ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 43
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Jèhófà pa dà kó àwọn èèyàn rẹ̀ jọ (1-7)

      • Kí àwọn ọlọ́run gbèjà ara wọn (8-13)

        • “Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí mi” (10, 12)

      • Wọ́n máa tú wọn sílẹ̀ láti Bábílónì (14-21)

      • “Jẹ́ ká gbé ẹjọ́ wa wá” (22-28)

Àìsáyà 43:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 100:3; Ais 43:15; 44:2, 21
  • +Ais 44:23; Jer 50:34

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 46-48

Àìsáyà 43:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 14:29
  • +Joṣ 3:15, 16; 2Ọb 2:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2019, ojú ìwé 3-4

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 47-48

Àìsáyà 43:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 48-49

Àìsáyà 43:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 19:5, 6
  • +Di 7:8; Jer 31:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2019, ojú ìwé 3

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 48-50

Àìsáyà 43:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “èso.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 41:10; 44:2; Jer 30:10
  • +Di 30:1-3; Sm 106:47; Ais 66:20; Isk 36:24; Mik 2:12; Sek 8:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 50

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1994, ojú ìwé 3-4

Àìsáyà 43:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 3:18
  • +Jer 31:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 50

Àìsáyà 43:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 33:16
  • +Sm 100:3; Ais 29:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 50

Àìsáyà 43:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 6:9, 10; 42:18, 19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 46-47

Àìsáyà 43:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ àwọn ohun tó máa kọ́kọ́ ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 41:1
  • +Ais 41:21, 22; 44:7
  • +1Ọb 18:24, 25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 51-53

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/15/1993, ojú ìwé 21-22

Àìsáyà 43:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “gbẹ́kẹ̀ lé mi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 1:8; Ifi 1:5
  • +Di 4:37
  • +Ais 41:4
  • +Ais 44:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 19

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2014, ojú ìwé 21-22

    9/1/1995, ojú ìwé 9-10, 12-13, 17

    7/1/1995, ojú ìwé 17

    5/15/1995, ojú ìwé 19

    1/15/1993, ojú ìwé 21-22

    1/15/1992, ojú ìwé 22

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 51-54

    Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà, ojú ìwé 5

Àìsáyà 43:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 6:4
  • +Ais 12:2; Ho 13:4; 1Ti 2:3; Jud 25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 51-54

Àìsáyà 43:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:12
  • +Ais 46:9, 10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2014, ojú ìwé 21-22

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 51-54

Àìsáyà 43:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 41:4; Ifi 1:8
  • +Di 32:39
  • +Ais 14:27; Da 4:35

Àìsáyà 43:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 44:6; 63:16
  • +Ais 54:5
  • +Ais 45:1, 2
  • +Jer 50:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 54-55

Àìsáyà 43:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 89:18
  • +Ais 43:1
  • +Di 33:5; Sm 74:12; Ais 33:22; Ifi 11:17

Àìsáyà 43:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 14:16; Joṣ 3:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 54-55

Àìsáyà 43:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 15:4
  • +Jer 51:39

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 54-55

Àìsáyà 43:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2007, ojú ìwé 9

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 55-56

Àìsáyà 43:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 42:9
  • +Ais 11:16; 40:3
  • +Ais 41:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 55-57, 60

Àìsáyà 43:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “akátá.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 41:17; Jer 31:9
  • +Sm 33:12; Ais 41:8; 1Pe 2:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 55-57

Àìsáyà 43:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 60:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    7/1/1995, ojú ìwé 17, 19

Àìsáyà 43:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 64:7
  • +Jer 2:5; Ho 7:10; Mik 6:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 57, 59

Àìsáyà 43:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 66:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 57-59

Àìsáyà 43:24

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Esùsú tó ń ta sánsán.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 3:14-16
  • +Ais 1:14, 15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 57-59

Àìsáyà 43:25

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìwà ọ̀tẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 1:18; Jer 50:20
  • +Sm 25:7; 79:8, 9; Isk 20:9
  • +Jer 31:34

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2007, ojú ìwé 10

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 59-60

Àìsáyà 43:26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 59-60

Àìsáyà 43:27

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ àwọn olùkọ́ Òfin ló ń tọ́ka sí.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 28:7; Jer 5:31

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 59-60

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 58

Àìsáyà 43:28

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 79:4; 137:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 59-60

Àwọn míì

Àìsá. 43:1Sm 100:3; Ais 43:15; 44:2, 21
Àìsá. 43:1Ais 44:23; Jer 50:34
Àìsá. 43:2Ẹk 14:29
Àìsá. 43:2Joṣ 3:15, 16; 2Ọb 2:8
Àìsá. 43:4Ẹk 19:5, 6
Àìsá. 43:4Di 7:8; Jer 31:3
Àìsá. 43:5Ais 41:10; 44:2; Jer 30:10
Àìsá. 43:5Di 30:1-3; Sm 106:47; Ais 66:20; Isk 36:24; Mik 2:12; Sek 8:7
Àìsá. 43:6Jer 3:18
Àìsá. 43:6Jer 31:8
Àìsá. 43:7Jer 33:16
Àìsá. 43:7Sm 100:3; Ais 29:23
Àìsá. 43:8Ais 6:9, 10; 42:18, 19
Àìsá. 43:9Ais 41:1
Àìsá. 43:9Ais 41:21, 22; 44:7
Àìsá. 43:91Ọb 18:24, 25
Àìsá. 43:10Iṣe 1:8; Ifi 1:5
Àìsá. 43:10Di 4:37
Àìsá. 43:10Ais 41:4
Àìsá. 43:10Ais 44:8
Àìsá. 43:11Di 6:4
Àìsá. 43:11Ais 12:2; Ho 13:4; 1Ti 2:3; Jud 25
Àìsá. 43:12Di 32:12
Àìsá. 43:12Ais 46:9, 10
Àìsá. 43:13Ais 41:4; Ifi 1:8
Àìsá. 43:13Di 32:39
Àìsá. 43:13Ais 14:27; Da 4:35
Àìsá. 43:14Ais 44:6; 63:16
Àìsá. 43:14Ais 54:5
Àìsá. 43:14Ais 45:1, 2
Àìsá. 43:14Jer 50:10
Àìsá. 43:15Sm 89:18
Àìsá. 43:15Ais 43:1
Àìsá. 43:15Di 33:5; Sm 74:12; Ais 33:22; Ifi 11:17
Àìsá. 43:16Ẹk 14:16; Joṣ 3:13
Àìsá. 43:17Ẹk 15:4
Àìsá. 43:17Jer 51:39
Àìsá. 43:19Ais 42:9
Àìsá. 43:19Ais 11:16; 40:3
Àìsá. 43:19Ais 41:18
Àìsá. 43:20Ais 41:17; Jer 31:9
Àìsá. 43:20Sm 33:12; Ais 41:8; 1Pe 2:9
Àìsá. 43:21Ais 60:21
Àìsá. 43:22Ais 64:7
Àìsá. 43:22Jer 2:5; Ho 7:10; Mik 6:3
Àìsá. 43:23Ais 66:3
Àìsá. 43:24Le 3:14-16
Àìsá. 43:24Ais 1:14, 15
Àìsá. 43:25Ais 1:18; Jer 50:20
Àìsá. 43:25Sm 25:7; 79:8, 9; Isk 20:9
Àìsá. 43:25Jer 31:34
Àìsá. 43:27Ais 28:7; Jer 5:31
Àìsá. 43:28Sm 79:4; 137:3
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 43:1-28

Àìsáyà

43 Ohun tí Jèhófà wá sọ nìyí,

Ẹlẹ́dàá rẹ, ìwọ Jékọ́bù, Ẹni tó dá ọ, ìwọ Ísírẹ́lì:+

“Má bẹ̀rù, torí mo ti tún ọ rà.+

Mo ti fi orúkọ rẹ pè ọ́.

Tèmi ni ọ́.

 2 Tí o bá gba inú omi kọjá, màá wà pẹ̀lú rẹ,+

Tí o bá sì gba inú odò kọjá, kò ní kún bò ọ́.+

Tí o bá rin inú iná kọjá, kò ní jó ọ,

Ọwọ́ iná ò sì ní rà ọ́.

 3 Torí èmi ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ,

Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì, Olùgbàlà rẹ.

Mo ti fi Íjíbítì ṣe ìràpadà fún ọ,

Mo sì ti fi Etiópíà àti Sébà dípò rẹ.

 4 Torí o ti wá ṣeyebíye ní ojú mi,+

A dá ọ lọ́lá, mo sì nífẹ̀ẹ́ rẹ.+

Torí náà, màá fi àwọn èèyàn rọ́pò rẹ,

Màá sì fi àwọn orílẹ̀-èdè dípò ẹ̀mí* rẹ.

  5 Má bẹ̀rù, torí mo wà pẹ̀lú rẹ.+

Màá mú ọmọ* rẹ wá láti ìlà oòrùn,

Màá sì kó ọ jọ láti ìwọ̀ oòrùn.+

 6 Màá sọ fún àríwá pé, ‘Dá wọn sílẹ̀!’+

Màá sì sọ fún gúúsù pé, ‘Má ṣe dá wọn dúró.

Mú àwọn ọmọkùnrin mi wá láti ọ̀nà jíjìn àti àwọn ọmọbìnrin mi láti àwọn ìkángun ayé,+

 7 Gbogbo ẹni tí wọ́n ń fi orúkọ mi pè,+

Tí mo sì dá fún ògo mi,

Tí mo ṣẹ̀dá, tí mo sì ṣe.’+

 8 Mú àwọn èèyàn tó fọ́jú jáde, bí wọ́n tiẹ̀ ní ojú,

Àwọn tó jẹ́ adití, bí wọ́n tiẹ̀ ní etí.+

 9 Kí gbogbo orílẹ̀-èdè pé jọ síbì kan,

Kí àwọn èèyàn sì kóra jọ.+

Èwo nínú wọn ló lè sọ èyí?

Àbí wọ́n lè mú ká gbọ́ àwọn ohun àkọ́kọ́?*+

Kí wọ́n mú àwọn ẹlẹ́rìí wọn wá, kí wọ́n lè fi hàn pé àwọn jàre,

Tàbí kí wọ́n gbọ́, kí wọ́n sì sọ pé, ‘Òótọ́ ni!’”+

10 “Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí mi,”+ ni Jèhófà wí,

“Àní ìránṣẹ́ mi tí mo ti yàn,+

Kí ẹ lè mọ̀, kí ẹ sì ní ìgbàgbọ́ nínú mi,*

Kó sì yé yín pé Ẹnì kan náà ni mí.+

Ṣáájú mi, kò sí Ọlọ́run tí a dá,

Lẹ́yìn mi, kò sí ìkankan.+

11 Èmi, àní èmi ni Jèhófà,+ kò sí olùgbàlà kankan yàtọ̀ sí mi.”+

12 “Èmi ni Ẹni tó kéde, tó gbani là, tó sì mú kó di mímọ̀,

Nígbà tí kò sí ọlọ́run àjèjì kankan láàárín yín.+

Torí náà, ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí mi,” ni Jèhófà wí, “èmi sì ni Ọlọ́run.+

13 Bákan náà, Ẹnì kan náà ni mí+ nígbà gbogbo;

Kò sì sí ẹni tó lè já ohunkóhun gbà kúrò lọ́wọ́ mi.+

Tí mo bá ń ṣe nǹkan kan, ta ló lè dá mi dúró?”+

14 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, Olùtúnrà yín,+ Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì:+

“Nítorí yín, màá ránṣẹ́ sí Bábílónì, màá sì gé gbogbo ọ̀pá ìdábùú ẹnubodè lulẹ̀,+

Àwọn ará Kálídíà sì máa ké jáde nínú ìdààmú, nínú àwọn ọkọ̀ òkun wọn.+

15 Èmi ni Jèhófà, Ẹni Mímọ́ yín,+ Ẹlẹ́dàá Ísírẹ́lì+ àti Ọba yín.”+

16 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,

Ẹni tó ń la ọ̀nà gba inú òkun,

Tó sì ń la ọ̀nà gba inú omi tó ń ru gùdù,+

17 Ẹni tó ń fa kẹ̀kẹ́ ogun àti ẹṣin jáde,+

Àwọn ọmọ ogun pẹ̀lú àwọn jagunjagun tó lákíkanjú:

“Wọ́n máa dùbúlẹ̀, wọn ò sì ní dìde.+

A máa fẹ́ wọn pa, a máa pa wọ́n bí òwú àtùpà tó ń jó.”

18 “Ẹ má ṣe rántí àwọn ohun àtijọ́,

Ẹ má sì máa ronú nípa ohun tó ti kọjá.

19 Ẹ wò ó! Mò ń ṣe ohun tuntun;+

Kódà, ní báyìí, ó ti ń rú yọ.

Ṣé ẹ ò mọ̀ ọ́n ni?

Màá la ọ̀nà kan gba inú aginjù,+

Màá sì mú kí odò gba inú aṣálẹ̀.+

20 Ẹran igbó máa bọlá fún mi,

Àwọn ajáko* àti ògòǹgò,

Torí mo pèsè omi ní aginjù,

Odò ní aṣálẹ̀,+

Fún àwọn èèyàn mi, àwọn àyànfẹ́ mi,+ kí wọ́n lè mu,

21 Àwọn èèyàn tí mo dá fún ara mi,

Kí wọ́n lè kéde ìyìn mi.+

22 Àmọ́ o ò ké pè mí, ìwọ Jékọ́bù,+

Torí ọ̀rọ̀ mi ti sú ọ, ìwọ Ísírẹ́lì.+

23 O ò mú àgùntàn wá fún mi láti fi rú àwọn odindi ẹbọ sísun rẹ,

O ò sì fi àwọn ẹbọ rẹ yìn mí lógo.

Mi ò fi dandan mú ọ pé kí o mú ẹ̀bùn wá fún mi,

Mi ò sì fi oje igi tùràrí tí mo ní kí o mú wá dá ọ lágara.+

24 O ò fi owó rẹ ra pòròpórò olóòórùn dídùn* fún mi,

O ò sì fi ọ̀rá àwọn ẹbọ rẹ tẹ́ mi lọ́rùn.+

Dípò ìyẹn, ṣe lo fi àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ di ẹrù wọ̀ mí lọ́rùn,

O sì fi àwọn àṣìṣe rẹ tán mi lókun.+

25 Èmi, àní èmi ni Ẹni tó ń nu àwọn àṣìṣe* rẹ+ kúrò nítorí tèmi,+

Mi ò sì ní rántí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ.+

26 Rán mi létí; jẹ́ ká gbé ẹjọ́ wa wá;

Ro ẹjọ́ rẹ, kí o lè fi hàn pé o jàre.

27 Baba ńlá rẹ àkọ́kọ́ ṣẹ̀,

Àwọn agbẹnusọ* rẹ sì ti ṣọ̀tẹ̀ sí mi.+

28 Torí náà, màá sọ àwọn ìjòyè ibi mímọ́ di aláìmọ́,

Màá mú kí wọ́n pa Jékọ́bù run,

Màá sì mú kí wọ́n sọ̀rọ̀ èébú sí Ísírẹ́lì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́