ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 62
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Orúkọ tuntun tí Síónì á máa jẹ́ (1-12)

Àìsáyà 62:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 102:13; Sek 2:12
  • +Ais 1:26
  • +Ais 51:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 335-337

Àìsáyà 62:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 54:1; 60:1
  • +Ais 49:23; 60:11
  • +Jer 33:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 337-338

Àìsáyà 62:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/1/2005, ojú ìwé 30

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 338

Àìsáyà 62:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 49:14; 54:6
  • +Ais 32:14
  • +Sm 149:4; Sef 3:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 338-340

Àìsáyà 62:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 65:18, 19; Jer 32:41

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 340-341

Àìsáyà 62:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 341-344

Àìsáyà 62:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 61:11; Jer 33:9; Sef 3:19, 20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 341-344

Àìsáyà 62:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:49-51; Jer 5:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 344-345

Àìsáyà 62:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 14:23; Ais 65:21, 22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 344-345

Àìsáyà 62:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “òpó tí a fi ṣe àmì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 40:3; 48:20
  • +Ais 57:14
  • +Ẹsr 1:1, 3; Ais 11:12; 49:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2014, ojú ìwé 3

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 345-346

Àìsáyà 62:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sek 9:9; Mt 21:5; Jo 12:15
  • +Ais 40:9, 10; Ifi 22:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 346-348

Àìsáyà 62:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 107:2, 3
  • +Ais 54:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 348

Àwọn míì

Àìsá. 62:1Sm 102:13; Sek 2:12
Àìsá. 62:1Ais 1:26
Àìsá. 62:1Ais 51:5
Àìsá. 62:2Ais 54:1; 60:1
Àìsá. 62:2Ais 49:23; 60:11
Àìsá. 62:2Jer 33:16
Àìsá. 62:4Ais 49:14; 54:6
Àìsá. 62:4Ais 32:14
Àìsá. 62:4Sm 149:4; Sef 3:17
Àìsá. 62:5Ais 65:18, 19; Jer 32:41
Àìsá. 62:7Ais 61:11; Jer 33:9; Sef 3:19, 20
Àìsá. 62:8Di 28:49-51; Jer 5:17
Àìsá. 62:9Di 14:23; Ais 65:21, 22
Àìsá. 62:10Ais 40:3; 48:20
Àìsá. 62:10Ais 57:14
Àìsá. 62:10Ẹsr 1:1, 3; Ais 11:12; 49:22
Àìsá. 62:11Sek 9:9; Mt 21:5; Jo 12:15
Àìsá. 62:11Ais 40:9, 10; Ifi 22:12
Àìsá. 62:12Sm 107:2, 3
Àìsá. 62:12Ais 54:7
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 62:1-12

Àìsáyà

62 Mi ò ní dákẹ́ torí Síónì,+

Mi ò sì ní dúró jẹ́ẹ́ nítorí Jerúsálẹ́mù,

Títí òdodo rẹ̀ fi máa tàn bí iná tó mọ́lẹ̀ yòò,+

Tí ìgbàlà rẹ̀ sì máa jó bí iná ògùṣọ̀.+

 2 “Àwọn orílẹ̀-èdè máa rí òdodo rẹ, ìwọ obìnrin,+

Gbogbo àwọn ọba sì máa rí ògo rẹ.+

A sì máa fi orúkọ tuntun pè ọ́,+

Èyí tí Jèhófà máa fi ẹnu ara rẹ̀ sọ ọ́.

 3 O máa di adé ẹwà ní ọwọ́ Jèhófà,

Láwàní ọba ní àtẹ́lẹwọ́ Ọlọ́run rẹ.

 4 Wọn ò ní pè ọ́ ní obìnrin tí a pa tì mọ́,+

Wọn ò sì ní pe ilẹ̀ rẹ ní ibi tó ti dahoro mọ́.+

Àmọ́ wọ́n máa pè ọ́ ní Inú Mi Dùn sí I,+

Wọ́n sì máa pe ilẹ̀ rẹ ní Èyí Tí A Gbé Níyàwó.

Torí inú Jèhófà máa dùn sí ọ,

Ilẹ̀ rẹ sì máa dà bí èyí tí a gbé níyàwó.

 5 Torí bí ọ̀dọ́kùnrin ṣe ń gbé wúńdíá níyàwó,

Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọkùnrin rẹ máa gbé ọ níyàwó.

Bí ọkọ ìyàwó ṣe máa ń yọ̀ nítorí ìyàwó,

Bẹ́ẹ̀ ni Ọlọ́run rẹ máa yọ̀ nítorí rẹ.+

 6 Mo ti yan àwọn olùṣọ́ sórí àwọn ògiri rẹ, ìwọ Jerúsálẹ́mù.

Nígbà gbogbo, láti àárọ̀ ṣúlẹ̀ àti ní gbogbo òru mọ́jú, wọn ò gbọ́dọ̀ dákẹ́.

Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń sọ̀rọ̀ Jèhófà,

Ẹ má sinmi,

 7 Ẹ má ṣe jẹ́ kó sinmi rárá, títí ó fi máa fìdí Jerúsálẹ́mù múlẹ̀ gbọn-in,

Àní, títí ó fi máa fi í ṣe ìyìn ayé.”+

 8 Jèhófà ti fi ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀, apá rẹ̀ tó lágbára, búra pé:

“Mi ò ní fi ọkà rẹ ṣe oúnjẹ fún àwọn ọ̀tá rẹ mọ́,

Àwọn àjèjì ò sì ní mu wáìnì tuntun rẹ mọ́, èyí tí o ṣiṣẹ́ kára fún.+

 9 Àmọ́ àwọn tó ń kó o jọ máa jẹ ẹ́, wọ́n sì máa yin Jèhófà;

Àwọn tó ń gbà á sì máa mu ún ní àwọn àgbàlá mímọ́ mi.”+

10 Ẹ kọjá, ẹ gba àwọn ẹnubodè kọjá.

Ẹ tún ọ̀nà ṣe fún àwọn èèyàn.+

Ẹ ṣe ọ̀nà, ẹ ṣe òpópó.

Ẹ ṣa òkúta kúrò níbẹ̀.+

Ẹ gbé àmì* sókè fún àwọn èèyàn.+

11 Ẹ wò ó! Jèhófà ti kéde títí dé àwọn ìkángun ayé pé:

“Ẹ sọ fún ọmọbìnrin Síónì pé,

‘Wò ó! Ìgbàlà rẹ ń bọ̀.+

Wò ó! Èrè rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀,

Ẹ̀san rẹ̀ sì wà níwájú rẹ̀.’”+

12 Wọ́n máa pè wọ́n ní àwọn èèyàn mímọ́, àwọn tí Jèhófà tún rà,+

A sì máa pè ọ́ ní Ẹni Tí A Wá, Ìlú Tí A Kò Pa Tì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́