ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 20
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ẹ́kísódù

      • Òfin Mẹ́wàá (1-17)

      • Ohun tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì rí dẹ́rù bà wọ́n (18-21)

      • Ìtọ́ni nípa ìjọsìn (22-26)

Ẹ́kísódù 20:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 5:22; Iṣe 7:38

Ẹ́kísódù 20:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 5:6; Ho 13:4

Ẹ́kísódù 20:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “láti fojú di mí.” Ní Héb., “níṣojú mi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 5:7-10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    2/2019, ojú ìwé 22-23

Ẹ́kísódù 20:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwòrán.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 26:1; Di 4:15, 16; Ais 40:25; Iṣe 17:29

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 14

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    2/2019, ojú ìwé 22-23

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2009, ojú ìwé 30

    Jí!,

    10/2008, ojú ìwé 12-13

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 65-66

Ẹ́kísódù 20:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 23:24; 1Kọ 10:20; 1Jo 5:21
  • +Ẹk 34:14; Mt 4:10; Lk 10:27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 14

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 53, 164-165

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2010, ojú ìwé 28-29

    2/1/2009, ojú ìwé 30

    3/15/2004, ojú ìwé 27

    Jí!,

    10/2008, ojú ìwé 12-13

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 65-66

Ẹ́kísódù 20:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Onw 12:13

Ẹ́kísódù 20:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 19:12
  • +Le 24:15, 16; Di 5:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    2/8/2004, ojú ìwé 19-20

    3/8/1999, ojú ìwé 26-27

    Orukọ Atọrunwa, ojú ìwé 14

Ẹ́kísódù 20:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 16:23; 31:13, 14; Di 5:12-14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/1998, ojú ìwé 18

Ẹ́kísódù 20:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 23:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/1998, ojú ìwé 18

Ẹ́kísódù 20:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “tó wà ní ẹnubodè rẹ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 16:29; 34:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/1998, ojú ìwé 18

Ẹ́kísódù 20:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 2:2

Ẹ́kísódù 20:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 21:15; Le 19:3; Owe 1:8
  • +Di 5:16; Mt 15:4; Ef 6:2, 3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àlàyé Àwọn Ẹsẹ Bíbélì, àpilẹ̀kọ 7

    Jí!,

    11/8/2003, ojú ìwé 28-29

Ẹ́kísódù 20:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 9:6; Di 5:17; Jem 2:11; 1Jo 3:15; Ifi 21:8

Ẹ́kísódù 20:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 39:7-9; Di 5:18; Owe 6:32; Mt 5:27, 28; Ro 13:9; 1Kọ 6:18; Heb 13:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, ojú ìwé 1692

Ẹ́kísódù 20:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 19:11; Di 5:19; Mk 10:19; 1Kọ 6:9, 10; Ef 4:28

Ẹ́kísódù 20:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 19:16; Di 5:20; 19:16-19

Ẹ́kísódù 20:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 5:28
  • +Di 5:21; Ro 7:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 4 2016 ojú ìwé 6

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2006, ojú ìwé 24-25

    6/15/2006, ojú ìwé 23-24

    10/1/1997, ojú ìwé 13

Ẹ́kísódù 20:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 19:16; Heb 12:18, 19

Ẹ́kísódù 20:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 7:38; Ga 3:19

Ẹ́kísódù 20:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 8:2
  • +Joṣ 24:14; Job 28:28; Owe 1:7

Ẹ́kísódù 20:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọsánmà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 5:5; Sm 97:2

Ẹ́kísódù 20:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 4:36; Ne 9:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 109

Ẹ́kísódù 20:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 17:29

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 109

Ẹ́kísódù 20:24

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ẹbọ àlàáfíà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 12:5, 6; 2Kr 6:6

Ẹ́kísódù 20:25

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “òkúta gbígbẹ́.”

  • *

    Tàbí “ohun èlò tí a fi ń gbẹ́ igi tàbí òkúta.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 27:5; Joṣ 8:30, 31

Ẹ́kísódù 20:26

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ìhòòhò.”

Àwọn míì

Ẹ́kís. 20:1Di 5:22; Iṣe 7:38
Ẹ́kís. 20:2Di 5:6; Ho 13:4
Ẹ́kís. 20:3Di 5:7-10
Ẹ́kís. 20:4Le 26:1; Di 4:15, 16; Ais 40:25; Iṣe 17:29
Ẹ́kís. 20:5Ẹk 23:24; 1Kọ 10:20; 1Jo 5:21
Ẹ́kís. 20:5Ẹk 34:14; Mt 4:10; Lk 10:27
Ẹ́kís. 20:6Onw 12:13
Ẹ́kís. 20:7Le 19:12
Ẹ́kís. 20:7Le 24:15, 16; Di 5:11
Ẹ́kís. 20:8Ẹk 16:23; 31:13, 14; Di 5:12-14
Ẹ́kís. 20:9Ẹk 23:12
Ẹ́kís. 20:10Ẹk 16:29; 34:21
Ẹ́kís. 20:11Jẹ 2:2
Ẹ́kís. 20:12Ẹk 21:15; Le 19:3; Owe 1:8
Ẹ́kís. 20:12Di 5:16; Mt 15:4; Ef 6:2, 3
Ẹ́kís. 20:13Jẹ 9:6; Di 5:17; Jem 2:11; 1Jo 3:15; Ifi 21:8
Ẹ́kís. 20:14Jẹ 39:7-9; Di 5:18; Owe 6:32; Mt 5:27, 28; Ro 13:9; 1Kọ 6:18; Heb 13:4
Ẹ́kís. 20:15Le 19:11; Di 5:19; Mk 10:19; 1Kọ 6:9, 10; Ef 4:28
Ẹ́kís. 20:16Le 19:16; Di 5:20; 19:16-19
Ẹ́kís. 20:17Mt 5:28
Ẹ́kís. 20:17Di 5:21; Ro 7:7
Ẹ́kís. 20:18Ẹk 19:16; Heb 12:18, 19
Ẹ́kís. 20:19Iṣe 7:38; Ga 3:19
Ẹ́kís. 20:20Di 8:2
Ẹ́kís. 20:20Joṣ 24:14; Job 28:28; Owe 1:7
Ẹ́kís. 20:21Di 5:5; Sm 97:2
Ẹ́kís. 20:22Di 4:36; Ne 9:13
Ẹ́kís. 20:23Iṣe 17:29
Ẹ́kís. 20:24Di 12:5, 6; 2Kr 6:6
Ẹ́kís. 20:25Di 27:5; Joṣ 8:30, 31
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Ẹ́kísódù 20:1-26

Ẹ́kísódù

20 Ọlọ́run wá sọ gbogbo ọ̀rọ̀ yìí, ó ní:+

2 “Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ, ẹni tó mú ọ kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì, kúrò ní ilé ẹrú.+ 3 O ò gbọ́dọ̀ ní ọlọ́run kankan yàtọ̀ sí mi.*+

4 “O ò gbọ́dọ̀ gbẹ́ ère kankan fún ara rẹ tàbí kí o ṣe ohun* kan tó dà bí ohunkóhun lókè ọ̀run tàbí ní ayé tàbí nínú omi nísàlẹ̀.+ 5 O ò gbọ́dọ̀ forí balẹ̀ fún wọn tàbí kí o jẹ́ kí wọ́n tàn ọ́ láti sìn wọ́n,+ torí èmi Jèhófà Ọlọ́run rẹ jẹ́ Ọlọ́run tó fẹ́ kí o máa sin òun nìkan ṣoṣo,+ tó ń fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ àwọn bàbá jẹ àwọn ọmọ, dórí ìran kẹta àti ìran kẹrin àwọn tó kórìíra mi, 6 àmọ́ tó ń fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí àwọn tó nífẹ̀ẹ́ mi títí dé ẹgbẹ̀rún ìran wọn, tí wọ́n sì ń pa àwọn àṣẹ mi mọ́.+

7 “O ò gbọ́dọ̀ lo orúkọ Jèhófà Ọlọ́run rẹ lọ́nà tí kò tọ́,+ torí Jèhófà kò ní ṣàìfi ìyà jẹ ẹni tó bá lo orúkọ Rẹ̀ lọ́nà tí kò tọ́.+

8 “Máa rántí ọjọ́ Sábáàtì, kí o lè yà á sí mímọ́.+ 9 Ọjọ́ mẹ́fà ni kí o fi ṣiṣẹ́, kí o sì fi ṣe gbogbo iṣẹ́ rẹ,+ 10 àmọ́ ọjọ́ keje jẹ́ sábáàtì fún Jèhófà Ọlọ́run rẹ. O ò gbọ́dọ̀ ṣiṣẹ́ kankan, ìwọ àti ọmọkùnrin rẹ àti ọmọbìnrin rẹ àti ẹrúkùnrin rẹ àti ẹrúbìnrin rẹ àti ẹran ọ̀sìn rẹ àti àjèjì tí ẹ jọ ń gbé.*+ 11 Torí ọjọ́ mẹ́fà ni Jèhófà fi dá ọ̀run àti ayé, òkun àti gbogbo ohun tó wà nínú wọn, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í sinmi ní ọjọ́ keje.+ Ìdí nìyẹn tí Jèhófà fi bù kún ọjọ́ Sábáàtì, tó sì yà á sí mímọ́.

12 “Bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ,+ kí ẹ̀mí rẹ lè gùn lórí ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa fún ọ.+

13 “O ò gbọ́dọ̀ pààyàn.+

14 “O ò gbọ́dọ̀ ṣe àgbèrè.+

15 “O ò gbọ́dọ̀ jalè.+

16 “O ò gbọ́dọ̀ jẹ́rìí èké sí ọmọnìkejì rẹ.+

17 “O ò gbọ́dọ̀ jẹ́ kí ilé ọmọnìkejì rẹ wọ̀ ọ́ lójú. Ojú rẹ ò sì gbọ́dọ̀ wọ ìyàwó ọmọnìkejì rẹ+ tàbí ẹrúkùnrin rẹ̀ tàbí ẹrúbìnrin rẹ̀ tàbí akọ màlúù rẹ̀ tàbí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀ tàbí ohunkóhun tó jẹ́ ti ọmọnìkejì rẹ.”+

18 Gbogbo àwọn èèyàn náà ń rí ààrá tó ń sán àti mànàmáná tó ń kọ yẹ̀rì, wọ́n ń gbọ́ ìró ìwo, wọ́n sì ń rí òkè tó ń yọ èéfín; àwọn ohun tí wọ́n rí yìí bà wọ́n lẹ́rù, wọ́n sì ń gbọ̀n, wọ́n wá dúró ní òkèèrè.+ 19 Torí náà, wọ́n sọ fún Mósè pé: “Ìwọ ni kí o máa bá wa sọ̀rọ̀, a ó sì fetí sílẹ̀. Má ṣe jẹ́ kí Ọlọ́run bá wa sọ̀rọ̀ ká má bàa kú.”+ 20 Mósè wá sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ má bẹ̀rù, torí ṣe ni Ọlọ́run tòótọ́ wá dán yín wò,+ kí ẹ lè máa bẹ̀rù rẹ̀ kí ẹ má bàa ṣẹ̀.”+ 21 Àwọn èèyàn náà ò kúrò ní ọ̀ọ́kán níbi tí wọ́n dúró sí, àmọ́ Mósè sún mọ́ ìkùukùu* tó ṣú dùdù náà níbi tí Ọlọ́run tòótọ́ wà.+

22 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Ohun tí ìwọ yóò sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nìyí, ‘Ẹ̀yin fúnra yín rí i pé láti ọ̀run ni mo ti bá yín sọ̀rọ̀.+ 23 Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣe àwọn ọlọ́run fàdákà láti máa sìn wọ́n pẹ̀lú mi, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ ṣe àwọn ọlọ́run wúrà fún ara yín.+ 24 Fi erùpẹ̀ mọ pẹpẹ fún mi, kí o sì rú àwọn ẹbọ sísun rẹ lórí rẹ̀, pẹ̀lú àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀* rẹ, agbo ẹran rẹ àti ọ̀wọ́ ẹran rẹ. Gbogbo ibi tí mo bá ti mú kí wọ́n rántí orúkọ mi+ ni màá ti wá bá ọ, tí màá sì bù kún ọ. 25 Tí o bá fi òkúta ṣe pẹpẹ fún mi, o ò gbọ́dọ̀ lo òkúta tí o fi irinṣẹ́ gbẹ́.*+ Torí tí o bá lo irinṣẹ́* rẹ lára rẹ̀, wàá sọ ọ́ di aláìmọ́. 26 O ò sì gbọ́dọ̀ fi àtẹ̀gùn gun pẹpẹ mi, kí abẹ́* rẹ má bàa hàn lórí rẹ̀.’

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́