Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
May 8, 2000
Ayé Tí a Mú Ṣọ̀kan—Ṣé Ilẹ̀ Yúróòpù Ló Ti Máa Bẹ̀rẹ̀ Ni?
Nínú ayé kan tó pín yẹ́lẹyẹ̀lẹ, ìròyìn ńlá ni ọ̀ràn nípa ìṣọ̀kan ilẹ̀ Yúróòpù jẹ́. Ṣùgbọ́n báwo ni ìrètí nípa ìṣọ̀kan ilẹ̀ Yúróòpù ti jẹ́ gidi tó? Ìrètí gidi kan ha wà fún ìṣọ̀kan àgbáyé bí?
3 Ìṣọ̀kan Ilẹ̀ Yúróòpù—Ṣe Nǹkan Pàtàkì Ni?
5 Ṣé Ilẹ̀ Yúróòpù Lè Ṣọ̀kan Lóòótọ́?
12 Ìròyìn Orí Tẹlifíṣọ̀n—Mélòó Ló Jẹ́ Ìròyìn Gidi?
18 “Ìjà Ogun Náà Kì í Ṣe Tiyín, Bí Kò Ṣe Ti Ọlọ́run”
25 Ẹ̀kọ́ Wo Lẹlẹ́wọ̀n Lè Rí Kọ́ Lára Ẹyẹ?
28 Wíwo Ayé
31 Àrùn Éèdì Ní Áfíríkà—Àyípadà Rere Wo Ni Ẹgbẹ̀rúndún Tuntun Fẹ́ Mú Wá?
32 “Ìwé Atọ́nà Tó Ń Sọ̀rọ̀ Síbi Tọ́rọ̀ Wà, Tó sì Gbéṣẹ́”
Ṣé Kéèyàn Bímọ La Fi Ń Mọ̀ Pọ́kùnrin Ni? 13
Ọ̀pọ̀ ọ̀dọ́ lónìí ló ń rò bẹ́ẹ̀. Ṣùgbọ́n kí la fi ń mọ̀ pọ́kùnrin lẹnì kan?
Kò sí èèyàn tí kì í sọ̀rètí nù. Báwo ni Bíbélì ṣe lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti kápá ìmọ̀lára àìnírètí tó le gan-an?