ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Pétérù 1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Pétérù

      • Ìkíni (1)

      • Ẹ jẹ́ kí pípè yín dá yín lójú (2-15)

        • Àwọn ànímọ́ tí a fi kún ìgbàgbọ́ (5-9)

      • Ọ̀rọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ tí a mú kó túbọ̀ dá wa lójú (16-21)

2 Pétérù 1:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìgbàgbọ́ tí àǹfààní rẹ̀ dọ́gba pẹ̀lú tiwa.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2002, ojú ìwé 6

    9/1/1997, ojú ìwé 9-10

2 Pétérù 1:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Kol 1:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/1997, ojú ìwé 10

2 Pétérù 1:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ti fún wa ní gbogbo ohun tó mú ká lè ní ìyè àti ìfọkànsìn Ọlọ́run lọ́fẹ̀ẹ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 17:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/1997, ojú ìwé 10

2 Pétérù 1:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “fi fún wa ní àwọn ìlérí tó ṣeyebíye, tó sì jẹ́ àgbàyanu lọ́fẹ̀ẹ́.”

  • *

    Tàbí “ìfẹ́ ọkàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 22:29, 30; Jo 14:2; Ga 3:29
  • +1Kọ 15:53; 1Pe 1:3, 4; 1Jo 3:2; Ifi 20:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/1997, ojú ìwé 10

2 Pétérù 1:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Flp 2:12; 2Ti 2:15; Heb 4:11; Jud 3
  • +Flp 4:8
  • +Jo 17:3; Heb 5:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2010, ojú ìwé 8

    9/1/1997, ojú ìwé 11

    8/15/1993, ojú ìwé 12-17

    7/15/1993, ojú ìwé 13-14, 18-23

    Yiyan, ojú ìwé 188-190

2 Pétérù 1:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 9:25; 2Ti 2:24
  • +2Pe 2:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2003, ojú ìwé 13

    7/15/2002, ojú ìwé 10-14

    9/15/1993, ojú ìwé 9-19

    8/15/1993, ojú ìwé 17-22

    7/15/1993, ojú ìwé 13-14

    Yiyan, ojú ìwé 188, 189-190

2 Pétérù 1:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Tẹ 4:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2009, ojú ìwé 14

    10/15/1993, ojú ìwé 12-16, 17-22

    7/15/1993, ojú ìwé 13-14

    Yiyan, ojú ìwé 188, 190-191

2 Pétérù 1:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Tit 3:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/1997, ojú ìwé 11

    8/15/1993, ojú ìwé 17

    Yiyan, ojú ìwé 191

2 Pétérù 1:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “ó ti fọ́jú, kò ríran jìnnà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Jo 2:9; Ifi 3:17
  • +Heb 9:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/1997, ojú ìwé 11

2 Pétérù 1:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 3:1
  • +2Ti 4:7, 8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2016, ojú ìwé 16

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2012, ojú ìwé 21

    9/1/1997, ojú ìwé 11

    4/15/1993, ojú ìwé 28

2 Pétérù 1:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ní ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ àǹfààní láti wọlé.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 2:44
  • +Lk 16:9; Jo 3:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2016, ojú ìwé 16

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2012, ojú ìwé 21

    9/1/1997, ojú ìwé 11

2 Pétérù 1:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2003, ojú ìwé 10

    9/1/1997, ojú ìwé 11-12

2 Pétérù 1:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, ara tó ní lórí ilẹ̀ ayé.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 5:1
  • +Ro 15:15; Jud 5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/1997, ojú ìwé 11-12

2 Pétérù 1:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 21:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/1997, ojú ìwé 11-12

    7/15/1993, ojú ìwé 15

2 Pétérù 1:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “sọ̀rọ̀ nípa.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/1997, ojú ìwé 12

2 Pétérù 1:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 17:2; Mk 9:2; Lk 9:29

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 144

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/1997, ojú ìwé 12

    5/15/1997, ojú ìwé 9-11

    7/15/1993, ojú ìwé 15-16

    Yiyan, ojú ìwé 36-38

2 Pétérù 1:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “jẹ́ kó gbọ́ irú ohùn yìí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 2:7; Mt 17:1, 5; Mk 9:7; Lk 9:35

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 144

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/1997, ojú ìwé 12

    5/15/1997, ojú ìwé 9-11

    7/15/1995, ojú ìwé 19

    7/15/1993, ojú ìwé 15-16

    Yiyan, ojú ìwé 36, 37-38

2 Pétérù 1:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 144

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/1997, ojú ìwé 12

    5/15/1997, ojú ìwé 9-11

    7/15/1993, ojú ìwé 15-16

    Yiyan, ojú ìwé 36, 37-38

2 Pétérù 1:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 119:105; Jo 1:9
  • +Nọ 24:17; Ifi 22:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 144

    Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, ojú ìwé 1704

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2008, ojú ìwé 22

    1/15/2005, ojú ìwé 16

    5/15/2000, ojú ìwé 17

    4/1/2000, ojú ìwé 14-16

    9/1/1997, ojú ìwé 12-13

    5/15/1997, ojú ìwé 11

    7/15/1993, ojú ìwé 16

    2/1/1991, ojú ìwé 29

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 318

    Yiyan, ojú ìwé 38-40

2 Pétérù 1:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìtúmọ̀.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 7

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2011, ojú ìwé 11-12

    4/1/2000, ojú ìwé 16

    4/1/1998, ojú ìwé 19

    Yiyan, ojú ìwé 40

2 Pétérù 1:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “sún wọn; mú kí wọ́n gba ìmísí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ti 3:16
  • +2Sa 23:2; Iṣe 1:16; 28:25; 1Pe 1:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 5

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2019, ojú ìwé 9-10

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2012, ojú ìwé 25-26

    6/15/1997, ojú ìwé 5

    Yiyan, ojú ìwé 40

Àwọn míì

2 Pét. 1:2Kol 1:9
2 Pét. 1:3Jo 17:3
2 Pét. 1:4Lk 22:29, 30; Jo 14:2; Ga 3:29
2 Pét. 1:41Kọ 15:53; 1Pe 1:3, 4; 1Jo 3:2; Ifi 20:6
2 Pét. 1:5Flp 2:12; 2Ti 2:15; Heb 4:11; Jud 3
2 Pét. 1:5Flp 4:8
2 Pét. 1:5Jo 17:3; Heb 5:14
2 Pét. 1:61Kọ 9:25; 2Ti 2:24
2 Pét. 1:62Pe 2:9
2 Pét. 1:71Tẹ 4:9
2 Pét. 1:8Tit 3:14
2 Pét. 1:91Jo 2:9; Ifi 3:17
2 Pét. 1:9Heb 9:14
2 Pét. 1:10Heb 3:1
2 Pét. 1:102Ti 4:7, 8
2 Pét. 1:11Da 2:44
2 Pét. 1:11Lk 16:9; Jo 3:5
2 Pét. 1:132Kọ 5:1
2 Pét. 1:13Ro 15:15; Jud 5
2 Pét. 1:14Jo 21:18
2 Pét. 1:16Mt 17:2; Mk 9:2; Lk 9:29
2 Pét. 1:17Sm 2:7; Mt 17:1, 5; Mk 9:7; Lk 9:35
2 Pét. 1:19Sm 119:105; Jo 1:9
2 Pét. 1:19Nọ 24:17; Ifi 22:16
2 Pét. 1:212Ti 3:16
2 Pét. 1:212Sa 23:2; Iṣe 1:16; 28:25; 1Pe 1:11
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
2 Pétérù 1:1-21

Ìwé Kejì Pétérù

1 Símónì Pétérù, ẹrú àti àpọ́sítélì Jésù Kristi, sí ẹ̀yin tí ẹ ti ní irú ìgbàgbọ́ tó ṣeyebíye tí àwa náà ní,* nípasẹ̀ òdodo Ọlọ́run wa àti Jésù Kristi Olùgbàlà:

2 Kí ìmọ̀ tó péye + nípa Ọlọ́run àti Jésù Olúwa wa mú kí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí àti àlàáfíà pọ̀ sí i fún yín, 3 torí agbára rẹ̀ tó wá láti ọ̀run ti jẹ́ ká ní gbogbo ohun tó mú ká lè ní ìyè àti ìfọkànsìn Ọlọ́run* látinú ìmọ̀ tó péye nípa Ẹni tó fi ògo àti ìwà mímọ́ rẹ̀ pè wá.+ 4 Àwọn nǹkan yìí ló fi jẹ́ ká ní àwọn ìlérí tó ṣeyebíye, tó sì jẹ́ àgbàyanu gan-an,*+ kí ẹ lè tipasẹ̀ wọn nípìn-ín nínú àwọn ohun ti ọ̀run,+ nígbà tí ẹ ti bọ́ lọ́wọ́ ìwà ìbàjẹ́ ayé tí ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́* máa ń fà.

5 Nítorí èyí, ẹ sa gbogbo ipá yín+ láti fi ìwà mímọ́ kún ìgbàgbọ́ yín,+ ìmọ̀ kún ìwà mímọ́ yín,+ 6 ìkóra-ẹni-níjàánu kún ìmọ̀ yín, ìfaradà kún ìkóra-ẹni-níjàánu yín,+ ìfọkànsin Ọlọ́run+ kún ìfaradà yín, 7 ìfẹ́ ará kún ìfọkànsin Ọlọ́run yín, ìfẹ́ kún ìfẹ́ ará yín.+ 8 Torí bí àwọn nǹkan yìí bá wà nínú yín, tí ẹ sì ní wọn lọ́pọ̀lọpọ̀, wọn ò ní jẹ́ kí ẹ di aláìṣiṣẹ́ tàbí aláìléso+ ní ti ìmọ̀ tó péye nípa Olúwa wa Jésù Kristi.

9 Ẹnikẹ́ni tí kò bá ní àwọn nǹkan yìí jẹ́ afọ́jú, ó ti di ojú rẹ̀ sí ìmọ́lẹ̀,*+ ó sì ti gbàgbé pé a wẹ òun mọ́ kúrò nínú àwọn ẹ̀ṣẹ̀+ tó ti dá tipẹ́tipẹ́. 10 Torí náà, ẹ̀yin ará, ẹ túbọ̀ ṣe gbogbo ohun tí ẹ lè ṣe, kí pípè+ àti yíyàn yín lè dá yín lójú, torí tí ẹ bá ń ṣe àwọn nǹkan yìí, ẹ ò ní kùnà láé.+ 11 Ní tòótọ́, èyí á mú kí ẹ wọlé fàlàlà* sínú Ìjọba ayérayé+ ti Olúwa àti Olùgbàlà wa Jésù Kristi.+

12 Ìdí nìyí tó fi wù mí kí n máa rán yín létí àwọn nǹkan yìí nígbà gbogbo, bí ẹ tiẹ̀ mọ̀ wọ́n, tí ẹ sì fẹsẹ̀ múlẹ̀ ṣinṣin nínú òtítọ́ tó wà nínú yín. 13 Àmọ́ mo rí i pé ó dáa, tí mo bá ṣì wà nínú àgọ́* yìí,+ láti máa rán yín létí kí n lè ta yín jí,+ 14 bí mo ṣe mọ̀ pé màá tó bọ́ àgọ́ mi kúrò, bí Olúwa wa Jésù Kristi ṣe jẹ́ kí n mọ̀ kedere.+ 15 Màá ṣe gbogbo ohun tí mo lè ṣe nígbà gbogbo, kó lè jẹ́ pé lẹ́yìn tí mo bá lọ, ẹ̀yin fúnra yín á lè rántí* àwọn nǹkan yìí.

16 Ó dájú pé kì í ṣe àwọn ìtàn èké tí a dọ́gbọ́n hùmọ̀ la tẹ̀ lé nígbà tí a jẹ́ kí ẹ mọ agbára Olúwa wa Jésù Kristi àti ìgbà tó máa wà níhìn-ín, àmọ́ a fi ojú ara wa rí ọlá ńlá rẹ̀.+ 17 Torí ó gba ọlá àti ògo láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run tó jẹ́ Baba, nígbà tí ògo ọlá ńlá sọ irú ọ̀rọ̀ yìí fún un* pé: “Èyí ni Ọmọ mi, àyànfẹ́ mi, ẹni tí èmi fúnra mi tẹ́wọ́ gbà.”+ 18 Àní, ọ̀rọ̀ yìí la gbọ́ láti ọ̀run nígbà tí a wà pẹ̀lú rẹ̀ ní òkè mímọ́.

19 Torí náà, a ní ọ̀rọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ tí a mú kó túbọ̀ dá wa lójú, ẹ sì ń ṣe dáadáa bí ẹ ṣe ń fiyè sí i bíi fìtílà+ tó ń tàn níbi tó ṣókùnkùn (títí ilẹ̀ fi máa mọ́, tí ìràwọ̀ ojúmọ́+ sì máa yọ) nínú ọkàn yín. 20 Nítorí ẹ kọ́kọ́ mọ̀ pé, kò sí àsọtẹ́lẹ̀ kankan nínú Ìwé Mímọ́ tó wá látinú èrò* ara ẹni èyíkéyìí. 21 Torí a ò fìgbà kankan rí mú àsọtẹ́lẹ̀ wá nípasẹ̀ ìfẹ́ èèyàn,+ àmọ́ àwọn èèyàn sọ̀rọ̀ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run bí ẹ̀mí mímọ́ ṣe darí wọn.*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́