ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kọ́ríńtì 10
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Kọ́ríńtì

      • Àpẹẹrẹ ìkìlọ̀ látinú ìtàn àwọn ọmọ Ísírẹ́lì (1-13)

      • Àpẹẹrẹ ìkìlọ̀ nípa ìbọ̀rìṣà (14-22)

        • Tábìlì Jèhófà àti tábìlì àwọn ẹ̀mí èṣù (21)

      • Òmìnira àti gbígba tàwọn ẹlòmíì rò (23-33)

        • “Ẹ máa ṣe ohun gbogbo fún ògo Ọlọ́run” (31)

1 Kọ́ríńtì 10:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọsánmà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 13:21
  • +Ẹk 14:21, 22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2001, ojú ìwé 14

1 Kọ́ríńtì 10:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọsánmà.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2001, ojú ìwé 14

1 Kọ́ríńtì 10:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 16:14, 15

1 Kọ́ríńtì 10:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “sì ni.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 17:6
  • +Nọ 20:11; Jo 4:10, 25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 50

1 Kọ́ríńtì 10:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 14:29, 35

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2001, ojú ìwé 14

1 Kọ́ríńtì 10:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 11:4, 34

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2010, ojú ìwé 27

    6/15/2001, ojú ìwé 14

    5/15/1999, ojú ìwé 16-17

    3/1/1995, ojú ìwé 16

1 Kọ́ríńtì 10:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 32:4, 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2010, ojú ìwé 27

    6/15/2001, ojú ìwé 15-16

    5/15/1999, ojú ìwé 16-17

    3/1/1995, ojú ìwé 16

1 Kọ́ríńtì 10:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

  • *

    Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 25:1, 9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run’, ojú ìwé 97-98

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2010, ojú ìwé 27

    4/1/2004, ojú ìwé 29

    6/15/2001, ojú ìwé 16-17

    5/15/1999, ojú ìwé 16-17

    3/1/1995, ojú ìwé 16-17

    7/15/1992, ojú ìwé 4-5

1 Kọ́ríńtì 10:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 6:16
  • +Nọ 21:5, 6; Mt 4:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2010, ojú ìwé 27

    6/15/2001, ojú ìwé 17

    3/1/1995, ojú ìwé 17

1 Kọ́ríńtì 10:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 14:2
  • +Nọ 14:36, 37

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2010, ojú ìwé 27

    6/15/2001, ojú ìwé 17

    3/1/1995, ojú ìwé 17

1 Kọ́ríńtì 10:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 15:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/15/1996, ojú ìwé 17-22

1 Kọ́ríńtì 10:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 28:14; Lk 22:33, 34; Ga 6:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2001, ojú ìwé 11-12

1 Kọ́ríńtì 10:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 5:8, 9
  • +Lk 22:31, 32; 2Pe 2:9
  • +Ais 40:29; Flp 4:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    4/2019, ojú ìwé 3

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    2/2017, ojú ìwé 29-30

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2016, ojú ìwé 10-11

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2015, ojú ìwé 26

    4/15/2014, ojú ìwé 21

    4/15/2012, ojú ìwé 27

    11/15/2010, ojú ìwé 27-28

    5/15/2009, ojú ìwé 22

    3/15/2008, ojú ìwé 13

    3/15/2001, ojú ìwé 11-12, 13-14

    6/15/1996, ojú ìwé 11

    10/1/1991, ojú ìwé 10-11

    Ṣọ́nà!, ojú ìwé 26

1 Kọ́ríńtì 10:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 4:25, 26; 2Kọ 6:17; 1Jo 5:21

1 Kọ́ríńtì 10:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 26:27, 28
  • +Mt 26:26; Lk 22:19; 1Kọ 12:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2006, ojú ìwé 22-24

1 Kọ́ríńtì 10:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 12:5

1 Kọ́ríńtì 10:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 7:15

1 Kọ́ríńtì 10:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:17
  • +Jud 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2004, ojú ìwé 5

    1/15/1993, ojú ìwé 22-24

1 Kọ́ríńtì 10:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 41:22; Mal 1:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 24

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2019, ojú ìwé 30

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    7/1/1994, ojú ìwé 8-13

1 Kọ́ríńtì 10:22

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 34:14; Di 32:21

1 Kọ́ríńtì 10:23

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “làyè gbà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 14:19; 15:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 35

    ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run’, ojú ìwé 72-73

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/1998, ojú ìwé 20

1 Kọ́ríńtì 10:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 10:32, 33; 13:4, 5; Flp 2:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 35

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2017, ojú ìwé 11

    ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run’, ojú ìwé 72-73

    Jọ́sìn Ọlọ́run, ojú ìwé 140-141

1 Kọ́ríńtì 10:25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2010, ojú ìwé 12

    10/15/1992, ojú ìwé 30

1 Kọ́ríńtì 10:26

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 24:1; 1Ti 4:4

1 Kọ́ríńtì 10:28

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 8:7, 10

1 Kọ́ríńtì 10:29

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 14:15, 16; 1Kọ 8:12

1 Kọ́ríńtì 10:30

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 14:6; 1Ti 4:3

1 Kọ́ríńtì 10:31

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 5:16; Kol 3:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 43

1 Kọ́ríńtì 10:32

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 14:13; 1Kọ 8:13; 2Kọ 6:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 43

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2007, ojú ìwé 22

    9/1/1992, ojú ìwé 21-22

    Jọ́sìn Ọlọ́run, ojú ìwé 140-141

1 Kọ́ríńtì 10:33

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 15:2; Flp 2:4
  • +1Kọ 9:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 52

Àwọn míì

1 Kọ́r. 10:1Ẹk 13:21
1 Kọ́r. 10:1Ẹk 14:21, 22
1 Kọ́r. 10:3Ẹk 16:14, 15
1 Kọ́r. 10:4Ẹk 17:6
1 Kọ́r. 10:4Nọ 20:11; Jo 4:10, 25
1 Kọ́r. 10:5Nọ 14:29, 35
1 Kọ́r. 10:6Nọ 11:4, 34
1 Kọ́r. 10:7Ẹk 32:4, 6
1 Kọ́r. 10:8Nọ 25:1, 9
1 Kọ́r. 10:9Di 6:16
1 Kọ́r. 10:9Nọ 21:5, 6; Mt 4:7
1 Kọ́r. 10:10Nọ 14:2
1 Kọ́r. 10:10Nọ 14:36, 37
1 Kọ́r. 10:11Ro 15:4
1 Kọ́r. 10:12Owe 28:14; Lk 22:33, 34; Ga 6:1
1 Kọ́r. 10:131Pe 5:8, 9
1 Kọ́r. 10:13Lk 22:31, 32; 2Pe 2:9
1 Kọ́r. 10:13Ais 40:29; Flp 4:13
1 Kọ́r. 10:14Di 4:25, 26; 2Kọ 6:17; 1Jo 5:21
1 Kọ́r. 10:16Mt 26:27, 28
1 Kọ́r. 10:16Mt 26:26; Lk 22:19; 1Kọ 12:18
1 Kọ́r. 10:17Ro 12:5
1 Kọ́r. 10:18Le 7:15
1 Kọ́r. 10:20Di 32:17
1 Kọ́r. 10:20Jud 6
1 Kọ́r. 10:21Isk 41:22; Mal 1:12
1 Kọ́r. 10:22Ẹk 34:14; Di 32:21
1 Kọ́r. 10:23Ro 14:19; 15:2
1 Kọ́r. 10:241Kọ 10:32, 33; 13:4, 5; Flp 2:4
1 Kọ́r. 10:26Sm 24:1; 1Ti 4:4
1 Kọ́r. 10:281Kọ 8:7, 10
1 Kọ́r. 10:29Ro 14:15, 16; 1Kọ 8:12
1 Kọ́r. 10:30Ro 14:6; 1Ti 4:3
1 Kọ́r. 10:31Mt 5:16; Kol 3:17
1 Kọ́r. 10:32Ro 14:13; 1Kọ 8:13; 2Kọ 6:3
1 Kọ́r. 10:33Ro 15:2; Flp 2:4
1 Kọ́r. 10:331Kọ 9:22
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
  • 32
  • 33
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Kọ́ríńtì 10:1-33

Ìwé Kìíní sí Àwọn Ará Kọ́ríńtì

10 Ní báyìí, ẹ̀yin ará, mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé gbogbo àwọn baba ńlá wa wà lábẹ́ ìkùukùu,*+ gbogbo wọn gba inú òkun kọjá,+ 2 a sì batisí gbogbo wọn láti jẹ́ ọmọlẹ́yìn Mósè nípasẹ̀ ìkùukùu* àti òkun, 3 gbogbo wọn jẹ oúnjẹ tẹ̀mí+ kan náà, 4 gbogbo wọn sì mu ohun mímu tẹ̀mí+ kan náà. Torí wọ́n ti máa ń mu látinú àpáta tẹ̀mí tó ń tẹ̀ lé wọn, àpáta náà sì dúró fún* Kristi.+ 5 Síbẹ̀, a pa wọ́n nínú aginjù+ nítorí inú Ọlọ́run kò dùn sí èyí tó pọ̀ jù lára wọn.

6 Àwọn nǹkan yìí di àpẹẹrẹ fún wa, kí àwọn ohun tó ń ṣeni léṣe má bàa máa wu àwa náà, bó ṣe wù wọ́n.+ 7 Bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ má ṣe di abọ̀rìṣà, bí àwọn kan nínú wọn ti ṣe; gẹ́gẹ́ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Àwọn èèyàn náà jókòó láti jẹ àti láti mu. Wọ́n sì dìde láti gbádùn ara wọn.”+ 8 Bákan náà, kí a má ṣe ìṣekúṣe,* bí àwọn kan nínú wọn ti ṣe ìṣekúṣe,* tí ẹgbẹ̀rún mẹ́tàlélógún (23,000) lára wọn fi kú ní ọjọ́ kan ṣoṣo.+ 9 Bẹ́ẹ̀ ni kí a má ṣe dán Jèhófà* wò,+ bí àwọn kan nínú wọn ṣe dán an wò, tí ejò sì ṣán wọn pa.+ 10 Bákan náà, kí ẹ má ṣe máa kùn, bí àwọn kan nínú wọn ṣe kùn,+ tí apanirun sì pa wọ́n.+ 11 Àwọn nǹkan yìí ṣẹlẹ̀ sí wọn kí ó lè jẹ́ àpẹẹrẹ fún wa,+ wọ́n sì wà lákọsílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìkìlọ̀ fún àwa tí òpin àwọn ètò àwọn nǹkan dé bá.

12 Nítorí náà, kí ẹni tó bá rò pé òun dúró kíyè sára kó má bàa ṣubú.+ 13 Kò sí àdánwò kankan tó ti bá yín àfi èyí tó máa ń ṣẹlẹ̀ sí àwọn èèyàn.+ Àmọ́ Ọlọ́run jẹ́ olóòótọ́, kò ní jẹ́ kí a dán yín wò kọjá ohun tí ẹ lè mú mọ́ra,+ ṣùgbọ́n nínú àdánwò náà, yóò ṣe ọ̀nà àbáyọ kí ẹ lè fara dà á.+

14 Nítorí náà, ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, ẹ sá fún ìbọ̀rìṣà.+ 15 Mo mọ̀ pé ẹ ní òye; ẹ fúnra yín pinnu lórí ohun tí mo sọ bóyá òótọ́ ni àbí irọ́. 16 Ife ìbùkún tí a súre sí, ṣebí láti pín nínú ẹ̀jẹ̀ Kristi ni?+ Ìṣù búrẹ́dì tí a bù, ṣebí láti pín nínú ara Kristi ni?+ 17 Nítorí pé ìṣù búrẹ́dì kan ló wà, àwa, bí a tilẹ̀ pọ̀, a jẹ́ ara kan,+ torí gbogbo wa ló ń jẹ nínú ìṣù búrẹ́dì kan yẹn.

18 Ẹ wo Ísírẹ́lì lọ́nà ti ara: Ǹjẹ́ àwọn tó ń jẹ ohun tí a fi rúbọ kì í ṣe alájọpín pẹ̀lú pẹpẹ?+ 19 Kí ni mo wá ń sọ? Ṣé pé ohun tí a fi rúbọ sí òrìṣà jẹ́ nǹkan kan tàbí pé òrìṣà jẹ́ nǹkan kan ni? 20 Bẹ́ẹ̀ kọ́; àmọ́ ohun tí mò ń sọ ni pé àwọn nǹkan tí àwọn orílẹ̀-èdè fi ń rúbọ, àwọn ẹ̀mí èṣù ni wọ́n fi ń rúbọ sí, kì í ṣe Ọlọ́run;+ mi ò sì fẹ́ kí ẹ di alájọpín pẹ̀lú àwọn ẹ̀mí èṣù.+ 21 Ẹ ò lè máa mu nínú ife Jèhófà* àti ife àwọn ẹ̀mí èṣù; ẹ ò lè máa jẹun lórí “tábìlì Jèhófà”*+ àti tábìlì àwọn ẹ̀mí èṣù. 22 Àbí ‘ṣé a fẹ́ máa mú Jèhófà* jowú ni’?+ A ò lágbára jù ú lọ, àbí a ní?

23 Ohun gbogbo ló bófin mu,* àmọ́ kì í ṣe ohun gbogbo ló ṣàǹfààní. Ohun gbogbo ló bófin mu, àmọ́ kì í ṣe ohun gbogbo ló ń gbéni ró.+ 24 Kí kálukú máa wá ire ti ẹlòmíì, kì í ṣe ti ara rẹ̀.+

25 Ẹ máa jẹ ohunkóhun tí wọ́n ń tà ní ọjà ẹran, láìṣe ìwádìí kankan kí ẹ̀rí ọkàn yín má bàa dà yín láàmú, 26 nítorí pé “Jèhófà* ló ni ayé àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀.”+ 27 Tí aláìgbàgbọ́ bá pè yín, tí ẹ sì fẹ́ lọ, ẹ jẹ ohunkóhun tó bá gbé síwájú yín, láìṣe ìwádìí kankan kí ẹ̀rí ọkàn yín má bàa dà yín láàmú. 28 Àmọ́ tí ẹnikẹ́ni bá sọ fún yín pé, “Ohun tí a fi rúbọ ni,” ẹ má ṣe jẹ ẹ́ nítorí ẹni tó sọ fún yín àti nítorí ẹ̀rí ọkàn.+ 29 Kì í ṣe ẹ̀rí ọkàn yín ni mò ń sọ, ti ẹni yẹn ni. Kí nìdí tí màá fi jẹ́ kí ẹnì kan fi ẹ̀rí ọkàn rẹ̀ dá mi lẹ́jọ́ lórí ohun tí mo lómìnira láti ṣe?+ 30 Tí mo bá ń jẹ ẹ́, tí mo sì ń dúpẹ́, kí nìdí tí a ó fi máa sọ̀rọ̀ mi láìdáa nítorí ohun tí mo dúpẹ́ lé lórí?+

31 Nítorí náà, bóyá ẹ̀ ń jẹ tàbí ẹ̀ ń mu tàbí ẹ̀ ń ṣe ohunkóhun míì, ẹ máa ṣe ohun gbogbo fún ògo Ọlọ́run.+ 32 Ẹ máa ṣọ́ra kí ẹ má bàa di ohun ìkọ̀sẹ̀ fún àwọn Júù àti àwọn Gíríìkì àti fún ìjọ Ọlọ́run,+ 33 bí mo ṣe ń gbìyànjú láti wu gbogbo èèyàn nínú ohun gbogbo, láìmáa wá ire ti ara mi+ bí kò ṣe ti ọ̀pọ̀ èèyàn, kí wọ́n lè rí ìgbàlà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́