ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 65
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Jèhófà máa dá àwọn abọ̀rìṣà lẹ́jọ́ (1-16)

        • Ọlọ́run Oríire àti Àyànmọ́ (11)

        • “Àwọn ìránṣẹ́ mi máa jẹun” (13)

      • Ọ̀run tuntun àti ayé tuntun (17-25)

        • A máa kọ́ ilé; a máa gbin ọgbà àjàrà (21)

        • Kò sẹ́ni tó máa ṣiṣẹ́ àṣedànù (23)

Àìsáyà 65:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 55:6, 7
  • +Ro 10:20, 21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 373

Àìsáyà 65:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 31:27; Ne 9:29; Sek 7:11
  • +Ais 59:7, 8; Jer 35:15
  • +Jer 5:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 374

Àìsáyà 65:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 17:16, 17; Jer 32:29
  • +Ais 1:29; 66:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 374-375

Àìsáyà 65:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “àwọn ahéré ìṣọ́.”

  • *

    Tàbí “aláìmọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 19:16
  • +Le 11:7, 8; Ais 66:17
  • +Di 14:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 374-375

Àìsáyà 65:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “Torí màá kó ìjẹ́mímọ́ mi ràn ọ́.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 374-375

Àìsáyà 65:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “sínú àyà wọn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 50:3, 21; Jer 16:18; Isk 11:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 376

Àìsáyà 65:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “sínú àyà wọn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 20:4, 5; Le 26:39
  • +1Ọb 22:41, 43; 2Ọb 12:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 376

Àìsáyà 65:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ìbùkún.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 30:11; Emọ 9:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 376-377

Àìsáyà 65:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “èso.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 60:21; Isk 37:21; Ọbd 17
  • +Ais 61:7; Sef 3:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 376-377

Àìsáyà 65:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Pẹ̀tẹ́lẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 33:9
  • +Joṣ 7:24; Ho 2:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 377

Àìsáyà 65:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 1:4
  • +2Kr 28:24; 34:25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 44

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2006, ojú ìwé 27-28

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 378-379

Àìsáyà 65:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 26:25; Isk 6:13
  • +Isk 9:6
  • +2Kr 36:15, 16
  • +Ais 66:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2006, ojú ìwé 27-28

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 378-379

Àìsáyà 65:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 37:19, 25; Emọ 8:11
  • +Ais 49:10
  • +Ais 66:14
  • +Ais 66:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, ojú ìwé 235

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 379-380

Àìsáyà 65:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 379-380

Àìsáyà 65:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 62:2; Jer 33:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 380-381

Àìsáyà 65:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “olóòótọ́.” Ní Héb., “Àmín.”

  • *

    Tàbí “olóòótọ́.” Ní Héb., “Àmín.”

  • *

    Tàbí “ìṣòro.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 6:13
  • +Ais 12:1; Jer 31:12; Sef 3:14, 15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 380-381

Àìsáyà 65:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹsr 5:2; Ais 51:16; 66:22; 2Pe 3:13
  • +Ifi 21:1, 4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 26

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    2/2017, ojú ìwé 7

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2012, ojú ìwé 19

    10/1/2008, ojú ìwé 8

    4/15/2000, ojú ìwé 9-11, 14

    6/15/1998, ojú ìwé 32

    7/15/1993, ojú ìwé 17-18

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 111, 301

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 381-383

    Ọlọrun Bikita, ojú ìwé 27-28

    Yiyan, ojú ìwé 121-122

Àìsáyà 65:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 51:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 383-384

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2000, ojú ìwé 9-10

    “Kí Ijọba Rẹ Dé,” ojú ìwé 183

Àìsáyà 65:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 62:4; Jer 32:41
  • +Ais 25:8; Jer 31:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 303

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 383-384

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2000, ojú ìwé 9-10

    “Kí Ijọba Rẹ Dé,” ojú ìwé 183

Àìsáyà 65:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “Ẹni ègún la sì máa ka ẹni tí kò bá lò tó ọgọ́rùn-ún ọdún sí.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    8/2018, ojú ìwé 11

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 384-385

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2000, ojú ìwé 15-16

Àìsáyà 65:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 31:4
  • +Ais 62:8; Emọ 9:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 27

    Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, ojú ìwé 232, 236-237

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2012, ojú ìwé 9

    4/15/2000, ojú ìwé 16-17

    7/15/1991, ojú ìwé 6-7

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 303

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 385-387

Àìsáyà 65:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 92:12-14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 27

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2018, ojú ìwé 5

    Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, ojú ìwé 232, 236-237

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2009, ojú ìwé 16

    5/15/2000, ojú ìwé 29

    4/15/2000, ojú ìwé 16-17

    3/1/1995, ojú ìwé 32

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 303

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 385-387

Àìsáyà 65:23

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ṣe làálàá.”

  • *

    Tàbí “ṣiṣẹ́ àṣedànù.”

  • *

    Ní Héb., “èso.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 26:3-5; Di 28:4
  • +Ais 61:9
  • +Ais 66:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 27

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 387

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2000, ojú ìwé 17

Àìsáyà 65:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 387

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2000, ojú ìwé 17

Àìsáyà 65:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 35:9; Ho 2:18
  • +Ais 2:3, 4; 11:6-9; Mik 4:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2012, ojú ìwé 9-10

    4/15/2000, ojú ìwé 17-18

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 388-389

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 174-175

Àwọn míì

Àìsá. 65:1Ais 55:6, 7
Àìsá. 65:1Ro 10:20, 21
Àìsá. 65:2Di 31:27; Ne 9:29; Sek 7:11
Àìsá. 65:2Ais 59:7, 8; Jer 35:15
Àìsá. 65:2Jer 5:23
Àìsá. 65:32Ọb 17:16, 17; Jer 32:29
Àìsá. 65:3Ais 1:29; 66:17
Àìsá. 65:4Nọ 19:16
Àìsá. 65:4Le 11:7, 8; Ais 66:17
Àìsá. 65:4Di 14:3
Àìsá. 65:6Sm 50:3, 21; Jer 16:18; Isk 11:21
Àìsá. 65:7Ẹk 20:4, 5; Le 26:39
Àìsá. 65:71Ọb 22:41, 43; 2Ọb 12:3
Àìsá. 65:8Jer 30:11; Emọ 9:8
Àìsá. 65:9Ais 60:21; Isk 37:21; Ọbd 17
Àìsá. 65:9Ais 61:7; Sef 3:20
Àìsá. 65:10Ais 33:9
Àìsá. 65:10Joṣ 7:24; Ho 2:15
Àìsá. 65:11Ais 1:4
Àìsá. 65:112Kr 28:24; 34:25
Àìsá. 65:12Le 26:25; Isk 6:13
Àìsá. 65:12Isk 9:6
Àìsá. 65:122Kr 36:15, 16
Àìsá. 65:12Ais 66:3
Àìsá. 65:13Sm 37:19, 25; Emọ 8:11
Àìsá. 65:13Ais 49:10
Àìsá. 65:13Ais 66:14
Àìsá. 65:13Ais 66:5
Àìsá. 65:15Ais 62:2; Jer 33:16
Àìsá. 65:16Di 6:13
Àìsá. 65:16Ais 12:1; Jer 31:12; Sef 3:14, 15
Àìsá. 65:17Ẹsr 5:2; Ais 51:16; 66:22; 2Pe 3:13
Àìsá. 65:17Ifi 21:1, 4
Àìsá. 65:18Ais 51:11
Àìsá. 65:19Ais 62:4; Jer 32:41
Àìsá. 65:19Ais 25:8; Jer 31:12
Àìsá. 65:21Jer 31:4
Àìsá. 65:21Ais 62:8; Emọ 9:14
Àìsá. 65:22Sm 92:12-14
Àìsá. 65:23Le 26:3-5; Di 28:4
Àìsá. 65:23Ais 61:9
Àìsá. 65:23Ais 66:22
Àìsá. 65:25Ais 35:9; Ho 2:18
Àìsá. 65:25Ais 2:3, 4; 11:6-9; Mik 4:2
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 65:1-25

Àìsáyà

65 “Mo ti jẹ́ kí àwọn tí kò béèrè mi wá mi;

Mo ti jẹ́ kí àwọn tí kò wá mi rí mi.+

Mo sọ fún orílẹ̀-èdè tí kò pe orúkọ mi pé, ‘Èmi nìyí, èmi nìyí!’+

 2 Mo ti tẹ́ ọwọ́ mi sí àwọn alágídí láti àárọ̀ ṣúlẹ̀,+

Sí àwọn tó ń rìn ní ọ̀nà tí kò dáa,+

Tí wọ́n ń tẹ̀ lé èrò tiwọn;+

 3 Àwọn èèyàn tó ń fìgbà gbogbo ṣe ohun tó ń bí mi nínú níṣojú mi, +

Tí wọ́n ń rúbọ nínú àwọn ọgbà,+ tí wọ́n sì ń mú ẹbọ rú èéfín lórí àwọn bíríkì.

 4 Wọ́n jókòó sáàárín àwọn sàréè,+

Wọ́n sì sun àwọn ibi tó pa mọ́* mọ́jú,

Wọ́n ń jẹ ẹran ẹlẹ́dẹ̀,+

Omi àwọn nǹkan tó ń ríni lára* sì wà nínú àwọn ohun èlò wọn.+

 5 Wọ́n sọ pé, ‘Dúró sí àyè rẹ; má ṣe sún mọ́ mi,

Torí mo mọ́ jù ọ́ lọ.’*

Èéfín ni àwọn yìí nínú ihò imú mi, iná tó ń jó láti àárọ̀ ṣúlẹ̀.

 6 Wò ó! A ti kọ ọ́ níwájú mi;

Mi ò kàn ní dúró,

Àmọ́ màá san wọ́n lẹ́san,+

Màá san wọ́n lẹ́san ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́*

 7 Torí ẹ̀ṣẹ̀ wọn àti ẹ̀ṣẹ̀ àwọn baba ńlá wọn pẹ̀lú,”+ ni Jèhófà wí.

“Torí pé wọ́n ti mú ẹbọ rú èéfín lórí àwọn òkè,

Wọ́n sì ti gàn mí lórí àwọn òkè,+

Màá kọ́kọ́ díwọ̀n èrè wọn ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́.”*

 8 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí:

“Bí ìgbà tí wọ́n rí wáìnì tuntun nínú òṣùṣù èso àjàrà,

Tí ẹnì kan wá sọ pé, ‘Má bà á jẹ́, torí ohun tó dáa* wà nínú rẹ̀,’

Bẹ́ẹ̀ ni màá ṣe nítorí àwọn ìránṣẹ́ mi;

Mi ò ní pa gbogbo wọn run.+

 9 Màá mú ọmọ* kan jáde látinú Jékọ́bù,

Màá sì mú ẹni tó máa jogún àwọn òkè mi jáde látinú Júdà;+

Àwọn àyànfẹ́ mi máa gbà á,

Àwọn ìránṣẹ́ mi á sì máa gbé níbẹ̀.+

10 Ṣárónì+ máa di ibi tí àgùntàn á ti máa jẹko,

Àfonífojì* Ákórì+ sì máa di ibi ìsinmi àwọn màlúù

Fún àwọn èèyàn mi tó ń wá mi.

11 Àmọ́ ẹ wà lára àwọn tó ń fi Jèhófà sílẹ̀,+

Àwọn tó ń gbàgbé òkè mímọ́ mi,+

Àwọn tó ń tẹ́ tábìlì fún ọlọ́run Oríire

Àti àwọn tó ń bu àdàlù wáìnì kún inú ife fún ọlọ́run Àyànmọ́.

12 Torí náà, màá yàn yín fún idà,+

Gbogbo yín sì máa tẹrí ba kí wọ́n lè pa yín,+

Torí mo pè, àmọ́ ẹ ò dáhùn,

Mo sọ̀rọ̀, àmọ́ ẹ ò fetí sílẹ̀;+

Ẹ̀ ń ṣe ohun tó burú lójú mi ṣáá,

Ẹ sì yan ohun tí inú mi ò dùn sí.”+

13 Torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí:

“Wò ó! Àwọn ìránṣẹ́ mi máa jẹun, àmọ́ ebi máa pa ẹ̀yin.+

Wò ó! Àwọn ìránṣẹ́ mi máa mu,+ àmọ́ òùngbẹ máa gbẹ ẹ̀yin.

Wò ó! Àwọn ìránṣẹ́ mi máa yọ̀,+ àmọ́ ojú máa ti ẹ̀yin.+

14 Wò ó! Àwọn ìránṣẹ́ mi máa kígbe ayọ̀ torí pé ayọ̀ kún inú ọkàn,

Àmọ́ ẹ̀yin máa ké jáde torí ìrora ọkàn,

Ẹ sì máa pohùn réré ẹkún torí ìbànújẹ́ ọkàn.

15 Ẹ máa fi orúkọ kan sílẹ̀ tí àwọn àyànfẹ́ mi máa fi gégùn-ún,

Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sì máa pa yín níkọ̀ọ̀kan,

Àmọ́ ó máa fi orúkọ míì pe àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀;+

16 Kí Ọlọ́run òtítọ́* lè bù kún

Ẹnikẹ́ni tó bá ń wá ìbùkún fún ara rẹ̀ ní ayé,

Kí ẹnikẹ́ni tó bá sì ń búra ní ayé

Lè fi Ọlọ́run òtítọ́* búra.+

Torí àwọn wàhálà* àtijọ́ máa di ohun ìgbàgbé;

Wọ́n máa pa mọ́ kúrò ní ojú mi.+

17 Torí wò ó! Mò ń dá ọ̀run tuntun àti ayé tuntun;+

Àwọn ohun àtijọ́ ò ní wá sí ìrántí,

Wọn ò sì ní wá sí ọkàn.+

18 Torí náà, ẹ yọ̀, kí inú yín sì máa dùn títí láé torí ohun tí mò ń dá.

Torí wò ó! Mò ń dá Jerúsálẹ́mù láti mú ayọ̀ wá

Àti àwọn èèyàn rẹ̀ láti jẹ́ orísun ìdùnnú.+

19 Inú mi máa dùn nínú Jerúsálẹ́mù, màá sì yọ̀ torí àwọn èèyàn mi;+

A ò ní gbọ́ igbe ẹkún tàbí igbe ìdààmú nínú rẹ̀ mọ́.”+

20 “Kò ní sí ọmọ ọwọ́ kankan tó máa lo ọjọ́ díẹ̀ níbẹ̀ mọ́,

Kò sì ní sí àgbàlagbà kankan tí kò ní lo ọjọ́ rẹ̀ dé ẹ̀kúnrẹ́rẹ́.

Torí pé ọmọdé lásán la máa ka ẹnikẹ́ni tó bá kú ní ọgọ́rùn-ún (100) ọdún sí,

A sì máa gégùn-ún fún ẹlẹ́ṣẹ̀, bó tiẹ̀ jẹ́ ẹni ọgọ́rùn-ún (100) ọdún.*

21 Wọ́n á kọ́ ilé, wọ́n sì máa gbé inú wọn,+

Wọ́n á gbin ọgbà àjàrà, wọ́n sì máa jẹ èso wọn.+

22 Wọn ò ní kọ́lé fún ẹlòmíì gbé,

Wọn ò sì ní gbìn fún ẹlòmíì jẹ.

Torí pé ọjọ́ àwọn èèyàn mi máa dà bí ọjọ́ igi,+

Àwọn àyànfẹ́ mi sì máa gbádùn iṣẹ́ ọwọ́ wọn dé ẹ̀kúnrẹ́rẹ́.

23 Wọn ò ní ṣiṣẹ́ kára* lásán,*+

Wọn ò sì ní bímọ fún wàhálà,

Torí àwọn ni ọmọ* tí wọ́n jẹ́ àwọn tí Jèhófà bù kún+

Àti àwọn àtọmọdọ́mọ wọn pẹ̀lú wọn.+

24 Kódà kí wọ́n tó pè, màá dáhùn;

Bí wọ́n ṣe ń sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, màá gbọ́.

25 Ìkookò àti ọ̀dọ́ àgùntàn máa jẹun pa pọ̀,

Kìnnìún máa jẹ pòròpórò bí akọ màlúù,+

Erùpẹ̀ sì ni ejò á máa jẹ.

Wọn ò ní ṣe ìpalára kankan, wọn ò sì ní fa ìparun kankan ní gbogbo òkè mímọ́ mi,”+ ni Jèhófà wí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́