Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
January 8, 2004
Lílóye Àwọn Tí Ìṣesí—Wọn Ṣàdédé Ń yí Padà
Àràádọ́ta ọ̀kẹ́ èèyàn kárí ayé lọ́kùnrin àti lóbìnrin ló ní àárẹ̀ ọkàn àti ìṣòro híhùwà lódìlódì. Báwo la ṣe lè ran irú àwọn èèyàn bẹ́ẹ̀ lọ́wọ́?
4 Kíkojú Ìṣòro Kí Ìṣesí Ẹni Máa Ṣàdédé Yí Padà
12 Bí Àwọn Ẹlòmíràn Ṣe Lè Ṣèrànwọ́
17 Bíbímọ Sínú Ayé Aláìnífẹ̀ẹ́
18 Ohun Tí Àwọn Ọmọ Ọwọ́ Nílò àti Ohun Tí Wọ́n Fẹ́
22 Pípèsè Ohun Tí Àwọn Ọmọdé Nílò fún Wọn
29 Iṣẹ́ Ọwọ́ Ẹlẹ́dàá Ni Wọ́n Wò Ṣe É
32 ‘Ṣókí Lọ̀rọ̀ Inú Ẹ̀, Ṣùgbọ́n ó Kún Fún Ẹ̀kọ́’
Ewé àti Egbò Ṣé O Lè Lò Ó fún Ìwòsàn? 26
Lílo ewé àti egbò ti wá ń wọ́pọ̀ ju ti tẹ́lẹ̀ lọ báyìí o. Àwọn nǹkan wo ló máa bọ́gbọ́n mu pé ká ṣọ́ra fún?
Ǹjẹ́ Ọgbọ́n Ìṣèlú Lè Mú Àlàáfíà Kárí Ayé Wá? 30
Kí ló fà á táwọn àpérò àlàáfíà táráyé ń ṣe fi ń kùnà ṣáá ní gbogbo ìgbà?