ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 146
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sáàmù

      • Gbẹ́kẹ̀ lé Ọlọ́run, má ṣe gbẹ́kẹ̀ lé èèyàn

        • Nígbà tí èèyàn bá kú, èrò inú rẹ̀ á ṣègbé (4)

        • Ọlọ́run ń gbé àwọn tó sorí kodò dìde (8)

Sáàmù 146:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Halelúyà!” “Jáà” ni ìkékúrú Jèhófà.

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 19:6
  • +Sm 103:1

Sáàmù 146:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kọrin.”

Sáàmù 146:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “èèyàn pàtàkì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 62:9; 118:8, 9; Ais 2:22; Jer 17:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2005, ojú ìwé 21-22

    8/15/1998, ojú ìwé 6

Sáàmù 146:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Èémí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 3:19; Sm 104:29; Onw 3:20; 12:7
  • +Onw 9:5, 10; Ais 38:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/1999, ojú ìwé 16-17

    Nígbà Tí A Bá Kú, ojú ìwé 24

    Ìmọ̀, ojú ìwé 81-82

Sáàmù 146:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 46:7
  • +Sm 71:5; Jer 17:7

Sáàmù 146:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 4:24; Ifi 14:7
  • +Di 7:9

Sáàmù 146:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àwọn tí a dè.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 107:9; 145:16
  • +Sm 107:14; 142:7

Sáàmù 146:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 29:18; 35:5
  • +Sm 145:14; 2Kọ 7:6

Sáàmù 146:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “sọ ọ̀nà àwọn ẹni burúkú di wíwọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 10:18; Sm 68:5
  • +Sm 145:20

Sáàmù 146:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Halelúyà!” “Jáà” ni ìkékúrú Jèhófà.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 15:18; Da 6:26; Ifi 11:15

Àwọn míì

Sm 146:1Ifi 19:6
Sm 146:1Sm 103:1
Sm 146:3Sm 62:9; 118:8, 9; Ais 2:22; Jer 17:5
Sm 146:4Jẹ 3:19; Sm 104:29; Onw 3:20; 12:7
Sm 146:4Onw 9:5, 10; Ais 38:18
Sm 146:5Sm 46:7
Sm 146:5Sm 71:5; Jer 17:7
Sm 146:6Iṣe 4:24; Ifi 14:7
Sm 146:6Di 7:9
Sm 146:7Sm 107:9; 145:16
Sm 146:7Sm 107:14; 142:7
Sm 146:8Ais 29:18; 35:5
Sm 146:8Sm 145:14; 2Kọ 7:6
Sm 146:9Di 10:18; Sm 68:5
Sm 146:9Sm 145:20
Sm 146:10Ẹk 15:18; Da 6:26; Ifi 11:15
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Sáàmù 146:1-10

Sáàmù

146 Ẹ yin Jáà!*+

Kí gbogbo ara* mi yin Jèhófà.+

2 Màá yin Jèhófà ní gbogbo ọjọ́ ayé mi.

Màá kọ orin ìyìn* sí Ọlọ́run mi nígbà tí mo bá wà láàyè.

3 Ẹ má ṣe gbẹ́kẹ̀ lé àwọn olórí*

Tàbí lé ọmọ èèyàn, tí kò lè gbani là.+

4 Ẹ̀mí* rẹ̀ jáde lọ, ó pa dà sínú ilẹ̀;+

Ọjọ́ yẹn gan-an ni èrò inú rẹ̀ ṣègbé.+

5 Aláyọ̀ ni ẹni tí Ọlọ́run Jékọ́bù jẹ́ olùrànlọ́wọ́ rẹ̀,+

Tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀,+

6 Aṣẹ̀dá ọ̀run àti ayé,

Òkun àti gbogbo ohun tó wà nínú wọn,+

Ẹni tó jẹ́ olóòótọ́ nígbà gbogbo,+

7 Ẹni tó ń ṣe ìdájọ́ òdodo fún àwọn tí wọ́n lù ní jìbìtì,

Ẹni tó ń fún àwọn tí ebi ń pa lóúnjẹ.+

Jèhófà ń dá àwọn ẹlẹ́wọ̀n* sílẹ̀.+

8 Jèhófà ń la ojú àwọn afọ́jú;+

Jèhófà ń gbé àwọn tó sorí kọ́ dìde;+

Jèhófà nífẹ̀ẹ́ àwọn olódodo.

9 Jèhófà ń dáàbò bo àwọn àjèjì;

Ó ń fún ọmọ aláìníbaba àti opó lókun,+

Àmọ́, ó ń sọ èrò àwọn ẹni burúkú dòfo.*+

10 Jèhófà yóò jẹ Ọba títí láé,+

Àní Ọlọ́run rẹ, ìwọ Síónì, láti ìran dé ìran.

Ẹ yin Jáà!*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́