ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Oníwàásù 7
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Oníwàásù

      • Orúkọ rere àti ọjọ́ ikú (1-4)

      • Ìbáwí tí ọlọ́gbọ́n fúnni (5-7)

      • Òpin nǹkan sàn ju ìbẹ̀rẹ̀ rẹ̀ lọ (8-10)

      • Àǹfààní ọgbọ́n (11, 12)

      • Ọjọ́ rere àti ọjọ́ burúkú (13-15)

      • Yẹra fún àṣejù (16-22)

      • Àwọn ohun tí akónijọ kíyè sí (23-29)

Oníwàásù 7:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Orúkọ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 10:7; 22:1; Ais 56:5; Lk 10:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2008, ojú ìwé 24-25

    8/15/2003, ojú ìwé 3

    11/15/1998, ojú ìwé 32

    4/15/1997, ojú ìwé 27

    2/15/1997, ojú ìwé 12-13

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 313-314

Oníwàásù 7:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 5:11, 12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    7/8/2003, ojú ìwé 15

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2002, ojú ìwé 4

Oníwàásù 7:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 119:71; Lk 6:21
  • +2Kọ 7:10; Heb 12:11

Oníwàásù 7:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìgbádùn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 25:36; Owe 21:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2008, ojú ìwé 22

Oníwàásù 7:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 141:5; Owe 15:31

Oníwàásù 7:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Onw 2:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/2006, ojú ìwé 15

    3/15/1996, ojú ìwé 4

Oníwàásù 7:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 23:8; Di 16:19; 1Sa 8:1-3; Owe 17:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2010, ojú ìwé 4

    7/1/1992, ojú ìwé 4

Oníwàásù 7:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 13:10; Jem 5:10; 1Pe 5:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2000, ojú ìwé 4

    6/15/1995, ojú ìwé 10-11

    Yiyan, ojú ìwé 15-16

Oníwàásù 7:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “kánjú ní ẹ̀mí láti.”

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “ìbínú ni àmì àwọn òmùgọ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 16:32; Jem 1:19
  • +Jẹ 4:5; Ẹst 5:9; Owe 14:17, 29; 29:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/1/2005, ojú ìwé 13-15

    2/1/1991, ojú ìwé 24

    Ìwé fún Gbogbo Ènìyàn, ojú ìwé 25-26

Oníwàásù 7:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 9:62

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2020, ojú ìwé 25

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2012, ojú ìwé 25-26

    12/1/2002, ojú ìwé 32

    Jí!,

    12/22/1996, ojú ìwé 15

Oníwàásù 7:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, àwọn tó wà láàyè.

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2004, ojú ìwé 28

Oníwàásù 7:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 4:5, 6
  • +Owe 10:15
  • +Owe 3:13, 18; 8:35; 9:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 37

    Jí!,

    7/2007, ojú ìwé 12-13

    9/22/1997, ojú ìwé 12

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2004, ojú ìwé 28

    8/1/2003, ojú ìwé 5

    5/15/1998, ojú ìwé 6

    2/15/1993, ojú ìwé 8-9

    Ayọ, ojú ìwé 56

Oníwàásù 7:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Job 9:12; Ais 14:27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/1999, ojú ìwé 29

Oníwàásù 7:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ṣàwárí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jem 5:13
  • +Job 2:10; Ais 45:7
  • +Owe 27:1; Onw 9:11; Jem 4:13, 14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/1999, ojú ìwé 29

Oníwàásù 7:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 39:5
  • +Jẹ 4:8; 1Sa 22:18
  • +Job 21:7; Sm 73:12

Oníwàásù 7:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 65:5; Mt 6:1; Ro 10:3; 14:10
  • +Owe 3:7; Ro 12:3
  • +Owe 16:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 35

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2010, ojú ìwé 9

    8/1/1998, ojú ìwé 11

    10/15/1995, ojú ìwé 31

    Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, ojú ìwé 228

Oníwàásù 7:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 14:1; Owe 14:9
  • +Sm 55:23; Owe 10:27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/15/1991, ojú ìwé 5-6

Oníwàásù 7:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Flp 4:5

Oníwàásù 7:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 21:22; 24:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/2006, ojú ìwé 15

Oníwàásù 7:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 6:36; Sm 51:5; Ro 3:23; 1Jo 1:8

Oníwàásù 7:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ṣépè fún.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 24:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 51

    Jí!,

    11/8/2001, ojú ìwé 24

Oníwàásù 7:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jem 3:2, 8, 9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 51

    Jí!,

    11/8/2001, ojú ìwé 24

Oníwàásù 7:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 36:6; 139:6; Ais 55:9; Ro 11:33

Oníwàásù 7:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Onw 1:17; 2:12

Oníwàásù 7:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 39:7-9
  • +Owe 5:3, 14; 7:22, 23; 22:14

Oníwàásù 7:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Onw 1:1

Oníwàásù 7:28

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn mi.”

  • *

    Tàbí “ọkùnrin kan tó jẹ́ adúróṣinṣin.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2015, ojú ìwé 28-29

    1/15/2007, ojú ìwé 31

Oníwàásù 7:29

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 1:26, 31
  • +Jẹ 3:6; 6:12; Di 32:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/1999, ojú ìwé 28-29

Àwọn míì

Oníw. 7:1Owe 10:7; 22:1; Ais 56:5; Lk 10:20
Oníw. 7:2Ais 5:11, 12
Oníw. 7:3Sm 119:71; Lk 6:21
Oníw. 7:32Kọ 7:10; Heb 12:11
Oníw. 7:41Sa 25:36; Owe 21:17
Oníw. 7:5Sm 141:5; Owe 15:31
Oníw. 7:6Onw 2:2
Oníw. 7:7Ẹk 23:8; Di 16:19; 1Sa 8:1-3; Owe 17:23
Oníw. 7:8Owe 13:10; Jem 5:10; 1Pe 5:5
Oníw. 7:9Owe 16:32; Jem 1:19
Oníw. 7:9Jẹ 4:5; Ẹst 5:9; Owe 14:17, 29; 29:11
Oníw. 7:10Lk 9:62
Oníw. 7:12Owe 4:5, 6
Oníw. 7:12Owe 10:15
Oníw. 7:12Owe 3:13, 18; 8:35; 9:11
Oníw. 7:13Job 9:12; Ais 14:27
Oníw. 7:14Jem 5:13
Oníw. 7:14Job 2:10; Ais 45:7
Oníw. 7:14Owe 27:1; Onw 9:11; Jem 4:13, 14
Oníw. 7:15Sm 39:5
Oníw. 7:15Jẹ 4:8; 1Sa 22:18
Oníw. 7:15Job 21:7; Sm 73:12
Oníw. 7:16Ais 65:5; Mt 6:1; Ro 10:3; 14:10
Oníw. 7:16Owe 3:7; Ro 12:3
Oníw. 7:16Owe 16:18
Oníw. 7:17Sm 14:1; Owe 14:9
Oníw. 7:17Sm 55:23; Owe 10:27
Oníw. 7:18Flp 4:5
Oníw. 7:19Owe 21:22; 24:5
Oníw. 7:202Kr 6:36; Sm 51:5; Ro 3:23; 1Jo 1:8
Oníw. 7:211Sa 24:9
Oníw. 7:22Jem 3:2, 8, 9
Oníw. 7:24Sm 36:6; 139:6; Ais 55:9; Ro 11:33
Oníw. 7:25Onw 1:17; 2:12
Oníw. 7:26Jẹ 39:7-9
Oníw. 7:26Owe 5:3, 14; 7:22, 23; 22:14
Oníw. 7:27Onw 1:1
Oníw. 7:29Jẹ 1:26, 31
Oníw. 7:29Jẹ 3:6; 6:12; Di 32:5
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Oníwàásù 7:1-29

Oníwàásù

7 Orúkọ rere* sàn ju òróró dáradára,+ ọjọ́ ikú sì sàn ju ọjọ́ tí a bíni lọ. 2 Ó sàn láti lọ sí ilé ọ̀fọ̀ ju láti lọ sí ilé àsè,+ torí pé ìyẹn ni òpin gbogbo èèyàn, ó sì yẹ kí àwọn alààyè fi sọ́kàn. 3 Ìbànújẹ́ sàn ju ẹ̀rín lọ,+ torí ojú tó fà ro ń mú kí ọkàn túbọ̀ ṣiṣẹ́ dáadáa.+ 4 Ọkàn ọlọ́gbọ́n wà ní ilé ọ̀fọ̀, àmọ́ ilé ìdùnnú* ni ọkàn òmùgọ̀ wà.+

5 Ó sàn kéèyàn fetí sí ìbáwí ọlọ́gbọ́n+ ju kéèyàn máa gbọ́ orin àwọn òmùgọ̀. 6 Torí pé bí ẹ̀gún tó ń jó lábẹ́ ìkòkò ṣe máa ń ta pàrà, bẹ́ẹ̀ ni ẹ̀rín òmùgọ̀ rí;+ asán sì ni èyí pẹ̀lú. 7 Ìnilára lè mú kí ọlọ́gbọ́n ṣe bíi wèrè, àbẹ̀tẹ́lẹ̀ sì ń sọ ọkàn dìdàkudà.+

8 Òpin nǹkan sàn ju ìbẹ̀rẹ̀ rẹ̀ lọ. Ó sàn kéèyàn ní sùúrù ju pé kéèyàn ní ẹ̀mí ìgbéraga.+ 9 Má ṣe máa yára* bínú,+ torí pé àyà àwọn òmùgọ̀ ni ìbínú ń gbé.*+

10 Má sọ pé, “Kí nìdí tí àwọn ọjọ́ àtijọ́ fi sàn ju ti ìgbà yìí lọ?” torí pé kì í ṣe ọgbọ́n ló mú kí o béèrè bẹ́ẹ̀.+

11 Ọgbọ́n pẹ̀lú ogún jẹ́ ohun tó dáa, ó sì jẹ́ àǹfààní fún àwọn tó ń rí ìmọ́lẹ̀ ọjọ́.* 12 Nítorí ọgbọ́n jẹ́ ààbò+ bí owó ṣe jẹ́ ààbò,+ àmọ́ àǹfààní ìmọ̀ ni pé: Ọgbọ́n máa ń dá ẹ̀mí àwọn tó ní in sí.+

13 Kíyè sí iṣẹ́ Ọlọ́run tòótọ́, ta ló lè mú kí ohun tó ṣe ní wíwọ́ tọ́?+ 14 Ní ọjọ́ tí nǹkan bá dáa, jẹ́ kó hàn lójú rẹ,+ àmọ́ ní ọjọ́ àjálù, fiyè sí i pé Ọlọ́run ti ṣe àkọ́kọ́ àti èkejì,+ kí aráyé má bàa lè sọ ní pàtó* ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí wọn lọ́jọ́ iwájú.+

15 Ohun gbogbo ni mo ti rí ní gbogbo ìgbé ayé asán mi,+ látorí olódodo tó ṣègbé nínú òdodo rẹ̀,+ dórí ẹni burúkú tó pẹ́ láyé bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìwà burúkú ló ń hù.+

16 Má ṣe òdodo àṣelékè,+ bẹ́ẹ̀ ni kí o má ṣe gbọ́n ní àgbọ́njù.+ Àbí o fẹ́ pa ara rẹ ni?+ 17 Má sọ ìwà burúkú dàṣà, má sì ya òmùgọ̀.+ Ṣé ó yẹ kí o kú láìtọ́jọ́ ni?+ 18 Ó sàn kéèyàn gba ìkìlọ̀ àkọ́kọ́, kó má sì jẹ́ kí èkejì bọ́ mọ́ òun lọ́wọ́;+ nítorí ẹni tó bá bẹ̀rù Ọlọ́run yóò pa méjèèjì mọ́.

19 Ọgbọ́n máa ń mú kí ọlọ́gbọ́n lágbára ju akíkanjú ọkùnrin mẹ́wàá tó ń ṣọ́ ìlú.+ 20 Nítorí kò sí olódodo kankan láyé tó ń ṣe rere nígbà gbogbo tí kì í dẹ́ṣẹ̀.+

21 Bákan náà, má ṣe máa fọkàn sí gbogbo ọ̀rọ̀ tí àwọn èèyàn bá sọ;+ àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, o lè gbọ́ tí ìránṣẹ́ rẹ ń bú* ọ; 22 torí o mọ̀ lọ́kàn rẹ dáadáa pé ọ̀pọ̀ ìgbà ni ìwọ fúnra rẹ ti bú àwọn míì.+

23 Gbogbo èyí ni mo ti fi ọgbọ́n dán wò, mo sì sọ pé: “Màá di ọlọ́gbọ́n.” Àmọ́, ó kọjá agbára mi. 24 Ohun tó ti wà, ọwọ́ ò lè tó o, ó sì jinlẹ̀ gidigidi. Ta ló lè lóye rẹ̀?+ 25 Mo darí ọkàn mi kí n lè mọ̀, kí n lè wádìí, kí n sì lè wá ọgbọ́n àti ohun tó ń fa àwọn nǹkan tó ń ṣẹlẹ̀, mo sì darí rẹ̀ kí n lè lóye aburú tó wà nínú ìwà ẹ̀gọ̀ àti àìlọ́gbọ́n tó wà nínú ìwà wèrè.+ 26 Mo wá rí i pé: Ohun tó korò ju ikú lọ ni obìnrin tó dà bí àwọ̀n ọlọ́dẹ, tí ọkàn rẹ̀ dà bí àwọ̀n ńlá, tí ọwọ́ rẹ̀ sì dà bíi ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀. Ẹni tó bá ń ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run tòótọ́ á bọ́ lọ́wọ́ rẹ̀,+ àmọ́ ẹlẹ́ṣẹ̀ á kó sọ́wọ́ rẹ̀.+

27 Akónijọ+ sọ pé, “Wò ó! èyí ni mo ti rí. Mo gbé àwọn nǹkan yẹ̀ wò lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan kí n lè mọ ibi tí màá parí èrò sí, 28 àmọ́ mi* ò tíì rí ohun tí mò ń fi ìgbà gbogbo wá. Mo rí ọkùnrin kan* nínú ẹgbẹ̀rún, àmọ́ mi ò tíì rí obìnrin kan nínú wọn. 29 Èyí nìkan ṣoṣo ni mo ti rí pé: Ọlọ́run tòótọ́ dá aráyé ní adúróṣinṣin,+ àmọ́ wọ́n ti wá ọ̀pọ̀ ètekéte.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́