ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 2
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Léfítíkù

      • Ọrẹ ọkà (1-16)

Léfítíkù 2:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 9:17; Nọ 15:2-4
  • +Ẹk 29:1-3; Le 6:14, 15; Nọ 7:13

Léfítíkù 2:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ohun ìrántí (ìṣàpẹẹrẹ) látinú rẹ̀.”

  • *

    Tàbí “tó tuni lójú.” Ní Héb., “atura.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 5:25, 26

Léfítíkù 2:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 7:9, 10
  • +Le 10:12; Nọ 18:9

Léfítíkù 2:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 8:26, 28; Nọ 6:13, 19

Léfítíkù 2:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 6:20, 21

Léfítíkù 2:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 28:9

Léfítíkù 2:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ohun ìrántí (ìṣàpẹẹrẹ) látinú rẹ̀.”

  • *

    Tàbí “tó tuni lójú.” Ní Héb., “atura.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 2:2; 5:11, 12
  • +Ẹk 29:38-41; Nọ 28:4-6

Léfítíkù 2:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 18:9

Léfítíkù 2:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 6:14, 17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 11/2020, ojú ìwé 2

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2004, ojú ìwé 21-22

Léfítíkù 2:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tó tuni lójú.” Ní Héb., “atura.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 23:19; Nọ 15:20; 2Kr 31:5; Owe 3:9

Léfítíkù 2:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 43:23, 24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2004, ojú ìwé 22

    8/15/1999, ojú ìwé 32

Léfítíkù 2:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ṣírí tútù.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 23:16; 34:22; Nọ 28:26

Léfítíkù 2:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ohun ìrántí (ìṣàpẹẹrẹ) látinú rẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 5:11, 12; 6:14, 15

Àwọn míì

Léf. 2:1Le 9:17; Nọ 15:2-4
Léf. 2:1Ẹk 29:1-3; Le 6:14, 15; Nọ 7:13
Léf. 2:2Nọ 5:25, 26
Léf. 2:3Le 7:9, 10
Léf. 2:3Le 10:12; Nọ 18:9
Léf. 2:4Le 8:26, 28; Nọ 6:13, 19
Léf. 2:5Le 6:20, 21
Léf. 2:6Nọ 28:9
Léf. 2:9Le 2:2; 5:11, 12
Léf. 2:9Ẹk 29:38-41; Nọ 28:4-6
Léf. 2:10Nọ 18:9
Léf. 2:11Le 6:14, 17
Léf. 2:12Ẹk 23:19; Nọ 15:20; 2Kr 31:5; Owe 3:9
Léf. 2:13Isk 43:23, 24
Léf. 2:14Ẹk 23:16; 34:22; Nọ 28:26
Léf. 2:16Le 5:11, 12; 6:14, 15
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Léfítíkù 2:1-16

Léfítíkù

2 “‘Tí ẹnì* kan bá fẹ́ mú ọrẹ ọkà+ wá fún Jèhófà, kó jẹ́ ìyẹ̀fun tó kúnná, kó da òróró sórí rẹ̀, kó sì fi oje igi tùràrí sórí rẹ̀.+ 2 Kó wá gbé e wá fún àwọn ọmọ Áárónì, tí wọ́n jẹ́ àlùfáà, kí àlùfáà sì bu ẹ̀kúnwọ́ ìyẹ̀fun náà tí wọ́n pò mọ́ òróró àti gbogbo oje igi tùràrí rẹ̀, kó sì mú kó rú èéfín lórí pẹpẹ bí ọrẹ ìṣàpẹẹrẹ,*+ ọrẹ àfinásun sí Jèhófà, tó ní òórùn dídùn.* 3 Kí ohunkóhun tó bá ṣẹ́ kù lára ọrẹ ọkà náà jẹ́ ti Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀,+ ohun mímọ́ jù lọ ló jẹ́+ látinú àwọn ọrẹ àfinásun sí Jèhófà.

4 “‘Tí o bá fẹ́ fi ohun tí wọ́n yan nínú ààrò ṣe ọrẹ ọkà, kó jẹ́ èyí tí wọ́n fi ìyẹ̀fun tó kúnná ṣe, búrẹ́dì aláìwú tí wọ́n fi òróró pò, tó rí bí òrùka tàbí búrẹ́dì aláìwú pẹlẹbẹ tí wọ́n fi òróró pa.+

5 “‘Tó bá jẹ́ ohun tí wọ́n ṣe nínú agbada+ lo fẹ́ fi ṣe ọrẹ ọkà, kó jẹ́ èyí tí wọ́n fi ìyẹ̀fun tó kúnná ṣe, tí wọ́n pò mọ́ òróró, tí kò sì ní ìwúkàrà. 6 Kí o gé e sí wẹ́wẹ́, kí o sì da òróró sórí rẹ̀.+ Ọrẹ ọkà ni.

7 “‘Tó bá jẹ́ ohun tí wọ́n sè nínú páànù lo fẹ́ fi ṣe ọrẹ ọkà, kó jẹ́ èyí tí wọ́n fi ìyẹ̀fun tó kúnná pẹ̀lú òróró ṣe. 8 Àwọn nǹkan yìí ni kí o fi ṣe ọrẹ ọkà tí o máa mú wá fún Jèhófà, kí o gbé e fún àlùfáà, yóò sì gbé e sún mọ́ pẹpẹ. 9 Kí àlùfáà mú lára ọrẹ ọkà náà láti fi ṣe ọrẹ ìṣàpẹẹrẹ,*+ kó mú kó rú èéfín lórí pẹpẹ bí ọrẹ àfinásun tó ní òórùn dídùn* sí Jèhófà.+ 10 Kí ohun tó bá ṣẹ́ kù lára ọrẹ ọkà náà jẹ́ ti Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, ohun mímọ́ jù lọ ló jẹ́ látinú àwọn ọrẹ àfinásun+ sí Jèhófà.

11 “‘Ẹ má ṣe mú ọrẹ ọkà kankan tó ní ìwúkàrà+ wá fún Jèhófà, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ mú kí àpòrọ́ kíkan tàbí oyin èyíkéyìí rú èéfín bí ọrẹ àfinásun sí Jèhófà.

12 “‘Ẹ lè mú wọn wá fún Jèhófà láti fi ṣe ọrẹ àwọn àkọ́so+ yín, àmọ́ ẹ má ṣe mú un wá sórí pẹpẹ láti mú òórùn dídùn* jáde.

13 “‘Kí ẹ fi iyọ̀ dun gbogbo ọrẹ ọkà tí ẹ bá mú wá; ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ́ kí iyọ̀ májẹ̀mú Ọlọ́run yín di àwátì nínú ọrẹ ọkà yín. Kí ẹ máa fi iyọ̀+ sí gbogbo ọrẹ yín.

14 “‘Tí o bá fẹ́ ṣe ọrẹ ọkà àkọ́pọ́n èso rẹ fún Jèhófà, ọkà tuntun* tí o yan lórí iná ni kí o mú wá, kóró tuntun tí o kò lọ̀ kúnná, kí o fi ṣe ọrẹ ọkà àkọ́pọ́n èso+ rẹ. 15 Kí o da òróró sórí rẹ̀, kí o sì fi oje igi tùràrí sórí rẹ̀. Ọrẹ ọkà ni. 16 Kí àlùfáà mú kó rú èéfín bí ọrẹ ìṣàpẹẹrẹ,*+ ìyẹn, díẹ̀ lára ọkà tí ẹ kò lọ̀ kúnná àti òróró pẹ̀lú gbogbo oje igi tùràrí rẹ̀, kó fi ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́