ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 39
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jeremáyà

      • Ìṣubú Jerúsálẹ́mù (1-10)

        • Sedekáyà fẹsẹ̀ fẹ, ṣùgbọ́n wọ́n gbá a mú (4-7)

      • Wọ́n máa dáàbò bo Jeremáyà (11-14)

      • Ọlọ́run máa dá ẹ̀mí Ebedi-mélékì sí (15-18)

Jeremáyà 39:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Nebukadirésárì,” ọ̀nà míì tí wọ́n ń gbà kọ orúkọ yìí.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 25:1, 2; Jer 52:4, 5; Isk 24:1, 2

Jeremáyà 39:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 25:3, 4; Jer 52:6, 7; Isk 33:21

Jeremáyà 39:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Nẹgali-ṣárésà, Samugari-nébò, Sásékímù, Rábúsárísì.” Gẹ́gẹ́ bí wọ́n ṣe ń pín ọ̀rọ̀ Hébérù lọ́nà tó yàtọ̀.

  • *

    Tàbí “olórí onídán (awòràwọ̀).”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 1:15

Jeremáyà 39:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:25
  • +2Ọb 25:4-7; Jer 52:7-11

Jeremáyà 39:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Nebukadirésárì,” ọ̀nà míì tí wọ́n ń gbà kọ orúkọ yìí.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 32:4; 38:18
  • +2Ọb 23:31, 33
  • +2Ọb 17:24

Jeremáyà 39:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 21:7; 34:18-20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 5/2017,

Jeremáyà 39:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 12:13

Jeremáyà 39:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ààfin.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 5:9; Jer 38:18
  • +2Ọb 25:9-11; 2Kr 36:17, 19; Ne 1:3; Jer 52:13-15

Jeremáyà 39:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 25:20; Jer 40:1; 52:12

Jeremáyà 39:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “ṣiṣẹ́ ọ̀ranyàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 25:12; Jer 52:16

Jeremáyà 39:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Nebukadirésárì,” ọ̀nà míì tí wọ́n ń gbà kọ orúkọ yìí.

Jeremáyà 39:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 40:2, 4

Jeremáyà 39:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “olórí òṣìṣẹ́ láàfin.”

  • *

    Tàbí “olórí onídán (awòràwọ̀).”

Jeremáyà 39:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 38:28
  • +2Ọb 25:22; Jer 40:5; 41:2
  • +2Kr 34:20, 21; Jer 26:24
  • +2Ọb 22:8

Jeremáyà 39:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 32:2; 37:21

Jeremáyà 39:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 38:7

Jeremáyà 39:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2012, ojú ìwé 31

Jeremáyà 39:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Wàá sá àsálà fún ọkàn rẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 45:2, 5
  • +Sm 37:39, 40; Jer 17:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2012, ojú ìwé 31

Àwọn míì

Jer. 39:12Ọb 25:1, 2; Jer 52:4, 5; Isk 24:1, 2
Jer. 39:22Ọb 25:3, 4; Jer 52:6, 7; Isk 33:21
Jer. 39:3Jer 1:15
Jer. 39:4Di 28:25
Jer. 39:42Ọb 25:4-7; Jer 52:7-11
Jer. 39:5Jer 32:4; 38:18
Jer. 39:52Ọb 23:31, 33
Jer. 39:52Ọb 17:24
Jer. 39:6Jer 21:7; 34:18-20
Jer. 39:7Isk 12:13
Jer. 39:8Ais 5:9; Jer 38:18
Jer. 39:82Ọb 25:9-11; 2Kr 36:17, 19; Ne 1:3; Jer 52:13-15
Jer. 39:92Ọb 25:20; Jer 40:1; 52:12
Jer. 39:102Ọb 25:12; Jer 52:16
Jer. 39:12Jer 40:2, 4
Jer. 39:14Jer 38:28
Jer. 39:142Ọb 25:22; Jer 40:5; 41:2
Jer. 39:142Kr 34:20, 21; Jer 26:24
Jer. 39:142Ọb 22:8
Jer. 39:15Jer 32:2; 37:21
Jer. 39:16Jer 38:7
Jer. 39:18Jer 45:2, 5
Jer. 39:18Sm 37:39, 40; Jer 17:7
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Jeremáyà 39:1-18

Jeremáyà

39 Ní ọdún kẹsàn-án Sedekáyà ọba Júdà, ní oṣù kẹwàá, Nebukadinésárì* ọba Bábílónì àti gbogbo ọmọ ogun rẹ̀ wá sí Jerúsálẹ́mù, wọ́n sì dó tì í.+

2 Ní ọdún kọkànlá Sedekáyà, ní oṣù kẹrin, ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù náà, wọ́n fọ́ ògiri ìlú náà wọlé.+ 3 Gbogbo ìjòyè ọba Bábílónì wọlé, wọ́n sì jókòó ní Ẹnubodè Àárín,+ àwọn ni, Nẹgali-ṣárésà tó jẹ́ Samugari, Nebo-sásékímù tó jẹ́ Rábúsárísì,* Nẹgali-ṣárésà tó jẹ́ Rábúmágì* àti gbogbo àwọn tó kù lára àwọn ìjòyè ọba Bábílónì.

4 Nígbà tí Sedekáyà ọba Júdà àti gbogbo ọmọ ogun rí wọn, wọ́n fẹsẹ̀ fẹ,+ wọ́n gba ọ̀nà ọgbà ọba jáde kúrò nínú ìlú náà lóru, wọ́n gba ẹnubodè tó wà láàárín ògiri oníbejì kọjá, wọ́n sì gba ọ̀nà Árábà jáde.+ 5 Àmọ́ àwọn ọmọ ogun Kálídíà lé wọn, wọ́n sì bá Sedekáyà ní aṣálẹ̀ tó wà ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Jẹ́ríkò.+ Wọ́n gbá a mú, wọ́n sì mú un wá sọ́dọ̀ Nebukadinésárì* ọba Bábílónì ní Ríbúlà+ ní ilẹ̀ Hámátì,+ ibẹ̀ ló sì ti dá a lẹ́jọ́. 6 Ọba Bábílónì ní kí wọ́n pa àwọn ọmọ Sedekáyà níṣojú rẹ̀ ní Ríbúlà, ọba Bábílónì sì ní kí wọ́n pa gbogbo èèyàn pàtàkì Júdà.+ 7 Lẹ́yìn náà, ó fọ́ ojú Sedekáyà, ó sì fi ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ bàbà dè é kó lè mú un wá sí Bábílónì.+

8 Ìgbà náà ni àwọn ará Kálídíà dáná sun ilé* ọba àti ilé àwọn èèyàn náà,+ wọ́n sì wó àwọn odi Jerúsálẹ́mù lulẹ̀.+ 9 Nebusarádánì+ olórí ẹ̀ṣọ́ kó àwọn tó ṣẹ́ kù lára àwọn èèyàn tó wà ní ìlú náà lọ sí ìgbèkùn ní Bábílónì àti àwọn tó sá wá sọ́dọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú ẹnikẹ́ni tí ó ṣẹ́ kù.

10 Àmọ́ Nebusarádánì olórí ẹ̀ṣọ́ fi lára àwọn aláìní sílẹ̀ ní ilẹ̀ Júdà, àwọn tí kò ní nǹkan kan. Lọ́jọ́ yẹn, ó tún fún wọn ní ọgbà àjàrà àti oko láti máa ṣiṣẹ́.*+

11 Nebukadinésárì* ọba Bábílónì sì pàṣẹ fún Nebusarádánì olórí ẹ̀ṣọ́ nípa Jeremáyà, pé: 12 “Mú un, kí o sì tọ́jú rẹ̀; má hùwà ìkà sí i, kí o sì fún un ní ohunkóhun tó bá béèrè lọ́wọ́ rẹ.”+

13 Torí náà, Nebusarádánì olórí ẹ̀ṣọ́ àti Nebuṣásíbánì tó jẹ́ Rábúsárísì* àti Nẹgali-ṣárésà tó jẹ́ Rábúmágì* pẹ̀lú gbogbo èèyàn sàràkí-sàràkí ọba Bábílónì ránṣẹ́ 14 pé kí wọ́n mú Jeremáyà jáde kúrò ní Àgbàlá Ẹ̀ṣọ́,+ wọ́n sì fà á lé ọwọ́ Gẹdaláyà+ ọmọ Áhíkámù+ ọmọ Ṣáfánì,+ láti mú un wá sí ilé rẹ̀. Torí náà, ó ń gbé ní àárín àwọn èèyàn náà.

15 Nígbà tí Jeremáyà wà nínú àhámọ́ ní Àgbàlá Ẹ̀ṣọ́,+ Jèhófà bá a sọ̀rọ̀, ó ní: 16 “Lọ sọ fún Ebedi-mélékì+ ará Etiópíà pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì, sọ nìyí: “Wò ó, màá mú ọ̀rọ̀ tí mo sọ sórí ìlú yìí ṣẹ, pé àjálù ni màá mú bá a, kì í ṣe ire, á ṣojú rẹ lọ́jọ́ tó bá ṣẹlẹ̀.”’

17 “‘Àmọ́, màá gbà ọ́ lọ́jọ́ yẹn,’ ni Jèhófà wí, ‘wọn kò sì ní fà ọ́ lé ọwọ́ àwọn èèyàn tí ò ń bẹ̀rù.’

18 “‘Nítorí ó dájú pé màá jẹ́ kí o sá àsálà, idà kò sì ní pa ọ́. Wàá jèrè ẹ̀mí rẹ,*+ torí pé o gbẹ́kẹ̀ lé mi,’+ ni Jèhófà wí.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́