Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
November 8, 2004
Kí Lẹni Tó Bá Sanra Jọ̀kọ̀tọ̀ Lè Rí Ṣe sí I?
Ìṣòro tó kárí ayé ni kéèyàn sanra jọ̀kọ̀tọ̀. Kí ló ń fà á ná? Ṣó tiẹ̀ yẹ kéèyàn máa wá bó ṣe máa dín sísanra kù?
3 Ṣé Ìṣòro Ni Pé Kéèyàn Sanra Jọ̀kọ̀tọ̀?
4 Kí Ló Ń Jẹ́ Kéèyàn Sanra Jọ̀kọ̀tọ̀?
7 Kí Lẹni Tó Bá Sanra Jọ̀kọ̀tọ̀ Lè Rí Ṣe Sí I?
10 Ǹjẹ́ Àǹfààní Kankan Wà Nínú Kéèyàn Dín Bó Ṣe Sanra Jọ̀kọ̀tọ̀ Kù?
13 Báwo Ni Kíkọ́ Ọmọ Láti Kékeré Ti Ṣe Pàtàkì Tó?
15 Bó Ṣe Ṣe Pàtàkì Tó Pé Kó O Tọ́ Ọmọ Rẹ
21 Àtikékeré Ni Wọ́n Ti Kọ́ Mi Láti Nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run
31 Àwọn Àǹfààní Tó Wà Nínú Kíkàwé Fáwọn Ọmọdé
32 Wọ́n Lè Tu Àwọn Tí Ọ̀fọ̀ Ṣẹ̀ Nínú
Fífi Ìbáwí Ọlọ́run Tọ́ Àwọn Ọmọ 26
Báwo làwọn ìlànà Bíbélì ṣe lè ran àwọn òbí lọ́wọ́ láti tọ́ àwọn ọmọ wọn?