Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
July 8, 2000
Ṣé Ẹ̀mí Èèyàn Kò Jẹ́ Nǹkan Kan Mọ́ Ni?
Ní àwọn ọdún àìpẹ́ yìí, ó jọ pé àwọn ọ̀dọ́ ti bẹ̀rẹ̀ sí í dá “àṣà ká máa pààyàn.” Kí ló ń fà á? Ojútùú kan ha wà bí?
3 Ṣé Ẹ̀mí Èèyàn Kò Jẹ́ Nǹkan Kan Mọ́ Ni?
5 Báwo Ni Wọ́n Ṣe Ń Gbé “Àṣà Ká Máa Pààyàn” Lárugẹ?
8 Ríran Àwọn Ọ̀dọ́ Lọ́wọ́ Láti Bọ́ Lọ́wọ́ “Àṣà Ká Máa Pààyàn”
24 Àwọn Ewu Tó Wà Nínú Wíwọkọ̀ Ọ̀fẹ́ Kiri
30 Ṣé Kí N Máa Lo Oògùn Aspirin Lójoojúmọ́—Àbí Kí N Má Lò Ó?
32 “Mo Fẹ́ràn Bó Ṣe Ń Ṣàlàyé Ọ̀rọ̀”
Ẹ̀rín Músẹ́—Á Ṣe Ẹ́ Láǹfààní! 11
Ǹjẹ́ rírẹ́rìn-ín músẹ́ lè yí nǹkan padà nínú ìgbésí ayé rẹ ojoojúmọ́?
Lẹ́yìn Ìjì Tó Jà—Ìpèsè Ìrànwọ́ ní Ilẹ̀ Faransé 17
Kà nípa ohun tí wọ́n ṣe láti ran ọ̀pọ̀ ènìyàn lọ́wọ́ láti fara da ohun tí ìjì bà jẹ́, ìjì tó tíì burú jù lọ ní ilẹ̀ Faransé láti ohun tó lé ní ọ̀ọ́dúnrún ọdún.
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Fọ́tò AP/Laura Rauch
Courtesy of Geron Corporation