síhónì ọba Hẹ́ṣíbónì (24-37)

Diutarónómì 2:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 14:25

Diutarónómì 2:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 20:14; Di 23:7
  • +Jẹ 27:39, 40; 36:8, 9
  • +Ẹk 15:15; 23:27

Diutarónómì 2:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ẹ má ṣe múnú bí wọn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:8; Joṣ 24:4; Iṣe 17:26

Diutarónómì 2:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 20:18, 19

Diutarónómì 2:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 29:5; Ne 9:21; Sm 23:1; 34:9, 10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2022, ojú ìwé 5-6

Diutarónómì 2:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 20:20, 21
  • +2Kr 8:17
  • +Nọ 21:13; Ond 11:17, 18; 2Kr 20:10

Diutarónómì 2:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 19:36, 37

Diutarónómì 2:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 14:5

Diutarónómì 2:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 3:11; 1Kr 20:6
  • +Nọ 13:22, 33

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 5/2021,

Diutarónómì 2:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 14:6; 36:20
  • +Jẹ 27:39, 40

Diutarónómì 2:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 21:12

Diutarónómì 2:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 14:33; 32:11; Di 1:35; Sm 95:11; Heb 3:18; Jud 5

Diutarónómì 2:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 10:1, 5

Diutarónómì 2:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 26:63, 64

Diutarónómì 2:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 19:36, 38; Di 2:9; Ond 11:15; 2Kr 20:10; Iṣe 17:26

Diutarónómì 2:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 15:18-20; Di 3:11

Diutarónómì 2:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 13:33; Di 9:1, 2

Diutarónómì 2:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 36:8
  • +Jẹ 14:6; Di 2:12

Diutarónómì 2:23

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, Kírétè.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 10:19
  • +Jẹ 10:13, 14

Diutarónómì 2:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 21:13
  • +Nọ 21:23

Diutarónómì 2:25

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “wọ́n á ní ìrora bíi ti ẹni tó ń rọbí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 15:14; 23:27; Di 11:25; Joṣ 2:9, 10

Diutarónómì 2:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 13:15, 18; 21:8, 37
  • +Di 20:10

Diutarónómì 2:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 21:21, 22

Diutarónómì 2:30

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 9:18
  • +Nọ 21:25

Diutarónómì 2:31

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 32:33; Sm 135:10-12

Diutarónómì 2:32

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 21:23, 24; Ond 11:20

Diutarónómì 2:34

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 20:16, 17

Diutarónómì 2:36

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 3:12; 4:47, 48; Joṣ 13:8, 9
  • +Sm 44:3

Diutarónómì 2:37

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 3:16; Ond 11:15
  • +Nọ 21:23, 24

Àwọn míì

Diu. 2:1Nọ 14:25
Diu. 2:4Nọ 20:14; Di 23:7
Diu. 2:4Jẹ 27:39, 40; 36:8, 9
Diu. 2:4Ẹk 15:15; 23:27
Diu. 2:5Di 32:8; Joṣ 24:4; Iṣe 17:26
Diu. 2:6Nọ 20:18, 19
Diu. 2:7Di 29:5; Ne 9:21; Sm 23:1; 34:9, 10
Diu. 2:8Nọ 20:20, 21
Diu. 2:82Kr 8:17
Diu. 2:8Nọ 21:13; Ond 11:17, 18; 2Kr 20:10
Diu. 2:9Jẹ 19:36, 37
Diu. 2:10Jẹ 14:5
Diu. 2:11Di 3:11; 1Kr 20:6
Diu. 2:11Nọ 13:22, 33
Diu. 2:12Jẹ 14:6; 36:20
Diu. 2:12Jẹ 27:39, 40
Diu. 2:13Nọ 21:12
Diu. 2:14Nọ 14:33; 32:11; Di 1:35; Sm 95:11; Heb 3:18; Jud 5
Diu. 2:151Kọ 10:1, 5
Diu. 2:16Nọ 26:63, 64
Diu. 2:19Jẹ 19:36, 38; Di 2:9; Ond 11:15; 2Kr 20:10; Iṣe 17:26
Diu. 2:20Jẹ 15:18-20; Di 3:11
Diu. 2:21Nọ 13:33; Di 9:1, 2
Diu. 2:22Jẹ 36:8
Diu. 2:22Jẹ 14:6; Di 2:12
Diu. 2:23Jẹ 10:19
Diu. 2:23Jẹ 10:13, 14
Diu. 2:24Nọ 21:13
Diu. 2:24Nọ 21:23
Diu. 2:25Ẹk 15:14; 23:27; Di 11:25; Joṣ 2:9, 10
Diu. 2:26Joṣ 13:15, 18; 21:8, 37
Diu. 2:26Di 20:10
Diu. 2:27Nọ 21:21, 22
Diu. 2:30Ro 9:18
Diu. 2:30Nọ 21:25
Diu. 2:31Nọ 32:33; Sm 135:10-12
Diu. 2:32Nọ 21:23, 24; Ond 11:20
Diu. 2:34Di 20:16, 17
Diu. 2:36Di 3:12; 4:47, 48; Joṣ 13:8, 9
Diu. 2:36Sm 44:3
Diu. 2:37Di 3:16; Ond 11:15
Diu. 2:37Nọ 21:23, 24
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
  • 32
  • 33
  • 34
  • 35
  • 36
  • 37
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Diutarónómì 2:1-37

Diutarónómì

2 “Lẹ́yìn náà, a ṣẹ́rí pa dà, a sì gba ọ̀nà Òkun Pupa lọ sí aginjù, bí Jèhófà ṣe sọ fún mi gẹ́lẹ́,+ ọ̀pọ̀ ọjọ́ la sì fi rìn yí ká Òkè Séírì. 2 Níkẹyìn, Jèhófà sọ fún mi pé, 3 ‘Èyí tí ẹ rìn yí ká òkè yìí tó. Ó yá, ẹ yí sí apá àríwá. 4 Kí o sì pàṣẹ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ààlà ilẹ̀ àwọn arákùnrin yín, àwọn àtọmọdọ́mọ Ísọ̀,+ tí wọ́n ń gbé ní Séírì,+ lẹ máa gbà kọjá, ẹ̀rù yín á sì máa bà wọ́n,+ torí náà, ẹ ṣọ́ra gidigidi. 5 Ẹ má ṣe bá wọn fa wàhálà kankan,* torí mi ò ní fún yín ní ìkankan lára ilẹ̀ wọn, bí ò tiẹ̀ ju ìwọ̀n àtẹ́lẹsẹ̀ kan lọ, torí mo ti fún Ísọ̀ ní Òkè Séírì kó lè di tirẹ̀.+ 6 Kí ẹ san owó oúnjẹ tí ẹ bá jẹ fún wọn, kí ẹ sì san owó omi tí ẹ bá mu.+ 7 Torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ti bù kún ọ nínú gbogbo ohun tí o ṣe. Ó mọ gbogbo bí o ṣe ń rìn nínú aginjù tó tóbi yìí dáadáa. Jèhófà Ọlọ́run rẹ ti wà pẹ̀lú rẹ jálẹ̀ ogójì (40) ọdún yìí, o ò sì ṣaláìní ohunkóhun.”’+ 8 Torí náà, a gba ọ̀dọ̀ àwọn arákùnrin wa kọjá, àwọn àtọmọdọ́mọ Ísọ̀,+ tí wọ́n ń gbé ní Séírì, a ò gba ọ̀nà Árábà, Élátì àti Esioni-gébérì.+

“A wá yí gba ọ̀nà aginjù Móábù.+ 9 Jèhófà wá sọ fún mi pé, ‘Má ṣe bá Móábù fa wàhálà kankan, má sì bá wọn jagun, torí mi ò ní fún ọ ní ìkankan lára ilẹ̀ rẹ̀ pé kó di tìrẹ, torí mo ti fún àwọn àtọmọdọ́mọ Lọ́ọ̀tì ní Árì kó lè di tiwọn.+ 10 (Àwọn Émímù+ ló ń gbé ibẹ̀ tẹ́lẹ̀, èèyàn ńlá ni wọ́n, wọ́n pọ̀ gan-an, wọ́n sì ga bí àwọn Ánákímù. 11 Àwọn Réfáímù+ náà rí bí àwọn Ánákímù,+ àwọn ọmọ Móábù sì máa ń pè wọ́n ní Émímù. 12 Séírì ni àwọn Hórì+ ń gbé tẹ́lẹ̀, àmọ́ àwọn àtọmọdọ́mọ Ísọ̀ lé wọn kúrò, wọ́n pa wọ́n run, wọ́n sì wá ń gbé ilẹ̀ wọn,+ ohun tí Ísírẹ́lì máa ṣe sí ilẹ̀ tó jẹ́ tiwọn nìyẹn, èyí tó dájú pé Jèhófà máa fún wọn.) 13 Ó yá, lọ sọdá Àfonífojì Séréédì.’ Bí a ṣe lọ sọdá Àfonífojì Séréédì+ nìyẹn. 14 Ọdún méjìdínlógójì (38) la fi rìn láti Kadeṣi-bánéà títí a fi sọdá Àfonífojì Séréédì, títí gbogbo ìran àwọn ọkùnrin ogun fi pa run láàárín àpéjọ, bí Jèhófà ṣe búra fún wọn gẹ́lẹ́.+ 15 Jèhófà fi ọwọ́ rẹ̀ jẹ wọ́n níyà kó lè pa wọ́n run láàárín àpéjọ náà títí wọ́n fi ṣègbé.+

16 “Gbàrà tí gbogbo àwọn ọkùnrin ogun ti kú tán láàárín àwọn èèyàn náà,+ 17 Jèhófà tún sọ fún mi pé, 18 ‘Lónìí, kí ẹ gba ilẹ̀ Móábù kọjá, ìyẹn Árì. 19 Tí o bá ti sún mọ́ ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Ámónì, má yọ wọ́n lẹ́nu, má sì múnú bí wọn, torí mi ò ní fún ọ ní ìkankan lára ilẹ̀ àwọn ọmọ Ámónì kó lè di tìrẹ, nítorí mo ti fún àwọn àtọmọdọ́mọ Lọ́ọ̀tì kó lè di tiwọn.+ 20 Ilẹ̀ àwọn Réfáímù+ ni wọ́n máa ń ka ibí yìí náà sí tẹ́lẹ̀. (Ibẹ̀ ni àwọn Réfáímù ń gbé tẹ́lẹ̀, àwọn ọmọ Ámónì sì máa ń pè wọ́n ní Sámúsúmímù. 21 Èèyàn ńlá ni wọ́n, wọ́n pọ̀ gan-an, wọ́n sì ga bí àwọn Ánákímù;+ àmọ́ Jèhófà pa wọ́n run níwájú àwọn ọmọ Ámónì, wọ́n lé wọn jáde, wọ́n sì ń gbé ilẹ̀ wọn. 22 Ohun tó ṣe fún àwọn àtọmọdọ́mọ Ísọ̀ tí wọ́n ń gbé ní Séírì+ báyìí nìyẹn, nígbà tó pa àwọn Hórì+ run níwájú wọn, kí wọ́n lè lé wọn kúrò, kí wọ́n sì máa gbé ilẹ̀ wọn títí di òní yìí. 23 Ní ti àwọn Áfímù, ibi tí wọ́n ń gbé nasẹ̀ dé Gásà,+ títí àwọn Káfítórímù tí wọ́n wá láti Káfítórì*+ fi pa wọ́n run, tí wọ́n sì ń gbé ilẹ̀ wọn.)

24 “‘Ẹ dìde, kí ẹ sì rí i pé ẹ sọdá Àfonífojì Áánónì.+ Wò ó, mo ti fi Síhónì+ ọba Hẹ́ṣíbónì, tó jẹ́ Ámórì lé yín lọ́wọ́. Torí náà, ẹ bẹ̀rẹ̀ sí í gba ilẹ̀ rẹ̀, kí ẹ sì bá a jagun. 25 Lónìí yìí, màá mú kí ẹ̀rù yín máa ba gbogbo èèyàn tó wà lábẹ́ ọ̀run tí wọ́n bá gbọ́ ìròyìn nípa yín. Ọkàn wọn kò ní balẹ̀, jìnnìjìnnì á sì bò wọ́n* torí yín.’+

26 “Mo wá ní kí àwọn ìránṣẹ́ láti aginjù Kédémótì+ lọ jíṣẹ́ àlàáfíà+ yìí fún Síhónì ọba Hẹ́ṣíbónì pé, 27 ‘Jẹ́ kí n gba ilẹ̀ rẹ kọjá. Mi ò ní kọjá ojú ọ̀nà, mi ò sì ní yà sí ọ̀tún tàbí òsì.+ 28 Oúnjẹ àti omi tí o bá tà fún mi nìkan ni màá jẹ tí màá sì mu. Ṣáà jẹ́ kí n fi ẹsẹ̀ mi rìn kọjá, 29 títí màá fi sọdá Jọ́dánì sí ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run wa fẹ́ fún wa. Ohun tí àwọn àtọmọdọ́mọ Ísọ̀ tí wọ́n ń gbé ní Séírì àtàwọn ọmọ Móábù tí wọ́n ń gbé ní Árì ṣe fún mi nìyẹn.’ 30 Àmọ́ Síhónì ọba Hẹ́ṣíbónì kò jẹ́ ká kọjá, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ gbà á láyè pé kó ṣorí kunkun,+ kí ọkàn rẹ̀ sì le, kó lè fi í lé ọ lọ́wọ́ bó ṣe rí báyìí.  +

31 “Jèhófà wá sọ fún mi pé, ‘Wò ó, mo ti ń fi Síhónì àti ilẹ̀ rẹ̀ lé ọ lọ́wọ́. Bẹ̀rẹ̀ sí í gba ilẹ̀ rẹ̀.’+ 32 Nígbà tí Síhónì àti gbogbo èèyàn rẹ̀ jáde wá gbógun jà wá ní Jáhásì,+ 33 Jèhófà Ọlọ́run wa fi í lé wa lọ́wọ́, a sì ṣẹ́gun òun àtàwọn ọmọ rẹ̀ pẹ̀lú gbogbo èèyàn rẹ̀. 34 A gba gbogbo ìlú rẹ̀ nígbà yẹn, a sì pa gbogbo ìlú náà run, títí kan àwọn ọkùnrin, àwọn obìnrin àtàwọn ọmọdé. A ò dá ẹnikẹ́ni sí.+ 35 Àwọn ẹran ọ̀sìn nìkan la kó bọ̀ láti ogun pẹ̀lú àwọn ẹrù tí a kó láti àwọn ìlú tí a ṣẹ́gun. 36 Láti Áróérì,+ èyí tó wà ní etí Àfonífojì Áánónì, (títí kan ìlú tó wà ní àfonífojì náà), títí dé Gílíádì, kò sí ìlú tí apá wa ò ká. Gbogbo wọn ni Jèhófà Ọlọ́run wa fi lé wa lọ́wọ́.+ 37 Àmọ́, ẹ ò sún mọ́ ilẹ̀ àwọn ọmọ Ámónì,+ gbogbo etí Àfonífojì Jábókù+ àtàwọn ìlú tó wà ní agbègbè olókè àti gbogbo ibi tí Jèhófà Ọlọ́run wa kà léèwọ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́