ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 14
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jeremáyà

      • Ọ̀dá, ìyàn àti idà (1-12)

      • Ọlọ́run dá àwọn wòlíì èké lẹ́bi (13-18)

      • Jeremáyà sọ ẹ̀ṣẹ̀ tí àwọn èèyàn náà dá (19-22)

Jeremáyà 14:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọ̀gbẹlẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:24

Jeremáyà 14:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joẹ 1:10

Jeremáyà 14:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ẹni kékeré.”

  • *

    Tàbí “àwọn àmù; àwọn ìkùdu.”

Jeremáyà 14:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 26:20; Di 28:23

Jeremáyà 14:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “akátá.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 12:4; Joẹ 1:18

Jeremáyà 14:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 7:9; Sm 25:11; 115:1, 2
  • +Ẹsr 9:6; Ne 9:33; Da 9:5, 8

Jeremáyà 14:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 106:8, 21; Ais 45:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    5/8/2004, ojú ìwé 21

Jeremáyà 14:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 29:45; Di 23:14
  • +Da 9:19

Jeremáyà 14:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 2:23
  • +Jer 2:25
  • +Jer 6:20
  • +Ho 8:13

Jeremáyà 14:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 7:16; 11:14

Jeremáyà 14:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àìsàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 1:15; 58:3; Jer 11:11; Isk 8:18
  • +Ais 1:11
  • +Jer 9:16; Isk 5:12

Jeremáyà 14:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 4:10; 5:31; 6:13, 14; 23:16, 17; 27:8-10; Isk 13:10; Mik 3:11

Jeremáyà 14:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 23:25, 26; 29:21
  • +Jer 23:21; 27:15
  • +Ida 2:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2008, ojú ìwé 5

Jeremáyà 14:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 5:12, 13; 23:15; Isk 12:24; 13:9

Jeremáyà 14:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 79:2, 3; Jer 9:22
  • +Jer 4:18

Jeremáyà 14:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 8:18, 21; 9:1
  • +Ida 1:15

Jeremáyà 14:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 7:15
  • +Ida 5:10
  • +Di 28:36

Jeremáyà 14:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn rẹ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 12:8; Ida 5:22
  • +2Kr 36:15, 16
  • +Jer 8:15

Jeremáyà 14:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹsr 9:7; Da 9:5, 8

Jeremáyà 14:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 36:22; Da 9:15
  • +Ẹk 32:13; Le 26:41, 42; Sm 106:43-45

Jeremáyà 14:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:12; Ais 30:23; Joẹ 2:23

Àwọn míì

Jer. 14:1Di 28:24
Jer. 14:2Joẹ 1:10
Jer. 14:4Le 26:20; Di 28:23
Jer. 14:6Jer 12:4; Joẹ 1:18
Jer. 14:7Joṣ 7:9; Sm 25:11; 115:1, 2
Jer. 14:7Ẹsr 9:6; Ne 9:33; Da 9:5, 8
Jer. 14:8Sm 106:8, 21; Ais 45:15
Jer. 14:9Ẹk 29:45; Di 23:14
Jer. 14:9Da 9:19
Jer. 14:10Jer 2:23
Jer. 14:10Jer 2:25
Jer. 14:10Jer 6:20
Jer. 14:10Ho 8:13
Jer. 14:11Jer 7:16; 11:14
Jer. 14:12Ais 1:15; 58:3; Jer 11:11; Isk 8:18
Jer. 14:12Ais 1:11
Jer. 14:12Jer 9:16; Isk 5:12
Jer. 14:13Jer 4:10; 5:31; 6:13, 14; 23:16, 17; 27:8-10; Isk 13:10; Mik 3:11
Jer. 14:14Jer 23:25, 26; 29:21
Jer. 14:14Jer 23:21; 27:15
Jer. 14:14Ida 2:14
Jer. 14:15Jer 5:12, 13; 23:15; Isk 12:24; 13:9
Jer. 14:16Sm 79:2, 3; Jer 9:22
Jer. 14:16Jer 4:18
Jer. 14:17Jer 8:18, 21; 9:1
Jer. 14:17Ida 1:15
Jer. 14:18Isk 7:15
Jer. 14:18Ida 5:10
Jer. 14:18Di 28:36
Jer. 14:19Jer 12:8; Ida 5:22
Jer. 14:192Kr 36:15, 16
Jer. 14:19Jer 8:15
Jer. 14:20Ẹsr 9:7; Da 9:5, 8
Jer. 14:21Isk 36:22; Da 9:15
Jer. 14:21Ẹk 32:13; Le 26:41, 42; Sm 106:43-45
Jer. 14:22Di 28:12; Ais 30:23; Joẹ 2:23
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Jeremáyà 14:1-22

Jeremáyà

14 Ohun tí Jèhófà bá Jeremáyà sọ nípa ọ̀dá* nìyí:+

 2 Júdà ń ṣọ̀fọ̀,+ àwọn ẹnubodè rẹ̀ ti dá páropáro.

Wọ́n ti wọlẹ̀ torí pé wọ́n ti pa á tì,

Igbe ẹkún Jerúsálẹ́mù ti dé ọ̀run.

 3 Àwọn ọ̀gá wọn ń rán àwọn ìránṣẹ́* wọn lọ pọn omi.

Wọ́n dé ìdí àwọn kòtò omi,* àmọ́ wọn ò rí omi kankan.

Òfìfo ìkòkò ni wọ́n gbé pa dà.

Ojú tì wọ́n, ìjákulẹ̀ bá wọn,

Wọ́n sì bo orí wọn.

 4 Ilẹ̀ náà ti sán,

Torí òjò kò rọ̀ sórí rẹ̀,+

Ìrẹ̀wẹ̀sì ti bá àwọn àgbẹ̀, wọ́n sì bo orí wọn.

 5 Kódà, abo àgbọ̀nrín inú pápá ń pa àwọn ọmọ tó ṣẹ̀ṣẹ̀ bí tì

Nítorí kò sí koríko.

 6 Àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ igbó dúró lórí àwọn òkè.

Wọ́n ń mí hẹlẹhẹlẹ bí ajáko;*

Ojú wọn ò ríran dáadáa torí pé kò sí ewéko.+

 7 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìwà wa jẹ́rìí sí i pé a ti ṣe àṣìṣe,

Jèhófà, ràn wá lọ́wọ́ nítorí orúkọ rẹ.+

Nítorí ìwà àìṣòótọ́ wa pọ̀,+

Ìwọ sì ni a dẹ́ṣẹ̀ sí.

 8 Ìwọ, ìrètí Ísírẹ́lì, Olùgbàlà rẹ̀+ ní àkókò wàhálà,

Kí nìdí tí o fi dà bí àjèjì ní ilẹ̀ náà

Àti bí arìnrìn-àjò tó kàn dúró láti sùn mọ́jú?

 9 Kí nìdí tí o fi dà bí ọkùnrin tí nǹkan tojú sú,

Bí alágbára ọkùnrin tí kò lè gbani là?

Nítorí o wà láàárín wa, Jèhófà,+

Wọ́n sì ń fi orúkọ rẹ pè wá.+

Má fi wá sílẹ̀.

10 Ohun tí Jèhófà sọ nípa àwọn èèyàn yìí rèé: “Wọ́n fẹ́ láti máa rìn kiri,+ wọn ò ṣọ́ ìrìn ẹsẹ̀ wọn.+ Nítorí náà, inú Jèhófà ò dùn sí wọn.+ Ní báyìí, á rántí àṣìṣe wọn, á sì pè wọ́n wá jíhìn nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn.”+

11 Jèhófà sì sọ fún mi pé: “Má ṣe gbàdúrà pé kí ire bá àwọn èèyàn yìí.+ 12 Tí wọ́n bá gbààwẹ̀, mi ò ní fetí sí ẹ̀bẹ̀ wọn,+ tí wọ́n bá sì fi odindi ẹbọ sísun àti ọrẹ ọkà rúbọ, inú mi ò ní dùn sí wọn,+ nítorí pé idà àti ìyàn àti àjàkálẹ̀ àrùn* ni màá fi pa wọ́n.”+

13 Ni mo bá sọ pé: “Áà, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ! Wò ó, àwọn wòlíì ń sọ fún wọn pé, ‘Ẹ kò ní rí idà, ìyàn kò sì ní dé bá yín, ṣùgbọ́n Ọlọ́run á fún yín ní àlàáfíà gidi ní ibí yìí.’”+

14 Jèhófà wá sọ fún mi pé: “Àsọtẹ́lẹ̀ èké ni àwọn wòlíì náà ń sọ ní orúkọ mi.+ Mi ò rán wọn, bẹ́ẹ̀ ni mi ò pàṣẹ fún wọn, mi ò sì bá wọn sọ̀rọ̀.+ Ìran èké àti ìwoṣẹ́ asán àti ẹ̀tàn ọkàn wọn ni wọ́n ń sọ tẹ́lẹ̀ fún yín.+ 15 Nítorí náà, ohun tí Jèhófà sọ nìyí: ‘Ní ti àwọn wòlíì tó ń sọ tẹ́lẹ̀ ní orúkọ mi, bó tilẹ̀ jẹ pé mi ò rán wọn, tí wọ́n ń sọ pé idà tàbí ìyàn kò ní wáyé ní ilẹ̀ yìí, idà àti ìyàn ni yóò pa àwọn wòlíì náà.+ 16 Àwọn èèyàn tí wọ́n sì ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ fún yóò di òkú tí wọ́n á gbé jù sí àwọn ojú ọ̀nà Jerúsálẹ́mù nítorí ìyàn àti idà. Ẹnì kankan kò sì ní sin wọ́n,+ látorí àwọn fúnra wọn dórí àwọn ìyàwó wọn àti àwọn ọmọkùnrin wọn pẹ̀lú àwọn ọmọbìnrin wọn, torí màá mú àjálù tí ó tọ́ sí wọn bá wọn.’+

17 “Sọ ọ̀rọ̀ yìí fún wọn pé,

‘Kí omijé ṣàn ní ojú mi tọ̀sántòru, kí ó má sì dá,+

Nítorí wọ́n ti lu wúńdíá àwọn èèyàn mi ní àlùbolẹ̀,+

Wọ́n sì dá ọgbẹ́ sí i lára yánnayànna.

18 Bí mo bá jáde lọ sínú pápá, tí mo sì wò,

Àwọn tí idà pa ni mò ń rí!+

Bí mo bá sì wá sínú ìlú,

Àwọn àrùn tí ìyàn fà ni mò ń rí!+

Nítorí wòlíì àti àlùfáà ti lọ káàkiri ní ilẹ̀ tí wọn ò mọ̀.’”+

19 Ṣé o kọ Júdà sílẹ̀ pátápátá ni, àbí o* ti kórìíra Síónì dé góńgó ni?+

Kí nìdí tí o fi lù wá débi tí a ò fi lè rí ìwòsàn?+

À ń retí àlàáfíà, àmọ́ ohun rere kan ò dé,

À ń retí àkókò ìwòsàn, àmọ́ ìpayà là ń rí!+

20 Jèhófà, a mọ̀ pé a ti hùwà burúkú,

A sì mọ̀ pé àwọn baba ńlá wa ti ṣàṣìṣe,

Nítorí a ti ṣẹ̀ ọ́.+

21 Nítorí orúkọ rẹ, má kọ̀ wá sílẹ̀;+

Má ṣe fojú àbùkù wo ìtẹ́ ògo rẹ.

Rántí, má sì da májẹ̀mú tí o bá wa dá.+

22 Ǹjẹ́ ìkankan lára àwọn òrìṣà lásánlàsàn tí àwọn orílẹ̀-èdè ń bọ lè rọ òjò,

Àbí ṣé ọ̀run fúnra rẹ̀ pàápàá lè dá rọ ọ̀wààrà òjò?

Ìwọ nìkan lo lè ṣe é, Jèhófà Ọlọ́run wa.+

A sì ní ìrètí nínú rẹ,

Nítorí ìwọ nìkan ló ń ṣe gbogbo nǹkan yìí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́