ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Pétérù 1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Pétérù

      • Ìkíni (1, 2)

      • Ìbí tuntun tó jẹ́ ká lè ní ìrètí tó wà láàyè (3-12)

      • Ẹ jẹ́ mímọ́ bí ọmọ tó ń ṣègbọràn (13-25)

1 Pétérù 1:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àtìpó.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 10:2
  • +Iṣe 2:5, 9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    3/2018, ojú ìwé 14

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2012, ojú ìwé 19

    3/15/2012, ojú ìwé 20

    8/15/2007, ojú ìwé 10-11

    7/15/2004, ojú ìwé 24-25

    9/1/1997, ojú ìwé 8

    Jíjẹ́rìí Kúnnákúnná, ojú ìwé 26

    Yiyan, ojú ìwé 98-99, 100-102

1 Pétérù 1:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 8:29
  • +2Tẹ 2:13
  • +Heb 12:22, 24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 98-99

1 Pétérù 1:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 1:23
  • +Ifi 20:6
  • +1Kọ 15:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2016, ojú ìwé 17-18

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2012, ojú ìwé 20

    4/1/2009, ojú ìwé 3

    Yiyan, ojú ìwé 30-33

1 Pétérù 1:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 15:53; 2Ti 1:10; 1Pe 5:4
  • +Jo 14:2; 2Ti 4:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 30-31, 33

1 Pétérù 1:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2012, ojú ìwé 27-31

    6/15/2007, ojú ìwé 18

    Yiyan, ojú ìwé 30, 33-34, 41, 118

1 Pétérù 1:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 4:17; 2Ti 3:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2009, ojú ìwé 12

    5/15/1998, ojú ìwé 16

    Yiyan, ojú ìwé 118-119

1 Pétérù 1:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “yọ́ ọ mọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jem 1:2, 3
  • +2Tẹ 1:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2008, ojú ìwé 21

    8/15/2007, ojú ìwé 14

    8/1/2001, ojú ìwé 32

    5/15/1998, ojú ìwé 16

    Yiyan, ojú ìwé 118, 119-122

1 Pétérù 1:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/1997, ojú ìwé 14-19

    Yiyan, ojú ìwé 50

1 Pétérù 1:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìgbàlà ọkàn yín.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 6:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 15-16

1 Pétérù 1:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 13:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2002, ojú ìwé 13

    Yiyan, ojú ìwé 16, 18-19

1 Pétérù 1:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 9:24-27
  • +Ais 53:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2002, ojú ìwé 13

    Yiyan, ojú ìwé 16-19

1 Pétérù 1:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 15:26; Iṣe 2:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2009, ojú ìwé 24

    11/15/2008, ojú ìwé 21

    Yiyan, ojú ìwé 16, 19, 20-22

1 Pétérù 1:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 12:35
  • +Ef 5:17; 1Pe 4:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2021, ojú ìwé 13

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2012, ojú ìwé 23

    3/1/2006, ojú ìwé 22

    10/1/1997, ojú ìwé 27-28

    Yiyan, ojú ìwé 22-23

1 Pétérù 1:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tún máa sún yín ṣe nǹkan.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 24

1 Pétérù 1:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:9; Ro 12:1; Heb 12:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2021, ojú ìwé 2, 15

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    2/2017, ojú ìwé 9

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    8/1/1996, ojú ìwé 15-20

    Yiyan, ojú ìwé 24-25

1 Pétérù 1:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 11:44; 19:2; 20:7, 26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2021, ojú ìwé 2, 3-4

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 40

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    2/2017, ojú ìwé 9

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 34-35

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2008, ojú ìwé 26

    Yiyan, ojú ìwé 24-25

1 Pétérù 1:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àtìpó.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 10:17
  • +2Kọ 7:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    7/1/1992, ojú ìwé 15

    Yiyan, ojú ìwé 25-26

1 Pétérù 1:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “la fi rà yín pa dà; dá yín nídè.”

  • *

    Tàbí “tí ẹ jogún bá.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 6:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 26-28

1 Pétérù 1:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 53:12; Heb 9:14
  • +Ẹk 12:5; Le 22:20; Jo 1:29
  • +1Kọ 5:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 26-28

1 Pétérù 1:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 17:5; Ef 1:4
  • +Kol 1:26, 27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2006, ojú ìwé 23-24

    Yiyan, ojú ìwé 34-36

1 Pétérù 1:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 14:6
  • +Iṣe 2:24
  • +Heb 2:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 34, 35-36

1 Pétérù 1:22

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn yín.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 12:9; 1Jo 3:17
  • +1Ti 1:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2021, ojú ìwé 22-23

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 56

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 227-228

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/15/1993, ojú ìwé 12

    Yiyan, ojú ìwé 48

1 Pétérù 1:23

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, irúgbìn tó lè méso jáde tàbí kó bí sí i.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 3:3; 2Kọ 5:17; 1Pe 1:3; 1Jo 3:9
  • +Jo 3:6
  • +Jo 6:63; Jem 1:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/2009, ojú ìwé 3

    3/15/1991, ojú ìwé 22

    Yiyan, ojú ìwé 48

1 Pétérù 1:24

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “gbogbo èèyàn.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    9/2017, ojú ìwé 18

    Yiyan, ojú ìwé 48

1 Pétérù 1:25

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “àsọjáde.”

  • *

    Wo Àfikún A5.

  • *

    Ní Grk., “Àsọjáde.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 40:6-8
  • +Tit 1:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    9/2017, ojú ìwé 18

    Yiyan, ojú ìwé 48

Àwọn míì

1 Pét. 1:1Mt 10:2
1 Pét. 1:1Iṣe 2:5, 9
1 Pét. 1:2Ro 8:29
1 Pét. 1:22Tẹ 2:13
1 Pét. 1:2Heb 12:22, 24
1 Pét. 1:31Pe 1:23
1 Pét. 1:3Ifi 20:6
1 Pét. 1:31Kọ 15:20
1 Pét. 1:41Kọ 15:53; 2Ti 1:10; 1Pe 5:4
1 Pét. 1:4Jo 14:2; 2Ti 4:8
1 Pét. 1:62Kọ 4:17; 2Ti 3:12
1 Pét. 1:7Jem 1:2, 3
1 Pét. 1:72Tẹ 1:7
1 Pét. 1:9Ro 6:22
1 Pét. 1:10Mt 13:17
1 Pét. 1:11Da 9:24-27
1 Pét. 1:11Ais 53:5
1 Pét. 1:12Jo 15:26; Iṣe 2:4
1 Pét. 1:13Lk 12:35
1 Pét. 1:13Ef 5:17; 1Pe 4:7
1 Pét. 1:15Di 28:9; Ro 12:1; Heb 12:14
1 Pét. 1:16Le 11:44; 19:2; 20:7, 26
1 Pét. 1:17Di 10:17
1 Pét. 1:172Kọ 7:1
1 Pét. 1:181Kọ 6:20
1 Pét. 1:19Ais 53:12; Heb 9:14
1 Pét. 1:19Ẹk 12:5; Le 22:20; Jo 1:29
1 Pét. 1:191Kọ 5:7
1 Pét. 1:20Jo 17:5; Ef 1:4
1 Pét. 1:20Kol 1:26, 27
1 Pét. 1:21Jo 14:6
1 Pét. 1:21Iṣe 2:24
1 Pét. 1:21Heb 2:9
1 Pét. 1:22Ro 12:9; 1Jo 3:17
1 Pét. 1:221Ti 1:5
1 Pét. 1:23Jo 3:3; 2Kọ 5:17; 1Pe 1:3; 1Jo 3:9
1 Pét. 1:23Jo 3:6
1 Pét. 1:23Jo 6:63; Jem 1:18
1 Pét. 1:25Ais 40:6-8
1 Pét. 1:25Tit 1:3
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Pétérù 1:1-25

Ìwé Kìíní Pétérù

1 Pétérù, àpọ́sítélì+ Jésù Kristi, sí ẹ̀yin olùgbé fún ìgbà díẹ̀* tí ẹ wà káàkiri Pọ́ńtù, Gálátíà, Kapadókíà,+ Éṣíà àti Bítíníà, sí ẹ̀yin àyànfẹ́ 2 gẹ́gẹ́ bí ohun tí Ọlọ́run tó jẹ́ Baba ti mọ̀ tẹ́lẹ̀,+ tí ẹ̀mí sọ di mímọ́,+ kí ẹ lè ṣègbọràn, kí a sì wọ́n ẹ̀jẹ̀ Jésù Kristi sí yín lára:+

Kí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí àti àlàáfíà yín máa pọ̀ sí i.

3 Ẹ yin Ọlọ́run àti Baba Olúwa wa Jésù Kristi, torí nínú àánú rẹ̀ tó pọ̀, ó fún wa ní ìbí tuntun+ ká lè ní ìrètí tó wà láàyè+ nípasẹ̀ àjíǹde Jésù Kristi kúrò nínú ikú,+ 4 ká lè ní ogún tí kì í bà jẹ́, tí kò lábààwọ́n, tí kò sì lè ṣá.+ A tọ́jú rẹ̀ sí ọ̀run de ẹ̀yin+ 5 tí agbára Ọlọ́run dáàbò bò nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ fún ìgbàlà kan tí a ṣe tán láti ṣí payá ní àkókò ìkẹyìn. 6 Ẹ̀ ń yọ̀ gidigidi nítorí èyí, bó tiẹ̀ jẹ́ pé fún ìgbà díẹ̀, ó lè pọn dandan kí oríṣiríṣi àdánwò kó ìdààmú bá yín,+ 7 kí ìgbàgbọ́ yín tí a dán wò+ ní ti bó ṣe jẹ́ ojúlówó tó, èyí tó níye lórí gidigidi ju wúrà tó máa ń ṣègbé láìka pé a fi iná dá an wò* sí, lè jẹ́ orísun ìyìn àti ògo àti ọlá nígbà ìfihàn Jésù Kristi.+ 8 Bí ẹ ò tiẹ̀ rí i rí, ẹ nífẹ̀ẹ́ rẹ̀. Bí ẹ ò tiẹ̀ rí i báyìí, síbẹ̀ ẹ ní ìgbàgbọ́ nínú rẹ̀, inú yín sì ń dùn gan-an, ayọ̀ yín kọjá àfẹnusọ, ó sì jẹ́ ológo, 9 bí ọwọ́ yín ṣe ń tẹ èrè ìgbàgbọ́ yín, ìgbàlà yín.*+

10 Ní ti ìgbàlà yìí, àwọn wòlíì tí wọ́n sọ tẹ́lẹ̀ nípa inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tó jẹ́ tiyín, fara balẹ̀ wádìí, wọ́n sì fẹ̀sọ̀ wá a.+ 11 Wọn ò yéé wádìí àkókò náà gan-an tàbí ìgbà tí ẹ̀mí tó wà nínú wọn ń tọ́ka sí nípa Kristi,+ bó ṣe jẹ́rìí ṣáájú nípa àwọn ìyà tí Kristi máa jẹ+ àti ògo tó máa tẹ̀ lé e. 12 A ṣí i payá fún wọn pé wọ́n ń ṣe òjíṣẹ́, kì í ṣe fún ara wọn, àmọ́ fún yín, nípa àwọn ohun tí àwọn tó kéde ìhìn rere fún yín ti wá sọ fún yín nípasẹ̀ ẹ̀mí mímọ́ tó wá láti ọ̀run.+ Ó wu àwọn áńgẹ́lì gan-an pé kí wọ́n wo àwọn nǹkan yìí fínnífínní.

13 Nítorí náà, ẹ múra ọkàn yín sílẹ̀ láti ṣiṣẹ́;+ ẹ máa ronú bó ṣe tọ́ nígbà gbogbo;  + ẹ máa retí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tí a máa fún yín nígbà ìfihàn Jésù Kristi. 14 Bí ọmọ tó ń ṣègbọràn, ẹ má ṣe jẹ́ kí àwọn ohun tí ẹ nífẹ̀ẹ́ sí tẹ́lẹ̀ torí àìmọ̀kan yín tún máa darí yín,* 15 àmọ́ bíi ti Ẹni Mímọ́ tó pè yín, kí ẹ̀yin náà di mímọ́ nínú gbogbo ìwà yín,+ 16 nítorí a ti kọ ọ́ pé: “Ẹ gbọ́dọ̀ jẹ́ mímọ́, torí èmi jẹ́ mímọ́.”+

17 Tí ẹ bá sì ń ké pe Baba tó ń fi iṣẹ́ ọwọ́ ẹnì kọ̀ọ̀kan ṣèdájọ́ láìṣe ojúsàájú,+ ẹ máa fi ìbẹ̀rù hùwà+ ní àkókò tí ẹ fi jẹ́ olùgbé fún ìgbà díẹ̀.* 18 Torí ẹ mọ̀ pé kì í ṣe àwọn ohun tó lè bà jẹ́, bíi fàdákà tàbí wúrà la fi tú yín sílẹ̀,*+ kúrò nínú ìgbésí ayé asán tí àwọn baba ńlá yín fi lé yín lọ́wọ́.* 19 Ẹ̀jẹ̀ iyebíye ni,+ bí ẹ̀jẹ̀ ọ̀dọ́ àgùntàn tí kò ní àbààwọ́n, tí kò sì ní èérí kankan,+ ìyẹn ẹ̀jẹ̀ Kristi.+ 20 Lóòótọ́, a ti mọ̀ ọ́n tẹ́lẹ̀, ká tó fi ìpìlẹ̀ ayé lélẹ̀,+ àmọ́ nítorí yín, a wá fi hàn kedere ní ìparí àwọn àkókò.+ 21 Nípasẹ̀ rẹ̀ lẹ gba Ọlọ́run gbọ́,+ ẹni tó jí i dìde nínú ikú,+ tó sì fún un ní ògo,+ kí ìgbàgbọ́ àti ìrètí yín lè wà nínú Ọlọ́run.

22 Ní báyìí tí ẹ ti fi ìgbọràn yín sí òtítọ́ wẹ ara yín* mọ́, tí èyí sì mú kí ẹ ní ìfẹ́ ará láìsí ẹ̀tàn,+ kí ẹ ní ìfẹ́ tó jinlẹ̀ sí ara yín látọkàn wá.+ 23 Torí a ti fún yín ní ìbí tuntun,+ kì í ṣe nípasẹ̀ irúgbìn* tó lè bà jẹ́, àmọ́ nípasẹ̀ irúgbìn tí kò lè bà jẹ́,+ nípasẹ̀ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run alààyè, tó wà títí láé.+ 24 Torí “gbogbo ẹran ara* dà bíi koríko, gbogbo ògo rẹ̀ sì dà bí ìtànná àwọn ewéko; koríko máa ń gbẹ, òdòdó sì máa ń rẹ̀ dà nù, 25 àmọ́ ọ̀rọ̀* Jèhófà* wà títí láé.”+ “Ọ̀rọ̀”* yìí ni ìhìn rere tí a kéde rẹ̀ fún yín.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́