Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
February 8, 2000
Àwọn Ìdílé Tí Kò Ti Sí Bàbá—Fífòpin sí Ìṣòro Náà
Ńṣe ni àwọn ọmọ tí a ń tọ́ láìsí bàbá ń pọ̀ sí i. Kí ló ń fa ìṣòro tó ń jà kálẹ̀ yìí? Báwo ni a ṣe lè ran àwọn ìdílé lọ́wọ́ láti fara mọ́ra?
3 Àwọn Ìdílé Tí Kò Ti Sí Bàbá—Àmì Ìgbàlódé Ni
4 Àwọn Bàbá—Ìdí Tí Wọ́n Fi Ń di Àwátì
8 Àwọn Ìdílé Tí Kò Ti Sí Bàbá—Fífòpin Sí Ìṣòro Náà
15 Ǹjẹ́ o Mọ̀?
18 Àjàkálẹ̀ Àrùn Black Death—Ó Gbo Yúróòpù ní Sànmánì Ìbẹ̀rẹ̀ Ọ̀làjú
22 Lílo Àkàbà—Ǹjẹ́ O Máa Ń Ṣe Àyẹ̀wò Wọ̀nyí Tó Lè Dáàbò Bò Ẹ́?!
25 Ìrètí Ló Ń fún Mi Lókun Láti Fara Da Àwọn Àdánwò
29 Wíwo Ayé
31 Ọ̀tọ̀ Làwọn Tó Ń Bógun Lọ Lóde Òní
32 ‘Ó Ràn Mí Lọ́wọ́ Láti Ronú Nípa Ìgbésí Ayé Mi’
Fífárùngbọ̀n 12
Ojoojúmọ́ ni àwọn ọkùnrin níbi gbogbo lágbàáyé ń fá irùngbọ̀n wọn. Ibo ni irùngbọ̀n fífá ti bẹ̀rẹ̀? Báwo lo sì ṣe lè fá a dán?
Irọ́ Pípa—Ǹjẹ́ Àwíjàre Kankan Wà fún Un? 16
Ọ̀pọ̀ èèyàn rò pé irú irọ́ tí wọ́n ń pè ní irọ́ funfun kì í ṣèpalára. Ṣùgbọ́n ṣé Bíbélì gbà pẹ̀lú èrò tó wọ́pọ̀ yìí?