ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 23
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Sámúẹ́lì

      • Ọ̀rọ̀ tí Dáfídì sọ kẹ́yìn (1-7)

      • Ohun tí àwọn jagunjagun Dáfídì tó lákíkanjú gbé ṣe (8-39)

2 Sámúẹ́lì 23:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ẹni àrídunnú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 49:1; Di 33:1
  • +1Sa 17:58; Mt 1:6
  • +2Sa 7:8
  • +1Sa 16:13
  • +1Kr 16:9

2 Sámúẹ́lì 23:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mk 12:36; 2Ti 3:16
  • +Iṣe 1:16; 2Pe 1:21

2 Sámúẹ́lì 23:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:4; Sm 144:1
  • +Owe 29:2; Ais 9:7; 32:1
  • +Ẹk 18:21; Ais 11:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2009, ojú ìwé 14

    12/15/1995, ojú ìwé 26

2 Sámúẹ́lì 23:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mal 4:2; Mt 17:2; Ifi 1:16
  • +Sm 72:1, 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    12/15/1995, ojú ìwé 26

2 Sámúẹ́lì 23:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 7:16, 19; 1Kr 17:11; Sm 89:3, 28, 29; 132:11
  • +Ais 9:7; 11:1; Emọ 9:11

2 Sámúẹ́lì 23:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 37:10

2 Sámúẹ́lì 23:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 10:7; 20:7; 1Kr 11:10
  • +1Kr 11:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2005, ojú ìwé 10

2 Sámúẹ́lì 23:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 11:12-14
  • +1Kr 27:1, 4

2 Sámúẹ́lì 23:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìgbàlà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ond 8:4
  • +Ond 15:14, 16; 1Sa 14:6; 19:5

2 Sámúẹ́lì 23:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìgbàlà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 3:8; 44:3

2 Sámúẹ́lì 23:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ibùdó àgọ́.”

  • *

    Tàbí “Pẹ̀tẹ́lẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 15:20, 35; 1Sa 22:1
  • +Joṣ 15:1, 8; 2Sa 5:22; 1Kr 11:15-19

2 Sámúẹ́lì 23:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 22:1, 4; 1Kr 12:16

2 Sámúẹ́lì 23:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 9:9; 17:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run’, ojú ìwé 77

2 Sámúẹ́lì 23:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “fọkàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 9:4; Le 17:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run’, ojú ìwé 77

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2005, ojú ìwé 19

2 Sámúẹ́lì 23:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 26:6; 2Sa 21:17
  • +2Sa 2:18; 1Kr 2:15, 16
  • +1Kr 11:20, 21

2 Sámúẹ́lì 23:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ọmọ ọkùnrin kan tó lákíkanjú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 8:18; 20:23; 1Ọb 1:8; 2:29; 1Kr 27:5, 6
  • +Joṣ 15:21
  • +1Kr 11:22-25; Owe 30:30

2 Sámúẹ́lì 23:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 2:18, 23; 1Kr 2:15, 16; 27:1, 7
  • +1Kr 11:26-41

2 Sámúẹ́lì 23:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 27:1, 10
  • +1Kr 27:1, 9

2 Sámúẹ́lì 23:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 27:1, 12
  • +Joṣ 21:8, 18; Jer 1:1

2 Sámúẹ́lì 23:28

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 27:1, 13

2 Sámúẹ́lì 23:30

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 27:1, 14
  • +Ond 2:8, 9

2 Sámúẹ́lì 23:34

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 15:31; 16:23; 17:23; 1Kr 27:33

2 Sámúẹ́lì 23:38

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 2:53

2 Sámúẹ́lì 23:39

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 11:3; 1Ọb 15:5

Àwọn míì

2 Sám. 23:1Jẹ 49:1; Di 33:1
2 Sám. 23:11Sa 17:58; Mt 1:6
2 Sám. 23:12Sa 7:8
2 Sám. 23:11Sa 16:13
2 Sám. 23:11Kr 16:9
2 Sám. 23:2Mk 12:36; 2Ti 3:16
2 Sám. 23:2Iṣe 1:16; 2Pe 1:21
2 Sám. 23:3Di 32:4; Sm 144:1
2 Sám. 23:3Owe 29:2; Ais 9:7; 32:1
2 Sám. 23:3Ẹk 18:21; Ais 11:3
2 Sám. 23:4Mal 4:2; Mt 17:2; Ifi 1:16
2 Sám. 23:4Sm 72:1, 6
2 Sám. 23:52Sa 7:16, 19; 1Kr 17:11; Sm 89:3, 28, 29; 132:11
2 Sám. 23:5Ais 9:7; 11:1; Emọ 9:11
2 Sám. 23:6Sm 37:10
2 Sám. 23:82Sa 10:7; 20:7; 1Kr 11:10
2 Sám. 23:81Kr 11:11
2 Sám. 23:91Kr 11:12-14
2 Sám. 23:91Kr 27:1, 4
2 Sám. 23:10Ond 8:4
2 Sám. 23:10Ond 15:14, 16; 1Sa 14:6; 19:5
2 Sám. 23:12Sm 3:8; 44:3
2 Sám. 23:13Joṣ 15:20, 35; 1Sa 22:1
2 Sám. 23:13Joṣ 15:1, 8; 2Sa 5:22; 1Kr 11:15-19
2 Sám. 23:141Sa 22:1, 4; 1Kr 12:16
2 Sám. 23:16Le 9:9; 17:13
2 Sám. 23:17Jẹ 9:4; Le 17:10
2 Sám. 23:181Sa 26:6; 2Sa 21:17
2 Sám. 23:182Sa 2:18; 1Kr 2:15, 16
2 Sám. 23:181Kr 11:20, 21
2 Sám. 23:202Sa 8:18; 20:23; 1Ọb 1:8; 2:29; 1Kr 27:5, 6
2 Sám. 23:20Joṣ 15:21
2 Sám. 23:201Kr 11:22-25; Owe 30:30
2 Sám. 23:242Sa 2:18, 23; 1Kr 2:15, 16; 27:1, 7
2 Sám. 23:241Kr 11:26-41
2 Sám. 23:261Kr 27:1, 10
2 Sám. 23:261Kr 27:1, 9
2 Sám. 23:271Kr 27:1, 12
2 Sám. 23:27Joṣ 21:8, 18; Jer 1:1
2 Sám. 23:281Kr 27:1, 13
2 Sám. 23:301Kr 27:1, 14
2 Sám. 23:30Ond 2:8, 9
2 Sám. 23:342Sa 15:31; 16:23; 17:23; 1Kr 27:33
2 Sám. 23:381Kr 2:53
2 Sám. 23:392Sa 11:3; 1Ọb 15:5
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
  • 32
  • 33
  • 34
  • 35
  • 36
  • 37
  • 38
  • 39
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
2 Sámúẹ́lì 23:1-39

Sámúẹ́lì Kejì

23 Ọ̀rọ̀ tí Dáfídì sọ kẹ́yìn nìyí:+

“Ọ̀rọ̀ Dáfídì ọmọ Jésè,+

Àti ọ̀rọ̀ ọkùnrin tí a gbé ga,+

Ẹni àmì òróró+ Ọlọ́run Jékọ́bù,

Olórin ìtura* tó ń kọ àwọn orin Ísírẹ́lì.+

 2 Ẹ̀mí Jèhófà gba ẹnu mi sọ̀rọ̀;+

Ọ̀rọ̀ rẹ̀ wà lórí ahọ́n mi.+

 3 Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ̀rọ̀;

Àpáta Ísírẹ́lì+ sọ fún mi pé:

‘Nígbà tí ẹni tó ń ṣàkóso aráyé bá jẹ́ olódodo,+

Tó ń fi ìbẹ̀rù Ọlọ́run ṣàkóso,+

 4 Á dà bí ìmọ́lẹ̀ òwúrọ̀ nígbà tí oòrùn yọ,+

Tí ojúmọ́ mọ́, tí kò sí ìkùukùu.

Bí ìmọ́lẹ̀ tó yọ lẹ́yìn tí òjò dá,

Tó ń mú kí ewéko yọ láti inú ilẹ̀.’+

 5 Ǹjẹ́ kì í ṣe bí ilé mi ṣe rí nìyẹn lójú Ọlọ́run?

Torí ó ti bá mi dá májẹ̀mú ayérayé,+

Tó wà létòlétò, tó sì wà lábẹ́ ààbò.

Nítorí ó jẹ́ ìgbàlà mi látòkèdélẹ̀ àti gbogbo ìdùnnú mi,

Ǹjẹ́ kì í ṣe ìdí tó fi ń mú kó gbilẹ̀+ nìyẹn?

 6 Àmọ́ a kó àwọn aláìníláárí dà nù+ bí igi ẹlẹ́gùn-ún,

Nítorí a kò lè fi ọwọ́ mú wọn.

 7 Kí ẹnì kan tó lè fọwọ́ kàn wọ́n,

Ó ní láti gbára dì, kí ó ní irin àti ọ̀kọ̀ lọ́wọ́,

Ó sì gbọ́dọ̀ dáná sun wọ́n pátápátá ní ibi tí wọ́n wà.”

8 Orúkọ àwọn jagunjagun Dáfídì tó lákíkanjú+ nìyí: Joṣebi-báṣébétì tó jẹ́ Tákímónì, olórí àwọn mẹ́ta náà.+ Ìgbà kan wà tó fi ọ̀kọ̀ rẹ̀ pa ọgọ́rùn-ún mẹ́jọ (800) ọkùnrin. 9 Ẹni tí ó tẹ̀ lé e ni Élíásárì+ ọmọ Dódò+ ọmọ Áhóhì, ó wà lára àwọn jagunjagun mẹ́ta tó lákíkanjú tó wà pẹ̀lú Dáfídì nígbà tí wọ́n pe àwọn Filísínì níjà. Wọ́n ti kóra jọ láti jagun níbẹ̀, nígbà tí àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì sá pa dà, 10 ó dúró, ó sì ń pa àwọn Filísínì, títí apá fi ń ro ó, tí ọwọ́ rẹ̀ sì gan nítorí idà tó dì mú.+ Torí náà, Jèhófà mú kí ìṣẹ́gun* ńlá wáyé ní ọjọ́ yẹn;+ àwọn èèyàn náà pa dà sẹ́yìn rẹ̀ láti wá bọ́ nǹkan kúrò lára àwọn tí ó ti pa.

11 Ẹni tí ó tẹ̀ lé e sì ni Ṣámà ọmọ Ágéè tó jẹ́ Hárárì. Àwọn Filísínì kóra jọ sí Léhì, sórí ilẹ̀ kan tí ẹ̀wà lẹ́ńtìlì pọ̀ sí; àwọn èèyàn náà sì sá nítorí àwọn Filísínì. 12 Àmọ́ ó dúró ní àárín ilẹ̀ náà, kò jẹ́ kí wọ́n gbà á, ó sì ń pa àwọn Filísínì náà, tó fi jẹ́ pé Jèhófà mú kí ìṣẹ́gun*+ ńlá wáyé.

13 Mẹ́ta lára ọgbọ̀n (30) ọkùnrin tó jẹ́ olórí lọ sọ́dọ̀ Dáfídì lásìkò ìkórè nígbà tó wà nínú ihò àpáta ní Ádúlámù,+ àwùjọ* àwọn Filísínì sì pàgọ́ sí Àfonífojì* Réfáímù.+ 14 Nígbà yẹn, Dáfídì wà ní ibi ààbò,+ àwùjọ ọmọ ogun Filísínì tó wà ní àdádó sì wà ní Bẹ́tílẹ́hẹ́mù. 15 Lẹ́yìn náà, Dáfídì sọ ohun tó ń wù ú, ó ní: “Ì bá dára ká ní mo lè rí omi mu láti inú kòtò omi tó wà ní ẹnubodè Bẹ́tílẹ́hẹ́mù!” 16 Ni àwọn jagunjagun mẹ́ta tó lákíkanjú náà bá fipá wọnú ibùdó àwọn Filísínì, wọ́n fa omi láti inú kòtò omi tó wà ní ẹnubodè Bẹ́tílẹ́hẹ́mù, wọ́n sì gbé e wá fún Dáfídì; àmọ́ ó kọ̀, kò mu ún, ńṣe ló dà á jáde fún Jèhófà.+ 17 Ó sọ pé: “Jèhófà, kò ṣeé gbọ́ sétí pé mo ṣe nǹkan yìí! Ṣé ó yẹ kí n mu ẹ̀jẹ̀+ àwọn ọkùnrin tó fẹ̀mí* ara wọn wewu yìí?” Torí náà, ó kọ̀, kò mu ún. Àwọn ohun tí àwọn jagunjagun rẹ̀ mẹ́ta tó lákíkanjú ṣe nìyẹn.

18 Ábíṣáì+ ẹ̀gbọ́n Jóábù ọmọ Seruáyà+ ni olórí àwọn mẹ́ta míì; ó fi ọ̀kọ̀ rẹ̀ pa ọgọ́rùn-ún mẹ́ta (300), òun náà sì lórúkọ bí àwọn mẹ́ta àkọ́kọ́.+ 19 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé òun ló ta yọ jù láàárín àwọn mẹ́ta kejì, tó sì jẹ́ olórí wọn, kò wọ ẹgbẹ́ àwọn mẹ́ta àkọ́kọ́.

20 Bẹnáyà+ ọmọ Jèhóádà jẹ́ akíkanjú ọkùnrin* tó gbé ọ̀pọ̀ nǹkan ṣe ní Kábúséélì.+ Ó pa àwọn ọmọkùnrin méjèèjì tí Áríélì ará Móábù bí, ó wọ inú kòtò omi lọ́jọ́ kan tí yìnyín bolẹ̀, ó sì pa kìnnìún.+ 21 Ó tún mú ọkùnrin ará Íjíbítì kan tó tóbi fàkìàfakia balẹ̀. Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ọ̀kọ̀ wà ní ọwọ́ ará Íjíbítì náà, ó fi ọ̀pá bá a jà, ó já ọ̀kọ̀ náà gbà ní ọwọ́ ará Íjíbítì náà, ó sì fi ọ̀kọ̀ òun fúnra rẹ̀ pa á. 22 Àwọn ohun tí Bẹnáyà ọmọ Jèhóádà ṣe nìyẹn, ó lórúkọ bí àwọn akíkanjú jagunjagun mẹ́ta náà. 23 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ta yọ ju àwọn ọgbọ̀n (30) náà, kò wọ ẹgbẹ́ àwọn mẹ́ta àkọ́kọ́. Àmọ́ Dáfídì yàn án ṣe olórí àwọn ẹ̀ṣọ́ rẹ̀.

24 Ásáhélì+ arákùnrin Jóábù wà lára àwọn ọgbọ̀n (30) náà, àwọn ni: Élíhánánì ọmọ Dódò ará Bẹ́tílẹ́hẹ́mù,+ 25 Ṣámà ará Háródù, Élíkà ará Háródù, 26 Hélésì+ tó jẹ́ Pálútì, Írà+ ọmọ Íkéṣì ará Tékóà, 27 Abi-ésérì+ ọmọ Ánátótì,+ Mébúnáì ọmọ Húṣà, 28 Sálímónì ọmọ Áhóhì, Máháráì+ ará Nétófà, 29 Hélébù ọmọ Báánà ará Nétófà, Ítáì ọmọ Ríbáì ará Gíbíà ti àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì, 30 Bẹnáyà+ ará Pírátónì, Hídáì tó wá láti àwọn àfonífojì Gááṣì,+ 31 Abi-álíbónì tó jẹ́ Ábátì, Ásímáfẹ́tì ará Báhúmù, 32 Élíábà tó jẹ́ Ṣáálíbónì, àwọn ọmọ Jáṣénì, Jónátánì, 33 Ṣámà tó jẹ́ Hárárì, Áhíámù ọmọ Ṣárárì tó jẹ́ Hárárì, 34 Élífélétì ọmọ Áhásíbáì ọmọ ará Máákátì, Élíámù ọmọ Áhítófẹ́lì+ ará Gílò, 35 Hésírò ará Kámẹ́lì, Pááráì ará Árábù, 36 Ígálì ọmọ Nátánì ará Sóbà, Bánì ọmọ Gádì, 37 Sélékì ọmọ Ámónì, Náháráì ará Béérótì, tó ń bá Jóábù ọmọ Seruáyà gbé ìhámọ́ra, 38 Írà tó jẹ́ Ítírì, Gárébù tó jẹ́ Ítírì,+ 39 Ùráyà+ ọmọ Hétì, gbogbo wọn jẹ́ mẹ́tàdínlógójì (37).

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́