ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìsíkíẹ́lì 47
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìsíkíẹ́lì

      • Omi tó ń ṣàn láti tẹ́ńpìlì (1-12)

        • Omi ń jìn sí i (2-5)

        • Omi Òkun Òkú rí ìwòsàn (8-10)

        • Àwọn irà ò rí ìwòsàn (11)

        • Igi tó ń so èso fún jíjẹ àti ìwòsàn (12)

      • Àwọn ààlà ilẹ̀ náà (13-23)

Ìsíkíẹ́lì 47:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 41:2
  • +Sek 13:1; 14:8; Ifi 22:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 202-203, 205-208

    Ilé Ìṣọ́,

    8/1/2007, ojú ìwé 11

    3/1/1999, ojú ìwé 10-11, 18-20

Ìsíkíẹ́lì 47:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 40:20
  • +Isk 40:6; 44:1, 2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 206

Ìsíkíẹ́lì 47:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó ń tọ́ka sí ìgbọ̀nwọ́ tó gùn.Wo Àfikún B14.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 40:3; Ifi 21:15

Ìsíkíẹ́lì 47:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 202-203, 206-208

Ìsíkíẹ́lì 47:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 22:1, 2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/1999, ojú ìwé 10-11

Ìsíkíẹ́lì 47:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “aṣálẹ̀ tó tẹ́jú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 4:47, 49
  • +Sek 14:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 202-205, 209-210

Ìsíkíẹ́lì 47:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

  • *

    Ní Héb., “tí odò méjèèjì.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 202-207, 209-210

    Ilé Ìṣọ́,

    8/1/2007, ojú ìwé 11

    3/1/1999, ojú ìwé 10-11, 18-19, 21-22

Ìsíkíẹ́lì 47:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, Òkun Mẹditaréníà.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 15:20, 62; 2Kr 20:2
  • +Nọ 34:2, 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 203-205

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/1999, ojú ìwé 21

Ìsíkíẹ́lì 47:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 29:22, 23; Sm 107:33, 34; Jer 17:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 203-208, 209-210

    Ilé Ìṣọ́,

    8/1/2007, ojú ìwé 11

    3/1/1999, ojú ìwé 21-22

Ìsíkíẹ́lì 47:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 47:1
  • +Ifi 22:1, 2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 202-203, 205-206, 207-208, 210

    Ilé Ìṣọ́,

    8/1/2007, ojú ìwé 11

    3/1/1999, ojú ìwé 20-22

Ìsíkíẹ́lì 47:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 48:5; 1Kr 5:1; Isk 48:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 213-215

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/1999, ojú ìwé 17-18, 22-23

Ìsíkíẹ́lì 47:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “kálukú bí arákùnrin rẹ̀.”

  • *

    Ní Héb., “ó sì ti bọ́ sọ́wọ́ yín.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 26:3; 28:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 213-216

Ìsíkíẹ́lì 47:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 48:1
  • +Nọ 34:2, 8

Ìsíkíẹ́lì 47:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 13:21
  • +2Sa 8:8
  • +Isk 47:18

Ìsíkíẹ́lì 47:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 34:2, 9
  • +Isk 48:1

Ìsíkíẹ́lì 47:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, Òkun Òkú.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 32:1

Ìsíkíẹ́lì 47:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “apá gúúsù.”

  • *

    Ìyẹn, Àfonífojì Íjíbítì.

  • *

    Ní Héb., “apá gúúsù.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:51
  • +Isk 48:28

Ìsíkíẹ́lì 47:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àbáwọlé Hámátì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 34:2, 8

Ìsíkíẹ́lì 47:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 216-217

Àwọn míì

Ìsík. 47:1Isk 41:2
Ìsík. 47:1Sek 13:1; 14:8; Ifi 22:1
Ìsík. 47:2Isk 40:20
Ìsík. 47:2Isk 40:6; 44:1, 2
Ìsík. 47:3Isk 40:3; Ifi 21:15
Ìsík. 47:7Ifi 22:1, 2
Ìsík. 47:8Di 4:47, 49
Ìsík. 47:8Sek 14:8
Ìsík. 47:10Joṣ 15:20, 62; 2Kr 20:2
Ìsík. 47:10Nọ 34:2, 6
Ìsík. 47:11Di 29:22, 23; Sm 107:33, 34; Jer 17:6
Ìsík. 47:12Isk 47:1
Ìsík. 47:12Ifi 22:1, 2
Ìsík. 47:13Jẹ 48:5; 1Kr 5:1; Isk 48:5
Ìsík. 47:14Jẹ 26:3; 28:13
Ìsík. 47:15Isk 48:1
Ìsík. 47:15Nọ 34:2, 8
Ìsík. 47:16Nọ 13:21
Ìsík. 47:162Sa 8:8
Ìsík. 47:16Isk 47:18
Ìsík. 47:17Nọ 34:2, 9
Ìsík. 47:17Isk 48:1
Ìsík. 47:18Nọ 32:1
Ìsík. 47:19Di 32:51
Ìsík. 47:19Isk 48:28
Ìsík. 47:20Nọ 34:2, 8
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Ìsíkíẹ́lì 47:1-23

Ìsíkíẹ́lì

47 Lẹ́yìn náà, ó mú mi pa dà wá sí ẹnu ọ̀nà tẹ́ńpìlì náà,+ mo sì rí omi tó ń ṣàn lọ sí ìlà oòrùn láti abẹ́ ẹnu ọ̀nà tẹ́ńpìlì náà,+ torí iwájú tẹ́ńpìlì náà dojú kọ ìlà oòrùn. Omi náà ń ṣàn wálẹ̀ láti abẹ́ tẹ́ńpìlì náà ní apá ọ̀tún, ní gúúsù pẹpẹ.

2 Ó wá mú mi gba ẹnubodè àríwá jáde,+ ó mú mi lọ síta, ó sì mú mi yí ká ẹnubodè ìta tó dojú kọ ìlà oòrùn,+ mo sì rí i tí omi ń sun láti apá ọ̀tún.

3 Nígbà tí ọkùnrin náà jáde lọ sí apá ìlà oòrùn tó sì mú okùn ìdíwọ̀n dání,+ ó wọn ẹgbẹ̀rún (1,000) ìgbọ̀nwọ́,* ó sì mú mi gba inú omi náà; omi náà dé kókósẹ̀.

4 Ó tún wọn ẹgbẹ̀rún (1,000) ìgbọ̀nwọ́, ó sì mú mi gba inú omi náà. Ó dé orúnkún.

Ó tún wọn ẹgbẹ̀rún (1,000) ìgbọ̀nwọ́, ó mú mi gba inú rẹ̀, omi náà sì dé ìbàdí.

5 Nígbà tó tún wọn ẹgbẹ̀rún (1,000) ìgbọ̀nwọ́, mi ò lè fi ẹsẹ̀ rin omi náà kọjá torí ó kún, ó sì jìn débi pé èèyàn ní láti lúwẹ̀ẹ́ kọjá ni, àní alagbalúgbú omi téèyàn ò lè fi ẹsẹ̀ rìn kọjá ni.

6 Ó bi mí pé: “Ṣé o rí èyí, ọmọ èèyàn?”

Ó wá mú mi rìn pa dà sí etí odò náà. 7 Nígbà tí mo pa dà, mo rí i pé igi pọ̀ gan-an ní ẹ̀gbẹ́ méjèèjì etí odò náà.+ 8 Ó wá sọ fún mi pé: “Omi yìí ń ṣàn lọ sí agbègbè ìlà oòrùn títí lọ dé Árábà,*+ ó sì ń ṣàn wọnú òkun. Tó bá wọnú òkun,+ yóò wo omi ibẹ̀ sàn. 9 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀dá alààyè* yóò máa wà láàyè níbikíbi tí omi* náà bá ṣàn dé. Ẹja máa pọ̀ gan-an níbẹ̀ torí omi yìí máa ṣàn débẹ̀. Yóò wo omi òkun náà sàn, gbogbo ohun tó bá sì wà níbi tí omi náà ṣàn dé yóò máa wà láàyè.

10 “Àwọn apẹja yóò dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀ láti Ẹ́ń-gédì+ títí lọ dé Eni-égíláímù, níbi tí wọ́n ń sá àwọ̀n sí. Oríṣiríṣi ẹja yóò pọ̀ gan-an níbẹ̀, bí àwọn ẹja inú Òkun Ńlá.*+

11 “Yóò ní irà àti àbàtà, wọn kò sì ní rí ìwòsàn. Wọ́n á di ilẹ̀ iyọ̀.+

12 “Onírúurú igi tó ń so èso fún jíjẹ yóò hù lẹ́gbẹ̀ẹ́ méjèèjì odò náà. Ewé wọn ò ní rọ; èso wọn ò sì ní tán. Oṣooṣù ni wọ́n á máa so èso tuntun, torí láti ibi mímọ́ ni omi ti ń ṣàn dé ọ̀dọ̀ wọn.+ Èso wọn yóò jẹ́ oúnjẹ, ewé wọn á sì wà fún ìwòsàn.”+

13 Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Ilẹ̀ tí ẹ máa yàn bí ogún fún ẹ̀yà Ísírẹ́lì méjìlá (12) nìyí, Jósẹ́fù yóò sì ní ìpín méjì.+ 14 Ẹ máa jogún rẹ̀, ìpín kálukú yóò sì dọ́gba.* Mo búra pé màá fún àwọn baba ńlá yín ní ilẹ̀ yìí,+ mo sì ti pín in fún yín* láti jẹ́ ogún yín ní báyìí.

15 “Ààlà ilẹ̀ náà ní apá àríwá nìyí: Ó lọ láti Òkun Ńlá títí lọ dé Hẹ́tílónì,+ sí ọ̀nà Sédádì,+ 16 Hámátì,+ Bérótà+ àti Síbúráímù, tó wà láàárín agbègbè Damásíkù àti Hámátì, ó dé Haseri-hátíkónì, tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ ààlà Háúránì.+ 17 Ààlà náà yóò jẹ́ láti òkun dé Hasari-énónì,+ lẹ́bàá ààlà Damásíkù sí àríwá àti ààlà Hámátì.+ Ààlà tó wà ní àríwá nìyí.

18 “Ààlà tó wà ní ìlà oòrùn gba àárín Háúránì àti Damásíkù, títí lọ dé ẹ̀gbẹ́ Jọ́dánì láàárín Gílíádì+ àti ilẹ̀ Ísírẹ́lì. Kí ẹ wọ̀n ọ́n láti ibi tí ààlà wà dé òkun ìlà oòrùn.* Ààlà tó wà ní ìlà oòrùn nìyí.

19 “Ààlà tó wà ní gúúsù* yóò jẹ́ láti Támárì dé omi Mẹriba-kádéṣì,+ yóò dé Àfonífojì* àti Òkun Ńlá.+ Ààlà tó wà ní gúúsù* nìyí.

20 “Òkun Ńlá ló wà ní apá ìwọ̀ oòrùn, láti ibi tí ààlà wà dé ibì kan tó wà ní òdìkejì Lebo-hámátì.*+ Ààlà tó wà ní ìwọ̀ oòrùn nìyí.”

21 “Kí ẹ pín ilẹ̀ yìí láàárín ara yín, láàárín ẹ̀yà méjìlá (12) Ísírẹ́lì. 22 Kí ẹ pín in kó jẹ́ ogún láàárín ara yín àti láàárín àwọn àjèjì tó ń gbé pẹ̀lú yín tí wọ́n sì ti bímọ nígbà tí wọ́n ń gbé pẹ̀lú yín; bí ọmọ Ísírẹ́lì ni wọ́n á jẹ́ sí yín. Àwọn náà yóò rí ogún gbà bíi tiyín láàárín àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì. 23 Agbègbè tó jẹ́ ti ẹ̀yà tí àjèjì náà ń gbé ni kí ẹ ti fún un ní ogún,” ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́